|
haywhy (m)
|
erekere ni eyin mejeeji nse yen! Emi o ki n wo ere yoru ba oo! Ko ti le ki n she ere yoruba nikan! Bi ose ma dara fun mi ni mo n bakakiri!
|
|
|
|
|
|
|
|
mukina2 (f)
|
 can't read a thing today  bawoni 
|
|
|
|
|
|
minute (f)
|
LOL  are u guys always like this on this forum? @mukina2 daadaa ni. mukinatu. hmmm , are u frm sieria leone?
|
|
|
|
|
|
haywhy (m)
|
she is from ilu awon oku kokuku gbo yoruba Mo n sere ni oo, siria loonu lo tiwa!
|
|
|
|
|
|
|
|
haywhy (m)
|
Muki you should know i can't wrong you now! All i said was mumu ni mukina or aren't you a beautiful lady?
|
|
|
|
|
|
mukina2 (f)
|
 na I'm be all that wey you post? wey ika o  ur ticha don misplace her yoruba brain 
|
|
|
|
|
|
haywhy (m)
|
She's beautiful & she's soo beautiful that guys are all over her what's d big difference
|
|
|
|
|
|
mukina2 (f)
|
oya leave that yarn please . .the wall has ears  ki lon se le  na this you suppose talk ;Ds
|
|
|
|
|
|
|
|
mukina2 (f)
|
ka kan
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
richylaw (m)
|
eni to ba fi ara re sile lati ta ni won yo o ta o,kini Mukinatu na wa de ibi bi kii ba se ayojuran
|
|
|
|
|
|
haywhy (m)
|
Ko ni se alai darafun e! O seun jare richy law Fi omo ti on seju bi alakan eti odo yen sile! ere la n ba o se oo
|
|
|
|
|
|
minute (f)
|
eti e fife han haba!
ofe ko,ode fe mon loje kowa sibi.
mon gbadun eyin mejeeji sha. ego on soun jo!
|
|
|
|
|
|
|
|
richylaw (m)
|
mo sare lo si oju ewe ti mukinatu se apejuwe ara re si, mo ro wipe aworan alakan eti odo ni n ba nibe nitooto, sugbon iyalenu lo je fun mi lati ri wipe awon agbabolu lo wa ni be. Haywhy se inu ile re ni mukinatu n gbe ni ti o fi mo wipe o jo alakan eti odo? 
|
|
|
|
|
|
obo_nyunmi (f)
|
ejowo ta ni oloko nla ninu awon okunrin ti o wa nibi o.
|
|
|
|
|
|
richylaw (m)
|
M o so wipe omo ni o , iwo si ni oga ninu egbe re! na you bi i ko 
|
|
|
|
|
|
haywhy (m)
|
mo sare lo si oju ewe ti mukinatu se apejuwe ara re si, mo ro wipe aworan alakan eti odo ni n ba nibe nitooto, sugbon iyalenu lo je fun mi lati ri wipe awon agbabolu lo wa ni be. Haywhy se inu ile re ni mukinatu n gbe ni ti o fi mo wipe o jo alakan eti odo?  Iseju ni mo n bawi jare ko n se mukinatu ko n kolo!  ejowo ta ni oloko nla ninu awon okunrin ti o wa nibi o.
Segoye2 ati richy law ni oooo sugbon ma gba e ni imoran ki o ma ta felefele de odo won oo nitori wipe emi re ko gbe!
|
|
|
|
|
|
minute (f)
|
LOL  @haywhy- shemi ni mon seju bi alakan?
|
|
|
|
|
|
richylaw (m)
|
Minutes, o ye ki mukinatu mo wipe akojopo oniyeye eniyan ni o wa ni abala oju iwe yi, ti o ba ke ko yoruba ki o ba awon t won lee so ni egbe re soro , abi nigbati o so wipe o fe oluko lana , sebi mo yo n da ara mi fun o. Emi ko ni le k mukinatu ni yoruba sha nitori wipe mo wipe osu meji ni yo fi ko ABD lasan!
|
|
|
|
|
|
haywhy (m)
|
LOL  @haywhy- shemi ni mon seju bi alakan? Fi staili wo eyin re, iwo yoo ri kini kan ni ipako ree. Kini yen gaan ni mo n bawi!  lol
|
|
|
|
|
|
richylaw (m)
|
Minutes, igba wo ni odi alakan eti odo , nitori a ko ti ko ifa ti ifa fi i n se. Iwe ti o ju sowo ranse nisiyi ni alakan meta ti o n seju pakopako ni be o.
Haywhy, ibo lo tun wa gbe oro lo yen na,emi ko ni ohun kohun lati ba onisokuso yen so o. Sebi o ri bi o se ta si mi ni oju iwe bi i meji sehin
|
|
|
|
|
|
|
|
richylaw (m)
|
i am running away till my yoruba returns  Come back here, ni bo lo n saa lo, ki lo wa de ibi tele.
|
|
|
|
|
|
minute (f)
|
@haywhy- oden yoo simi bi ojo.kini mo she fun e? @richy - jowo bami bi haywhy o,to den tasimi beyen.  And i hope mukinatu doesnt get someone to tranlate that for her because if she does,dude u are in deep shit!
|
|
|
|
|
|
haywhy (m)
|
Jowo fi muki kon kolo sile, je ko sere lo,ko de tun jeun soke bi adaba!
Nipa ti arabinrin yen, fi sile! Se bi awo ni iwo se! Mo fe fi asiko yi ran o leti pe bi ako ba gbagbe oro ana ako ni ri eni basere!
Won ko ni un fi e she, A ki fi omo ore bore O gbo abo o dahun? Fi si le, ewe re o ma je ooo be si ni egbo re yoo ma wa!
seju n seju mo n ba esere ni, se awon efcc ti deliva awon eru yen? I'll be back guys i need to watch prison break
|
|
|
|
|
|
richylaw (m)
|
se looto ni iwo se oju bayi  o ti so wipe ere ni o n ba ese o. Ti emi na ba ti wo "prison break" tan ma tun gbohun soke.
|
|
|
|
|
|
|
|