|
ayefele200 (m)
|
@femi me too men, mo sese de lati ibi se ni, so bawo ni weather ni canada
|
|
|
|
|
|
fe_mi (m)
|
weather ti da baje baje, a bo lowo akanbo
|
|
|
|
|
|
lizzy (f)
|
o ga ooo, ki ni o n sele bayi eyin eeyan mi. mo kan so wipe ki n ki yin ni, se nkan lo deede?. epele, e ya se ooo, olorun a maa wa pelu wa, aa ko ere oko dele o. e shamin adura ooo.
|
|
|
|
|
|
ikejoe (m)
|
mobolowonwo!!!!!!!!!!!!!!!
|
|
|
|
|
|
Bolarge (m)
|
@ikejoe Se aye ntele e tele ni?  @gbogbo omo kaaro oojire N'land Ase e po to bayi.O ga gaan O! Oya ko maa roll! 
|
|
|
|
|
|
desorlah (f)
|
mobolowonwo!!!!!!!!!!!!!!!
Igbawo lo di D' Banj. Eyin temi, bawo ni dede, se ko si wahala. Eniti o le akori yi (If you Can speak Yoruba, Talk it in Here) ko ba ti ko akori yen ni ede yoruba yaato si ede geesi ti o fi ko yen, sibe sibe, O ku ise oo. E maa se faaji lo jare, emi na n pada bo.
|
|
|
|
|
|
boraddo (m)
|
ejo, bawo ni won shey so LOL ni yoruba ?
|
|
|
|
|
|
moela
|
se yoruba le yin wonyi so bayi o ma se o! e pada si ile eko yoruba
|
|
|
|
|
|
excel12 (m)
|
Laisi ani ani ,omo ale ni gbogbo yin.Bawo ni e se n so yoruba bi abirun bayi? Ka ni aye atijo la wa ni,o ye ki a gbe gbogbo yin lo si idi ogun ,ka lo be yin lori ni.Ki oluwa dari ji yin.
|
|
|
|
|
|
cherish (m)
|
waala wa oo, so, eyin omo yoruba esi e le ko ede niede yoruba, oga fun yinoo se e ka A B D ni? abi eti fi je Eko ati Ole.
|
|
|
|
|
|
segoye2 (m)
|
Eyin Omo Oduduwa,
Se lo o to ni won ni baba iyabo ta refineri poti ha co tu? to ba je oto ni, ko da ra ra oooo.
Ati pe, se gbogbo yin ti MIGRIMORE? ani jeun so ke?
Ma wa ki yin ni ale oni, e wa omo sile fun mi oooo
|
|
|
|
|
|
desorlah (f)
|
ejo, bawo ni won shey so LOL ni yoruba ?
se omo yoruba ko ni iwo ni, abi o ko se aayan ogbufo ni ile - iwe ni. fun akiyesi re, lol ni yoruba ni rerin sita (rrst).  oda na, mo n pada bo.
|
|
|
|
|
|
babadee (m)
|
abi aiye e fe baje ni? won shepe fun e ni? o lon demo, ma bogo le ori e!!!
|
|
|
|
|
|
omotofine (f)
|
@segoye2 ole ni e o, o fe fe omo obasanjo, ko le pay e nitori ko ni pe kuuro, omo yaradua nii ko fee, mo gbo pe o dabi chimpanzee, iyen gan gan lo ma fit e. omo jaguda.
|
|
|
|
|
|
ayefele200 (m)
|
eyin omo ODUDUWA, kin lo HAPPEN?
|
|
|
|
|
|
segoye2 (m)
|
@ omotofine,
Se omo baba lo jo chipanze abi omo yar'adua? mo gbagbo pe omo baba ni ooo, ni to ri, omo ni lati jo baba e e.
