Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,150,430 members, 7,808,537 topics. Date: Thursday, 25 April 2024 at 01:12 PM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (6) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (197461 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / Do You Speak Yoruba? / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (100) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluespice(f): 4:51pm On Feb 09, 2009
ahn ahn
iru ibeere oshi le wan bere lowo oko mi?

ke sho ra yin oh
angry angry angry
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 4:56pm On Feb 09, 2009
farotika,

O se lopolopo,

Osan ti o ri gbajumo ti ko pon, Eiye ori igi lo ma fi mu. ni oro Toyosi, sugbon emi gbagbo pe omode lon see.

Goodass,

O kare lai, Ogunna gbongbo tin dato lenu igbin ni o je. Ati wipe ogidi omo Karo oojire ni o.

Sadankata re!!!!

Oya farotika. Kini awon Osu ni ede Yoruba (January-December)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluespice(f): 5:01pm On Feb 09, 2009
boda dayo mo fe
dahun ibeere yen

Sere- January

Erele- February

Erena- March

Ibe- April

Ebibi- May

Okudu- June

Agemo- July

Ogun- August

Owewe- September

Owara- October

Beelu- November

Ope- December
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 7:54pm On Feb 09, 2009
Bluespice,

Ojoro lo se.

Toyosi lo ko e.

Bluespice, Kini apere Fwelii aranmupe ati airanmupe?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 8:20pm On Feb 09, 2009
farotika:

Kamoteesi,

Ki lo de ti o fi nwa agbo jedi kiri, se oko re o le daadaa mo ni So fun mi kin ba le ba e beere lowo opele nkan ti a le se sii cool

argent:

Chamo, i bo lo wa, wa jewo funwa oh. Se oko o le mo nitoto?

emi Chamo, ado obinrin bi eni nlagi, to n gbona feli feli bi omi gbigbona.
Eni koo o mo, eni moo o ko, ab'obinrin sun mi eni ti o ri obinrin fun ojo mewa.
Oko mi fe le pa ni.

Agbo jedi jedi ma ni mon wa o. Mo ti je ijekuje lati bi ojo mefa seyin. Idi mi ti fe yobo o. Ejo eba mi wa agbo jedi to ki daada. Ese modupe.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluespice(f): 9:03pm On Feb 09, 2009
dayo
o dun mi tooto pe o so pe enikan lo ko mi cry cry cry
sebi o ti man tele toyosi kakri
o de bere lowo e boya oti ba mi soro ri? cry
igba ti mo wa ni pahmary school ni won ko mi ni orin yen
ati orin days of the week na cool

ko s'aburu sad

si nkan te bere
ema ba mi se nkan,
yooba mi o se to awon
oro te so
so ema bami
bere nkan mi
i dont fully understand the question
woudnt wanna embarass myself embarassed
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 9:05pm On Feb 09, 2009
Kilon whazzup ni ahin? tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 9:52pm On Feb 09, 2009
Bluespice,

Mo n bere nipa Faweli (vowels) Yoruba

Faweli Aranmupe- Nasal vowels

Se o le fi amin si ori oro yi

Ogbontarigi ----------
Alaafia
Olopa
e.g Farotika (mi-mi-do-do) Dayokanu (re-do-mi-re)

Chamoteesi,
Paga!!! Iwo ni won pe ni Okobo!!! okobo o feran iyawo, oloriburuku ko feran Olorire cheesy cheesy cheesy cheesy cheesy
O ye ki o fihan iyawo farotika pe Okunrin to a danto ni e. Ti o ba fun Toyin iyawo farotika ni Bowleg
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 10:12pm On Feb 09, 2009
E kale ni ibi yi o. Se dada le wa?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 10:26pm On Feb 09, 2009
Daada ni a wa o iwo na nko? Se daada lo wa?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 1:19am On Feb 10, 2009
dayokanu:

