Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,148,846 members, 7,802,704 topics. Date: Friday, 19 April 2024 at 07:27 PM

.. - Culture (91) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1826536 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (88) (89) (90) (91) (92) (93) (94) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by Hert777: 8:39pm On Mar 24, 2017
08101646045atwp:
OSOLE OWO TIMU OWO NLA TI ALE FI KOLE LARIN OSU META!
Sugbon nigbati Emi danwo, Mio kole'o
Sugbon hmmm!!!
Nkan Ti mofise komabaje'o!!!
:- EWE BARA MESAN TI OOJO, AOGUN MO ERU ALAMO IYEKIYE, AOPO LOSE, AOFI EJE EIYELE funfun PO OSE NA DADA, AOKO ose na SINU IGBA OLOMORI, AOGBE PAMO FUN 16DAYS. Aoma buwe lararo, pelu ogo Eledumare owo ti ama fi kole nlala yio wa larin osu meta pere. IKILO: enikeni kogbodo ri igba yi ki ojo na tope. Osole yi Koni daun daada na.

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- 08101646045
OR
https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS
bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o
ama ju wa se o. Ase. Ejowo se sale lo ike olomori funfun lati ko ISE yii si. Ese pupo.
Re: .. by Jerrydollar(m): 7:58am On Mar 26, 2017


Awon Ika eeyan ko le je ki a fi iru Oogun bee sita lori Afefe. Eyi ti mo ni lewu pupo, o le ya obinrin na ni were bi okunrin to sa Oogun yi fun ko ba fe. idi niyi ti o fi lewu die lati fi sori afefe.


Awon Ika eeyan ko le je ki a fi iru Oogun bee sita lori Afefe. Eyi ti mo ni lewu pupo, o le ya obinrin na ni were bi okunrin to sa Oogun yi fun ko ba fe. idi niyi ti o fi lewu die lati fi sori afefe.


Awon Ika eeyan ko le je ki a fi iru Oogun bee sita lori Afefe. Eyi ti mo ni lewu pupo, o le ya obinrin na ni were bi okunrin to sa Oogun yi fun ko ba fe. idi niyi ti o fi lewu die lati fi sori afefe.

okare! Ejo se elebami fi ran se si ori e-mail:adeoyeJeremiahadesakin@gmail.com.....KULADE A GBEWA O!
Re: .. by ifadamilola: 10:04am On Apr 06, 2017
Re: .. by ifadamilola: 6:14pm On Apr 06, 2017
ejowo talo ni Ogun ti eniyan le ma fi hun aso ofi bi pack merin tabi marun lojumo eseun gan mo nreti esi padA aboru aboye
Re: .. by Canme4u(m): 6:49am On Apr 08, 2017
Just seeing this.

Well done everyone
Re: .. by skolat1: 11:43am On Apr 12, 2017
Adupe lowo gbogbo eyin baba ati eyin iya wa ti en orisirisi ognon ati oye se omo araye Ni anfani. Eseun gan.
Re: .. by skolat1: 11:45am On Apr 12, 2017
Hmmmmmm
Re: .. by agbakuonida(m): 12:08pm On Apr 21, 2017
Aboru boye oo. ejo kin Biscuit Okin ati wipe kini ogun ti ale lo fun ofa tio saka kakiri ara eniyan ti ko ni fi gburo re mo. ese oo ewe amaje oo.
Re: .. by agbakuonida(m): 1:00pm On Apr 21, 2017
baba kini ama fi omi ti aju igbin sinu re fun bi iseju marundilogun Se. ati wipe se igbin ti o gbonu daada leso. ese moreti idahun yin
Re: .. by agbakuonida(m): 1:51pm On Apr 21, 2017
se gbogbo ikan ti ajo yen la ma da si ori epo yen le kanna abi die die fun ijo miran abi se elomiran le lo ninu ogun yi. ati wipe iru Ishana wo la so nipa re gan
Re: .. by agbakuonida(m): 2:07pm On Apr 21, 2017
[quote author=seanjizzyayo post=52803943]


kini itumo biscuit okin ati ewe ekuya ati ikilo tio owa ninu ise Yi
Re: .. by agbakuonida(m): 2:17pm On Apr 21, 2017
[quote author=seanjizzyayo post=52007305]

ejo bi Ibo ni a tule lo yato si ori apata tori wipe gbogbo eniyan ko lo sumo ibi ti apata wa. ati wipe she osan ni a man lo la mole ni abi ale. ese gan
Re: .. by raymonddodo(m): 9:49pm On Apr 23, 2017
HorlarhMheporzy:
Ejo mo ni di ogun ti mofa ti ara eyan ati awon mo gbon lai ri inka iberu (scared thing) ta bi wa nibi ti oro posi (in public). so gbon mogbo pe aisan isan (vein fever) ni. eda kun mo nidi ogun yi gidi gidi gan ni.