Emi fe fe omo na, ati omo yar'adua, mo gbagbo pe ti mo ba fe chipanze kekere, chipanze nla a fun mi ni eyo kan ninu awon refineri to wa ni orile ede yi (olorun lo so bee)
Ehen, ejoo mon wa iyawo oooo, ele te mi ni ago lori ero yi. odo, mejo, odo, meji, mejo, mefa, meje, mejo, mejo, meji, meji, tiankiu, ese.
And hey, obirin ni mo so ooo, mi o fe iya oo, abi mama arugbo ooo. ti e ba pe mi, e ni e fe ba Ife soro, ma je yin.
|
|
|
|
|
|
bodsibobo (m)
|
Aaaaah! O ma she o! Eh?
Se ede wa naa lo wa di wahala lati so bayi?
Oro aje ma ti so awon omo yoruba nu bi oko o!
Olorun a ko gbogbo wa yo o!
Amin.
|
|
|
|
|
|
Olumide7 (m)
|
gbo gbo yin pata pata le'n misyan. Ki ni gbo gbo rada rada yii. e kon dissapoint me sha honestly speaking. Omode lo'n se yin o. se e mo pe kokoro ti'n je'fo idi efo lo wa.
|
|
|
|
|
|
breeolan (f)
|
eyi oyinbo , ewa fun mi ni visa,  @ ayefele, ki lon so? iso ku so plc
|
|
|
|
|
|
PrincessM (f)
|
Mo ni kin ki gbogbo yin ni o, se dada le wa. ejo oo gbogbo awon ti won fi ede geesi ko yoruba, ki won jo, ki won so itumo re. nitori pe eni ti o ba pa owe ni ile na, oun na ni so itumo re. a o tun ma kan si ra 
|
|
|
|
|
|
haywhy (m)
|
Awon momo yoruba ti owa ni ori tred yi ko jasi rara! Afi awon konkan to fi ajasa si! Mo ro pe awon ti o da idan mo po ni sugbo won ko po! O mase ooo! Anyway, awa ti yoboro yobonsin lan soro ooo! Ko ma lo beeee!
|
|
|
|
|
|
segoye2 (m)
|
Si Baba Olumide7,
Ekapo, se dada le de, oyinbo soro oyinbo powe, oni, Inforgidi magidi, alogo where were you? eyen ni pe, nibo le gbe yoruba yin si, ti en so ede oyibi repete?
Ani so oyibo nile ana e, ooow nnn la tumo ee. nitorina, kini itumo disappoint? e tie gbo ede yoruba,
Si gbogbo wa,
Mo sope mon wa Iyawo, se e ti ba mi ri omo yoruba to sanra dada fun aya!?
Ejo oo, ore mi ju kini yi simi, e mi ole ka ede yi rara ra ooo, ebami tumo e side abinibi wa:-
One aboki was coming to Lagos on a Sunday morning on getting to ogoja he bought a goat to give to his neighbour .When they finally got to Berger people were coming down from the bus and the goat took advantage of that for an easy escape. Immediately, the bus driver alerted the aboki that his goat had fled instead of running after the goat the aboki sat unruffled in the bus laughing at the goat and when he was asked why he did not chase the goat he said” kai whalahi no mind am por ze goat, make e run, ze address wey e dey go dey my focket”
Ese, oooo, ma ma reti itumo eee ooo,
Si PricessM, E se fun owe yen ooo, emi yan gbasigbe, se ale ferawa abi okunrin ni yin ma?
|
|
|
|
|
|
haywhy (m)
|
Segoye baba! I wo jasi ntie! Sugbon o ye ki o ma sha awon slangi yoruba bi tiborobo, ike ni imu si inu awon oro re! O kare!
|
|
|
|
|
|
PrincessM (f)
|
segoye, obirin to re wa ni emi ooo. o wa la mo mi be yen pe ofe fe mi, hmmnn, mo ma roo naa
|
|
|
|
|
|
desorlah (f)
|
Segoye, se iwo ni on wa obirin ti o rewa lati fi se aaya? se o ni ise lowo sha, nitori wipe owo ni obirin mo o.
