₦airaland Forum

Welcome, Guest: Join Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 2,008,545 members, 4,258,982 topics. Date: Friday, 25 May 2018 at 07:49 AM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! - Culture (71) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! (115229 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (1) (2) (3) (4)

(0) (1) (2) ... (68) (69) (70) (71) (72) (Reply) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by EzePromoe: 10:55pm On May 11, 2013
ekale o, awon omo Yoruba, inu mi dun lati mo yin smiley
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 8:03am On May 13, 2013
Eze Promoe: ekale o, awon omo Yoruba, inu mi dun lati mo yin smiley
Boo ni oo je e Eze puomo, se dada lo wa ? O ku ojumo !!!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by EzePromoe: 1:41pm On May 13, 2013
donroxy: Boo ni oo je e Eze puomo, se dada lo wa ? O ku ojumo !!!
E jo o, ko ye mi, N kò
le ye èdè Yorùbá
daradara, emi ni learner cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 9:02pm On May 14, 2013
donroxy: Boo ni oo je e Eze puomo, se dada lo wa ? O ku ojumo !!!
How are you Eze promoe,Hope u re fine,Good morning !!!

Eze Promoe:
E jo o, ko ye mi, N kò
le ye èdè Yorùbá
daradara, emi ni learner cool
eh eh eh grin

Nle oo jee omo Nna ....... Emi nio ye o nbe ? Laa hon mi kin salaye fun o ?

O kun ooo !!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by EzePromoe: 3:51am On May 15, 2013
donroxy: How are you Eze promoe,Hope u re fine,Good morning !!!

eh eh eh grin

Nle oo jee omo Nna ....... Emi nio ye o nbe ? Laa hon mi kin salaye fun o ?

O kun ooo !!
You were using Boo ni instead of Bawo ni, that is you're using your dialect, that's why i got confused.
THANKS ANYWAY!
Mo wa pa!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 12:43pm On May 16, 2013
Eze Promoe:
You were using Boo ni instead of Bawo ni, that is you're using your dialect, that's why i got confused.
THANKS ANYWAY!
Mo wa pa!
Tis not a Dialect but a way of shortening ''Bawo ni'' while speaking Yoruba ''Boo ni''


Just like shortening Yoruba=Yooba !!!!

Ndewo ooo !!!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by topazjosh(m): 10:08pm On Sep 13, 2013
Ejoo o,ogbeni seun ogagun abga NAIRALANDI,e so fun awon modireto kan gbe tiredi yii lo is fronti peji,"koko oju iwe"mo n. Fiili e,in other words
Ale o,ke n ti ri in ondo dialect!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by lushvox: 6:45pm On Dec 11, 2013
in the days of the colonial era - ni aiye awon ekolo ati ira

gone are the days - ibon ni awon ojo na

when things were good - ni igba ti agolo dara

but when things were bad - sugbon ni igba ti agolo baje

hence forth - adiye nja

... I forgot the rest...

2 Likes

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by abiolz(m): 11:50am On Sep 01, 2014
E ku osu titun yi o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by fuckluv(f): 7:29am On Sep 04, 2014
lushvox: in the days of the colonial era - ni aiye awon ekolo ati ira

gone are the days - ibon ni awon ojo na

when things were good - ni igba ti agolo dara

but when things were bad - sugbon ni igba ti agolo baje

hence forth - adiye nja

... I forgot the rest...
Yooba dun gan ooo! Ewo tiransilation aye! grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by CokerAnne(f): 10:42pm On Sep 08, 2014
E ku ale gbogbo ile o! E ku ise atooro o, se ko re ara ju?
Oruko mii ni omo-obabirin Adediwura Adeola, mo wa lati ilu kekere kan ni ipinle Ogun, mo je omo odun mejidin logbon, mo feran lati maa ka, iwe, mo is tun maa ngbadun ere alafe, mp je eni ti o ko eniyan mora lopolopo, mo is ni emi irele ati iteriba eleyi lo mu ki ifee mi l'okan omode ati agba. Month fee lati danu duro nibi yi naa. Ngo maa tesiwaju ni ojo miran. O daaro o, Oorun ire la o sun....
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 9:08am On Sep 09, 2014
CokerAnne: E ku ale gbogbo ile o! E ku ise atooro o, se ko re ara ju?
Oruko mii ni omo-obabirin Adediwura Adeola, mo wa lati ilu kekere kan ni ipinle Ogun, mo je omo odun mejidin logbon, mo feran lati maa ka, iwe, mo is tun maa ngbadun ere alafe, mp je eni ti o ko eniyan mora lopolopo, mo is ni emi irele ati iteriba eleyi lo mu ki ifee mi l'okan omode ati agba. Month fee lati danu duro nibi yi naa. Ngo maa tesiwaju ni ojo miran. O daaro o, Oorun ire la o sun....

