Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,143,304 members, 7,780,716 topics. Date: Thursday, 28 March 2024 at 08:20 PM

Oro Po Ninu Iwe Kobo - Family (2) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Family / Oro Po Ninu Iwe Kobo (5187 Views)

Before You Say "I Do", My 2 Kobo (2) (3) (4)

(1) (2) (Reply) (Go Down)

Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by itstpia1: 3:04am On Sep 16, 2014
spanzed: A kii binu ori ki a fi fila de idi
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by CAMNEWTON4PRES: 3:13am On Sep 16, 2014
Eko oni baje
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by spanzed(m): 7:40am On Sep 16, 2014
[quote author=itstpia1][/quote]eyan na da..karo sir
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by angeldupe(f): 8:47am On Sep 16, 2014
Adie funfun, ko month ra re lagba.

Ibi ko ju ibi lo, ba se bi eru la bi omo.

Anjuwon ko se wi lejo, ija ilara ko tan boro.
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by sholay2011(m): 10:16am On Sep 16, 2014
CAMNEWTON4PRES: Eko oni baje
grin grin grin grin

@ topic. ..

Koju ma ri tpia ibi, gbogbo ara loogun re.
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by Nobody: 10:58am On Sep 16, 2014
[quote author=itstpia1][/quote]

Oju kii ri arewa obirin ki enu ma pe.

Wa tpia, je ka jo soro tutu, oro ife cheesy
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by Nobody: 4:14pm On Sep 16, 2014
A ki n so fun omode ko ma dete to ba tile dagbo gbe.
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by itstpia1: 4:24pm On Sep 16, 2014
adolfebad:

ko si alamala to nso pe toun o yi, aladalu nikan lo sooto
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by itstpia1: 4:25pm On Sep 16, 2014
petylv: ogbon a dako kere ko to ti a yowo ma raa
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by itstpia1: 4:27pm On Sep 16, 2014
angeldupe: e pa ayejenku, a pa iyalode aniwura, igba ti e pa iyapo e gbagbe ogun
Re: Oro Po Ninu Iwe Kobo by itstpia1: 4:28pm On Sep 16, 2014
sholay2011:
grin grin grin grin

@ topic. ..

ebi ti i kun emo loju, oun ni nyi i lepon sehin

(1) (2) (Reply)

Attraction Of Babies----does It Happen To You?does It Mean A Thing? / Secret Thing Some Wives Do? / Why Deceive Ourselves With This "Gender Equality" Phrase

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 7
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.