₦airaland Forum

Welcome, Guest: Join Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 2,023,583 members, 4,314,674 topics. Date: Saturday, 23 June 2018 at 06:50 PM

Post Yoruba Christian Hymns Here - Religion (4) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Religion / Post Yoruba Christian Hymns Here (171407 Views)

Post Your Favourite Christian Hymns / Share Your Best Hymns / Christian Hymns/songs And Copyrights (1) (2) (3) (4)

(0) (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (Reply) (Go Down)

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Enigma(m): 8:59pm On Jun 14, 2012
Spambot ha! Well, so much for joining thread with gusto. grin

Enuwe, e no fit catch me this time AS I only remember first verse.

Ẹmi Ọrun Gb'adura Wa by Thomas Ẹkundayọ Phillips http://africlassical.blogspot.co.uk/2011/08/christopher-oyesiku-reviews-thomas.html

Ẹmi ọrun, gb'adura wa
Wa gbe 'nu ile yi
Sọkalẹ pẹl'agbara Rẹ
Wa, Ẹmi Mimọ, wa.

Another one that, firstly, I like but also which has international critical recognition and sometimes sung by even 'highbrow' Anglican churches in UK (and also in churches in the US as I've just discovered) is:

Wa Wa Wa Ẹmi Mimọ

Wa Wa Wa Ẹmi Mimọ
Ẹmi Olore
Wa wa wa Alagbara
Alagbara Giga (or Mẹta) oh
Wa oh, wa oh, wa oh


https://www.youtube.com/watch?v=Aw-_bSn90lE


https://www.youtube.com/watch?v=kPXiQ0I1HcM

1 Like

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by dayokanu(m): 9:36pm On Jun 14, 2012
Ore bi Jesu ko si laiye yi

Jesu nikan lore otito

ore aiye le ko e sile

Sugbon Jesu ko je gbagbe mi
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Miroslavklose: 10:27pm On Jun 14, 2012
Baa wo le se to bi to oluwa
OLORUN gbogbo aiye, e ese tobi to?
Gbogbo aiye ko le gba yin
Gbogbo Orun ko le gba yin
Oluwa ese tobi to

1 Like

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Enigma(m): 12:30pm On Jul 06, 2012
Ah, one post I saw on another thread like that reminded me of this thread. smiley

Jesu N'pe Wa L'Ọsan L'Oru (I can only remember the first two verses clearly, I'm afraid)

Jesu n'pe wa l'ọsan l'oru
L'arin irumi aiye
L'ojojumọ la n'ngbohun rẹ
Wipe Kristẹn tẹle Mi

Awọn apọsteli 'gbani
Ni odo Galili ni
Wọn kọ ile ọna s'ilẹ
Gbogbo wọn si n'tọ l'ẹhin

. . .

cool

2 Likes

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Ptolomeus(m): 8:26pm On Jul 06, 2012
A cult abroad (foreign), who left the slave conquiistadores, sung in the vernacular.
In the eyes of a researcher, it is interesting ... and leads to several conclusions.
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Enigma(m): 10:49am On Jul 07, 2012
Another one of which I can only just remember two verses (and bits of others) and perhaps not fully accurately.

Anyhooooos , here goes:

Ẹ jẹ ka jumọ f'ọpẹ f'Ọlọrun
Orin iyin atọpẹ lo yẹ wa
Iyanu n'ifẹ rẹ si gbogbo wa
Ẹ kọrin iyin s'ọba olore wa.

Chorus: Halleluya ogo ni f'Ọlọrun
A f'ijo ilu yin Ọlọrun wa
Alaaye ni o yin ọ bo ti yẹ
Halleluya ogo ni f'Ọlọrun

Ki l'a fi san j'awọn t'iku ti pa
Iwọ l'o f'ọwọ wọ wa di oni
Iwọ l'o nṣọ wa t'on gba wa lọw'ewu
Oba wa aiku Onibu ọrẹ

Hallelujah ogo ni f'Ọlọrun etc etc etc

cool

2 Likes 1 Share

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by OmoNaija4uk: 2:41pm On Aug 08, 2012
wow! this is sooo nice!!! smileyOlori Ijo t'orun

https://www.youtube.com/watch?v=x2kMYqKSqQI

4 Likes

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by ayoola17: 3:05pm On Sep 21, 2012
Olorun mi boju wo mi
Fi yanu fe nla re han mi
ma je ki ngbero funrami
Tori wo ni gbeero fun mi
Baba mi to mi laye yi
Je ki gbala re to fun mi

