Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,143,264 members, 7,780,593 topics. Date: Thursday, 28 March 2024 at 05:08 PM

Ogun Awon Bàba Wa - Culture (5) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Ogun Awon Bàba Wa (325214 Views)

Asiri Aiye Siwa Lowo Awon Agba Woli / Asiri Ijinle Awon Woli Lailai / Asiri Ogun Awon Baba Wa (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (Reply) (Go Down)

Re: Ogun Awon Bàba Wa by Tayo1one: 6:36pm On May 27, 2016
E Jo, ewe WO ni won npe ni EWE OGUNBO(ewe oko) ati pe nibo Lara ireke ni won npe ni Ade ori ireke. E Jo, inu mi ma dun gon.. ti nba ri idahun. a tun da ti n ba le ri aworan Ade ori ireke.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 1:25am On Jun 07, 2016
Osole:olongbo dudu,eyele dudu, eye kowe kan,obi abata oloju merin,ao ge obi na si 200,ewe igi ose 200,kaka iru 200,igba ademo nla kan,ao ko Gbogbo nkan yi sinu igba na,ao gbe sinu agbada ,ao jo ao ro sinu sere,ao mafi oti lo,tabi ka ma fi fo eko mu,odaju wa mari owo nla gba Lori isere.

4 Likes 1 Share

Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 1:31am On Jun 07, 2016
Ogun ti Obinrin fi ma gba owo lowo OKUNRIN, owo eyo kudi kan,OBINRIN na yi o fi si oju ara re mojumo,yi o yo laro ojo keji yio lo pelu ikode kan, 08135072961,fun bose pari Ise yi tori o lagbara mi le ko tan si ibi,tori arudale ni ti oko tipa,ni Awon OKUNRIN a ma ru owo nla owo won dale fun OBINRIN na,odaju saka.

1 Like

Re: Ogun Awon Bàba Wa by KolaBELIEVE: 7:29pm On Jul 25, 2016
ayokomi1010:
ori eye Awo ni ti a tun peni etu
e jowo baba Ayokomi graduate ni mi mo nilo ogun lati rise gidi. ati ogun arisiki to joju iba. ooooooo ke pe ooo ama ju yin se oooo
Re: Ogun Awon Bàba Wa by KolaBELIEVE: 7:54pm On Jul 25, 2016
ALIUDAVID:
OGUN ISE WIWA
Oga gbibe,
Ile eiye aro,
Ewe igi ti eye aro ko ile si,
Gbongbo igi ti eye aro ko ile si,
Odindin atare kan, ao jo gbogbo re po ao wa da si inu ado ijamo,
Ofo re: ire loni ki e fi ire owo wa mi ri, aro loni ki ire owo ro mo mi, aki fi alagemo si le ki atun bo orisa mi ran, atare kin kere ko ma le gba inu oko...
Ale LO pelu otin,eko tutu.. Odaju o
IBA EYIN AGBAGBA IBA EYIN TO NI AYE.
ejo baba oruko miran wo ni eiye aro n je?
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Nobody: 10:42pm On Jul 25, 2016
ayokomi1010:
moki gbogbo omo Yoruba mosi ikanni yi fun afani opolopo omo odudua fun Ogun nla Awon baba wa ni ile karo ojire ti o ti sonu ti Ati sodi ohun igbagbe ti awon alawo funfun si fi etan ati owo gba kuro lowo wa,esin o sope ka ma se ASA ibile wa o,omo Yoruba eje karonu o,Ikilo mi o fi aiye gba enikeni lori ikanni yi fun oro ti koye omo Yoruba tabi ebu iwa ibaje fifi ago ibanisoro sori afefe,atipe oun gbogbo tabafe ko si ori afefe komu ogbon dani kosi wulo fun Awon eniyan ki o si ma pawonlara odua agbe wa o
0

Aboru boye o, eku ise o, Oduduwa agbe wa o
Ejowo kini ale fi se ogun tin mu onise owo ma ri se
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 4:40am On Aug 08, 2016
e karo ninu ile yi e ku ojo meta o,ojumo aje loni je aje a yale wa wa o

