Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,150,582 members, 7,809,112 topics. Date: Thursday, 25 April 2024 at 11:34 PM

.. - Culture (18) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1827246 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (15) (16) (17) (18) (19) (20) (21) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by kadunasouth(m): 10:27am On Aug 06, 2015
Ogun Asegbe
Ewe imi esu ati alubosa elewe ao gun papo ao da sinu kolobo ao da ogere epo pupa si ao mala
NB Ise yi dara pupo lona eto gege bi owo fun awan janduku wan ko nile diwa lowo toba lo lona aito koni sise kokinsepe man jemu ise nani

8 Likes 3 Shares

Re: .. by dominicson: 8:52pm On Aug 06, 2015
ziddy:
E ku ise oluwa o.

E jowo kini eniyan le lo lati ma ranti daradara ohun ti a ba ka ninu iwe, ki a si ma gbagbe ohun ti a ba ka rara. E seun.



Akii ka owo ki a gbagbe eni
Orisa kii gbagbe ati ko ila owo(hand)
Omo irunla kii so loko (at farm) ko mala
Gbogbo eko ti mo ba ti nko, ki o ma la si mi lokan!

2 Likes

Re: .. by dominicson: 8:59pm On Aug 06, 2015
kadunasouth:
Eyonu odaju
Ewe imin esu epo obo ao gun papo month ose dudu ao mafi we, iseyi kere loju sugbon odara pupo


Ogbo ato e! Eyonu nla ni, confirmed!

2 Likes 2 Shares

Re: .. by dominicson: 9:10pm On Aug 06, 2015
Sobandemojisola:
e jowo, mo fe oogun ki oko mi (husband) ma le ba elomii (another person) sun nita, ayafi emi nikan soso

mo tun fee oogun ifetosomobibi (pregnancy prevention)

e se gan an , olorun a maa ranyin lowo. e o ni sise lagbara odumare.

inu mi a dun (happy) ti e ba le dahun si ibeere mi ni kiakia. e se pupo.




I guess you are a woman, the very reason I decide to reply you! We initiates are taught to respect women. But my sister, man is polygamous. In fact, all animals, except doves, are polygamous. But if you insist to do it, you must let me why before I can release it, because it is not a child play, if you understand what I mean!


With regards to birth control, is your husbant in support of it?

Best regards.

PS: I type in English to make myself clear to you, I actually understand Yoruba more than other languages I speak.

3 Likes 1 Share

Re: .. by dominicson: 9:20pm On Aug 06, 2015
Isholex1love:
E KU ISE BABA,EWE AMA JE O , E JO MO NEED OGUN KI OGUN MA TETE DAUN LARA


Ajeegun ni awon baba wa ma n pe ogun ti o bere yii, erupe (yepe) orita meta ni ki o lo wa, pelu iwerenjeje meta, ati omo atare meta. Lo meteta ninu olo, fi sin igbere yipo orun owo mejeji.


Sugbon ju gbogbo re lo, ki i se gbogbo oogun ti o ba ba o laramu ni o ma ba emi lara mu, iseda eni kokan yato, koko lo se iwadi iru eda ti o je, ki o to le mo iru oogun ti o le je bi idan lara re.

2 Likes

Re: .. by Isholex1love: 9:06pm On Aug 07, 2015
E JO SELE BA MI SE AYEWO LELORI

1 Like

Re: .. by kadunasouth(m): 3:07am On Aug 08, 2015
EBE Awon Agba
Epo obo ata ijosi osun yoba ao gun papo mo ose dudu ao ma fiwe opari

4 Likes

Re: .. by Nobody: 2:20pm On Aug 08, 2015
dominicson:



Akii ka owo ki a gbagbe eni Orisa kii gbagbe ati ko ila owo(hand) Omo irunla kii so loko (at farm) ko mala Gbogbo eko ti mo ba ti nko, ki o ma la si mi lokan!
E seun, modupe o.

1 Like

Re: .. by kadunasouth(m): 1:37am On Aug 09, 2015
¤EYONU¤
Ao gun Ewe rerinkomi pomo ori. Ao maafi pa idodo.