2 Likes

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by jahbless2: 11:27am On Oct 05, 2012
dayokanu: Ore bi Jesu ko si laiye yi

Jesu nikan lore otito

ore aiye le ko e sile

Sugbon Jesu ko je gbagbe mi

Chorus
(ko je gbagbe mi o) Ah ko je gbagbe mi e wo 're otito o
Ah ko je gbagbe mi... halleluya
Sugbon Jesu ko je gbagbe mi
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by jahbless2: 11:32am On Oct 05, 2012
Jerusalem to 'run
Orin mi ilu mi
Ile mi bi mba'ku
Ekun ose ko si

Chorus
Ibi ayo... nigba mo pe
nko roju re Olorun mi

N.B: We've changed all this beautiful hymns to orin oku.(for burials) I tire for 9ja self

2 Likes

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by OmoAlata(f): 11:47am On Oct 05, 2012
moremi2008:

ps - I know a lot of these songs! I can't even believe I am singing them right now! angry

Why are you cross about it
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Sorarena(f): 9:20am On Oct 14, 2012
Olorun to mu isreli la okun ja
To si gba won kuro loko eru
To rojo mana sile,la toke wa
Ohun ni Mo un gbadura si
Okan,okan na loni 2x
Bi akoko to mu isreli,la okun ja
Omo re ni o,je tori oro re so
Pe oka na ni Olorun iyanu loni.

I am not very sure of the lyrIcs

2 Likes

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by jido52(m): 8:20am On Oct 15, 2012
For more yoruba hymns visit http://www.yorubahymns.com
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by tioshewo: 5:06am On Oct 17, 2012
Jesu Oluwa Oba mi
Gbohun mi nigba ti mo pe
Gbohun mi lati gbugbe re
Rojo Ore-ofe sile
Chorus
Oluwa mi mo feran e
Jeki nle ma feran e si.

My family's favourite verse
Jesu ki lo ri ninu mi
Ti fe naa fi po to bayi
Ore re si mi ti po to
Otaa gbogbo ero mi yo.
Chorus
My favourite is

Jesu wo o je orin mi
Tire laya at'okan mi
Tire ni gbogbo ini mi
Olugbala wo ni temi
Chorus.

2 Likes

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by EreluY(f): 12:06am On Oct 28, 2012
The OP and all those who have posted hymn stanzas here have catapulted me back to not only my primary and secondary (Anglican mission) school days when SOP, the hymnal, was on the list of books, but also to the days when I sang in the church choir. Incidentally, I've since mutated from theism to agnosticism.
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by seyibrown(f): 9:06pm On Oct 30, 2012
grin
samuelorija218: Wa sa Adura owuro
kun le ka gba Adura!
Adura ni opa Kristien lati bOlorun rin

losan wo le labe Nigba to d'oganjo
je kawi li emi pe
mosun sugbon okan mi ji
lati ba o sona.

Je kii gbo gbo Ile,

The above is one of my favourites!

Je ki gbogbo Ile
Wa s'adura l'ale
Ki ile wa di t'olorun
At'ibode Orun

L'osan wo'le l'abe
Apata ayeraye
Itura ojiji re dun
Nigba t'orun ba mu

Mo wo'le l'ese re
Jo ko dariji mi
......
......

don't remember the last two lines .... lol!
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by dayokanu(m): 9:25pm On Oct 30, 2012
Wa sodo Jesu Ma se duro

Nu oro re lo ti f'ona han wa

Oduro ni aarin wa loni

O wi jeje pe wa

Ipade wa yi o je ayo, gbo kan wa ba o lowo ese

A o si wa pelu re Jesu

Ni ile wa lailai
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by seyibrown(f): 9:47pm On Oct 30, 2012
Igbagbo mi duro l'ori
Eje at'ododo Jesu
N ko je gbe'kele ohun kan
Lehin oruko nla Jesu

Chorus:
Mo duro le
Kristi apata
Ile miran
Iyanrin ni
Mo duro le
Kristi apata
Ile miran
Iyanrin ni