Chamoteesi,
Paga!!! Iwo ni won pe ni [b]Oko[/b]bo!!! okobo o feran iyawo, oloriburuku ko feran Olorire cheesy cheesy cheesy cheesy cheesy
O ye ki o fihan iyawo farotika pe Okunrin to a danto ni e. Ti o ba fun Toyin iyawo farotika ni Bowleg

e feran oro oko sha. Oko o ni won yi o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 1:27am On Feb 10, 2009
Chamoteesi,

Gbe enu re soun jor, Alagabagebe. Olorun ko ni gba oko lowo ni Ko si ni je ki obo won mi

Amin ase!!!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by MrCrackles(m): 1:31am On Feb 10, 2009
eyin thread derailers tun ti de? angry
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 1:37am On Feb 10, 2009
MrCrackles:

eyin thread derailers tun ti de? angry

ti o ba tun so geesi ni ibi bayi, o ma je egba '50 strokes'
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 1:44am On Feb 10, 2009
brash,
Se iwo ko gbo ede Yoruba ni abi ki lon je railer?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 9:46am On Feb 10, 2009
dayokanu:

farotika,

O se lopolopo,

Osan ti o ri gbajumo ti ko pon, Eiye ori igi lo ma fi mu. ni oro Toyosi, sugbon emi gbagbo pe omode lon see.

Goodass,

O kare lai, Ogunna gbongbo tin dato lenu igbin ni o je. Ati wipe ogidi omo Karo oojire ni o.

Sadankata re!!!!

Oya farotika. Kini awon Osu ni ede Yoruba (January-December)

Sipaisi alawo aro ti dahun ibeere re, o si dahun daadaa wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 9:50am On Feb 10, 2009
dayokanu:

Bluespice,

Ojoro lo se.

Toyosi lo ko e.

Bluespice, Kini apere Fwelii aranmupe ati airanmupe?

Faweli aranmupe ni: an on en in un undecided

Faweli airanmupe: a e e i o o u cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 9:52am On Feb 10, 2009
chamotex:

emi Chamo, ado obinrin bi eni nlagi, to n gbona feli feli bi omi gbigbona.
Eni koo o mo, eni moo o ko, ab'obinrin sun mi eni ti o ri obinrin fun ojo mewa.
Oko mi fe le pa ni.

Agbo jedi jedi ma ni mon wa o. Mo ti je ijekuje lati bi ojo mefa seyin. Idi mi ti fe yobo o. Ejo eba mi wa agbo jedi to ki daada. Ese modupe.

Kamoteesi, enu lo ni bi tajakara tongue oko e o le gberi cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 10:00am On Feb 10, 2009
dayokanu:

Bluespice,

Mo n bere nipa Faweli (vowels) Yoruba

Faweli Aranmupe- Nasal vowels

Se o le fi amin si ori oro yi

Ogbontarigi ----------
Alaafia
Olopa
e.g Farotika (mi-mi-do-do) Dayokanu (re-do-mi-re)

Chamoteesi,
Paga!!! Iwo ni won pe ni Okobo!!! okobo o feran iyawo, oloriburuku ko feran Olorire cheesy cheesy cheesy cheesy cheesy
O ye ki o fihan iyawo farotika pe Okunrin to a danto ni e. Ti o ba fun Toyin iyawo farotika ni Bowleg

Ogbontarigi ------- do mi do re do do

Alaafia -------------- do mi mi do

Olopa -------------- re mi domi.

E patewo fun mi jooooooooooooooooooo grin cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 10:04am On Feb 10, 2009
dayokanu:

Chamoteesi,

Gbe enu re soun jor, Alagabagebe. Olorun ko ni gba oko lowo ni Ko si ni je ki obo won mi

Amin ase!!!

