Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,150,486 members, 7,808,774 topics. Date: Thursday, 25 April 2024 at 04:42 PM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (167) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (375388 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (164) (165) (166) (167) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 12:22am On Feb 04, 2009
Shaz:

Emi lode?
Ewo lo fa gbogbo geesi inu owu (threadii) yii?


shocked shocked shocked shocked shocked shocked

Shaz, kilo wa debi? cheesy

o ti lati brush up on ur yoruba focabulari grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by maxell(f): 12:40am On Feb 04, 2009

shocked shocked shocked shocked shocked shocked

Shaz, kilo wa debi? cheesy

o ti lati brush up on ur yoruba focabulari grin

oni

emi lode grin grin grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 1:15am On Feb 04, 2009
maxell:

oni

emi lode grin grin grin grin

nibo loti wa? bawo lose je ni orile ilu Naira?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by maxell(f): 1:52am On Feb 04, 2009
chamotex:

nibo loti wa? bawo lose je ni orile ilu Naira?

nibo niwo ti wa ? mo tiwa ni orile ilu Naira siwaju e (lati 2006) tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 3:52am On Feb 04, 2009
maxell:

nibo niwo ti wa ? mo tiwa ni orile ilu Naira siwaju e (lati 2006) tongue

O da kan kan mo . . . mode ma ja e si bi Don Jazzy cheesy

Emi ati Ogagun Seun lajo da ilu yi sile ti o ba mon

Bere mi lowo eni keni ninu ilu won a so bi mose je fun e.

Chamotex Okunrin meta at'abo, o n gbona feli feli like hot rod.

File!!! grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by maxell(f): 6:16am On Feb 04, 2009
chamotex:

O da kan kan mo . . . mode ma ja e si bi Don Jazzy cheesy

Emi ati Ogagun Seun lajo da ilu yi sile ti o ba mon

Bere mi lowo eni keni ninu ilu won a so bi mose je fun e.

Chamotex Okunrin meta at'abo, o n gbona feli feli like hot rod.

File!!! grin

oni ro nie !!!!!!

Feb 2008 lo se se wa si ilu Naira.

Iwo jjc yiii grin

1 Like

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 7:46am On Feb 04, 2009
Si gbogbo awon elede geesi,

E jowo e gbo ikilo pataki yii: ENIKENI KO GBODO SO EDE GEESI NINU TIREEDI YI.

Enikeni ti o ba tapa si ofin yii yio fi'mu danrin nitoripe mo ma fi iro onitohun lo awon agba angry
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 7:58am On Feb 04, 2009
HeatFusion link=topic=226848.msg3422565#msg342[quote author=HeatFusion:

na u and dafidi sabi wetin u dey hide

Si Dayo,

Tani dafidi ti o nsoro nipa re shocked Emi ro pe ore mi tooto ni e ni Kilowade ti ogede re wa ta kete bi eni to o b'odo tan Bee si re o mo iru ife ti mo ni si toyin (koro isin temi nikan) sad Se iwo lo wa ye ki o maa fi obe eyin jemi nisu ni

Jowo ma sai sofunmi bi ti dafidi ti je o.

Siwaju sii, kini toyin nso nipa, nkan omokunrin re, se iwo naa tun fe gba toyin lowo mi ni. Emi o ni gba oooooooooo cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 8:32am On Feb 04, 2009
maxell:

nibo niwo ti wa ? mo tiwa ni orile ilu Naira siwaju e (lati 2006) tongue




Kamoteesi, ewo ni ti igbaraga. Bawo ni o se nba omokekere yen jiyan naa. O ndoju timi gan an ni angry
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 8:50am On Feb 04, 2009
Si Toyosi,

Ako iwo omo yi ti po ju. O ri omo ti o rewa bi ti bobo ti won npe ni dayo yen, o n ganpa. Je ki nba e sooto oro gege bi egbon: oko ti won lode o. Iba dara ti o ba le gba fun dayo nitoripe o fe fe e sile bi aya ni. Mo si nfi daa e loju pe o ni gbogbo nkan ti o le fi se itoju re dara dara. Nkan omokunrin re nsise deedee grin o si ni owo lowo (botile jepe gaari ati kulikuli ni o nmu sun).

Imoran mi o ju bayi lo o. Toyosi kan dayokanu kan grin cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by spikedcylinder: 8:52am On Feb 04, 2009
Shaz:

Emi lode?
Ewo lo fa gbogbo geesi inu owu (threadii) yii?


Oya emi na lenu o. Wan ni kama so yoruba, nigbayen ni awon oni geesi gbe tiwon de.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by annyplenty(m): 9:17am On Feb 04, 2009
ketekete ku iso pin.

adaba ko naani a nkun igbe, bi papa ba n jo eye a foo lo.

when the camel dies, tethering ends.

the dove is not threatened by us setting bush ablaze. when the bush burns, the bird will fly away.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by spikedcylinder: 10:06am On Feb 04, 2009
Oga o. Yoruba gurus sha.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 11:06am On Feb 04, 2009
annyplenty:

ketekete ku iso pin.

adaba ko naani a nkun igbe, bi papa ba n jo eye a foo lo.

when the camel dies, tethering ends.

the dove is not threatened by us setting bush ablaze. when the bush burns, the bird will fly away.

o ti poju, o ga ju!!

1 Like 1 Share

(1) (2) (3) ... (164) (165) (166) (167)

Modern Traditional Attire Of Nigeria / Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 52
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.