E ni aamu s'aya kiss
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by bolorunfem(f): 4:23pm On Nov 26, 2014
Eyin temi, ibo le wa? O to jo meta? Se alafia ni e wa gege bi emi naa se wa nihin? Se ise nlo? Ile nko? E de ku ipalemo odun, a a ba wa layo ati alafia. E jowo e ma je ki okun yi ku o, e je ko maa lo bee. Yoruba dunn ka, Yoruba dun lede. One Love!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by bolorunfem(f): 7:40am On Mar 25, 2015
lushvox:
in the days of the colonial era - ni aiye awon ekolo ati ira

gone are the days - ibon ni awon ojo na

when things were good - ni igba ti agolo dara

but when things were bad - sugbon ni igba ti agolo baje

hence forth - adiye nja

... I forgot the rest...

Well, well, well - Kanga, kanga, kanga
Who knows? - Imu tani
Nobody knows - Kii se imu enikeni
Only God knows - Imu Olorun ni
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Carriacou1985(f): 5:04pm On Mar 25, 2015
Greetings to you all,

I am trying to learn more about my culture, although I am not of Nigerian or even African blood but I hope maybe someone can help me. I have recently created a post here to find out if some ancient songs and dances originated from the Igbo people of Nigeria passed down to us from our ancestors taken from west Africa in the slave trade. I had 2 replies which said that the language of the songs sounded more like Yoruba than Ibo. So maybe someone here can clarify it for me?

In our tradition we perform a big drum dance for weddings and funerals and other events to receive blessings from our ancestors gone before us.

The song is called: Ibole Ibole woy yo

Gongo banan plantain
Me wo yo
Ibole Ibole woy yo
Hele bu Legba wo yo


We also have another song entitled: Ogun maa se sile wa

Can someone pls tell me if this could be the Yoruba language?
Many thanks in advance
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by seedorfg(m): 6:20pm On Apr 04, 2015
e ku iyaleta o, eyin omo ile kaaro o'jire, se dada lawa, e si ku osu titun yi o, emi ishola agbo, omo a'ji lala eso, a'fi gbogbo ara da bi egbin, ala i gbagbe oju o r'eje, fi gbogbo oju sunkun omi, nki gbogbo yin oooo !
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by tpiadotcom: 12:54am On May 12, 2015
tunnytox:
@Ileke idi

Ekiti wo ni ti yin o? Mo feran Orin Chief Commander Ebenezer Obey pupo ninu awon rekodu re kan lo ti daruko gbogbo awon Ekiti gege bi awon akinkanju omo yoruba. rekodu naa ni Evergreen songs 4, ni ibere rekodu na o bere pelu lagos state, ki o to wa ki Ekiti bayi pe:

Awon omo Ekiti won n ka'we won mura 2ce
Ado ekiti to fi de iyin ekiti, iyin ekiti to fi de ilawe ekiti,
ilawe ekiti to fi de'poti ekiti
Ipoti ekiti to fi de aramoko
oga ni won je won n ka'we won mura

Iyin ara omo ilu ekiti jeje na mi se won o ya'ra ria n

I hope you can understand the lyrics lol, e je ki a mo ti e ba ma n gbo rekodu Obey.

Oun kan ti mo beru pelu awon Ekiti nikan ni iwa agidi, ah awon ekiti kan won ti won ni agidi gan!
sugbon sibe sibe omo atata yoruba ni awon ekiti je coolwhere did an ogbomoso man learn to speak ekiti?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 11:07pm On May 13, 2015
tpiadotcom:where did an ogbomoso man learn to speak ekiti?

iwo ko tie le ko ede abinibi re. geesi ni ki o ma a so nibe. ko ra re kuro lori tiredi yi jare.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Ousmaf(m): 7:43am On Sep 14, 2015
Eku ojumo nle se alafia laji bii?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Ousmaf(m): 7:45am On Sep 14, 2015
Ekaaro nile yi o se dada laji?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by minato015(m): 10:50am On Nov 11, 2016
[color=#000099][/color] E karo ni yara yi oo... She gbogbo yin wa pa
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Olu317(m): 2:40pm On Nov 11, 2016
E ka san eyin eyan mi, se da da ni awa
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by YourNemesis: 6:03pm On Nov 11, 2016
Olu317:
E ka san eyin eyan mi, se da da ni awa

