Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,149,956 members, 7,806,767 topics. Date: Tuesday, 23 April 2024 at 11:05 PM

Awon Itan Wo Ni E Ranti Nigba Kekere Yin??? - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Awon Itan Wo Ni E Ranti Nigba Kekere Yin??? (3809 Views)

#yorubanews Iru Idajọ Wo Ni Ile-ẹjọ Fẹ Da Fun Seun Egbegbe / [Audio] "Bayii Ni E Se Le Se Awari Ebun Yin": Alaye Lati Enu Olayemi Oniroyin / Ogun Awon Bàba Wa (2) (3) (4)

(1) (Reply) (Go Down)

Awon Itan Wo Ni E Ranti Nigba Kekere Yin??? by SisiGbeborun(f): 3:40pm On Jul 15, 2015
Itan je ohun to se pataki lati igba awon baba baba wa, le yi to je pe won tun fi le awa odo isin yi l'owo. E je ki a wo itan "Akara Oogun" ninu iwe "Ogboju Ode Ninu Igbo Irunmole". Itan yi je okan pataki ninu awon itan isembaye ti o is je wipe sasa ni ogidi omo Yoruba ti ko ti ni gbo ri.

O daa, ewo ni eyin ranti E je ka sare se ere opolo yen ni pa pa pa....

1 Like

Re: Awon Itan Wo Ni E Ranti Nigba Kekere Yin??? by ahmedtijani(m): 3:47pm On Jul 15, 2015
[color=#000099][/color] Idamu paadi
Re: Awon Itan Wo Ni E Ranti Nigba Kekere Yin??? by Wealthyone: 3:48pm On Jul 15, 2015
Mo ka itan lopolopo ni igba timo wa ni ile iwe girama. Awon eyi ti aka ni yara ikawe ati awon eyi ti baba mi ma nra fun akagbadun. Iwe D.O Fagunwa ama po, aasi tun ma dunka. Inumi dun pupo pee mo mo yooba ko, mo si mooka daada.

1. Ireke onibudo
2. Eru Obodo
3. Ogbuju Ode ninu igbo Olodumare
4. Adiitu.........
5. Idaamu Mikailu ati Paadi
6. Ati awon mi ti mio ranti mo
Re: Awon Itan Wo Ni E Ranti Nigba Kekere Yin??? by omitooguns(m): 3:52pm On Jul 15, 2015
Sisigbeborun, oruko e yi le kuu oo. Oda na...emi ko ka itan ni ri.

Die ninu eyi ti moka ni "Sisi jet'we"..."Tijapa tiroko"..."Ruutu abokoku" ati be be lo...oya e sa wo...ki ni itan ti o da ru ko ye da le lori.
Re: Awon Itan Wo Ni E Ranti Nigba Kekere Yin??? by SisiGbeborun(f): 4:41pm On Jul 15, 2015
omitooguns:
Sisigbeborun, oruko e yi le kuu oo. Oda na...emi ko ka itan ni ri.

Die ninu eyi ti moka ni "Sisi jet'we"..."Tijapa tiroko"..."Ruutu abokoku" ati be be lo...oya e sa wo...ki ni itan ti o da ru ko ye da le lori.


Itan yen da le ori awon akoni meje ti won won lo si'nu igbo irunmole. L'ara won ni Akara oogun, Imodoye, Olohun Iyo, Kako onikumo ekun, ati bee bee lo. Ibi ti mo feran ju ninu iwe yi ni ibi ti won ti so wipe "Awa ti a je akoni je meje"....hehehe

1 Like

Re: Awon Itan Wo Ni E Ranti Nigba Kekere Yin??? by omitooguns(m): 4:56pm On Jul 15, 2015
SisiGbeborun:


"Awa ti a je akoni je meje"....hehehe

se o si ni iwe yin?...ma fe lati ka won...mo ti n ka iwe ede oyinbo poju...ati ede faranse.
Re: Awon Itan Wo Ni E Ranti Nigba Kekere Yin??? by scholes0(m): 7:04pm On Jul 15, 2015
Wealthyone:
Mo ka itan lopolopo ni igba timo wa ni ile iwe girama. Awon eyi ti aka ni yara ikawe ati awon eyi ti baba mi ma nra fun akagbadun. Iwe D.O Fagunwa ama po, aasi tun ma dunka. Inumi dun pupo pee mo mo yooba ko, mo si mooka daada.

1. Ireke onibudo
2. Eru Obodo
3. Ogbuju Ode ninu igbo Olodumare
4. Adiitu.........
5. Idaamu Mikailu ati Paadi
6. Ati awon mi ti mio ranti mo

Emi naa ka Igbo Olodumare ati Aditu Olodumare.
mo ka Ireke onibudo ati beee bee lo

(1) (Reply)

Ogun Omo Ise Tabi Omo Ile Iwe / Is This Not AROCHUKWU KINGS? Who Is OGANE To The East Of Bini? / Tell Me About Okpella People Of Edo State.

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 13
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.