Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,148,928 members, 7,803,045 topics. Date: Saturday, 20 April 2024 at 07:56 AM

Ogun Awon Bàba Wa - Culture (7) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Ogun Awon Bàba Wa (325839 Views)

Asiri Aiye Siwa Lowo Awon Agba Woli / Asiri Ijinle Awon Woli Lailai / Asiri Ogun Awon Baba Wa (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (Reply) (Go Down)

Re: Ogun Awon Bàba Wa by highque: 11:58am On Apr 06, 2017
frontpage79:
frontpage79:
eku ise Baba,ewe ama je o,ejowo baba kini molese si okunrin kan ti o Rent ile lowo mi,kope ti o ko wole ni moto mo wipe amugbo ati odaran paraku ni,bii koja loni ki won ma fi olopa wa kiri ati wipe orisirisi awon oju ti koseri loma nwa wasi ile,moni ki o jade loba so di ija,EJOWO BABA KINI MOLE SE TI YIO FI KO JADE FUNRARE,EJOWO E SANU MI.

Elowa AYOGO Todajusaka, funrare ni yio kojade pelu pelepele faa.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Obaf1(m): 12:03pm On Jun 08, 2017
ayokomi1010:
moki gbogbo omo Yoruba pe aku dede asikoyi o a si ku ojonla Jimo toni koni je ase mo wa o,esin kan o sope kama se ajo o,oun ta lo gba wa lati ile ajeji ema je kopa ti awon baba wa Lara o,mi sope ki a ma sin olorun Oba okan soso o,eledunmare o,sugbon karanti pe larubawa ni asa Ati itoju ara nipa ilane tiwon won o parun o,Israeli na be,oyibo alawo funfun na,ki omo Yoruba madi atemere lagbaye Ati ki iya maje wa mo ni mose sin ikanni yi o,Ohun gbogbo ti o Ba je ododo le ma ri lati Odo mi,tikosini ni ipalara,be ni mosi fe ki gbogbo away taba darapo mo ikanni yi Na ma se,karanti pe eni riwatan to mo korowa iwo wa o,so ododo fun enikejire oje Idunnu eledunmare ESE ewe amaje Ogun ama je o odua agbe wa o Ase.
;;;;;;;;;;;mojiba agba ooh, ejor se ogun to daju si wa tooto, gbogbo ogun ti mo ri ni forum yi ti mo si se koje fun mi, leyin eyonu, ejo ti e ba ni confirm ogun, aworo, iparada, anasare, afose, aferi, iferan obinrin, OKIKI, amudo, ti o daju ejo e fun mi plz, omo odua nimi, i really need it so that i can clear my doulbt lori ogun, so that o ma damiloju pe oogun wa tooto, ise se agbewa oooh ase
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 11:33am On Jun 09, 2017
alafia fun Gbogbo omo odudua,e Ku a mojubami,a de Ku orugbe emi a laja o,eledunmare OBA abanise abawa se tiwa o Ase
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 12:00pm On Jun 09, 2017
alafia Olorun ko ma bayin,moti de pada,Gbogbo Iwo ti o bani Iwo se ogun koje,papa ninu oun ti mo ba kosi ikanni yi,lo ye ara re wo,se ogun ti je fun e ri bi beko lo se igbinyanju ti mu Ki ogun ma je fun ni,saju Ki o to ma se ogun Miran Ki o mo ba ma fi owo re sofo oo,fun Gbogbo woli alfa babaonisegun,babaalawo,sora fun gbaju e,jibiti,ogun ti o ba mo jewo pe o mo,idiyele ti eroja ogun ti ofe se fun Eniti o wa sodo re je ni Dede owo ti o gbodo gba ti o ba fe Ki ogun re je,Ki o si duro de idupe lati odo alejo re,bi okanjua aisododo bati wa lowo re ogun re koni je mo o fun awon ti wa se ajo lodo re,boti wu Ki o rewonje to wa pada pon laso kehin ni,tori na ododo di Iwo wa,Iwo ti won si so ododo fun na ti ajo re je,ma puro fun olore re,San esan toda fun Ki ayo na le ba o di ale,die lara eko ti a ko lara awon baba wa niyin,e se a ma juwa se o
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 11:05am On Jul 29, 2017
OSOLE OWO TODAJU FUN CONTRACTOR ATI OMO YAHOO
:-Okan maalu nla kan, iho merin lo nbe ni ara re, iho ti aarin ao ki ori eye osin kan si, iho keji oba owo tuntun kan ao bu ewe ola si ninu a o wee papo ao kibo iho keji, iho keta odindi atare kan la o ki bo, iho kerin eran NLA tutu ekiri kan la o ki bo.
Ao gbe si inu ape tuntun odi jijo ti aba joo tan ao ro sinu ado ide nla ti yio gba gbogbo ebu yen, a o wa mu akuko adie pupa to ti gbo daada ao pa, ao ro eje re si ara ado ide yen, a o fi iye re le ado ide yen lara.
a o wa se adie yen toritese re, lepo niyo niru, ti o ba jina!!

