|
ikamefa (f)
|
Ikamefa oo. ose se fe ma she bi obinrin ni! Iwo n gbiyanju, o n tiraka! Sugbo ko to. Nje iwo ti le mo oruko ti oogun n je ni?
Arakunrin, ti o ba ni ife si ikamefa, o le je ki n mo ni tori wipe oti yaju si mi. Ma ba e de mo inu agadagodo, yoo si ma se tire titi aye
ROFLMAO! "  " very funny! o le se nattin! ologun eke!  agadagodo nikan ni? you for find safety pin! efizii ti poju! 
|
|
|
|
|
|
haywhy (m)
|
omode re ko mo oogun o n pe ni efo! Sugbon sha, ma se suuru titi ti ma a fi ri owo e, Ni igba naa wa mo pe sanma meje lowa
|
|
|
|
|
|
|
|
segoye2 (m)
|
Oga Ikomi,
Se e ti lo san ohun ti awon omo iya yin ni ki e san?
We will fine him the following:
7 tubers of yam 7 kolanut, don't forget ose oji too 7 bottles of shnapp 4 yards of akwa ocha 3 white oke okuko i know he can't afford atulu, so we'll take a white goat.
all in favor say aye
Oro Ounje sa ni ti awon omo nna.
|
|
|
|
|
|
haywhy (m)
|
Egba mi ooooooooo! Mi o she nkan kan fun ikamefa ooo! Abi kiwa lode ti kole soro? Owo temi ree loke fun fun nene oo
|
|
|
|
|
|
segoye2 (m)
|
Babalawo, Gbagbe bobo yi jare, ko da yin mooo.
|
|
|
|
|
|
Ikomi (m)
|
@Segoye2, lo shora e ooohh. Iwo paddy egbe, ma se paddy le seoo. lol
|
|
|
|
|
|
|
|
haywhy (m)
|
Ikamefa wooo, efrebo oo! Eeti ri naa! A a ma ti itori pe afe je maalu ki a ma pe maalu ni buroda ni! Iro oo!
Bobo segoye, dakun mo ni lati ba e chaati ni ori ero yawu mesenja! Kini ero re. Oro naa se pataki pupo ooo!
|
|
|
|
|
|
segoye2 (m)
|
Ogbeni Ikamefa, se ire ni babalawo daadaa, oda na, ole ran mi lowo ni yen kee
|
|
|
|
|
|
ThiefOfHearts (f)
|
Ikomi, o shi wa nibi? Mo ri pe awon ara ilu re tin sekun pe o ti parapo pelu awa yoruba "buruku".
O tete kuro nibi before a koba re
|
|
|
|
|
|
segoye2 (m)
|
babalawo mu owun, ki ni e fe ba mi sooo, omo iya ni gbogbo wa ni bi yi, nitori na, e je ka ma so lo ni bi yi abi e le te mi ni ago lori segoye2@itsabove.com emi o ni messenja yahoo ra ra ra msn ni mo ni,
|
|
|
|
|
|
haywhy (m)
|
Oseun ore mi tooto, Odua yoo gbe o! em es en yen naa daara too! Ose un!
|
|
|
|
|
|
segoye2 (m)
|
Oda,, Babalawo, Kini oruko ti anpe Mouse ni ede Yoruba? ati wipe kini pasti tensi Mango ati table, ti e ko ba gbaa ajepe, babalawo ironi ti yin!
|
|
|
|
|
|
haywhy (m)
|
Fun mi ni msn e bobo yi! Em es en!
|
|
|
|
|
|
segoye2 (m)
|
oruko mi @ hotmail dot com
|
|
|
|
|
|
|
|
niceuzor
|
 Oluwa jesu  What kind of a thread is this? ****Seun this is tribalism****
|
|
|
|
|
|
haywhy (m)
|
segoye ur not online ooooo? I don add u now!
|
|
|
|
|
|
segoye2 (m)
|
Ma binu jare, mo se woo ni, ati wipe, mo ti acepti re, sugbo mi ko ri oo mooo ooo
|
|
|
|
|
|
segoye2 (m)
|
Eyin omo iya mi, ema binu si mi rara, babalawo mi fe bami soro kekere kan.
|
|
|
|
|
|
ikamefa (f)
|
Ogbeni Ikamefa, se ire ni babalawo daadaa, oda na, ole ran mi lowo ni yen kee
ha ha! maka ogbeni?  ngbo haywhy won ba e wi! 
|
|
|
|
|
|
segoye2 (m)
|
Babalawo Iro gba emaalii mi, ko de ba mi soro, okan addii mi ni,, I ro ni bobo yen so jare, tire ni mo gbagbo, so ro fun mi, bawo ni ase ma se ise na?
Abi kin lo si soo si ni?
|
|
|
|
|
|
amor4ce (m)
|
Hey y'all, i'm new here. i don't know how to speak yoruba even though i am proud of our heritage. even the encyclopaedia britannica described us as the most urbanised in sub-saharan africa. I will be very grateful if this forum could be used to teach the nigerian tongues.
|
|
|
|
|
|
mukina2 (f)
|
ikame  bawoni 
|
|
|
|
|
|
|
|
segoye2 (m)
|
I nu mi dun pe o pari ile eko jiga ti a mosi Encyclopedia ti Ilu Britannica, sugbon bawo ni asele ko e ni yoruba lai si ami? ani ami oke, isale and Arin? pa pa julo ami isale isale? so fun wa jooo
|
|
|
|
|
|
ijogbon (m)
|
een lee ni oko'o!
|
|
|
|
|
|
mukina2 (f)
|
ika ki lo sen le 
|
|
|
|
|
|
Nite Angel (m)
|
Mo ti rin arin ta'kiti, eyi le ju comedy lo. Awon to de ti so'nu abi ti won ti s'omo nu bi oko, eleda a je ke wa ri o. Ede wa, asa wa, ti a ni; e je ka gbe l'aruge.
Mo kira, mo tun gbe di fa'won to moye okun yi o. Ise'dale a gbe wa o. Ase.
|
|
|
|
|
|
WesleyanA (f)
|
ma fi thread yi practice yoruba mi.  mo o mo pe yoruba le la ti ka to yi. lmao @ mobolowowon
|
|
|
|
|
|
richylaw (m)
|
segoye o ,segoye o,segoye o, e melo ni mo pe o.
Asin de Arin de opa jini jini loruko ti a n pe eti agbon titi lo,ruko ti an pe iwo ese baa mu afi laka sonu juajua loruko ta n pe emi olokan ewe alesonso joba loko tan won gbagbe ati ro
Segoye se oro wipe mo ti lo ni, mo ni mo n wole agbara lo, o si ti gbagbe mi ki n to de . O ti fe ma kanju la obe gbigbona. Se o ti gbagbe ni, wipe oniwara ni i fun wara kiniun, A ki i kan ju tu olu oran nitori igba re ko to ni se lobe.Awon eke babalawo po lode o. So ara re gidigidi. Ipin loju ikun nimu ara ile eni ni ba ni mu were sansan lara ta pee. To o , mo ti de pada o. Mo ri wipe ki n to de , awon olugbodi (ikamefa) ati arabinrin Mukinatu ti ro le, won si tun sa pa lati fi gboro jeka, okun o!
Olufidu, emi ko ni ba o jiyan ede, ti o ba lee ri eni ti o ba tun mo ijinle ede yi beere lowo re wipe nje a a le pe oga ni alagemo. Mo mo dakodako daradara sugbon oga gangan ni eranko ti a n pe ni alagemo.Ninu oruko eranko yi ni a si ti mu owe ti arabinrin olulayo pa jade
|
|
|
|
|
|