1 Like

Re: Ogun Awon Bàba Wa by Nostradamus: 10:57am On Aug 08, 2016
ayokomi1010:
e karo ninu ile yi e ku ojo meta o,ojumo aje loni je aje a yale wa wa o
amin ase.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by KolaBELIEVE: 3:25pm On Aug 18, 2016
ayokomi1010:
OSOLE OWO
Okan maalu ti ko wo omi,omudun ewe akoko 101,pati omonigedegede,epo jebo,ao lo awon ewe yi,ao ge okan maalu yan si 16,ao se pelu epo iyo,ati ata ijosi,ti o ba tutu,ao da sinu Awo funfun,ao wo aso to dara,ao joko si aye to dara,ao pe Ohun re si,ao wa je obe na,
Ohunre:- igbe nla ni eran nla ke,e ma GBE owo nla wa fun mi,enikan kiridi omonigede, gede o,ki e wa Fi owo nla bemi nise loni. ao ma je obe na diedie fun ojo merin tabi marun,osise ga. mmn ni o
ejo baba oruko miran wo ni eiye aro n je? kini oruko miran fun omonigedegede?

1 Like

Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 8:38am On Aug 30, 2016
ekaro gbogbo ile ojumo ayo ni oni fun wa loni mofe fi awon ise nla si ori ikanni yi loni mafi se ibi

1 Like 2 Shares

Re: Ogun Awon Bàba Wa by Sego4(m): 12:05pm On Sep 08, 2016
Eku ise takuntakun ni thread yi ewe ama je funwa ooo, amin.......... Inu midun pupo
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Sego4(m): 7:33pm On Sep 12, 2016
Mojuba oo, Eku ise oooo, ewe ama je ooo, asini si ogun wa oo, ase.
Ejowo esanumi, oje ontiji funmi wipe lati bi odun meta lo bayi ni mio tile pe {ri} dada mon, Eyi ma nje edun okan funmi. Ejowo sir kinni solution funmi
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Zenlife: 3:08pm On Sep 14, 2016
ayokomi1010:
ekaro gbogbo ile ojumo ayo ni oni fun wa loni mofe fi awon ise nla si ori ikanni yi loni mafi se ibi

Awon ise na da ooo?
Re: Ogun Awon Bàba Wa by zang: 11:39am On Sep 15, 2016
EGUNGUN FESTIVAL IN ITA- OGBOLU, AKURE ONDO STATE.

I was at my hometown last week 4 d burial of my grandma... I came across this set of ppl dancing and chantings song. I make inquire and was told that its d annual village festival. I was told many secret abt dem. To be continued
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 9:20am On Oct 05, 2016
ago'onile'o, fun eyin ti enbere ibeere nipa osu, tabi ti nta nso'oye,
opolopo ntaso koseyin akose jaye, dida ara eni mo, iwadi nipa eto igbe aye wa, boba wa laye
bi okoba da arare mo inira amawa ni igba kokan, tojepe bi oba se oogun gan
koni sise, sugbon aje, oso, emere lama ndi lelori, bi akose jaye ba ndani laamun
bi eyi tojepe eyan si aye wa ni, tori bore waju pabo ni, bore yin pabo ni, atotun atosi bi alai monse ni
bi oro bari bai, owo Ori lati nbeere, tori ori eni lawure eni, ogun loni ojo iponju
kafola fori tolojo gbogbo. fun iwo ti obafe lati wo akose jaye re onilati fi ojo ibi re ranse. ati paapa eyin Omo June 22 to July 23 ati 2/19to3/20 haa! Afiti ori won bagbe alawore kowon nitori hmm olagbara'o ajuwase'o
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Adetolasegun: 10:00pm On Oct 11, 2016
E kuse oooo
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Adetolasegun: 10:03pm On Oct 11, 2016
Mo nilo ona ibile lati wa nkan eyan to sonu ti asiri eni to ji a fi tu
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 12:25pm On Oct 22, 2016
Ise ti afi nwa nkan ti ole bajilo!
Ewe Ina ati ewe esisi ati ako alangba ao gun papo, ao Sa ti yio gbe.
Lilore: Ao wa eyin na sinu akufo ikoko ni dede ago mokanla, ao maafin Lai nije Ki o fin si Awa na Lara
Pelu gbogbo bai wipe gbogbo iyeju awon ti ogbe nkan baibai lo tabi iyeju awon ti ogbe nkan lagbaja Ki ara maani komaroju raaye Ile aye re mon'o!
Afi tobada pada
Ao Sa bee ni ijo kini ikeji ati ijo keta!

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori number yi:-ni wasp 08101646045 bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add number yen si odo'e
Kede fi orukoyin sowo ni ekun rere:-Fun apere...emi ni arole onikoyi(chief egbeji)omo bibi ilu osun ni mi,ni ilu Ikoyi,ise onisegun ibile ni mo de nse ni ijebu ode

Atipelu iye Omo odun bai nimi

Eo si fi ise ti etiseri tosi dayin loju kan tabi meji sile lobatan!