EEWO REE:- Akogbodo to obe yi woo....

ETUTU RE:- Ao fi ewe iyalode meta tele inu awo ipese nla ti o le gba gbogbo obe yen ao daa sinu awo ipese yi, ao se adua si daada bi a ti se nfe, a o gbe losi ikorita meta lagogo mokanla oru, fun awon iya mi osoronga.
Ti o ba di ojo keji a o lo mu awo yen

LILO RE:- To ba di agogo kan oru ao ma fi oti schnapp original lo ebu yen lati inu ado ide yen.
ao lo lojoojumo for 21days

EWO RE:- Ako gbodo sunmo obinrin fun 21days ti a fi loo'o lowo ba de!!!

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS :- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o
Re: Ogun Awon Bàba Wa by doctuw(m): 2:29pm On Aug 03, 2017
Aboru aboye oo. E jowo, kini won pe. Ni omo onigelegele.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 7:41am On Aug 13, 2017
Moki gbogbo ile wipe ototo meta'o
Mofi asiri yi sile fun awon ti won wadi Ola, sugbon ti won ti kolu eewo towa ninu'e, ti won wa nba inu fuu'aya fuu kaakiri,
Ema bami kalo!
Ti aba seso ola ti asije eewo ti won ka ni eewo ni awon baba wa ma nse iseyi,
Ni akoko ao akoko se ado gbekude ti ao mu:- Igba ewe ape, igba obi abata, igba orogbo, igba atare, pelu ori akalamagbo kan. adi jijo pelu omo'owu toti sise lagbede daada ohun ni ao maafi ro Lori INA, nigbati abajo tan, ao ro sinu ado, kekere kosi iye ado ti akole rosi
Ao fi iye idi akalamagbo ha lenu tobaje Fifi korun ni afese,tobaje gbi gbe mi ni aofi ewe ape di lenu aogbe ado kekere na mi.

Ni elekeji
Ewe ayajo IFA ewe atibirokun, abamoda, alupaida, ewe roro, eku eliri kan, aojo ao po mose
Ao we fun IJO meje pelu ewe awede !

Iketa ni etutu inu ogbe irete!

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS :- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o
(M
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 7:43am On Aug 13, 2017

Re: Ogun Awon Bàba Wa by tasland(m): 11:04pm On Oct 11, 2017
Moki Eyin aworo sasa ooo, ejowo bami WA atunse si aye mi, kini nkan ti ele se fun mi lati ba egbe pe ati lati raje jeun. E jowo o ti sun mi
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 4:13pm On Oct 14, 2017
Esunmo awon agba ki won se aye ekun rere fun yin sir
ki e le mon igbese kikun
akonisasise'o
ajuwase
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 9:54pm On Oct 26, 2017
ago'onile'o, fun eyin ti enbere ibeere nipa osu, tabi ti nta nso'oye,
opolopo ntaso koseyin akose jaye, dida ara eni mo, iwadi nipa eto igbe aye wa, boba wa laye
bi okoba da arare mo inira amawa ni igba kokan, tojepe bi oba se oogun gan
koni sise, sugbon aje, oso, emere lama ndi lelori, bi akose jaye ba ndani laamun
bi eyi tojepe eyan si aye wa ni, tori bore waju pabo ni, bore yin pabo ni, atotun atosi bi alai monse ni
bi oro bari bai, owo Ori lati nbeere, tori ori eni lawure eni, ogun loni ojo iponju
kafola fori tolojo gbogbo. fun iwo ti obafe lati wo akose jaye re onilati fi ojo ibi re ranse. ajuwase'o
Re: Ogun Awon Bàba Wa by FORTHNIGHT(f): 11:29am On Nov 07, 2017
ayokomi1010:
OGUN IWOSAN AYE
ewe ela,ewe alupayida odidi atare kan, ao jo po ao da sinu omori isaasun ao wa ko oruka irin si,ao wa da epo pupa si ao ro po, ao wa fa Ogun yan si enu akuko adie,ni emeta,ao ma fi oruka ni si lenu ni okokan yio ma gbemi,ti o bawa di OJO keje ao pa adie na,ao lainure ao Ba awon oruka na,ao ko ao ma fun eniti Asian ba nse yio fi bowo re,aisan re yio San ni OJO na ase eledunmare ni,iba eyin agba o aiye mojuba o,mowole mo pa igbunmo o,mofori bale fun gbogbo ajunilo.

