Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,150,471 members, 7,808,696 topics. Date: Thursday, 25 April 2024 at 03:34 PM

Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re - Culture (5) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (285221 Views)

Owe Yoruba / Akpaala Okwu (idioms). / Igbo Idioms (Ilu) (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (Reply) (Go Down)

Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by Akanniade(m): 8:36pm On Feb 27, 2011
Iku npa alagemo to yole nrin, kambelete opolo to ngbe are re shonle.
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by Akanniade(m): 8:37pm On Feb 27, 2011
Iku npa alagemo to yole nrin, kambelete opolo to ngbe are re shonle.
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by KennyG6(m): 8:38pm On Feb 27, 2011
^^^^meaning
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by Akanniade(m): 10:03pm On Feb 28, 2011
^^^^The chameleon that approaches with caution dies, how much more the toad that slams its body with every step.

The moral in the proverb is to approach life delicately.
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by KennyG6(m): 10:49pm On Mar 02, 2011
Orí tí yóó gbeni ní gbé aláwo ‘re ko ni. Meaning: your destiny is in your hands
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by dbabahimse(m): 11:35pm On Mar 02, 2011
Akini n je akini, afinihan n je afinihan, ewo ni pele ara ijaye ti o n koja lojude Ogunmola
meaning, if u are greetin, greet and if u want to expose me, do so why say good day a native of Ijaye land passing infront of Ogunmola's court
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by KennyG6(m): 9:06pm On Mar 06, 2011
Àifète m'éte, àìfèrò m'erò, ọmọ iya mẹfa kú si oko ẹgbàafà.
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by Akanniade(m): 10:00pm On Mar 07, 2011
Iku npa agiliti alawo, kambelete eni ti fi awo re sogun aaiku.

Meaning: Agiliti is a resilient type of lizard of the Iguana family, whose tough skin is often used in making longevity charms. The moral of the idiom is, just as the agiliti eventually dies, so will owner of the charm. No one lives forever.
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by bababuff(m): 10:49am On Mar 10, 2011
Elete lete nye  -- The treacherous one understands his treachery.

Meaning - You understand your tricks or actions.

1 Like

Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by KennyG6(m): 10:13pm On Mar 14, 2011
bami na omo mi ko denu olomo
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by tubabie(f): 10:31pm On Mar 14, 2011
Ile la ti n ko eso rode-- charity begins at home
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by KennyG6(m): 10:33pm On Mar 14, 2011
Eni tí ó n ko orin tí kò dùn, o ṣa nfeti ara e gbo
mea ning:Be careful whatever you do,you might be affecting yourself indirectly
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by Akanniade(m): 11:59am On Mar 15, 2011
A pa emo loko ila, a se sinu ilasa. Oko emo lemo lo.
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by KennyG6(m): 9:32pm On Mar 15, 2011
olodo rabata oju eja lo mo je
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by Akanniade(m): 9:19pm On Mar 30, 2011
oo semu logbe, o toguro lofa, o gbenu soke sidi ope. Ofe lemu ro ni?
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by Remii(m): 9:16pm On Apr 10, 2011
Lapalapa ni ibere ete, ki eniti o ba ni ifo lehin orun kiyesi ara e. (leprosy starts like ringworm, whoever has ezcema should should take care) =  Respond to early warnings signs.
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by Remii(m): 8:26pm On May 08, 2011
Ota eni kii pa odu oya, baa so ileke, baa wo akun, igi ata laa jo l'oju abinu eni
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by tubabie(f): 8:39pm On May 08, 2011
Owo omode ko to pepe, ti agbalagba k'owo keregbe
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by KennyG6(m): 8:42pm On May 08, 2011
enu agba ni obu tin gbo; meaning: The aged are best at handling matters that are otherwise distasteful or unpleasant
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by tubabie(f): 8:54pm On May 08, 2011
Aigbo'fa la n wo'ke, Ifa kan k'o si ni pepe . . . . . . we often look up searching for answers that aren't there when bewildered !
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by Dotman01(m): 6:12pm On May 10, 2011
sapatara lan sinto meaning wat is worth doing is worth doing well
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by abdurrazaq(m): 12:38pm On May 22, 2011
Ejo to n yo je lo n to itan - Only a cautious snake grow to the size of a thigh.

It can be used to warn someone of overconfidence or to desist from troubles
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by Akanniade(m): 8:42pm On May 22, 2011
Dotman01:

sapatara lan sinto meaning wat is worth doing is worth doing well

sapatara lan sinto. Bito ba nyi layiju, o ndi takurawapa.
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by lucabrasi(m): 12:23am On May 23, 2011
kaka ki kiniun she akapo ekun onikaluku a she ode loto, loosely translates that rather than the lion (kiniun i think?)being the keeper of the meat belonging to both it and the leopard,each one ll go off and keep its own meat(i know the explanation sounds dodgy but theres no easy way lol)
the rationale of the proverb is that rather than someone cheating and making your situation worse you ll rather go it on your own terms as it will be better than the present situation
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by lucabrasi(m): 12:26am On May 23, 2011
orisa bi oo le gbemi she mi bi o she bami loosely translates diety/god if you cant help me/my situation then pls leave me be in my present situation.
the rationale behind this proverb is that rather than worsen my situation from bad to worse,fryingpan to fire let me be in my present situation
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by Remii(m): 11:02am On Sep 11, 2011
Isu ata yan an yan an = state of chaos, when one problem is leading to another making the situation uncontrollable
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by Remii(m): 6:57pm On Jul 03, 2012
Egbirin ote, baa ti npakan lokan nru
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by lawani: 12:49am On Apr 27, 2016
Akanniade:
Abu ni nje abuni, afini han nje afini han, ewo nti ewo ara ibadan ti nlo lojude ogunmola.
Used when someone while seemingly making a joke is really putting you in trouble.

It is Nle ara Ijesa or Nle ara Ijaye ti nlo lode Ogunmola. The proverb was because Ibadan was at one time or the other at war with Ijesa and Ijaye and Ogunmola was Basorun Ibadan.
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by professore(m): 9:16pm On May 17, 2016
This is a nice thread.
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by Nobody: 9:49am On Nov 09, 2017
God bless you all life savers!

1 Like

Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by AJIKOLA: 8:42am On Dec 03, 2018
hg
Re: Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re by AJIKOLA: 8:43am On Dec 03, 2018
Wow this is a good thread, I have added lots of proverbs to thebones I know

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (Reply)

Keggites Members : Introduce Yourself & Ilya / Igbo Kwenu! Kwezuo Nu! Join Us If You're Proud To Be An Igbo Guy/lady / Nigerian Pidgin English And Their Meanings

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 19
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.