Ajuwase'o
Re: Ogun Awon Bàba Wa by rubbyplus: 12:09pm On Oct 24, 2016
Agoo nile yi o, iba oo iba, mo se ba gbogbo eyin awo lori ikani yi,
iba okunrin iba obinrin lori ikani yio, idunnu mi loje lati darapo moyin

@Baba Ayokomi1010 & others
E jowo e la mi loye lori ibere mi yi:
Nje ti eniyan ba lo ise imule agba, nje o le tun ma lo ise awure ie osole?
Ama ju se. Isese a gbe wa.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 1:54pm On Oct 24, 2016
Fun idahun onibere nipa IMULE!
Ose Pataki kamaase IMULE tabi EBE awon Agba!
Ki ohun gbogbo le maaja si irorun!

FUN AKIESI:- Semi Ki nse'o nigi'oko fi ngbade bori, ifa lodoke, Emi na lodi ibigeregere, diafun orunmila nigbati baba ti ikole orun bo wasi taye, orunmila dele ayetan gbogbo ntorunmila nse awon eleye ojeo lojutu, orunmila kejo ododo eledumare eledumare ni kilose'o iwo orunmila, orunmila ni gbogbo nto nse laye awon eleye yi'oje kikankan'o lojutu nbe!
Eledumare ni komon pada rele'aye
Kolomu okete koko ewe aje'obale lelori
Koman lo
Kigbogbo eleye aye'o dowo fun
Ebagbokete'egbebe
Eyin eleye aye'o
Eyin eleye ode'orun ebagbokete emon gbaniyan
Ki gbogbo eleye keleye'o rokere fefe kiwon'o lorese shiii
Fun idi eyi, ose Pataki pupo Ki ama se awon nkan Yi. Koni hunwa'o
Ajuwase'o
Re: Ogun Awon Bàba Wa by rubbyplus: 6:58pm On Oct 24, 2016
08101646045atwp(m):
Fun idahun onibere nipa IMULE!
Ose Pataki kamaase IMULE tabi EBE awon Agba!
Ki ohun gbogbo le maaja si irorun!

Mo dupe pupo fun idahun ati alaye yin. Mo ti se awon igbiyanju die lori imule agba.
Sugbon mo fe mo boya o DARA tabi o LEWU lati se OSOLE. Kini EWU to wa nibe.

1 Like

Re: Ogun Awon Bàba Wa by rubbyplus: 7:07pm On Oct 24, 2016
08101646045atwp(m):
Fun idahun onibere nipa IMULE!
Ose Pataki kamaase IMULE tabi EBE awon Agba!
Ki ohun gbogbo le maaja si irorun!

Mo dupe pupo fun idahun ati alaye yin. Mo ti se awon igbiyanju die lori imule agba.
Sugbon mo fe mo boya o DARA tabi o LEWU lati se OSOLE lehin ti. Eniyan
Ba ti se. IMULE AGBA. Kini EWU to wa nibe tabi anfani.

Ejoo e lami loye!!!

IBA AGBA. Ajuwase ooooo
Re: Ogun Awon Bàba Wa by rubbyplus: 4:38pm On Oct 25, 2016
Agoo nile yi o, iba oo iba,

E jowo mo ni ibere:
Iru ise aajo wo ni yio je fun eniti irawo re je ERUPE.

Baba ayokomi1010, gbogbo iile e bami foju agba woo, e bami dahun si

Ama juwa se

Amin!!!!!
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 9:28pm On Oct 28, 2016
Okare fun ibere re Yi.
Fun idahun:-ewe amaje Lara irawo erupe daada.
Iyen Ti koba sowo lara'o
Akni sasise'o
Ajuwase'o
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 9:46am On Oct 29, 2016
Maran todaju gan,omo ile3,ao ko tele agbada,ao bu sibi epo pupa meta si,sibi iyo meta,ao wa jopo,ao wa fi singbere lati arin idodo yio pade nibi idodo pada ao wa tun sin meta sisale
Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori number yi:-ni wasp 08101646045 bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add number yen si odo'e
Kede fi orukoyin sowo ni ekun rere:-Fun apere...emi ni arole onikoyi(chief egbeji)omo bibi ilu osun ni mi,ni ilu Ikoyi,ise onisegun ibile ni mo de nse ni ijebu ode

Atipelu iye Omo odun bai nimi

Eo si fi ise ti etiseri tosi dayin loju kan tabi meji sile lobatan!

