|
jintujinta (m)
|
Aye nyi aanto. Ede yoruba naa tin ri ayipada pupo. Ewo ni iwo ti sakiyesi nibe? Tabi ewo ni ole tokasi?
Ni aye atijo awon yoruba maa npe Radio ni "ero a soro ma gbesi", sugbon pelu gbogbo ero alagbeka ati ero ibanisoro ori tabili eyiti awon oyinbo npe ni telifonu, inkan ti yipada o. Awon eniyan maa n pe ero ibanisoro lati ba eni to wa lori Radio soro. Ni idi eyi, ko to ki a maa pe Radio ni ero asoro ma gbesi mo.
Abi ki leti wi eyin ara mi? Oruko wo ni ki yoruba maa pe Radio bayi? Awon oro wo ni iwo naa mo ti otun ti yipada?
Hun, aye nyi aantoo!
|