EJO SIR E BAMI SALAYE BI ASE MA FA OGUN YAN SI ENU AKUKO YEN, TORI MO TI LO OGUN OFA SI ARA MI TITI PELU OGUN OYINBO SIBE KO SI IYATO, NKAN MA NRIN KAKIRI ARA MI
Re: Ogun Awon Bàba Wa by rafiham1990: 12:22pm On Nov 07, 2017
Ekasan sir.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by rafiham1990: 12:29pm On Nov 07, 2017
Emi ni abiodun to peyin lati ibadan sir.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 5:23pm On Dec 04, 2017
Ikanni yi pe 3years ni oni,openi fun Olorun, torina opo enia loti se orire latara ikanni mi yi,kosi Si Eniti oleni mo gba owo kan ni owo oun tabi pe mo lu owun ni jibiti,koda awon ti o wami wa yin Olorun logo,ikanni yi ti di Egbe nla ni Ori WhatsApp, leyiti ati se ipade ojukoju re kakiri state, sugbon woli,alfa,babalawo,nikan ni a gba wole sibe kiwon le je olododo Ki won si ni imo Lori oun ti won gbe dani,Ki won ba matun ma dakun isoro awon ti o wa Sa bawon ,sugbon toripe ikanni yi pe 3years loni,ma sin whatsapp ti o je ti Gbogbo enia lati ma wa ojutu Si isoro enikeni,bakan ma fi awon ise kan Mark ayeye ojo oni,mosi fejeki awon omo wa olopolo pipe ri owo nla gba lowo awon agent won Ki won le fi ayo se odun,but mini fi ise omo Yahoo na sile ni Ori ikan ni yi o,Pemi tabi bami soro ni WhatsApp pelu ede yoruba,ati ise ti afi je tete tita.by ayokomi1010.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 6:13pm On Dec 04, 2017
Ogun Didu IPO oba oye tabi oselu,ati isegun nipa ipo
***************************************************
Ododo ewe iroko kan,moriwo ope kan eyiti yo soke Dada,eyo atare kan,ao lopo gbere kan ni Ori,
Gbolohun re*" Igbo Ki di Ki iroko mayo,larin igbago ni mariwo ti yo soso,emi lagbaja omo lagbaja Niki de Ori ipo Yi.

Asina
Omo adie ti o sonu lehin iyare,ao jo pelu odidi atare kan,ao wa toju oga gbigbe kan,ao wa lo oga gbigbe na Dada,ao da pomo ebu ti ajo yan,ao ro sinu igo kan,ao mafi sinap lo larolaro,lehin ti abati lo tan,ao fi omo odo lu iya odo ni emeta,iyan odo ti afi gun iyan je ni o.

Ohunmo Iwo ise
Ori igun,Ori akala,Ori eiye karo,etu ti won wo ninu ibon,iyo isebe die,ao gun papo, ao wafi te ifa irete meji,
| |
| |
|| ||
| |
ao wa pe oun re si,ao mafi fo eko mu die die,
Ohunre" kedere ni oju igun tole aye,kedere ni oju akala tode odun,kedere ni oju karo tole odo,kedere ni oju etu tole ibon,kedere ni oju iyo role obe,kedere niki ojumi maa to Gbogbo oun ti won ba nbawa Si odo mi.

