Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,150,468 members, 7,808,686 topics. Date: Thursday, 25 April 2024 at 03:21 PM

.. - Culture (5) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1827200 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by Nobody: 6:23pm On May 18, 2015
mhicrotee:
E jowo mo nilo iranlowo yin,ara ile mi kan nse aare(she is sick),mo de waa funra pe ti mo ba daa ina tan yio waa mu eyin ina(hot charcoal) ti mo fi dana kuu,e jowo se ko si ewu nibe(Am I safe)? e jowo e dahun Kia kia

Hmmm...ko si wahala fun yin rara.
Re: .. by Nobody: 6:25pm On May 18, 2015
scholes0:

Haa!! Imo ati asa Yoruba leke, O ta gbogbo awon iyoku yo.

Beeni...ohun to daju saka ni...Imo ati Asa Yoruba kii se egbe gbogbo won.
Re: .. by scholes0(m): 6:39pm On May 18, 2015
healthFirst:

Beeni...ohun to daju saka ni...Imo ati Asa Yoruba kii se egbe gbogbo won.

Ododo oro.
Nigba miran ti n ba beju weyin, ti mo wo gbogbo Asa, Imo ati Ise ti awon baba nla wa fi sile fun wa, mo maa n gboriyin fun won, tori ise ribiribi won ninu okan mi. O wa ku si owo wa bayii, lati ri wipe gbogbo awon ohun asa isedale ati isenbaye wonyii, ko ni di nkan Ipadanu ni ojo iwaju. Ki a ma baa kabamo ni ojo ola wipe: "Haa!! a ba ti mo, awa nba ti se itoju gbogbo nkan asa wonyii.
E ku ise ewe ati egbogi ....

2 Likes 1 Share

Re: .. by mhicrotee: 7:12pm On May 18, 2015
healthFirst:

Hmmm...ko si wahala fun yin rara.
Ah !!!!
Re: .. by scholes0(m): 7:17pm On May 18, 2015
mhicrotee:
Ah !!!!

Hhahahahaha
Se eru n ba yin ni, egbon?
Re: .. by nisai: 7:30pm On May 18, 2015
Nko ri idahun yin si ibere mi nipa Aparun ati Ap'ogun.Mo lero pe ibere mi yen koda to?
Re: .. by Nobody: 7:36pm On May 18, 2015
scholes0:

Ododo oro.
Nigba miran ti n ba beju weyin, ti mo wo gbogbo Asa, Imo ati Ise ti awon baba nla wa fi sile fun wa, mo maa n gboriyin fun won, tori ise ribiribi won ninu okan mi. O wa ku si owo wa bayii, lati ri wipe gbogbo awon ohun asa isedale ati isenbaye wonyii, ko ni di nkan Ipadanu ni ojo iwaju. Ki a ma baa kabamo ni ojo ola wipe: "Haa!! a ba ti mo, awa nba ti se itoju gbogbo nkan asa wonyii.
E ku ise ewe ati egbogi ....

Hmmm..Oro ijinle le so yi...looto alagemo ti bimo re na, ai mo jo ku sowo omo alagemo. Bi a ba ro arojinle nipa bi awon baba nla wa se se iwadi awon asa wonyi, yio je ohun iyalenu fun wa nitori wipe imon ijinle patapata ni awon Imo ati ise wonyi.

Eto abala yi je ikan lara igbese lati rii wipe awon Imo ati Ise wonyi ko di ohun igbagbe laarin awa omo Yoruba. E je ki a fi owo so owo po lati te siwaju ati lati gbe asa wa laruge ni gbogbo ibi ti a ba wa.

2 Likes 1 Share

Re: .. by Nobody: 7:37pm On May 18, 2015
nisai:
Nko ri idahun yin si ibere mi nipa Aparun ati Ap'ogun.Mo lero pe ibere mi yen koda to?

E pada sehin die, mo ti fi Oogu Apagun ranse si ibeere yin.

1 Like

Re: .. by Nobody: 7:38pm On May 18, 2015
mhicrotee:
Ah !!!!