Amin ase edumare, ati emi na o wink cheesy grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 10:14am On Feb 10, 2009
dayokanu:

Bluespice,

Mo n bere nipa Faweli (vowels) Yoruba

Faweli Aranmupe- Nasal vowels

Se o le fi amin si ori oro yi

Ogbontarigi ----------
Alaafia
Olopa
e.g Farotika (mi-mi-do-do) Dayokanu (re-do-mi-re)

Chamoteesi,
Paga!!! Iwo ni won pe ni Okobo!!! okobo o feran iyawo, oloriburuku ko feran Olorire cheesy cheesy cheesy cheesy cheesy
O ye ki o fihan iyawo farotika pe Okunrin to a danto ni e. Ti o ba fun Toyin iyawo farotika ni Bowleg

dayo, dayo, dayo, eemelo ni mo pe o, O un tona wo oju ekun mi o, o si fe maa fi omi ata boju. O ye ki o mo pe emi o kii fi iyawo mi sere rara angry

Ikilo pataki ni yi: ti Kamoteesi ba fi owo kan toyin, oko e ba pare patapata ni angry
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 5:29pm On Feb 10, 2009
farotika:

dayo, dayo, dayo, eemelo ni mo pe o, O un tona wo oju ekun mi o, o si fe maa fi omi ata boju. O ye ki o mo pe emi o kii fi iyawo mi sere rara angry

Ikilo pataki ni yi: ti Kamoteesi ba fi owo kan toyin, oko e ba pare patapata ni angry

farotika:
Se o ni e-magun ni tabi e-tesho? ma dan awon eniyan wo o.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 6:32pm On Feb 10, 2009
Farotika,

Oya se iwo le sun ijala ode?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluespice(f): 8:30pm On Feb 10, 2009
Se o le fi amin si ori oro yi

Ogbontarigi ---------- do mi re mi mi
Alaafia                       do mi re do
Olopa                        re mi domi
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 9:04pm On Feb 10, 2009
Bluespice,
Odo ni o gba o. O shi jina jina
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluespice(f): 10:26pm On Feb 10, 2009
tooto sha? embarassed embarassed embarassed

ko si problem
kini correct pronounciation won? tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 11:25pm On Feb 10, 2009
Ogbontarigi ---------- do do re do do
Alaafia                       do mi mi do
Olopa                        re mi do mi
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 11:26pm On Feb 10, 2009
Hehehe @ Bluspice o!!! cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 11:34pm On Feb 10, 2009
toyin, toyin, toyin,

Igba melo ni mo pe o, o si nse mi, o nse mi o

Kini mo se? embarassed lipsrsealed
se iwo nan oori wipe Bro Dayo lo n tele mi kakiri? shocked

Chamoteesi,
Paga!!! Iwo ni won pe ni Okobo!!! okobo o feran iyawo, oloriburuku ko feran Olorire
O ye ki o fihan iyawo farotika pe Okunrin to a danto ni e. Ti o ba fun Toyin [/b]iyawo farotika ni Bowleg
farotika:

dayo, dayo, dayo, eemelo ni mo pe o, O un tona wo oju ekun mi o, o si fe maa fi omi ata boju. O ye ki o mo pe emi o kii fi iyawo mi sere rara angry

Ikilo pataki ni yi: ti Kamoteesi ba fi owo kan [b]toyin
, oko e ba pare patapata ni angry

I'm begining to think there's another toyin on nl shocked Make una take it slow na, my name is sacred
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 1:49am On Feb 11, 2009
I'm begining to think there's another toyin on nl Make una take it slow na, my name is sacred

Kini itumo gbogbo oun ti o ko sibiyi? Kini on je sakara she ilu agidigbo ni on so nipa re?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 1:53am On Feb 11, 2009
dayokanu:

Kini itumo gbogbo oun ti o ko sibiyi? Kini on je sakara she ilu agidigbo ni on so nipa re?
ahhh Uncle Dayo, I missed your wahala o.
How u dey? smiley

Chaecks to see if TOYOSI is around tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 1:56am On Feb 11, 2009
O kare omo daada. Ba mi wa Toyosi mi lo jare.

Ife re nmu mi lokab gidigan

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (100)

Ònkà Yorùbá: Numbers And Numbering System In Yorùbá / 20 Popular Yoruba Charms And Their Uses(With Direct English Translations) / Benin Art And Architecture

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 33
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.