Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,147,977 members, 7,799,324 topics. Date: Tuesday, 16 April 2024 at 06:57 PM

Asiri Agbara Lati Mu Ona Ola Si Kia Kia - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Asiri Agbara Lati Mu Ona Ola Si Kia Kia (8054 Views)

Queen Ola Ajoke Adeyemi (Throwback Photo As A Little Girl) / Ogun Owo World Wild Ati Irawo Wiwo 09079098548 Lati Owo Asiri Ifa Irawo Wiwo / Asiri Ijinle Awon Woli Lailai (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Asiri Agbara Lati Mu Ona Ola Si Kia Kia by Orisayemi05(m): 12:22pm On Jan 15, 2017
Gbogbo owo ti ahuna oga aiye kan ao mon fi owo yi han oga yi leyo koo kan titi ti yio fi gba awo owo won yi tan,ewe sawerepepe ojo,ewe dandan die,ewe aje sefunsefun,itana tanapaje,ewe olaa die,ewe tagiri ojo,awo ekun die,odidi atare kan,jijo ao mo lo pelu oti schnapps ni igba ti osu ba sese jade. odara fun okunrin odara fun Obinrin. Ogun todaju ni o.
(2) Odidi eiyele funfun kan,Eko elewe,ogede agbagba,omo oyoo die,odidi atare kan.jijo ao mon fi oti lo loro loro.
(3)Ori oka to tobi kan,ao fi eran ofafa si inu owo tuntun ao fi ewe olaa si ni oke ati isale ao we bi siga ao fi ha enu ori oka yii ao wa iru woro to po pelu odidi atare kan jijo ninu isasun tuntun,aoa da si ona meje ao lo fun ojo meje pelu oti.
(4)okan malu ti o wo omi,afomo iroko,ewe epinle,ewe aje,ewe sawewe ao gun po mon ose dudu ao mon we ni ago kan oru lori odo tabi aga pelu gbolohun pe epin pin temi fun mi loni,iwo lo pin ti afomo to fi je oloja igi,gbogbo ara ni sefunsefun fin se fun aje ti e,kin fi gbogbo ara sefun aje loni titi lailai,sawewe de omo olode abifa gburu,kin je ifa owo lowo olowo,gbogbo eya ara ni basiri okan,ki gbogbo olowo wa fi owo owo won bomi lasiri,nitori owo nla nla ni won fi ra malu. wiwe. Ogun Asiri owo yi wa lati owo baba mi Osayemi akoko..ibare ooo...sun re ooo. Emi ni Osayemi Ifalooba omo Osayemi Ilariogun. 09076586610

1 Like

(1) (Reply)

Translate This Yoruba Proverb To English / Pagan9ja - I Want To Clarify Something For You / Inside The Palace Of Ezechumagha Of Ogidi Kingdom HRM IGWE ALEX UZOR ONYIDO

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 8
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.