|
|
|
sima (f)
|
bawo ni 
|
|
|
|
|
|
minute (f)
|
daadaa ni sugbon oju yii kore lowo die  mofe lowa nkan je,oyii nko mi. Talo bimi lere ejo gan?  talo mo ibi tiwo npe ni LALUPON ni Oyo?
|
|
|
|
|
|
Pataki
|
LALUPON, emi ko mo ibi ti o wa o ninu ilu Ibadan. So mo wipe Ibadan tobi gan sha.
Kini itumo abala thread yii gangan?
|
|
|
|
|
|
sima (f)
|
abala thread keh. . kilon jebe 
|
|
|
|
|
|
Pataki
|
Ibeere Pataki lo beere yen o.
Ta lo le bami da lohun?
|
|
|
|
|
|
sima (f)
|
iwo ole dami loun abi. . ?
|
|
|
|
|
|
Pataki
|
Kilode ti ma se da e lohun? Se dandan ni?
|
|
|
|
|
|
timba_bng (m)
|
ise lo ye ki o da lohun, gege bi omo yoruba ijinle 
|
|
|
|
|
|
sima (f)
|
abi oO. . ori so jare timba  @pataki. . kilode ti iwo ole dami loun ? she ikan buruku ni ??
|
|
|
|
|
|
Pataki
|
Kilode to fe je ki da lohun? Se dandan ni?
|
|
|
|
|
|
toba1909 (m)
|
Dandan ko o!
Aku odun itunu awe ati ojo ibi orile-ede wa Emi wa yoo se pupo o
Omo ilu wo ni iwo?
|
|
|
|
|
|
abdurrazaq (m)
|
Omo bibi Ile Yoruba ni mi. A ku poposese Odun lorisirisi yii oo, emi wa a se pupo iru re l'aye ati l'aye wa o - Aamin.
Ta ni eni naa ti o n bere itumo abala thread yi lekan rii?
|
|
|
|
|
|
Pataki
|
So ni gbolohun lati so si ibeere yen ni?
|
|
|
|
|
|
sima (f)
|
she emi loun ba sori? ?
|
|
|
|
|
|
ayomifull (f)
|
oti iwo ko ni mo nba soro eniti o wa ni egbe mi nibi ni, se o gbo oun ti mo so fun ni?
|
|
|
|
|
|
big father (m)
|
Ewo lon tun je AGBALA THREAD O ? 
|
|
|
|
|
|
tollu (f)
|
he he he he he. Yeeparipa, nse ni Ayomifull gbe Sima ni agbele/ela pelu ogbon sha. Tee heee heeee
Ki wa ni itumo abala o? Ibeere yen lo si ori ero 'akowegbesi' Pataki ati abdurrazaq.
|
|
|
|
|
|
Moyola (f)
|
Kin maà fí oro gùn, "Àbàlà thread" tunmo sí Thread. . . . abi?  Tà lo ní ìbérè?
|
|
|
|
|
|
sima (f)
|
ki loun je Àbàlà thread ?? 
|
|
|
|
|
|
Pataki
|
Se e si wa lenu ibeere yi na? 
|
|
|
|
|
|
sima (f)
|
oda bee. . . abi seh inko buruku ni??
|
|
|
|
|
|
tRoOE (f)
|
i suck in yoruba but i will trueTa ni buruku, e mi abi
|
|
|
|
|
|
abdurrazaq (m)
|
Abala thread tumo si GBAGEDE tabi AAYE ti a ti n soro lowo yii. Tani ko ye ki o nowo re s'oke ki Oluko yin to lo? 
|
|
|
|
|
|
yemmyse (m)
|
eleyi ga gani o.O da bi a se n gbe ede wa laruge. E je ki amura si o. Olorun ama buku wa o.
|
|
|
|
|
|