Ko si iberu.
Re: .. by nisai: 7:40pm On May 18, 2015
healthFirst:

E pada sehin die, mo ti fi Oogu Apagun ranse si ibeere yin.
Oda oo,ese pupo.Ilakaka yin oni ja sasan.
Re: .. by scholes0(m): 7:45pm On May 18, 2015
healthFirst:

Hmmm..Oro ijinle le so yi...looto alagemo ti bimo re na, ai mo jo ku sowo omo alagemo. Bi a ba ro arojinle nipa bi awon baba nla wa se se iwadi awon asa wonyi, yio je ohun iyalenu fun wa nitori wipe imon ijinle patapata ni awon Imo ati ise wonyi.

Eto abala yi je ikan lara igbese lati rii wipe awon Imo ati Ise wonyi ko di ohun igbagbe laarin awa omo Yoruba. E je ki a fi owo so owo po lati te siwaju ati lati gbe asa wa laruge ni gbogbo ibi ti a ba wa.

E ti so oju abe ni iko!
Ejowo se e ni imo nipa Oju Iwe ero Ayelujara kankan, ti mo ti le ka nipa Asa isembaye eya Yoruba ati imo ijinle ni ekunrere?

1 Like

Re: .. by Kulrunner: 4:36am On May 19, 2015
EJO MONILO OGUN ADODUN

1 Like

Re: .. by mhicrotee: 7:44am On May 19, 2015
scholes0:

Hhahahahaha Se eru n ba yin ni, egbon?
Beeni oO
Re: .. by mhicrotee: 7:45am On May 19, 2015
healthFirst:

Ko si iberu.
Oda oO
Re: .. by orunmila76(m): 8:52am On May 19, 2015
Ara iwaju IBA!

Oogun Eyonu to daju

igbo die(Indian hemp),Irun Abe obirin die,aa lo po,aa daa sinu lofinda ti a BA feran.

Lilo re: pipara Ni aaro Monday.

Ofo re: Ojo ti omode BA mu igbo Ni igbo npaa,ojo ti agbalagba BA mu igbo Ni npaa,tomode tagba lo feran obo.

2 Likes

Re: .. by Lionhearted: 10:06am On May 19, 2015
9jacrip:

Eruwadaji!

Eku ise, Olodumare a ma ro yin l'agbara.

Ni afikun si awon eewo ti eti ko won yi:

1. A ko gbudo ni ibalopo rara ti a ba fe gun, jo tabi lo oogub (boya ni nkan osu tabi mimora).

2. Obinrin to ba nse nkan osu ko gbudo fi pwo kan eroja ogun kan kan tabi nkan ti a ba fe fi gun, ge tabi lor. Kosi tun gbudo fi owo or ara kan oogun taba ti pese tan.

Ni tootor, oogun kankan ni eewo re ti a ban ja ewe re, ti aba fe gun, jo tabi lor, ati eewo lilo naa. Boya ki eku ma fi awon eewo si ese awon oogun ti e kor si ori ibibi.

Ta ba lora loja nko bawo leyan se fe mo boya iru obinrin ti e so ti fi owo kan awon eroja na?
Re: .. by Nobody: 10:16am On May 19, 2015
orunmila76:
Ara iwaju IBA!

Oogun Eyonu to daju

igbo die(Indian hemp),Irun Abe obirin die,aa lo po,aa daa sinu lofinda ti a BA feran.

Lilo re: pipara Ni aaro Monday.

Ofo re: Ojo ti omode BA mu igbo Ni igbo npaa,ojo ti agbalagba BA mu igbo Ni npaa,tomode tagba lo feran obo.

Ki Iba Se O.

