₦airaland Forum

Welcome, Guest: Join Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 2,009,085 members, 4,260,987 topics. Date: Saturday, 26 May 2018 at 10:50 AM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (90) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (246282 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (1) (2) (3) (4)

(0) (1) (2) ... (87) (88) (89) (90) (91) (92) (93) ... (166) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 2:02pm On Aug 02, 2007
haba, baale!! ki lo nsele ni ilu ti apa yin o ka?
se rogbodiyan wa ninu ilu ni?
e fi okan yin bale.

how is work? [sub][/sub]
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 2:39pm On Aug 02, 2007
tafari:

haba, baale!! ki lo nsele ni ilu ti apa yin o ka?
se rogbodiyan wa ninu ilu ni?
e fi okan yin bale.

how is work? [sub][/sub]
Ko si ohun to bo nile ti , ile o gba o, apa oba ka ilu tepontepon. Sugbon nipa ti oye, je ki a mu dani si egbe kan na.
Ise wa pa o ( and yours?)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 3:26pm On Aug 02, 2007
richylaw:

Mishoo has been very sensitive to the richness of entertainment , culture and play of words in the album (kudos).
Mishoo boya ko o ju ti 'Bolanle Olomoge' ati 'Mummy' si ori afefe fun wa.

According to 'HIGH' Demand

http://download.yousendit.com/D4428F1E3FB86EE5
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 4:30pm On Aug 02, 2007
o fi dudu je won    bolanle
o fi pupa je won    bolanle
o fi kebe je won    bolanle
Ibadi aran o          bolanle
Face of africa,      he he
Ajoma gbadun ni le yi o  Bolanle    please don't hold me I want to dance

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 4:40pm On Aug 02, 2007
E pagbo !! E pagbo oooo!!

Abeg, Clear ground !!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 4:57pm On Aug 02, 2007
Baby baby Bolanle
bebebi sisi alakada
arewa fi wa sewa
omodun
bebebi olomoge
duro na ire la n bawi
danwo lo bi 'ya okere
emi gangan ni baba okere
o da wo mi ko tun mi wo baby
mo dun mo tun re ni tun fi jo
gbe mi wo bi jigi jigi
jigi jigi
baby mo ni ko fe mi
wa wa gba p'ori loni fila
wa tun gba p'ese lo ni bata
baby surulere, o sa mo levels ti mo wa
gbami  gbami towo tese yi o, olomoge

Baale has gone gaga and groovy    okay dig it , dig it  grin

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 5:12pm On Aug 02, 2007
You only need to really see me dancing. Play the song and watch these guys dig it grin grin grin.
Original ijoya level.

JUST A PRE-FRIDAY JOLLIFICATION

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 5:17pm On Aug 02, 2007
Ase o wa lara bale to bayi !!

Tani yio ba bale jo oo??

Nana, Ikamefa, Desorlah, minute, omoge, omoeko, nibo ni gbogbo yin wa oo??

Dance dey waste !!!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 5:23pm On Aug 02, 2007
emi naa fara mo ijo pelu baale jare, oya eyin omidan ilu, e jade kie bere si ni komole! cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 5:31pm On Aug 02, 2007
Mo tin komole but no one is spraying money on me.Mo like e o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 5:36pm On Aug 02, 2007
nana:

Mo tin komole but no one is spraying money on me.Mo like e o

Se loto ni Baale?? But Baale lowo lowo gan now !!!
Abi awon kan n sa owo yen nile ni??
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 5:38pm On Aug 02, 2007
O da ma na e lowo oo!!!

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 5:42pm On Aug 02, 2007
Mishoo angry Of all currencies ti Naija ni,awon owo kekeke yen ni on na fun mi.Abi o ti gba pension salary ni?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 5:48pm On Aug 02, 2007
nana:

.Abi o ti gba pension ni?
Oun lo ogun ni?
Bawo ni o se mo??
Eru re bami oo !!!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 5:53pm On Aug 02, 2007
Lol, so mo get e.Mo ko guess ni.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 5:55pm On Aug 02, 2007
Je ki nwa ebun kan fun e !!
Ki o ba le ranti ile !!

http://www.yousendit.com/download/ZUcyQ3Q5Q1JmVFkwTVE9PQ
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 5:59pm On Aug 02, 2007
O se o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 6:03pm On Aug 02, 2007
nana:

O se o

Ha !!!
Ori mi wu ooo !!!!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 6:16pm On Aug 02, 2007
je ki o ma wu o mishoo
Nana, iwo ma worry, baale ki na wo loju agbo, cheque e wa nibi yi je ki a jo tan!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 6:23pm On Aug 02, 2007
richylaw:

je ki o ma wu o mishoo
Nana, iwo ma worry, baale ki na wo loju agbo, cheque e wa nibi yi je ki a jo tan!
Baale !!
Bi awon agba ba n yo ile da, ohun abenu a ma yo won se oooo Yoruba proverb
Ojoro leleyi ooo!! A o si ni faramo !!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 7:40pm On Aug 02, 2007
@borrado
LOL ni edee yoruba tumo si ERIN NI YANTURU tabi OPOLOPO ERIN
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 7:44pm On Aug 02, 2007
@ola2k
Mo gbadun akosile ede yorubaa re gan ni o. Nje o le ko mi bi a ti se n lo ero komputa lati fi aami si ori ati idi oro yoruba. Nitori mo gbadun lati maa yan awon akosilee mi pelu ami ti o ye
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 8:00pm On Aug 02, 2007
si bodsibobo
aayan ongbufoo re dun ka
o yo kululu bi elubo ti a jo daada
sugbon O TAKE ADVANTAGE tumo si O LO ANFAANI
opolo e o nii ku
AMIN
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 9:15pm On Aug 02, 2007
aayan ogbufo gidi ni ogbeni ayanjide nse o! grin grin

Baale wa oye ki a wa ipo kan fun ogbeni ayanjide ni aafin, iru imoran yii ma wulo gan fun ise eto ilu ti Baale nse, pelu awon omo Londona ati Americana ti won po si ni ilu wa yii cheesy

Erin lopolopo (aka LOL) grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 4:06am On Aug 03, 2007
Debosky ,O ti da be na nu, sugbon yio dara ki alagba  Ayanjide fi ara mo wa dara dara ninu abule yi ki a to le mo iru eni ti won je gan.
F'otun we osi, f'osi we otun , ki owo sa ti mo ni
Isiwo iporo wo, ohun aba jo wo gigun ni gun
Ogidimolaja , Ayanjide ti d'awo ile Ife loni o, kawo mo gbe awo nigbowo loku, k'awo mo ba te , k'awo mo ba ya

Mishoo, o da mi loju wipe gege bii baale , n o ti jayo pa lati fun Nana ni iwe sowe dowo.Debosky oko re na o si binu si rara. O sa san ki a na owo fun eni ti o mo iyi re. Abi o ti gbagbe iyawo kekere ti a fe fun baale ni ojo kinni ana (Mukinatu)! awon da loni?Aini suuru ti mu won siyan lai duro gbobe ,owo ti o si ye ki a na fun iru won ni a pa ona re da si odo awon ti o mo iyi wura wonyi o. Se bi iwo na mo wipe ohun ti "agbalagba fi n jeko abe ewe lowa. Eyi ti o si fi ju omode lo, ko ni fihan, bi o ba fihan ko ni fi le lowo, bi o ba file lowo, ko ni ko bi yio se lo, bo ba situn wa ko wayi, ko ni fun lero re, amo sa o bi o ba fun lero re , ko wule ni fi ewe ti a fi n ki han tori ojo t'ewe o ba sun oko." Nitorina na agba t'emi o yo le da o
Ko je bo ti je , eje ki a ma rin erin yanturu bi asa Ayanjide grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by aloib(f): 4:21am On Aug 03, 2007
ahhhhhhhhhhhhhhhh, yoruba yi le ju temi lo o cry cry cry cry
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 9:37am On Aug 03, 2007
Aloib ki lo tii fa ekun ninu oro yi, fi suuru ka yoruba yi daadaa , yi o ye o. Sebi awa omo iya re na ni a ko si le. Ni gba ti iwo ko tire  awa na sa ka!

Desorlah bawo  lariya de se ma ke de ri loni ke? Ojo Eti miran tun leleyi o, je ki n fun e ni 'logo' ti o wa nisale yi ki o fi bere si se ajoyo Friday, emi na fe bo si enu ise ni akoko yi o.

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 9:44am On Aug 03, 2007
Baale ati gbogbo mutumuwa, e ku owuro oooo.
A a jirebi ?? A ke ojo eti miran oo!!!
A o se opolopo laye ati laaye wa !!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 10:24am On Aug 03, 2007
Eku Ojumo o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dblock(m): 10:26am On Aug 03, 2007
Yay Ojo friday ni

Tse mo wipe, mo fe gun enikan ni ogun, ma gun ijoku kin mu ogun mi, kin ni agbara kin gun enikan ti mofe gun ni ogun, to shele nisin sin ni Ogun state. grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 10:34am On Aug 03, 2007
La lale friday,Temi o ba sun le o.
Orin wale mon gbo o
Ti mo fi gbera gege,gbera gege,gbera gege
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 10:34am On Aug 03, 2007
dblock:

Yay Ojo friday ni

Tse mo wipe, mo fe gun enikan ni ogun, ma gun ijoku kin mu ogun mi, kin ni agbara kin gun enikan ti mofe gun ni ogun, to shele nisin sin ni Ogun state. grin
What?

(0) (1) (2) ... (87) (88) (89) (90) (91) (92) (93) ... (166)

Pictures Of African Traditional Clothing! / Post Pictures Of Traditional Weddings. / Nairaland Official Igbo, Hausa and Yoruba Dictionary

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (0) (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2018 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 82
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.