4 Likes

Re: .. by Lionhearted: 5:12am On Aug 09, 2015
kadunasouth:
EBE Awon Agba
Epo obo ata ijosi osun yoba ao gun papo mo ose dudu ao ma fiwe opari

Eku ise takun takun yin.

Ejowo e ma bawa gbiyanju lati lo punctuation ka le mo okan si ekeji ninu awon eroja gbogbo.
Re: .. by OPCNAIRALAND: 4:56pm On Aug 09, 2015
Redoil:
wicked and wow. Better you hid it in ur native language

How is that wicked? There are parallels to that everywhere in human cultures.
Re: .. by Shegofams(m): 11:54am On Aug 10, 2015
dominicson:



Ajeegun ni awon baba wa ma n pe ogun ti o bere yii, erupe (yepe) orita meta ni ki o lo wa, pelu iwerenjeje meta, ati omo atare meta. Lo meteta ninu olo, fi sin igbere yipo orun owo mejeji.


Sugbon ju gbogbo re lo, ki i se gbogbo oogun ti o ba ba o laramu ni o ma ba emi lara mu, iseda eni kokan yato, koko lo se iwadi iru eda ti o je, ki o to le mo iru oogun ti o le je bi idan lara re.
Ibo ni moti le sewadi iru eda ti mo je, elo ni yoo nami

1 Like

Re: .. by kadunasouth(m): 3:30pm On Aug 10, 2015
Aseje Owo togbona
Ewe imi esu eyokan tojo, ao loma iyere 3 ao fi din eyin ororo kanje pelu epo ati iyo die ninu koko Aseje ao wa ogorun nera ao fikale ao se adua iye ti anbafe si owo yi ao wa so aseje sori ibikan tobati jina ao nije ki idi isasun na kanle toba tutu die ao gbeka ori ogorun nera yi ao wa je aseje na ao wa lo fi owo na se sara fun oni bara odaju

3 Likes 3 Shares

Re: .. by Isholex1love: 5:52pm On Aug 10, 2015
E Jo Mo Need Ogun Ti Eyan Lefi Da Asasi Pada To Gboju, E Jo Sir
Re: .. by dominicson: 7:52pm On Aug 10, 2015
Isholex1love:
E JO SELE BA MI SE AYEWO LELORI


Beeni!
Re: .. by dominicson: 7:54pm On Aug 10, 2015
Shegofams:
Ibo ni moti le sewadi i
u eda ti mo je, elo ni yoo nami


Mo le ba yin se

2 Likes

Re: .. by dominicson: 8:02pm On Aug 10, 2015
OPCNAIRALAND:


How is that wicked? There are parallels to that everywhere in human cultures.


Leave them be, they are uncultured
Re: .. by Isholex1love: 8:38pm On Aug 10, 2015
Kini O Ma Nami Lati Se Iwadi Lori Ohun Ti Eleda Mi Fe Ati Eyi Tio Ko And Mo Fe Ke Se Alaye Ori Orisi Ogun Meta Tio Wa
Re: .. by Isholex1love: 11:19pm On Aug 10, 2015
Baba E Jo , Ise Awure Oni Ewe Emile Ati Ponmo Yen Mo Se Bi Emeji Sugbon Mi Ti Ri Kohun E Jo Kini O Le Fa
Re: .. by bigfatthing(m): 4:29pm On Aug 11, 2015
.

2 Likes

Re: .. by kadunasouth(m): 4:42pm On Aug 11, 2015
bigfatthing:

Baba e jowse ise yi ko ni nkan buruku leyin

Beeni koni aburu kankan ninu odara pupo

1 Like 1 Share

Re: .. by bosrote: 11:02pm On Aug 11, 2015
Eseun Baba ejo baba month need ogun tin eyan fi month aeiri nkan loju ala tabi oomo to daju
Re: .. by bigfatthing(m): 11:19pm On Aug 11, 2015
kadunasouth:


Beeni koni aburu kankan ninu odara pupo
Ese pupo Baba, e ma so pe wahala MI po, e jowo kini itumo Ewe imi esu
Re: .. by Nobody: 11:32pm On Aug 11, 2015
E joo eyin eeyan, e je ka sora nipa gbigbe Oogun owo tabi osole sita...awon Oogun wonyi ni opolopo eewo ati awon inkan miran to ro mo sise won...ti o lewu fun eeyan to ba se. nitori idi eyi, e jeki a sewopo nipa irufe Oogun to ba je mo oogun Owo tabi Osole.
Re: .. by kadunasouth(m): 1:12am On Aug 12, 2015
bigfatthing:

Ese pupo Baba, e ma so pe wahala MI po, e jowo kini itumo Ewe imi esu
Oruko miran to nje ni ewe rerinkomi tabi imi eran apakan nisale wan aman peni ewe kuo ati bebelo iwulo ewe na po pupo kolonka

2 Likes

Re: .. by kadunasouth(m): 2:07am On Aug 12, 2015
Ituma awan ogun ti kole pawalara tiko lewo tobasi ni ewo ogun yio baje ni taba kolu ewore fun apere aseje owo tabajetan akogbo do sunma obinrin fun ojo meje, lo ba sunma obinrin larin ojo keta iru ewo yi kole koba arare sugbon ogun na kokan ni sise fun o man ni
Laipe maa se ekun rere alaye lori awan ogun todara ati awon eyi tolewu sugbon gbogbo ogun tobajepe lati kadunasouth lati kosita koni ewo kankan kosi le fa ipalara funwa Adua wa yio gba

4 Likes 2 Shares

Re: .. by tundebadmus(m): 2:01pm On Aug 12, 2015
si ojo man ni afi mon we
Re: .. by tundebadmus(m): 2:08pm On Aug 12, 2015
kadunasouth:
Aseje Owo togbona
Ewe imi esu eyokan tojo, ao loma iyere 3 ao fi din eyin ororo kanje pelu epo ati iyo die ninu koko Aseje ao wa ogorun nera ao fikale ao se adua iye ti anbafe si owo yi ao wa so aseje sori ibikan tobati jina ao nije ki idi isasun na kanle toba tutu die ao gbeka ori ogorun nera yi ao wa je aseje na ao wa lo fi owo na se sara fun oni bara odaju
se ogun yin dayin ni ojun

1 Like 1 Share

Re: .. by kadunasouth(m): 2:39pm On Aug 12, 2015
tundebadmus:
se ogun yin dayin ni ojun
OLuwa loni wibe jebe ati idaniloju gbo gbo e owo eledua lowa awa kan gbiyanju ni
Atanni nisuru lomo adari hunrun ogun to nbere yi ogorun meji pere pari ogun na tafun yin laibere nkankan, wan se ogun aiku fun o, oni kosise sotikuri ni?
Ema bere ibere toma mu ogban dani ti awan elomiran na yio ma se anfani nibe Adua wa yio gba

8 Likes 2 Shares

Re: .. by kadunasouth(m): 2:47pm On Aug 12, 2015
Lara iwulo ewe imiesu tabari omo owo ton sunkun ai nidi pato tare toko ti kodake ao lo ja ewe yi sugbon katoja ao rerinsi ao fi owo gba lemeta ao peni ewe rerinkomi ao ja ao fi se kein kein tafiwe omona ao je atare 7/9 ao tusi kein kein na ao wa fi we omo na lati ori wa isale esekese ni omona yio dake yio si ma sere daradara pelu agbara oloun eleyi daju pupo

3 Likes 2 Shares

Re: .. by OJOTUNDEFELIX(m): 5:02pm On Aug 13, 2015
Ejowo mo ni lo Atude ati Eyonu ati ajegun todaju. Ewe ama je oo

2 Likes 2 Shares

Re: .. by tundebadmus(m): 9:46pm On Aug 13, 2015
iba eyin ti eledumare fi asiri ewe ati egbo ran ibayin oo,ejo wo inje ogun ti eni yan baji owo wa ti asi mon eni ti oji owo na inje ogun ti eyen lefi mon eni na inje owa eni ti oba ni iru ogun na ti osi daju ki oba wa fisi ta?iba eyin agba

1 Like 2 Shares

(1) (2) (3) ... (15) (16) (17) (18) (19) (20) (21) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 89
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.