Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,150,305 members, 7,808,034 topics. Date: Thursday, 25 April 2024 at 04:48 AM

.. - Culture (6) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1827135 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by scholes0(m): 1:22pm On May 20, 2015
Bmark:
eku ishe opolo.kilo le faa ki eeyan maa laagun lapoju lona ti o ribee tele.awon dokita oyinbo ni ko si nkan ti o she oluwa leyin ayewo bee ara onitohun ko si yaa.o ti lo oogun eje titi sibe ara e man weak gan.ejoo iru kileleyi le je?awon kan ni ofa?ejoo elami loye.

Alaye aisan ti e se yii jo eleyii ti awon elede geesi maa n pe ni "Anaemia", ti o maa n waye ti eje eniyan ba dinku ninu seeli eje funfun. E je ki eni yen pada lo si odo dokita onisegun oyinbo fun ayewo ara titun. Imoran mi niyen.
Ki alaare naa si tun maa fi oogun ibile tele iwosan re naa leyin.
Re: .. by Bmark: 6:17pm On May 20, 2015
healthFirst:

E je ki eni naa lo wa Egbo Akogun, ki o gun po daada ko kuna...ki o da omi osan wewe si fun mimun nigba gbogbo. O da mi loju wipe lehin igba die, yio bere si ri iyipada ninu ara.
ese gan.nkan ti mo tun fe moniwipe shey ofa ni oogun yen shishe fun ni tori ati lo ogun oyinbo titi ti ko shishe rara

1 Like

Re: .. by Nobody: 6:21pm On May 20, 2015
Bmark:
ese gan.nkan ti mo tun fe moniwipe shey ofa ni oogun yen shishe fun ni tori ati lo ogun oyinbo titi ti ko shishe rara

E se alaye lekun rere bi aisan na se n se eni na.
Re: .. by Bmark: 8:04pm On May 20, 2015
healthFirst:

E se alaye lekun rere bi aisan na se n se eni na.
gbogbo ara e weak,,oti lo oogun eje titi ko ri iyipada ojo ti aisan yii ma a bere o ni odab ti won ju nkan lu oun laya lojiji.lati ojo naa loti bere to ba ti rin irin die a maa laaguin gidigan.aa ni okan re oun ni.
Re: .. by sammyjay76(m): 8:13pm On May 20, 2015
Mo ki yin o, eku ise igbala, Asejere le o ma se o. Mo ni ibere fun aisan ti awon oloyinbo geesi npe ni SICKLE CELL ANEMIA, ejowo ki ni ona abayo si ati dekun iru fe aisan yi? Nje oni oogun bi? Ewe ma a je ooooo...
Re: .. by sammyjay76(m): 8:16pm On May 20, 2015
Mo ki yin o, eku ise igbala, Asejere le o ma se o. Mo ni ibere fun aisan ti awon oloyinbo geesi npe ni SICKLE CELL ANEMIA, ejowo ki ni ona abayo si ati dekun iru fe aisan yi? Nje oni oogun bi? Ewe ma a je ooooo...

2 Likes

Re: .. by Nobody: 8:28pm On May 20, 2015
sammyjay76:

Mo ki yin o, eku ise igbala, Asejere le o ma se o. Mo ni ibere fun aisan ti awon oloyinbo geesi npe ni SICKLE CELL ANEMIA, ejowo ki ni ona abayo si ati dekun iru fe aisan yi? Nje oni oogun bi? Ewe ma a je ooooo...

Ibeere ti o dara ni e bere. KI a maa reti baba fun idahun.

1 Like

Re: .. by Kulrunner: 11:31pm On May 20, 2015
ejo kini ale lo fun eni ti koma n se nkan osu lai loyun.

