|
kola oloye (m)
|
translate:
oruku tindin tintin, oruku tindin tintin, oruku b'igba omo, gbogbo l'ole tiro o. kini o?
Aalo apamo ni eyi, ki ise owe. Sibe-sibe itumo re ni EWA.
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
Ojo n pa iyo ori n du nun-----------------------
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
Ojo n pa iyo ori n dunun,
Ojo n pa iyo ori n dunun, ki ori mayo layoju nitori to'jo ba tida orun nbo.@bluehorizo se o wa pa?Agba ti ko ke'wun soro,_________________________
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
Kola mo wa pa. Se alaafia ni? Awon owe e yen ga ju. Nibo lo ti n gbe won wa na? 
|
|
|
|
|
|
|
|
tybanky (f)
|
Agba ti ko ke'wun soro,_________________________ Agba ti ko ke'wun soro, AKE TAN SAREEgberun odun ti kolo kolo ti ku sile, won _________________________________
|
|
|
|
|
|
|
|
tybanky (f)
|
Insert Quote Quote from: tybanky on Today at 02:56:49 PM Agba ti ko ke'wun soro, AKE TAN SARE Omo odo agba,o kare laye.Mo gba fun,o peregede. E se sir
|
|
|
|
|
|
OLAADEGBU (m)
|
Alangba to f'oju di ere,__________________________________
|
|
|
|
|
|
tybanky (f)
|
Egberun odun ti kolo kolo ti ku sile, won _________________________________ Egberun odun ti kolo kolo ti ku sile, won bi iya adie lati de be lo woran
|
|
|
|
|
|
OLAADEGBU (m)
|
Alangba to f'oju di ere,_________________________________
ikun ejo ni yo ba ara eAfopina to ni oun o pa fitila,_____________________________________
|
|
|
|
|
|
CH3COO (m)
|
ikun ejo ni yo ba ara e
Afopina to ni oun o pa fitila,_____________________________________
ara re nio pa.
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
Egbirin ote________________________
|
|
|
|
|
|
OLAADEGBU (m)
|
Egbirin ote________________________
Bi a ti npa ikan ni nkan nru ( This was copied from kola oloye) Eni aigbon pa lo po,___________________________________
|
|
|
|
|
|
OLAADEGBU (m)
|
Bi a ti npa ikan ni nkan nru ( This was copied from kola oloye) Eni aigbon pa lo po,___________________________________ eni ogbon pa o to nkanEni maa je oyin inu apata,______________________________
|
|
|
|
|
|
mishooo (m)
|
- - -- - Ki i wo enu aake.
@post
oo sa igi logbe, oo ta oguro lofa, o wa de idi ope, o gbe enu soke - - - -
|
|
|
|
|
|
OLAADEGBU (m)
|
- - -- - Ki i wo enu aake.
@post
oo sa igi logbe, oo ta oguro lofa, o wa de idi ope, o gbe enu soke - - - -
o fe mu emu Eni a wi fun ko gbo, eni a fo fun ko gba,___________________________
|
|
|
|
|
|
OLAADEGBU (m)
|
o fe mu emu Eni a wi fun ko gbo, eni a fo fun ko gba,___________________________ eyi ti ko gbo yo file boraMaalu ti o n'iru,______________________________
|
|
|
|
|
|
mishooo (m)
|
o fe mu emu  it continues - - - - - - - - Ofe ko ni yio ro. eyi ti ko gbo yo file bora
Maalu ti o n'iru,______________________________
olurun ni o m ba le esinsin !!
|
|
|
|
|
|
OLAADEGBU (m)
|
it continues - - - -
- - - - Ofe ko ni yio ro.
Thanks for the conclusion of the proverb as I had only gambled on that one. Were dun wo,_______________________________
|
|
|
|
|
|
Femonjay
|
Thanks for the conclusion of the proverb as I had only gambled on that one. Were dun wo,_____ko se bi lomo ile la awo -------------
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
Thanks for the conclusion of the proverb as I had only gambled on that one. Were dun wo,_____ko se bi lomo ile la awo ------------- ile la'wo ka to somo lorukoo fi nu we'nu----------------------
|
|
|
|
|
|
nana (f)
|
ile la'wo ka to somo loruko
o fi nu we'nu,
O mo pe inu jin ju orun lo. Larin egun ni- - -
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
O mo pe inu jin ju orun lo.
Larin egun ni- - -
Larin egun ni mariwo ti n sogeT'eni be'gi loju----------------------
|
|
|
|
|
|
mishooo (m)
|
of course - igi a ruwe  @post Ata aato (do-re re-do-do) OR oun ta ta ti aa to (meaning something - like an animal, shot but not traced/followed up) - - - Someone must find the answer oo
|
|
|
|
|
|
OLAADEGBU (m)
|
of course - igi a ruwe  @post Ata aato (do-re re-do-do) OR oun ta ta ti aa to (meaning something - like an animal, shot but not traced/followed up) - - - Someone must find the answer oo Eni ba ri he lo maa sun je Atele owo eni,________________________________________
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
Eni ba ri he lo maa sun je Atele owo eni,________________________________________ Atele owo eni,ki tan ni je Ope oyinbo fi dundun sewa---------------
|
|
|
|
|
|
mishooo (m)
|
Ata aato---- Someone must find the answer oo
ni o n di eran idin. (becomes meat for the maggots)
|
|
|
|
|
|
obuchineme
|
Agba to rofo ika,
|
|
|
|
|
|
olawunmi05 (f)
|
Agba to rofo ika,
omo re aje ni begbami gbami ko ye agba
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
gbami gbami ko ye agba
gbami gbami ko ye agba, eranko ni nle mi bo ko ye ode Alagbede t'onlu irin ni oju kan__________________________
|
|
|
|
|
|
OLAADEGBU (m)
|
Omo ti yo je asamu,____________________________
|
|
|
|
|
|