Majemu ati eje re
L'emi o romo
Bi iku mi de
Gbati ko s'atilehin mo
O je ireti nla fun mi

1 Like

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by zoedicus: 5:46pm On Nov 27, 2012
uhm, i feel like i wanna cry. . .trying to remember the sweet memories.
olorun awa fe,
ile ti ola re wa,
ayo ibukun RE,
ju gbogbo ayo lo.
2. Mo ja lejo niyin,
ni ile ajeji,
ile mi jin rere,
lor'ebute wura,
lati je iranse,
koja okun lohun,
mo jise mi fun oba mi.
egbe- eyi ni'se,
ti mo wa je,
se tawon angel ko lorin,
eb'olorun laja,
loluwa oba wi,
eba olorun yin laja.
that was the Royal Ambassador's anthem.
my oh my. Uhm. I wish i were still @ home.
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by dayokanu(m): 6:02pm On Nov 27, 2012
Kristian ma ti wa sinmi

Beni angeli re wi

Ni aarin Ota lo wa

Ma sooo raaaa

1 Like

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Segunagagu(m): 3:11am On Nov 28, 2012
JeSus christ!!!!!!!!!!!!!!!!!! Plsssssssss is dere any site where I can download dis hymns...my head is really swelling...it want to burst..plsssssss
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by johnch: 6:22am On Jan 11, 2013
I greatly greet people of the house,almighty God will continue to bless you as you continue to work for him.Amen
Please there was this album 1980 christian music by a man(Yoruba). This is the portion of the music i can only remember and it went like this............

Arakunrin mi elobere 2x
Tete bere oun edun okan re,
Lowo eleda re,
Nitoripe eni to bere lo ri gba,
Eni to ba bere lao fi fun............


And it continue like that.
I will be glad of getting the seller's shop address in Nigeria.
Or if there is any other means i will appreciate.

Thank you all.
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by rachael2257: 11:28pm On Jan 19, 2013
Ninu Gbogbo iji ti nja,
ninu gbogbo igbi iponju
abo kan mbe, ti o daju
o waa labee itee anu.
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Kayzeetee(f): 11:04am On Jan 20, 2013
Jesu oluwa oba mi,
Gbohun mi nigba ti mo npe,
Gbohun mi lati 'bugbe re,
Ro'jo ore ofe sile.

Chrs: oluwa mi month feran re e e,
Je ki nle ma feran re si.

Hymn No 2
1.Gba taye yi BA koja
Ti orun re BA si wo
Ti aba wonu ogo,
Ta boju wo eyin wa.
Gbana..oluwa uno mo
Bi gbese mi ti PO to.

Hymn3
B'aye ba nfa mi pelu ogo re,
Ko sewu omo olorun nimi,
Owo agbara re yo di mimu,
Lojo aye mi gbogbo....
Chrs: Mo lore to npese faini gbogbo
Mo Nile kan loke orun giga,
Wo nitori idi eyi naani
Emi nse nko aleluyah!

@Op,Nice mind-uplifting thread!..u remind me of my teen-years as a choir in CAC...
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by rachael2257: 1:11am On Jan 21, 2013
Iye wa ni wiwo eni taa kan mogi
iye wa ni sinsin yi fun o
je woo elese, kole ri igbala
wo eni ta kan mogi fun o

chr: wo! wo! wo! ko yee
iye wa ni wiwo eni taa kan mogi
iyw wa ni sinsin yi fun o.

1 Like

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by ayobarmy(m): 7:03am On Feb 22, 2013
Hi guy, pls doea any1 have the link where to download yoruba worship songs
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Nobody: 12:27pm On Feb 22, 2013
E fun pe naa kikan
Ipe ihinrere
Ko dun jake jado
L'eti gbogbo eda

Ch
Odun idansile ti de
Pada Elese pada
Odun idansile ti de
Pada Elese PadaAnother hymn
Itan iyanu t'ife
So fun mi l'ekan si
Itan Iyan t'ife
E gbe orin naa ga
Awon angeli royin re
Awon oluso si gbagbo
Elese iwo ki yo gbo
Itan Iyanu t'ife