1 Like

Re: .. by Mayorz200: 6:25am On May 21, 2015
Ejowo baba---se mo le salaye funyin ni bokele idi ti mo fe ti oniyepe subu. Ejowo baba
Re: .. by scholes0(m): 8:07am On May 21, 2015
Mayorz200:
Pls baba---se mo le salaye funyin ni (private) idi ti month fi need ti oniyepe subu. Ejowo baba

E fe so fun wa wipe e mo awon oro Yoruba fun:

Pls: ( E jòwó)
Private: (Ìkòkò tàbí Gbònkélé)
Month (Osù)
need: (Nílò)

1 Like

Re: .. by Lionhearted: 8:15am On May 21, 2015
?
Re: .. by scholes0(m): 8:19am On May 21, 2015
Lionhearted:
Kila le lo ti inu imun bawu ati ti eemi eni na ba n run gan? Igbami ran eemi eni na a ma run bi buredi.

E ni suuru die, e je ki baba Onisegun ibile wa o pada de, o da mi loju wipe won ni egbogi pato, fun isoro ti eni yii n dojuko.

1 Like

Re: .. by bolorunfem(f): 12:26pm On May 21, 2015
Baba, e ku ise iwosan, Olodumare a pin yin ni ere o. Ase. E jowo e fun wa ni oogun iju olojo-pipe, oogun eda ati aran latanlatan. E seun mo dupe.
Re: .. by Nobody: 2:35pm On May 21, 2015
E joo...mo lo irin ajo ranpe ni o. Bi n ba pada sile lola, ng o dahun gbogbo ibeere yin.
Re: .. by Nobody: 4:08pm On May 21, 2015
Bmark:
gbogbo ara e weak,,oti lo oogun eje titi ko ri iyipada ojo ti aisan yii ma a bere o ni odab ti won ju nkan lu oun laya lojiji.lati ojo naa loti bere to ba ti rin irin die a maa laaguin gidigan.aa ni okan re oun ni.

E je ki eni na pada lo si Ile Iwosan alayewo, ki won se ayewo Okan eni na..Alaye yin jo ti eni to ni aisan Okan oni pajawiri...bi o se ma n bere niyen. Sugbon lehin ayewo, bi awon dokita ba tun so wipe awon o ri inkankan, ki e pada fun wa labo.
Re: .. by Nobody: 4:46pm On May 21, 2015
..

2 Likes

Re: .. by Nobody: 5:00pm On May 21, 2015
Mayorz200:
Ejowo baba---se mo le salaye funyin ni bokele idi ti mo fe ti oniyepe subu. Ejowo baba

O ya, e se alaye ni bonkele.
Re: .. by sammyjay76(m): 8:07pm On May 21, 2015
healthFirst:

Oogun re niyi:

Eso Rere, ao lopo, ao ma fi mu eko tutu...lilore: Eegun itan adiye ni yio ma fi fa mu.

Oogun yi kere sugbon atakoro wonu ado ni o. O daju.

Eseun fun dahun yi....... Ejowo se dan dan ni o gbodo je. Pe eegun itan adie ni won yio ma fi mu ni? Se a o toju eegun adie naa ti a o ma fi mu ni igba de igba ni abi ekan soso naa nbi yio fi mu eko abi, ao ma pa adie ni gbogbo igba ti a ba fe fi oogun yi mu eko ni? E dakun e se alaye naa daradara fun wa.

1 Like

Re: .. by Mayorz200: 7:07am On May 22, 2015
.
Re: .. by Nobody: 9:48am On May 22, 2015
sammyjay76:

Eseun fun dahun yi....... Ejowo se dan dan ni o gbodo je. Pe eegun itan adie ni won yio ma fi mu ni? Se a o toju eegun adie naa ti a o ma fi mu ni igba de igba ni abi ekan soso naa nbi yio fi mu eko abi, ao ma pa adie ni gbogbo igba ti a ba fe fi oogun yi mu eko ni? E dakun e se alaye naa daradara fun wa.

Rara o eegun itan kan ti e ba ti fi bere na leo maa lo

1 Like

Re: .. by Nobody: 9:50am On May 22, 2015
Mayorz200:
E jowo baba, bawo ni mo se le salaye funyin ni bonkele___nitori ko si numba yin nibi yi. Ati wipe mimon boya month le peyin sori ago abi boya ki nfi ago temi sile te ba fe fi sile fun opo eniyan(08060131624)____e seun gan

E fi ranse si binaryteck@gmail.com
Re: .. by Nobody: 10:00am On May 22, 2015
..