Maa tun ma kan si yin laipe, ema flenjor.
|
|
|
|
|
|
bodsibobo (m)
|
Isi gaaju!!!
|
|
|
|
|
|
bodsibobo (m)
|
One aboki was coming to Lagos on a Sunday morning on getting to ogoja he bought a goat to give to his neighbour .When they finally got to Berger people were coming down from the bus and the goat took advantage of that for an easy escape. Immediately, the bus driver alerted the aboki that his goat had fled instead of running after the goat the aboki sat unruffled in the bus laughing at the goat and when he was asked why he did not chase the goat he said” kai whalahi no mind am por ze goat, make e run, ze address wey e dey go dey my focket”
is ekuol to:
Aboki kan bo l'Eko Ile l'owuro ojo Aiku, Bi o ti se nde Ogoja, o ra ewure kan ti o fe fun albagbele e. Ni igbeti won de ibuso Berger, awon kan ninu awon ero oko naa sin boole. Kini atiri? Bi ewure ti she (eeem, take advantage niyen). ni o ba fi ere ge. Ni kia mosa, ni direbaoko naa gbesi aboki l'eti pe kinni? Eran ti gbagi!!!
Sugbon kakaki aboki gba tele, nise l'ojoko bi enipe ko si nkakan, lo ban rerin. Nigba ti won bi pe kilode to ko gbagi tele eran ewure re, oni " walahi, e ma ma da ewure loun. ki o ma salo, sebi adiresi re mbe ni apo mi"
|
|
|
|
|
|
segoye2 (m)
|
Oga mi, Ese fun atunko ede yen, o se ye mi ni, akoti yen ma ri eran eee, ti o ba lo si adugbo awom aboki (aboki quarters) nitori na, oju won a tunra ri. Sugbon, ni bo ni gbaji wa ni ede oyibo yen? abi o wunni wonpe ni fled? Ehenn, ejo, bawo ni mo sele ba obirin soro ni ede yoruba, nitori mo ti ni iyawo tuntun, oruko re ni PrincessM, bawo ni mo se le to ise ee? e ran mi lowo ooo, Si Desorlah, Ha! Otun bere pe se mo ni ise lowo, tin ba nise, se ma ni intaneti ni ile ni? ani obirin to ba fe mi, ma gba fun lati ma browsi mi ati computer mi, sugbon oni lati sanra daa daa, mon wa eru lomo. Bawo ni, se oleee so aworan e si kolo ero akawe mi ti amo si emaili. Aunte, e ju si segoye2@itsabove.comOdara, ta lo mo orin ko ni ibiyi, ejo ekorin fun mi ni ede yoruba, ele ko remix, boya nka bi african queen at be be loo, mo fee gbo orin yoruba se ti, ani, emi n gbadun yin gan ooo, Si Bodsibobo, Inumi dun pe ati ni eniti ole tunmo gbogbo rada rada tin awon omo yibo wonyin ko si ibi. Abi emope mon kalo awon omo yibo to wa ni ori treadii yi? awon bi haywhy, abi omo odua wo ni a mo ton je HAY at WHY?, ejo fi yen le, omo no quamps
|
|
|
|
|
|
desorlah (f)
|
Segoye, lepa ni emi o, mi o kin se eyan sisanra rara rara, nitori na ki o wa iyawo e si iwaju o, sugbon ti o ba nife si lepa na, o le je kin gbo.
E maa rokii.
|
|
|
|
|
|
ayefele200 (m)
|
@desolah uhhhhhhhhhhhhhhh, oko ma da ni obo lepa, bawo le se fe, se iwa ju ni abi lati egbe, abi ofe lati arin, so fun mi,
|
|
|
|
|
|
desorlah (f)
|
Ayefele, mi o raye titie ni isin yi.
Mo ri wipe oni sokuso kan nie.
Iwaju ko Aarin ni.
|
|
|
|
|
|
ayefele200 (m)
|
lol mabi nu mo pratice si (5mins madness), well ki lon sele, bawo ni EKO, sey own bubble
|
|
|
|
|
|