Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,147,873 members, 7,798,930 topics. Date: Tuesday, 16 April 2024 at 12:29 PM

Iwulo Oyin Fun Alafia Arawa - Health - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Health / Iwulo Oyin Fun Alafia Arawa (12732 Views)

Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju / Iwulo Oyin Fun Alafia Arawa (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Iwulo Oyin Fun Alafia Arawa by kadunasouth(m): 10:31am On Jul 22, 2015
ARA RIRO BI(AROMOLEEGUN) Oyin igan,omi osan wewe todaju eyokan,osan mimu kan,ki a fun omi won,ogede omini kan ao po gbogbo re papo ki aro sinu igo,bi aba se fe ni awon osan yo se po to,ki ama mu ni eemeta lojojumo. ORIKE RIKE ARA RIRO Oyin igan,sibi nla meji ki a se ewe igi iyeye,eyi ti aba fe mun ni ao bu sibi meji oyin si kobu kekere kan lojoojumo. TI ENIYAN KOBA RI ITO TO Oyin igan igo kan,Habat Saudah lilo agolo miliki kan,ororo Alubosa Ayyu ko ma po ju,Hulba lilo ekun agolo tomato kan omi niwonba ni ao fi se gbogbo re papo lori ina fun asiko die ti oba ti ho fun asiko die a o so ki ama mu ni araro ki ato jehun. AISAN ONIGBA MEJI Oyin igan ilaji koobu,ororo Alubosa ayyu,ao po mora won ao ma mu lemeji lojumo fun ose meji. TI ENIYAN KO BA RI IGBE YA Oyin igan sibi kan pelu wara maalu,ao koko lo sibi kan ororo Alubosa ayyu,ki ato mun mejeeji ti apo papo ye fun bi ose kan. OBINRIN TI ARA MAN NI NIGBATI OYUN BA SESE DURO. Ni apejuwe bi aile jehun daada tabi efori ,tabi ki oma bi,tabi irewesi. Ki iru eni bee maa mun sibi meji oyin igan lale koto sun ati ni idaji koto jehun rara,tabi emeta ojumo fun eyi toba le die. ENITI ETI BANDUN Oyin igan ojuda ao se omi ti aba fe lo ti omi yi ba tutu die ao da oyin sinu re pelu iyo die ao ma kan si eti na ni ale ki ato sun. AISAN OLOJO PIPE Oyin igan to daju,halititi lilo,oro saitun(ororo olifu).Habat saudah,lilo,ati ororo hayyu,ao po gbogbo re po eni na yoo ma mun leemeji ojumo. AISAN ONA OFUN Ki ofun ma gbe tabi eyi to ba tun jo bee:-Oyin igan die iyo die osan wewe sibi meji ao mafi fo ona ofun bi eemeta lojumo. KI OMODE MA SE AISAN LERALERA. Oyin igan sibi kan osan wewe idaji,beeni orombo idaji pupa ti inu eyin(york)ki apo papo fun omo na,yio mun lekan ni ojoojumo Olohun yoo fun omo na ni alaafia. ENITI KOLEETO DAADA Eniti inira yi banyo lenu ni asiko ito oyin igan sibi kan lemeta ojumo. EJE RURU Oyin igan sibi kan leyin onje fun arin bi osu kan gbako,ki otun wa omi kariat ti won lo ki oma mu fun ose kan. ENI TI IGBOYA BANDALAMU Oyin igan sibi nla,meji,ki otoju oje igi agba lumo bi koobu kan ki o se ti oba se ki oda oyin yen mo to ba tutu,ki o ma mu bee fun ojo meta. OHUN TI KOLA LATI SORO,TABI ENITI KOLE SORO DAADA. Bu oyin igan sinu abo idana to bamo ninu ki ogbe kana ti oba ti ki ola enu si oru re ki oma faa sinu ona ofun bi emerin lojumo titi oun re yoo fi la. AMURUN(EJE IMU) Oyin igan deede ilaji koobu kekere pelu omi osan wewe sibi meta po mora won ki oma mu sibi meji lemeta ojumo fun ose kan OJU DIDUN Oyin igan ki apo mo Alubosa lilo ki asi ma kan si oju na,osi tun le po oyin mon tiro to badara ki oma kan si oju na. TI IRUN BANJA Oyin igan,ororo olifu(saetun),ao po mejeeji papo,ki ogbe kana ki ofi gbona die,ki ofi pa irun leyin bi ogun iseju ki olofo irun naa pelu omi to gbona die ni ekan losu. AISAN TI MAN BA KINDINRIN JA Atogbe:-Oyin igan sibi kan leemeta lojumo fun osu meta.i

OBINRIN TI INU MANRUN LASIKO INKAN OSUN Iru obinrin bayi yoo tima mu oyin igan ti oje ojulowo ti ki se adamodi oyin,ni igba ti asiko inkan osu re bati ku die yio ma lo sibi meji ni emeta ni ojumo titi ti yio fi pari inkan osu re KI INU MA KUN LAI NIDI
Ou can contact me for other spritual related issue

09090305775

3 Likes

Re: Iwulo Oyin Fun Alafia Arawa by kadunasouth(m): 2:15am On Jul 28, 2015
Oyin yi bakana owulo pupo ki amaje ki oyin wan ninu ilewa ile ti oyin gidi bawa osi koni wo ile na lara ase ti oloun fun oyin ni

2 Likes

(1) (Reply)

COVID-19 Update For January 2 2021 In Nigeria / South African Doctors Earn 3 Times More Than Those In Nigeria & Kenya / COVID-19 Update For October 16 2020 In Nigeria - (3,479 Tested)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 20
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.