Ise ti omo Yahoo fi gba obitibiti owo.ti a pe oruko ogun na ni oju AJA Ki gbo,
Omo AJA ti koti laju,atare nla kan,ata ijosi,ati igi aika lafijo,ojo ti o balo ojo keta ni onbara re a San owo nla fun ti kode ni le ba enikeni so,pe oun San owo nla bayi fun enikeni.

Mo bows,Pemi tabi bami soro ni WhatsApp 08135072961

1 Like

Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 1:40am On Dec 05, 2017
E karo Gbogbo omo odua,ao jire bi
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 3:00am On Dec 18, 2017
MOKI GBOGBO EYIN ENIYAN WA KUU DEDE AKOKO YIO, MOGBADUA FUN GBOGBO WA WIPE: GBOGBO IGBA KUUGBA TI YIO BAMA BAWA LAYE NI AO MAARI OPE RERE DA’O!
ADEKU’IMUNRA ODUN’O, AYO ATI ALAFIA NI AO FISE’O ¬¬(AMIN)

PATAKI ORO MI SI GBOGBO EYIN OLOLUFE IKANNI YI LOKUNRIN ATI LOBINRIN TI AN GBIYANJU LORI ASIRI EWE ATI EGBO LONA KAN TABI EKEJI NI WIPE: MOSE AKIESI WIPE OPO AWON ASIRI KAN WA TI AKIISE AKIESI NIPA’E, TABI KI NSO WIPE AKOKAASI PATAKI GEGE BI AWON BABA WA SE NKAASI PATAKI NIGBA TI WON.
FUN APERE: AWATI OLOHUN FUN NI ANFANI LATI MON NIPATEWE’TEGBO LONA KAN TABI IKEJI, ODAJU WIPE AKOGBODO MAAFI OJU DI AWON NKAN AGBARA TABI KI AMAAFI OJU RENA AWON OGUN TABI AWON ASIRI BII:
IMULE
ETUTU
ABEGBEPE
ISOYE
AFORAN
AROBI
ERO
AWISE
OHUNMO
AKOYA
ATI BE BE LO!!
SUGBON EYI TI MOFE KI AJO JI RORO LORIE NI IMUNLE.
OPO AWON ENIYAN LO MA NRO WIPE BI ABA TI NSORO TI ATI DORI IMULE YI, WON MA NRO WIPE KIA WO INU EGBE KAN TABI IKEJI NI ORO YI TUMON SI, SUGBON TI KODE RI BEE RARA, TI ABA NSORO LORI IMULE AJE WIPE ORO TI DE ORI IFA NIYEN
ORUMILA BABA AGBONMIREGUN LOMA NBA AWON IYAMI ELEYE MULE NITORI IDIKAN TABI EKEJI.
FUN APERE BAKANNA: ORUNMILA BABA AGBONMIREGUN LO NKI IFA OHEREMEKI LOJUDE AWON ELEYE LOJOKAN, NI AWON ELEYE BAYO SI ORUNMILA, WON NI KILODE TI ORUNMILA FI NKI IFA OHEREMEKI?
ORUMILA WIPE:NITORI AWON ALABOYUN KI WONLE BA BI WERE, ATI NITORI AGAN KI OLEEBA TI OWO ALABOSUN ATI NITORI AWON OKUNRUN ILE KI OLEE BA DIDE NILE, KI SISESISE LEBA LOWO ATI KI AWON ISOWO OJA KI WONLE BA RI ERE OJA.
AWON IYAMI ELEYE HA MON ORUNMILA WIPE KAI!
SE IWO KOMON WIPE SISESISE TI KONI OWOLOWO ERAN WA NIISE NI?
BE SINI SOWOSOWO TI KORI ERE OJA NA ERAN WA NIISE,
ALABOYUN TI KOBI ERAN WA NIISE
AGAN TI KORI OMOGBEPON ERAN WA NIISE
OKUNRUN ILE TI KODIDE ERANWA NIISE
ORUNMILA BABA AGBONMIREGUN DAHUN ONI MOMON
SUGBON MOWA BAWON BEBE NI!
ORUMILA BEWON TITI WON’OGBO
ORUNMILA SIPE TITITI WON’OGBA
ORUNMILA NI TI ONBA BEYIN TI EKOBAGBO NOKI IPONRI (…..) FUN YIN’O
WON NI TI ORUNMILA BAMON KI OMA KII’O!
NI ORUNMILA BA BERE SINI WI BAI PE: (…………..)
AWON IYAMI ELEYE BA WIPE: ODARA AWON TI GBO!
ORUNMILA NI TI EBAGBO TI OHUN WIPE TI AWON OMO OHUN NKO?
NITORI AWON OMO (AWO) OHUN PO NI ODE ISALU AYE
AWON IYAMI ELEYE WA SE APEJUWE AWON EWE IFA KAN FUN ORUNMILA EGE BII IPINHUN TI AMON SI IMULE WIPE TI OBADI WIPE AKOFE DA AWON OMO RE MON MON KI OMAFI SE IFA FUNWON WIPE TI AWON BATI NRI AWON NKAN WONYI WIPE GBOGBO NKAN TI AWON BATI NTANI KOKO NI AWON YIO SI MAATU!
AKIESI KOKO ORO WONYI NTOKA SI PATAKI OJUSE IMULE
NITORINA EYIN ENIYAN MII ODAJU WIPE> IMULE KIISE NKAN TI ENIYAN LEFI OWORO SEYIN FUN AWA TI ANI ANFANI LATI MAALO EWE ATI EGBO LONA KAN TABI EKEJI.
FUN IDI EYI EJEKI AJOJE ANFANI IFA IMULE TI OREMI KAN FI SE EMINA NI ANFANI KI OSE ELERI ORO NA