Ch
Iyanu! Iyanu!! Iyanu!!
Itan Iyanu t'ife


Anoda one

si O Olutunu Orun
Fun ore at' agbara re
An ko Aleluya

Si o Agbara eniti
O nwe ni mo to n'woni san
An ko Aleluya

Si O oluko at' ore
Amona wa to to d'opin
An ko Aleluya


Another one

Eyo n'u oluwa Eyo
Eyin t'okan re se dede
Eyin to ti yan oluwa
Le banuje at' aro lo

Ch
Eyo(3x)
Eyo n'u oluwa Eyo
Eyo (3x)
Eyo n'u Oluwa Eyo


Another one( I particularly love dis one)

Iwo to fe wa la o ma sin titi
Oluwa olore wa
Iwo to nso wa n'nu idanwo aye
Mimo l'ogo ola re

Ch
Baba iwo la o ma sin
Baba iwo la o ma bo
Iwo to fe wa la o ma sin titi
Mimo l'ogo Ola re

2
Iwo to nsuro s'ohun ta gbin s'aye
T'aye fi nrohun je o
Awon to mura lati ma s'oto
Won tun nyo n'nu ise re

3
Iwo to nf'agan l'omo to npe ranse
Ninu Ola re to ga
Eni t'o ti s'alaileso is dupe
Fun se ogo ola re

4
Eni t'ebi npa le ri ayo ninu
Agbara nla re to ga
Awon to ti nwoju re fun anu
Won tun nyo n'nu ise Re

5
F'alafia Re fun ijo re l'aye
K'ore ofe re ma ga
K'awon eni tire ko ma yo titi
Ninu ogo ise re

2 Likes

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by naijatoday: 10:31pm On Mar 05, 2013
There is this yoruba song that says..... God as I Go out today..... Cant remember much but can anyone help thanks
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by sublimes: 1:16pm On Mar 06, 2013
I remember anytime we are done with the yearly harvest and thanksgiving, we close with this hymn:

ojo ibukun yo si ro,
ileri ife leyi
a oni itura didun
La to do olugbala

chorus
ojo ibukun
ojo ibukun lan fe
iri anu she yi wa ka
shugbon ojo lan toro.

etc

2 Likes

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Psamist: 11:20pm On Mar 06, 2013
1. gbogbo aye, gbe jesu ga,
angel’ e wole fun
e mu ade oba re wa,
se l’oba awon oba

2. e se l’oba eyin martyr,
ti nke ni pepe re
gbe gbongbo igi jese ga
se l’oba awon oba

3. eyin iru omo isreal’
ti a ti rapada
e ki eni t’o gba yin la
se l’oba awon oba

4. gbogbo eyin elese
ranti ‘banuje yin
e te ‘kogun yin s’ese re
se l’oba awon oba

5. ki gbogbo orile ede
ni gbogbo agbaye
ki won ki, kabiyesile
se l’oba awon oba

6. a ba le pel’awon t’orun
lati ma juba re
k’a bale jo jumo korin
se l’oba awon oba.

3 Likes

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by AuntyB: 1:32pm On Mar 07, 2013
A nsoro ile bukun ni
Ile didan atile Ewan
Gbagbogbo la nso Togo re
Yo ti dun to Lati de be

A nsoro ita wura re
Oso odi re ti ko legbe
Faji re ko se fenu so
Yo ti dun to lati de be

Jo Oluwa tibi tire
Sa se emi wa ye fun orun
Laipe awa na yip mo
Bo ti dun to lati de be

3 Likes

Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by AuntyB: 1:44pm On Mar 07, 2013
Jesu Oluwa Oba mi
Gbohun mi nigbati mo npe
Gbohin mi lati bugbe Re
Rojo ore-ode sile
Oluwa mi mo reran Re
Je ki nle ma feran Re si

Another one
Nipa Ife Olugbala
Ki yo si nkan
Ojurere Re ki pada
Ki yo si nkan
Owon leje to wo wa san
Pipe ledidi or ofe
Agbara lowo to gba ni
Ko le si nkan

1 Like

(0) (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (Reply)

Daily Manna (DCLM) — A LOOK AT THE MIRROR / 42 Prayer Points To Tackle This Year 2015 By Dr D.k Olukoya / Marine Spirits...what Are They?how To Identify Them And Defeat Them.

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (0) (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2018 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 137
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.