1 Like

Re: .. by Nobody: 10:30am On May 19, 2015
Kulrunner:
EJO MONILO OGUN ADODUN

Hmmm...Ta le fe lo fun? Se e mo awon inkan to ro mo Oogun Adodun? Ikini, ko dara ki a lo fun Obinrin ti a ko ni fe se iyawo nitoripe ife wa ko ni kuro lokan re laelae, ikeji, ko dara ki a lo fun iyawo ile wa nitoripe, bi o ba pe ti a ti nlo fun, yio ma din orire Obinrin na ku diedie sugbon ko ni le fi wa sile laelae.

5 Likes

Re: .. by Lionhearted: 10:58am On May 19, 2015
healthFirst:

Hmmm...Ta le fe lo fun? Se e mo awon inkan to ro mo Oogun Adodun? Ikini, ko dara ki a lo fun Obinrin ti a ko ni fe se iyawo nitoripe ife wa ko ni kuro lokan re laelae, ikeji, ko dara ki a lo fun iyawo ile wa nitoripe, bi o ba pe ti a ti nlo fun, yio ma din orire Obinrin na ku diedie sugbon ko ni le fi wa sile laelae.

Ko boju mu ke fi si ori ategun.

Btw, Ta ba lora loja nko bawo leyan se fe mo boya iru obinrin ti e so ti fi owo kan awon eroja na?

2 Likes

Re: .. by Nobody: 11:45am On May 19, 2015
Lionhearted:

Ko boju mu ke fi si ori ategun.

Btw, Ta ba lora loja nko bawo leyan se fe mo boya iru obinrin ti e so ti fi owo kan awon eroja na?

Ni opolopo igba, awon eewo yi ro mo awon Oogun ti a ba n se won lowo. Ni igba miran, won ro mo bi a ba fe ja ewe won. Awon Obinrin onisegun wa daada ti oogun won n je. A ko le so wipe gbogbo oogun ni inkan osu obinrin le baje ati wipe ona miran wa lorisirisi ti a fi le maje ki awon eewo wonyi ni agbara lori Oogun ti a ba fe se. Idi niyi ti o fi je wipe bi a ba fe se oogun, ki a sun mo awon agbalagba to ni imo kikun. Lakotan, kii se gbogbo asiri la le tu lori afefe. Abo oro laa so fo'mo 'luabi.

5 Likes

Re: .. by Nobody: 12:49pm On May 19, 2015
Lionhearted:

Ta ba lora loja nko bawo leyan se fe mo boya iru obinrin ti e so ti fi owo kan awon eroja na?

Awon l'eku l'eja o kin wa ni idi o ja ti wan ba nse nkan osu.

Sugbon odo awon arugbo leku leja do dara ju lati ra eroja nitori wan o se nkan osu mo.
Re: .. by absoluteSuccess: 2:20pm On May 19, 2015
scholes0:

Ododo oro.
Nigba miran ti n ba beju weyin, ti mo wo gbogbo Asa, Imo ati Ise ti awon baba nla wa fi sile fun wa, mo maa n gboriyin fun won, tori ise ribiribi won ninu okan mi. O wa ku si owo wa bayii, lati ri wipe gbogbo awon ohun asa isedale ati isenbaye wonyii, ko ni di nkan Ipadanu ni ojo iwaju. Ki a ma baa kabamo ni ojo ola wipe: "Haa!! a ba ti mo, awa nba ti se itoju gbogbo nkan asa wonyii.
E ku ise ewe ati egbogi ....
Oro yi laba fiwe opiliki, ti yoo fi tie sile, tio maa gbo teni-eleni: Orunmila nio baa gbo tie na, erigialo. Alagemo ti bimo re na...
Re: .. by Kulrunner: 3:15pm On May 19, 2015
Ekuse o, yio ju yin se ooo. ejo motin se exam weac elekerin re, kini mole seh ti mafi bolowo ajaga yi? ifa agbeyin ooo.
Re: .. by Nobody: 5:51pm On May 19, 2015
Kulrunner:
Ekuse o, yio ju yin se ooo.
ejo motin se exam weac elekerin re, kini mole seh ti mafi bolowo ajaga yi?
ifa agbeyin ooo.