IMULE
Eyie adan,eyie onbe, atare odindi kan,a o Jo papo,ao wa ro sinu ado,lehin naa ao wa lowa Awo Sobi,Ao bu ebu yii sinu e pelu epo pupa lilo e ni ago kan oru ni ihoriho omoluabi ao fi ESE OSI ti ara ogiri ODAJU:::OFORE--BI OSO BADIN AJE NI TU NI,/ BI AJE BA DE NI OSO NI TUNI,/BI EMERE BA DE NI TOSO TAJE NI TU NI,/BI TOSO,TAJE,TEMERE,BA DE NI EYIN IYA MI OSOROGA NI TU NI SILE TO BA WA RI BEE GBOGBO IDE KU DE TI E DE EMI L OMO L KO MA TUU BAYI
IBA AWO TI OFUNMI NI ASIRIYIO

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS :- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
FUN ALAYE LEKUN RERE 08101646045
Ajuwase o
MAJEMU LAILAI?

1 Like

Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 6:42pm On Jan 10, 2018
AKIYESI ONA ABAYO ILE AIYEWA)
opolopo isoro ti osele si eda wa lati owo kadara ati egun idile ati afi owo fa,ati awon iya osoro nga ati awon egbe orun,awon nkankan tun sele si eda ti ojepe pupo ninu re irewesi tun se pupo ninu won titoripe kosi eda ti ELEDUMARE se aburu si,apere eda tiko ni owo lowo,eda tiko ri oko tabi aya rere fe,eda tiko ni oyun tabi eniti ose aisan,osese koje owo awon iya osoronga,ejeki agbo bi ifa oheren meki se so,orunmila ji nikutu kutu owuro onkoja lojude eleiye,owa da ifa ohenren meki,awon iya osoronga sope talodafa ohenrenmeki nibe yen?orunmila sope ohun alajogun weremogun ni,won sope kilode ti ofi da ifa ohenrenmeki?orunmila sope titori alaboyun tiko bimo were kole bimo were,titoripe agan tiko towo alabosun kole towo ala bosun ni ohun se dafa ohenren meki titoripe alaboyun tiko bimo were kole bimo were,ati okurunle ti ose aisan kole towo alabosun,eniti osise tiko ni owo lowo kobale ni owolowo kolefi owo nase nkan rere ni ile aiye lohun se dafa oherenmeki,awon iya da orunmila lohun pe alaboyun tikobimo woro ati agan tiko ti owo alabosun,ati eniti osise tiko ni owolowo,ati okurubule tose aisan pe eran awon niwon je pe awon lawon wa nidi oro won,awon fiwon pase ni,orunmila sope ohun mo pe ohun wabawon bebe ni,awon iya osoronga sope awon koni gbo ebe,orunmila sope tiwon kobagbo ebe ohun apitan iyawon fun won,awon iya sope ti orunmila bamo itan awon kopa,orunmila sope olupowo oruko ti iya eyin aje nje,arihoho jedun oruko ti iya eyin aje nje,owewe lakara oruko ti iya eyin aje nje,awon iya ni oto awon tigbo ebe,pe lati onilo alaboyun tiko bimo were abimo were,agan tiko towo ala bosun atowo alabosunokunrun bule ani alafia,eniti osise ani owo lowo afi owo se ohun rere,titoripe aje kiroro koje iwin ojo,oro ti okete bale so ni ile gbo,akiyesi pataki ni eyije ki amafura si oro aiye wa gbogbo aburu ti osele si eda pupo ninu re owo awon iya osoronga ni,ejeki amalo atude ati eyonu ipese awon agba fun ona abayo,emi aimo koni ni agbara loriwa tomotomo ase

