Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,149,966 members, 7,806,793 topics. Date: Wednesday, 24 April 2024 at 12:32 AM

Ekiti Kete - Culture (6) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Ekiti Kete (60110 Views)

Poll: Your Local Government Area

Ado Ekiti: 25% (1 vote)
Efon Alaaye: 50% (2 votes)
Ekiti East: 0% (0 votes)
Ekiti South West: 0% (0 votes)
Ekiti West: 25% (1 vote)
Emure: 0% (0 votes)
This poll has ended

Ekiti Kete: (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (12) (Reply) (Go Down)

Re: Ekiti Kete by IFELEKE(m): 5:43pm On Oct 04, 2009
In Okun oo
Re: Ekiti Kete by Oluschenco(m): 4:10pm On Oct 05, 2009
@ IFELEKE
ooooo, in pele lube o, (am i correct)

I sure trust you for your assistance, you too much my guy.

topsy, Iyangbali and the rest, se alafia ni kete ria wa.
Re: Ekiti Kete by IFELEKE(m): 5:18pm On Oct 05, 2009
olu wo gbiyanju, okun, se ala lu e se?
o ti jo meta, se kete re i lo deede?
Re: Ekiti Kete by IFELEKE(m): 10:41am On Oct 06, 2009
In okun kete u le
Re: Ekiti Kete by r231(m): 2:14pm On Oct 06, 2009
Ifaki Ekiti signing in
Re: Ekiti Kete by r231(m): 2:32pm On Oct 06, 2009
Re: Ekiti Kete by IFELEKE(m): 3:00pm On Oct 06, 2009
r231:

Ifaki Ekiti signing in
grin
okun awe, kaabo. . .
Welcome as we make this place our e-state.
Re: Ekiti Kete by r231(m): 3:05pm On Oct 06, 2009
IFELEKE:

grin
okun awe, kaabo. . .
Welcome as we make this place our e-state.

thank u sir
Re: Ekiti Kete by IFELEKE(m): 3:18pm On Oct 06, 2009
aii dupe ora eni. . .tell us about ifaki
Re: Ekiti Kete by r231(m): 3:24pm On Oct 06, 2009
IFELEKE:

aii dupe ora eni. . .tell us about ifaki

wow dats a big one o. all i knw is the current governor (Segun Oni) is from Ifaki and my grandpa is d Oba (Oba G O Aladegbami IV) i have not been to ifaki in yearrrrrrrrrrrrs but we are good people i mean ekiti pple entirely

1 Like

Re: Ekiti Kete by IFELEKE(m): 3:37pm On Oct 06, 2009
yes we are good people. . .so you are ekiti in diaspora like me ?
Re: Ekiti Kete by r231(m): 3:42pm On Oct 06, 2009
IFELEKE:

yes we are good people. . .so you are ekiti in diaspora like me ?

yes o
Re: Ekiti Kete by topsy25(m): 5:25pm On Oct 06, 2009
hin ara lubei o wink
Re: Ekiti Kete by IFELEKE(m): 5:34pm On Oct 06, 2009
tope-lobi!!!!!!!!!
ope ooo grin
Re: Ekiti Kete by topsy25(m): 7:53am On Oct 08, 2009
e nle nbehun o
Re: Ekiti Kete by r231(m): 9:13am On Oct 08, 2009
^^^^ooooo awe
Re: Ekiti Kete by IFELEKE(m): 11:34am On Oct 08, 2009
In okun l'ule o
Re: Ekiti Kete by Oluschenco(m): 4:57pm On Oct 09, 2009
So my town (Ifaki) now has a website, okun ooo kete ile.
Re: Ekiti Kete by r231(m): 7:15pm On Oct 09, 2009
Oluschenco:

So my town (Ifaki) now has a website, okun ooo kete ile.

of cus now,,,,,how u dey
Re: Ekiti Kete by Oluschenco(m): 9:30am On Oct 11, 2009
@r231
Mo wa daada, se alafia ni iow na wa. okun o awe.
the website was nicely deigned kudos to all you at home.

Ifeleke, se alafia ni
Re: Ekiti Kete by Oluschenco(m): 2:17pm On Oct 14, 2009
it's quite some days that you people visited this thread. se ko si nkan kan.

o to ijo meta, Ifeleke, r231, Topsy etc, se alafia ni e wa.
Re: Ekiti Kete by r231(m): 2:29pm On Oct 14, 2009
ojo kan pelu o baba bawo ni gbogbo nkan
se alafia ni
epele o ara ile kete

1 Like

Re: Ekiti Kete by IFELEKE(m): 5:26pm On Oct 14, 2009
In okun oo!
olu,r231,topsy, otijo meta, se alaafia ni?
Re: Ekiti Kete by Oluschenco(m): 11:15am On Oct 16, 2009
Alafia ni mo wa, mo gbagbo pe alafia ni kete yin wa, se gbogbo e nrosi.
r231, Ifeleke etc. ki e ni nice opin ose (weekend)
Re: Ekiti Kete by busybody20: 10:50pm On Oct 18, 2009
e ku ijo meta. e ku miliki
ara ile yi nkan
Re: Ekiti Kete by Oluschenco(m): 2:08pm On Oct 20, 2009
Se thread yi ti su awon omo ekiti ni, e ma je ko re yin, e je ka gbe ile baba wa laruge, ajo ko le da bi ule.
Re: Ekiti Kete by r231(m): 2:23pm On Oct 20, 2009
hello ma pples
Re: Ekiti Kete by Oluschenco(m): 3:41pm On Oct 21, 2009
your peoples are responding hiiiiiiiiiiiiiiiiiiiiiiiiiiiiiiiiiiiiii tongue
Re: Ekiti Kete by topsy25(m): 4:57pm On Oct 21, 2009
IFELEKE:

In okun oo!
olu,r231,topsy, otijo meta, se alaafia ni?

Ala li mee ha jare awe mi. Oro use ria i ti sun mi o. O ti fe pami patapata


Ekiti kete, hin okun o. How una dey?
Re: Ekiti Kete by Oluschenco(m): 9:31am On Oct 22, 2009
@Topsy25
o ku ijo meta, pele, Oluwa a pin wa ni ere, o ni ku bayi, pa lanboke, kokoko lanbokuta, wa dagba, wa darugbo, ise rere ni Oba oke yio fun o.

What is the meaning of: Ala li mee ha jare awe mi
Re: Ekiti Kete by IFELEKE(m): 12:38pm On Oct 28, 2009
busybody20:

e ku ijo meta. e ku miliki
ara ile yi nkan
okun busybody, se ekiti ni e ni? wink

Oluschenco:

Se thread yi ti su awon omo ekiti ni, e ma je ko re yin, e je ka gbe ile baba wa laruge, ajo ko le da bi ule.
olu, kare o ku akitiyan ati gbe tireedi wa yi laruge, aba ri a a gbe a oo, eye ria a ti a leyin.
Re: Ekiti Kete by IFELEKE(m): 12:43pm On Oct 28, 2009
r231:

hello ma pples
awe
okun o, otijo meta, se ala lu e se? se kete re i lo deede?
aba re a gbe o.

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (12) (Reply)

Enugwu Ukwu In Anambra Where Pythons & Human Beings Live In Harmony / 6 Lovely Indigenous Nigerian Wedding Attires And Bridal Looks (photos) / Meet The Koma People Of Adamawa State Where Cloth Is A Prized Possession (Photo)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 21
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.