Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,149,710 members, 7,805,915 topics. Date: Tuesday, 23 April 2024 at 08:26 AM

Tommorrow's Yoruba Examination Expo (waec)... - Jokes Etc - Nairaland

Nairaland Forum / Entertainment / Jokes Etc / Tommorrow's Yoruba Examination Expo (waec)... (2338 Views)

10 Places People Hide Expo In Examination Hall / June/July WAEC Examination Questions / I,m Getting Married Tommorrow, Hurray! (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Tommorrow's Yoruba Examination Expo (waec)... by Laitesmart(m): 12:50pm On Apr 09, 2013
TOMMORROW'S YORUBA EXAMINATION EXPO (WAEC)...

Dahun ibeere mewa ni ipin yii...

1. Awon wo ni yoruba n pe ni AARE ONA KAKANFO? 10mrks

2. Daruko ohun mewa ti a le ba pade loju ogun. 10mrks.

3. Kinni oruko miiran fun EWEDU?10mrks

4. Tani eni akoko to koko gun keke rally ni ile yoruba??10mrks

5. Daruko eewo akonilogbon marun ti o ba mo?10mrks

6. Salaye lekunrere awon ami ti a fi n da ogidi were mo..10mrks.

7. So iyato kan pato ti o wa laarin were ibo, were hausa ati were yoruba.10mrks

8. Bi won ba n ta moin-moin kan ni pon-un marundinlogun. Eelo ni won maa ta moin?10mrks

9. Tani eni akoko to koko din akara ta? Ilu wo si ni won ti din?10mrks

10. Pari owe yii... AKOBANI IYAWO KASUMU...10mrks

11. Pari owe yii... SAKATAPARA LA A SINTO...10mrks

12. Pari owe yii... PATAPATA LA A FOJU..10mrks.

13. Ta ni okunrin akoko ti o koko wu irungbon?10mrks

14. Se apejuwe oro oruko mewa ti o ni ami ohun "MI MI MI".10mrks

15. Bi oko ba je ole, ti iyawo je aje... Tani yio maa bawon so ile loru? 10mrks

(1) (Reply)

Photo: When You Attend Funeral Of Someone That Died Owing You Money / My Expensive Joke On President Muhammadu Buhari –gordons, Comedian / Hilarious! Special Shout Out To Aba Weed Lol (photos)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 7
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.