Opolopo igba lo ma n je wipe iwa ole nipa kika iwe lasiko to ye lo ma n fa ti awon akeko ode oni fi ma n kuna idanwo. Sugbon bi o ba je wipe iwo kii se ole nipa kika iwe lasiko, ona abayo wa fun o.

1 Like

Re: .. by Nobody: 6:08pm On May 19, 2015
..

3 Likes

Re: .. by Kulrunner: 6:30pm On May 19, 2015
Edakun ebami salaye awon egbogi yen

1 Like

Re: .. by Nobody: 6:54pm On May 19, 2015
Kulrunner:
Edakun ebami salaye awon egbogi yen

E lo ba awon elewe omo ki won ta fun yin tabi ki e wa awon agba ki won se alaye fun yin.
Re: .. by Mayorz200: 6:59pm On May 19, 2015
Ejowo baba ti awon ika eniyan ba n le eniyan bo ti won den ti fe ba eniyen. Iru ajesara abi iru kini eniyan le se sara to fi je pe to ba bu yepe(sand) lu awon to n lebo ti won a fi subu lule
Re: .. by Bmark: 10:50am On May 20, 2015
healthFirst:

Hmmm...Ta le fe lo fun? Se e mo awon inkan to ro mo Oogun Adodun? Ikini, ko dara ki a lo fun Obinrin ti a ko ni fe se iyawo nitoripe ife wa ko ni kuro lokan re laelae, ikeji, ko dara ki a lo fun iyawo ile wa nitoripe, bi o ba pe ti a ti nlo fun, yio ma din orire Obinrin na ku diedie sugbon ko ni le fi wa sile laelae.

eku ishe opolo.kilo le faa ki eeyan maa laagun lapoju lona ti o ribee tele.awon dokita oyinbo ni ko si nkan ti o she oluwa leyin ayewo bee ara onitohun ko si yaa.o ti lo oogun eje titi sibe ara e man weak gan.ejoo iru kileleyi le je?awon kan ni ofa?ejoo elami loye.
Re: .. by Bmark: 10:57am On May 20, 2015
eku ishe opolo.kilo le faa ki eeyan maa laagun lapoju lona ti o ribee tele.awon dokita oyinbo ni ko si nkan ti o she oluwa leyin ayewo bee ara onitohun ko si yaa.o ti lo oogun eje titi sibe ara e man weak gan.ejoo iru kileleyi le je?awon kan ni ofa? ejoo elami loye.
Re: .. by Nobody: 12:37pm On May 20, 2015
Bmark:
eku ishe opolo.kilo le faa ki eeyan maa laagun lapoju lona ti o ribee tele.awon dokita oyinbo ni ko si nkan ti o she oluwa leyin ayewo bee ara onitohun ko si yaa.o ti lo oogun eje titi sibe ara e man weak gan.ejoo iru kileleyi le je?awon kan ni ofa?ejoo elami loye.

E je ki eni naa lo wa Egbo Akogun, ki o gun po daada ko kuna...ki o da omi osan wewe si fun mimun nigba gbogbo. O da mi loju wipe lehin igba die, yio bere si ri iyipada ninu ara.

3 Likes 1 Share

Re: .. by Nobody: 12:39pm On May 20, 2015
Mayorz200:
Ejowo baba ti awon ika eniyan ba n le eniyan bo ti won den ti fe ba eniyen. Iru ajesara abi iru kini eniyan le se sara to fi je pe to ba bu yepe(sand) lu awon to n lebo ti won a fi subu lule

Asubusire tabi Aluwo oni yepe ni a le lo...Bi Subusere ba wa lara ti awon eeyan nle wa, won ko ni le le wa ba, bi o ba ku die ki won mu wa, won yio ma subu dide, subu dide ni. Bi a ba ni Oruka Aluwo oni yepe lowo, bi won ba n le wa, ao fi owo yen bu yepe, ao da lu gbogbo won, enikeni ti yepe ba ba, yio subu. sugbon ko se fi sile lori afefe nitori awon eeyan ika.

3 Likes 2 Shares

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 41
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.