Beeni, dada ni a wa.
Bawo ni gbogbo nkan se n lo? E ku asiko ti a wa yii o.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Olu317(m): 7:54am On Nov 12, 2016
E kaaro o gbogbo omo oduduwa. Mo dupe lowo Eledumare fun ore ofe ati abo e lori ebi mi ara ati oju lumo. Aku ifarada ijoba Buhari. Anu olorun a yiwa ka
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by scholes0(m): 8:07am On Nov 12, 2016
Olu317:
E kaaro o gbogbo omo oduduwa. Mo dupe lowo Eledumare fun ore ofe ati abo e lori ebi mi ara ati oju lumo. Aku ifarada ijoba Buhari. Anu olorun a yiwa ka

Inu mi dun lati ri wipe Yoruba kiko le ti owo omo Oodua dun ka bi eleyii.
Pupo ninu wa ni ko mo ede Yoruba kiko bi o se to, ati bi o ti ye.
Ki n maa fa oro gun sa, E ku ise. Olorun yio so agbara yin di otun.

1 Like

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Rilwayne001: 8:30am On Nov 12, 2016
grin grin
topazjosh:
Ejoo o,ogbeni seun ogagun abga NAIRALANDI,e so fun awon modireto kan gbe tiredi yii lo is fronti peji ,"koko oju iwe"mo n. Fiili e,in other words
Ale o,ke n ti ri in ondo dialect!

Aayan Ogbufo yin buru jai angry angry

1 Like

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Rilwayne001: 8:34am On Nov 12, 2016
Eku owuro ni ahin o. Oruko tawa ni Riliwanu Adigun. Inun mi dun, ayo mi kun lati ti ri awon omo iya mi lori tiredi yii.

Oodua agbewa ooo!

Ogagun Sukkot, a nreti yin nikale o wink cheesy

1 Like

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by haffaze777(m): 8:49am On Nov 12, 2016
L'esi omo oluware iyi da iru eleyi l'asa?too Dede eyin ojogbon iyi wa Ni ikale ree mo kii.Emabinu pe ede egba re emi fi ki yin oooo,ba ra'se n se n'ile lisabi agbongbo akala,ololajulo oba rilwayne001 e wa ko ede egba
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Rilwayne001: 9:15am On Nov 12, 2016
haffaze777:
L'esi omo oluware iyi da iru eleyi l'asa?too Dede eyin ojogbon iyi wa Ni ikale ree mo kii.Emabinu pe ede egba re emi fi ki yin oooo,ba ra'se n se n'ile lisabi agbongbo akala,ololajulo oba rilwayne001 e wa ko ede egba

grin grin

Ede Yoruba ponbele la n so ni ori tiredi eleyi. Ede egba yii le pupo, o yato gedegbe si Yoruba tiwa n'Ibadan. angry
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by sukkot: 11:27am On Nov 12, 2016
Rilwayne001:
Eku owuro ni ahin o. Oruko tawa ni Riliwanu Adigun. Inun mi dun, ayo mi kun lati ti ri awon omo iya mi lori tiredi yii.

Oodua agbewa ooo!

Ogagun Sukkot, a nreti yin nikale o wink cheesy
ekaro Sir. ekugbogbo e. shey gbogbo e nlo Sir ? akoba adaba oloun majari lolzzzzz <<< THE BOLDED IS HAUSA PRAYER WHEN I WAS DOING TIME IN LAGOS grin grin

2 Likes 2 Shares

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Justiceleague1: 5:18pm On Nov 12, 2016
Rilwayne001:
Eku owuro ni ahin o. Oruko tawa ni Riliwanu Adigun. Inun mi dun, ayo mi kun lati ti ri awon omo iya mi lori tiredi yii.

Oodua agbewa ooo!

Ogagun Sukkot, a nreti yin nikale o wink cheesy
ahhhh! Shebi mo sò tèlé. Mo mò pe orukò yi riliwanu.....haaahahahahaha....
Èèle,ooo, gbo gbo òmó ègbé..well orukò mi ni dafidi.. cheesy cheesy
mo kii gbogbo yii o...ka se ma dupè fun òlòhun fun Trumpu to ti di president ni ilu America. Gbogbo awa,afonja,inu awa dun.. grin

1 Like

(0) (1) (2) ... (68) (69) (70) (71) (72) (Reply)

Post Pics Of Fulani Girls! / A Picture Gallery Of Igbo Traditional Marriage Ceremony "Igbankwu" / Akan Of Ghana And Cote D'ivoire

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (0) (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2018 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 110
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.