Ajuwase'o
Re: Ogun Awon Bàba Wa by zenith329: 4:49am On Oct 30, 2016
ayokomi1010:
Osole:olongbo dudu,eyele dudu, eye kowe kan,obi abata oloju merin,ao ge obi na si 200,ewe igi ose 200,kaka iru 200,igba ademo nla kan,ao ko Gbogbo nkan yi sinu igba na,ao gbe sinu agbada ,ao jo ao ro sinu sere,ao mafi oti lo,tabi ka ma fi fo eko mu,odaju wa mari owo nla gba Lori isere.

Ejor sir, se odidi olongbo abi ori olongbo?
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 11:22pm On Oct 30, 2016
Osole:ododo rerinkomi pupo,oju maalu mejeji,#1000 note,padi atare kan jijo po ao maa fi peak milk loo.

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori number yi:-ni wasp 08101646045 bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add number yen si odo'e
Kede fi orukoyin sowo ni ekun rere:-Fun apere...emi ni arole onikoyi(chief egbeji)omo bibi ilu osun ni mi,ni ilu Ikoyi,ise onisegun ibile ni mo de nse ni ijebu ode

Atipelu iye Omo odun bai nimi

Eo si fi ise ti etiseri tosi dayin loju kan tabi meji sile lobatan!

Ajuwase'o
Re: Ogun Awon Bàba Wa by rubbyplus: 8:26am On Oct 31, 2016
IBA EYIN AGBAGBA!!!
E dakun enikeni to ba mo awon ise IMULE AGBA to daju to si lagbara
Ki won fi sori ikanni yi eg imule "owonrimiki" ati "alapamasise amona owo ma re"

@baba ayokomi1010 ati eyin aworo shasha e fi oju agba wooo
E gbami Oooooo!!!!!

IBA AGBA, EWE AMA JE

ASE EDUMARE
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 5:33am On Nov 01, 2016
ASINA OWO / KIWON LE OWO NLALA BERE WA. ileke itun, ileke ifa, abere, ewe anu, ewe ela. gigun pomo ose, aofi omi agbon po ose na pelu lofinda bittu. Aoma fiwe pelu ohun OHUN; Itun loni ki efi owo million tun mi se Ifa loni ki efi owo nlala fami mora Abere loni ki efi millions bere mi. Nibiti oka bakasi lonje oka nba Ki millions oto mi wa, kiwon wafi damilola.

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori number yi:-ni wasp 08101646045 bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add number yen si odo'e
Kede fi orukoyin sowo ni ekun rere:-Fun apere...emi ni arole onikoyi(chief egbeji)omo bibi ilu osun ni mi,ni ilu Ikoyi,ise onisegun ibile ni mo de nse ni ijebu ode

Atipelu iye Omo odun bai nimi

Eo si fi ise ti etiseri tosi dayin loju kan tabi meji sile lobatan!

Ajuwase'o
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 5:41am On Nov 01, 2016
Emi Mon alapa masise todaju Ti kode nira rara
But ijeun agba lawa mon si now!
Sawo niwo Ni
Toona Fe pade mi Ni wspp 08101646045!
Kiise ise ori afefe
Ti eba Fe ta iwe eyi Ti anfi sile Yi naa Tito sinu iwe!
Oroyi nipa tite iwe kiise fun onibere Yi rara'o
Bikiise fun awon onijibiti eda
Tori Olodumare lolepin awalere!
Imunle wa alapamasise na siwa!

Sugbon ekan Simi fun alapamasise
Koniibaje'o
Ajuwase!
Re: Ogun Awon Bàba Wa by sayyid(m): 1:43am On Nov 02, 2016
eku ise oooo, oluwa eledua a ma fun yin se oo. edakun oogun wo ni eniti oni arun Ovarian Cyst le lo? ese modupe pupo
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 1:03pm On Nov 06, 2016
Edakun fun idahun ojogbon Ti obere nipa ogun yi
(Ovarian Cyst)
Aiparo'o!
E Mio gbo iru aisan Yi rio
Tabi Ki nma Mon itumon re
Edakun kini Yoruba Ti ale fun aisan Yi Ni ede tiwa ntiwa.
Akonisasise'o
Ajuwase o

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (Reply)

Meet The Most Beautiful People On Earth- The Fulanis / Post Pictures Of Traditional Weddings. / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here!

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 47
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.