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS :- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
FUN ALAYE LEKUN RERE 08101646045
Ajuwase o
MAJEMU LAILAI?
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 12:28am On Jan 12, 2018
ATUDE OSE"
ewe lapa funfun mesan, ewe ewuro ojoo mesan, ewe efinrin mesan, ewe ajaobale mesan, yerupe ago kan osan ati toru, ao gun mose, ao fiwe fun ojo meta pere lori ni ago kan oru ni wiwe re o, ti abatiwe ose ye pari, ao tu kanhinkanhin yeka, ao sonu ni o. Odaju

ITUWO ATUDE- aowa ewe ajeobale, epo igi ajeobale, egbo ajeobale, aolopo mose aopin ose na si ona meje, ti abafe we aowa ajadi apere kan aoko sinu re aowa we ose mejeje na lekan na telera won ninu apere yi kain kain meje ni aofi we ooo, AKIYESI, ti aba nwe lowo aogbodo soro, aosi gbodo siju le afi ti aba wekan tan ti atun fewe imin

ATUDE TODAJU Ewe tude egbo tude iyere ao lo ti yio kuna dada ao ra isasun tuntun ao fi se odidi igbin kan je lepo niyo lodidi ni ao se igbin yi o akoni ge ti obajina ao so kale ao je ko tutu ao wa bo gbogbo aso orun wa ati oruka ao wa ni ihoho omoluabi ao wa da aseje na si ilele ao kunle ti ao wa ka owo wa mejeji seyin wa ao wa se adua itusile ao wa fi enu gbeje lodindi iseyi daju danwo kori botiri Ike oloun ola oloun komaba alayelorun NB ori ilele cement or tiles lamada aseje yi si leyin ti ati nunu dada ao dasi ao waje

EYONU AWON AGBA TODAJU
Ao wa Opolopo ewe imi esu ao japo ma ododo ati itanara ao jo po ma atare odidi kan ao mafi la epo pupa lalale pelu adua odara pupo atude ni pelu odaju

EYONU¤ Ewe Akoko ati Itanna re, epo ati egbo re ao jo pelu odindi ataare kan, ao maa fi epo la ki a to sun... Ti o baa di ojo keje ti a lo ise yii ao fi Akara elepo se sara fun enia meta pere odaju

EYONU¤ Eru oju aro, epo obo ao lo kuna daadaa ao mo mo ose Lux ao maa fi we lalale.... Odaju

EYONU AWON IYAMI TURARI NI O¤ Eku asin meta, Epo Obo, Epo Igi nla, Korowu ao gun papo, ao daa sinu try kan ao waa daa adin gidi si ao ro papo daadaa, ao saa si ategun, ao maa fin ni alale ki a to sun.... Awon Agba won yi maa yonu siwa

EYONU ASINA TIPATIPA¤ Ao gun ewe Afelorun kuna daadaa, ao waa po pelu Ose dudu, ao te Ifa Eji Ogbe si ori iyere Osun, ao se Adura Isina si daadaa ao waa po pelu ose yen ao ko sinu igba Olomori, ao maa fi we ni gbogbo igba..... Walahi Odaju

EBE/IMULE AWON AGBA TODAJU
Alubosa elewe tutu kopo die ao gun dada ao popo ma ose dudu ao wa eyin adie Oojo ao do gbon fo lori die ti korofo eyin yi konibaje ao jo omin eyin yi sinu ose yi ao tun gun dada ao wa igba olomori ao ko ose yi si ninu ao wa fi korofo eyin yi gun ose yi lori logan gan ibi ti ati fo eyin na ni yio koju sinu ose, ao ti koko dogban fowo jin ibibe kato fi eyin na gun ki korofo eyin na maba fo. Ao ma buwe nigba toba wuwa. Iseyi daju ijo taba bere wiwe re ojona ni yio bere ise