pemi
Re: .. by raymonddodo(m): 9:51pm On Apr 23, 2017
odabe
Re: .. by raymonddodo(m): 10:01pm On Apr 23, 2017
Ogun awure owo

ewe tagiri
aogun pelu ose dudu
aofi 200 te inu ike osena

aowa ko osena sinu ike na aoma we ki orun toyo

pemi fun Ogun gbewa ooo

09079098548

abi Ogun so ewe dowo
Re: .. by raymonddodo(m): 10:17pm On Apr 23, 2017
Ogun anu biro fun wae


aowa ewe anu

ewe jebure
atare eyo lilopo

aoro sinu ink biro tuntun odaju

ikilo Maya eni kenioo

09079098548
Re: .. by IBAAGBA1: 5:06pm On Apr 24, 2017
E jowo mo need ogun orobo to nyo nidi,o siti pe lara bakanna,e jowo e sanu mi
Re: .. by raymonddodo(m): 12:06am On Apr 25, 2017
ahhh moti mo unko tose ise NLA nio pemi 09079098548
whtsapp
09060525145
Re: .. by raymonddodo(m): 12:07am On Apr 25, 2017
ifadamilola:
ejowo talo ni Ogun ti eniyan le ma fi hun aso ofi bi pack merin tabi marun lojumo eseun gan mo nreti esi padA aboru aboye



aworo NLA waoo
Re: .. by IBAAGBA1: 12:51pm On Apr 26, 2017
E jowo e fun mi ni ogun ti idi eniyan ba nyo jade to ba nyagbe
Re: .. by skolat1: 11:52am On Apr 27, 2017
Ejowo ewe ama je o. Ejowo mo nilo Atona . Eyin ojogbon ejeki aje anfani re eseun.
Re: .. by Knight0777(m): 11:25pm On Apr 27, 2017
OGUN BIRO RIRE FUN IDANWO
Eso yerepe, ewe ina, odidi atare kan, ewe odan, a o jo gbogbo re papo, a o po mo oyin igan gidi, a o da si ibikan a o re biro meta sinu re, a o wa gbe pamo si ibi owo fun ojo meje, leyin ojo keje, a o ko kuro ninu oyin yen a o wa lo bo mo ori sare(grave) tiwon sin oku si fun ojo meta. Leyin ojo keta, okan yio salo ninu biro yen, a o ko meji yoku, odi lilo. Akiyesi: ti okankan ko ba ti salo, aje wipe ko sise niyen o. Ki a tun omiran se. Odaju saka.
Iba eyin agbagba ti Odumare ko ile aiye le lowo o.

1 Like 2 Shares

Re: .. by ipobarecriminals: 3:33pm On Apr 30, 2017
kadunasouth:
OGUN IKORIRA ati ITUSILE
Ao wa eyin ororo adie wa bora si ihoho omo luabi wa ma fi nu gbogbo arare pelu adua sise gbogbo isoro igbese ayere wase fun bi iseju marun wawa wo ewure pada walojusi ori akitan tabi orita meta tobati ju okogbodo soro siyan tabi koboju weyin toma fi wole re pada danwo okere sugbon olagbara pupo
Adurawa yio gba o!
E ka san ni be o.Aboru boye oo.E dakun,iru eyin wo ni a ma lo.se eyin ibile ni abi ewo? Iru ororo wo? E se gan
Re: .. by skolat1: 10:50am On May 02, 2017
Adupe baba, ewe amaa jee oo
Re: .. by HorlarhMheporzy(m): 12:58pm On May 02, 2017
Ejowo se mo le lo koko ti anfi se ounje ninu ile se agbo bi malaria tabi typhoid. abi dandan ni ki nwa koko agbo gangan ni.
Re: .. by jophins(m): 8:31pm On May 03, 2017
Ekale eyin Agbalagba ejowo e add me pada sori whatsapps 07031062770
Re: .. by babatunde199325: 2:09am On May 11, 2017


Hmmm...Ta le fe lo fun? Se e mo awon inkan to ro mo Oogun Adodun? Ikini, ko dara ki a lo fun Obinrin ti a ko ni fe se iyawo nitoripe ife wa ko ni kuro lokan re laelae, ikeji, ko dara ki a lo fun iyawo ile wa nitoripe, bi o ba pe ti a ti nlo fun, yio ma din orire Obinrin na ku diedie sugbon ko ni le fi wa sile laelae.

se ale lo condom pelu Ogun adodun?
Re: .. by babatunde199325: 2:12am On May 11, 2017
ejo se ale lo condom pelu Ogun adodun...?
Re: .. by omiaruk: 3:34pm On May 11, 2017
Eku ogbon. Oti pe ti Mo ti ma n ro PE she Kosi ogun ibile fun aisan HIV ni? Ejowo ebami daun. Eshe pupo
Re: .. by jentusoul: 6:40pm On May 14, 2017
Babawa KADUNASOUTH, Ejowo tiaba ju eyin naa si orita, se eyin naa konifo, atiwipe se ti eyin naa bafo, se kose nkankan sir
Re: .. by skolat1: 9:54am On May 17, 2017
Ejowo gbogbo eyin agbagba , efun WA OGUN ORIFIFO TUULU.Adupe ooooo
Re: .. by Wolad(m): 11:47pm On May 19, 2017
IBAAGBA1:
E jowo mo need ogun orobo to nyo nidi,o siti pe lara bakanna,e jowo e sanu mi

Ewe Agogo-igun, Eso Iwerejeje (oju ologbo), ako kanhun, ao gun po sinu OTI, mimu...

(1) (2) (3) ... (88) (89) (90) (91) (92) (93) (94) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 33
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.