1 Like

Re: .. by Nobody: 12:57pm On May 22, 2015
..

2 Likes

Re: .. by Lionhearted: 1:29pm On May 22, 2015
healthFirst:

E lo se ayewo lodo awon dokita ki e wa fun wa labo.

Ki eni naa lo Oogun yi ki o to lo fun ayewo

GBOGBO NISE (ANTI BiOtIC)
Egungun ara iganna (wall) ao yo die ni ibe ao ra atare aobo epo ara re ao wa jo epo yen papo mo egungun ara iganna ti abajo tan ao fi sin gbere kokan si orike rike arawa eyi to ba seku ao fi te ifa ejiogbe ao wasope gbogbo arunkarun ati owo kowo tin be lara mi oso lofi simi lara ni,aje ni eji ogbe bami gbe gbogbo re kuro ao wada si epo pupa ao mala

Eni na ti se ayewo. Esi re ni Sinusitis ati systemic yeast infection.

2 Likes

Re: .. by Nobody: 2:27pm On May 22, 2015
all dis igbo fools self
Re: .. by Nobody: 2:32pm On May 22, 2015
Lionhearted:

Eni na ti se ayewo. Esi re ni Sinusitis ati systemic yeast infection.

E je ki eni na lo Gbogbonise yen...ng o tun fi omiran sita fun yin.
Re: .. by bolorunfem(f): 4:23pm On May 22, 2015
healthFirst:

OOGUN ARAN
Iseta, eku-asin, egbo lara, egbo botuje, egbo osan-igu, aidan, eru ao gun won po mose dudu. Odi wiwe lalale.

TI EDA BA DAA OBINRIN LAAMU TO TI PE
Omi osan wewe, ao bu ose dudu si inu re, ao tun fi kaun die si, OBINRIN na yio maa mu die die.

TI IJU BA NDA OBINRIN LAAMU¤
Bara ao be, kaun bulala, paran pupa, paran funfun, ewe taba tutu, ao gbogbo sinu igo kan, ao da oti(HOT) si, OBINRIN naa yio ma mu

Awon Oogun wonyi daju.

Mo dupe, e seun o, baba. Ewe a maa je o. Olorun a se gbogbo ise yin ni asepe.

3 Likes

Re: .. by Nobody: 6:12pm On May 22, 2015
..

2 Likes

Re: .. by Nobody: 6:47pm On May 22, 2015
healthFirst:

Oogun re niyi:

Eso Rere, ao lopo, ao ma fi mu eko tutu...lilore: Eegun itan adiye ni yio ma fi fa mu.

Oogun yi kere sugbon atakoro wonu ado ni o. O daju.

E seun gan Baba fun idahun yi. Bi otileje pe ko si ogun oyinbo fun arun yi, Ogun ibile wa fun foniku-foladide (sickle cell).

2 Likes

Re: .. by Nobody: 7:15pm On May 22, 2015
walexy30:

E seun gan Baba fun idahun yi. Bi otileje pe ko si ogun oyinbo fun arun yi, Ogun ibile wa fun foniku-foladide (sickle cell).

beeni
Re: .. by Nobody: 7:27pm On May 22, 2015
walexy30:

E seun gan Baba fun idahun yi. Bi otileje pe ko si ogun oyinbo fun arun yi, Ogun ibile wa fun foniku-foladide (sickle cell).

Oogun re wa daada sugbon mo fi eleyi sita nitoripe a ti lo ri to sise daada.

1 Like

Re: .. by talktofemi: 4:46am On May 23, 2015
Eku ise o,
Nje ogun wa fun eniti ki gboran daadaa? Eniyan mi kan ni lo re,

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (99) (Reply)

Viewing this topic: 2 guest(s)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 38
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.