EYONU
Oga3,asin3,opolo3,eso ido,eso werenjeje,ewe ajeobale, ewe orijin,ewe kileofimise,odindi atare 3,ao Jo po ao ma fi epo ogere la ninu fitila oloju kan. Tested ok
IMULE AGBA
Akara elepo16,eran menu,ao to akara yi round ninu ape ao fi eran sarin re ati odindi atare kan ao Jo po ama fi otin lo lalale
Eyonu ,ogede omini ati epo obo ati igbo mimu ao gun papo mo ose ,odaju

Etutu awon eleye kan reo:- alubosa funfun ao fi din eran namo tikoiti womi tiagesi ona merindinlogun, ao jo ako alangba kan pomo odidi atare kan ao lokuna ao da sori ipese na ao da epopupa lelori ao daniyan si ao gbelo sorita loru oganjo, odaju

Tour!
Eyin isoro ope eyin nikiee bawa toroyise'o
Tori eku Ni awon ko nko nfilele awa'omon
Kaye omo olufe lebaagun gege nio
Kiya maba jomo'olufe nio
Edakun edabo efiye denu'o
Etanti imule'o
Bawobapawo ile loda'o...
Moseba agba.. Mowari faye'ooo

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS :- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
FUN ALAYE LEKUN RERE 08101646045
Ajuwase o
MAJEMU LAILAI?
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Makapounse(m): 7:36am On Feb 06, 2018
Moki gbogbo ile, eku ise opolo , Eledumare a ma fun yin se. Amin. Ejowo baba , Efunmi ni Ogun Madarikan Ola
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 9:03pm On Feb 21, 2018
ASETA TO LAGBARA GAN,,, , Oju ejo soro ao yo oju Otun ao lo pelu eyo atare kan gbere kan oju osi wa, ao tun mu toju osi ao lo pelu Atare kan gbere kan oju Otun, huuuummmmm ti won ba peri wa ni ibi ejo ni yoo lo bu onitohun je ooooo

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS :- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
FUN ALAYE LEKUN RERE 08101646045
Ajuwase o
MAJEMU LAILAI?
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 4:09pm On Feb 24, 2018
OGUN IKO ODAJU
Ao loo wa aidan ti kogbe tan ao ha ibi isu re ao ki sinu ike kan, alubosa elewe,ao da omiikan(omi ogi) le lori, ao je ko toro di bii irole ojo ti aki tabi aaro ojo keji. Ao maa mu laaro ati ale. Walahi talahi, ajebiidan ni. Ao nii saisan o!

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon nkan lara egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS . Fun ti majemu, abi eyi ti atun npe Ni:- ALUMONNI AWON AKONI:- https:///8ahrCpBnxgS3qHb0L63Hp8
Fun ti ALUMONNI AWON AKONI.
bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 6:39pm On Jun 22, 2018
OSOLE OWO TODAJU FUN CONTRACTOR ATI OMO YAHOO
:-Okan maalu nla kan, iho merin lo nbe ni ara re, iho ti aarin ao ki ori eye osin kan si, iho keji oba owo tuntun kan ao bu ewe ola si ninu a o wee papo ao kibo iho keji, iho keta odindi atare kan la o ki bo, iho kerin eran NLA tutu ekiri kan la o ki bo. 
Ao gbe si inu ape tuntun odi jijo ti aba joo tan ao ro sinu ado ide nla ti yio gba gbogbo ebu yen, a o wa mu akuko adie pupa to ti gbo daada ao pa, ao ro eje re si ara ado ide yen, a o fi iye re le ado ide yen lara.
a o wa se adie yen toritese re, lepo niyo niru, ti o ba jina!!

EEWO REE:- Akogbodo to obe yi woo....

ETUTU RE:- Ao fi ewe iyalode meta tele inu awo ipese nla ti o le gba gbogbo obe yen ao daa sinu awo ipese yi, ao se adua si daada bi a ti se nfe, a o gbe losi ikorita meta lagogo mokanla oru, fun awon iya mi osoronga.
Ti o ba di ojo keji a o lo mu awo yen

LILO RE:- To ba di agogo kan oru ao ma fi oti schnapp original lo ebu yen lati inu ado ide yen.
ao lo lojoojumo for 21days 

EWO RE:- Ako gbodo sunmo obinrin fun 21days ti a fi loo'o lowo ba de!!! 

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon nkan lara egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS . Fun ti majemu, abi eyi ti atun npe Ni:- ALUMONNI AWON AKONI:- https:///8ahrCpBnxgS3qHb0L63Hp8
Fun ti ALUMONNI AWON AKONI.
bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o
Re: Ogun Awon Bàba Wa by inyass2580(m): 7:54pm On Jun 23, 2018
ASEJE #16,000

Ewe sawerepepe 16 ina sawerepepe 16 ewe tanapowo 16 ina tanaposo 16 iyere 16 aolo papo ao fise edo malu 16 je lepo niyo.

BASIRI #41,000

oga gbigbe kan agbado omonla 41 eyo e ni o atare odidi kan aojo papo

aofi peak milk kan lo laro kutu

walahi tested ni

08166579753 u can add me on whatsapp
Re: Ogun Awon Bàba Wa by 08101646045atwp(m): 12:45pm On Sep 25, 2018
OGUN IFURA eja ojiji ao fi ikonde ha lenu pelu odindi atare kan ao Jo po ao sin gbenre yika orun ese mejeji

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon nkan lara egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS . Fun ti majemu, abi eyi ti atun npe Ni:- ALUMONNI AWON AKONI:- https:///8ahrCpBnxgS3qHb0L63Hp8
Fun ti ALUMONNI AWON AKONI.
bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Nobody: 1:05pm On Sep 25, 2018
Mo ki gbogbo omo oduaa o, mo ki gbogbo awa omo kaaro ojiree o grin
Re: Ogun Awon Bàba Wa by ayokomi1010(m): 8:04am On Nov 19, 2018
E karo e ku ojumo o,mofe ta awon ti o ni ohun kan gba lowo olowo,alagbara,oyinbo,ati bebe lo lore ise kan pemi labe aso,tabi eniti o ni lo lati gba iwe igbelu ni orilede alawo funfun,tabi eniti o koni ibujoko.mo de pada,gbogbo eyin ti e ti dan awon ise mi wo,Emi baba Ayokomi,e ma fun ile lesi,eo ripe kise gbogbo igba le ma ri emi lori ikanni yi,tori kisi aye fun emi rara.pe mi si 08135072961/08075198871. lati ojo ti moti da ikanni yi sile,enikeni kole pe mo lu owun ni jibiti ni ori ikanni yi rara.
Re: Ogun Awon Bàba Wa by sharaff6(m): 10:48am On Nov 19, 2018
e karo gbogbo ile.. Mo fe agbo iba to daju e shanu mi
Re: Ogun Awon Bàba Wa by daddio(m): 2:46pm On Nov 24, 2018
ayokomi1010:
OGUN AROBOKU OKUNRIN TI KOLE BA OBINRIN SUN
AO toju egbo Ajara,ao ge wewe sinu igo kan,ao jo eyin adie ibile 7 si,ao da opolopo omi agbon si,lehin OJO keta ao ma Mu.
Egbo sao,iyere,sugar onikoro die,ao gun papo ao mafi Mu eko gbigbona.

Please can I get your contact
Re: Ogun Awon Bàba Wa by Fumymy30(f): 3:14pm On Jan 21, 2019
ejowo moo need ogun ti a maa fin shi eyan tabi okan eyan kuro ni odidi ilu
Re: Ogun Awon Bàba Wa by dplanner: 3:43pm On Jan 24, 2019
NKAN TO YE KI ENIYAN KO KO MO , KO MA SE OGUN ABI NKANKAN OHUN NI AKOSEJAYE ATI IRAWO RE , KO LE MA IBI TO N LO , IWO TO BA FE RIN IRINJO NA , PE 07067796292, TABI KO WHATSAPP MI LORI NUMBER NA

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (Reply)

Meet The Most Beautiful People On Earth- The Fulanis / Post Pictures Of Traditional Weddings. / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here!

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 109
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.