|
minute (f)
|
otun npada sehin nii?  iwoyii ma funny gan o,aleti lapa lofe ya!!
|
|
|
|
|
|
ayefele200 (m)
|
otun npada sehin nii?  iwoyii ma funny gan o,aleti lapa lofe ya!! what do u mean?, ori re baje, abeg call me jare, are u using cingular or tmobile?
|
|
|
|
|
|
|
|
ayefele200 (m)
|
i tot my yoruba is conc, urs is concer, ori re ti doti, see this little abusing me, ti ba gba e mu, ma fi pankere ba gbogbo IDI kerere je ni, ode oshi 
|
|
|
|
|
|
minute (f)
|
 now mosheshe ri pe ori ndun e ni oye kan faagi boe lori ni.
|
|
|
|
|
|
ayefele200 (m)
|
 now mosheshe ri pe ori ndun e ni oye kan faagi boe lori ni. hahahahahhaha, well am goin back to study, a ma soro latter, bye
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
minute (f)
|
i know.
okay ama pade ayo nigba yen.
suite yourself!
|
|
|
|
|
|
excel12 (m)
|
Ayefele ati minute ,kini isoro yin?ki le n baka naa?
|
|
|
|
|
|
minute (f)
|
MOKO!!! iwo loni shoro.  baba oko mi(LOL)nkan timomaje ni bakiri o,pe mi lomo ofun toba wu e. e mio mo oun tayefele baka--toba tiri bilere!!! kini iwogaan badebi  tojubole eran nuru nie!!
|
|
|
|
|
|
mishooo (m)
|
Howu, ibeere ni o beere, eewo leebu  A muni je amuni, eewo ni oo ni bo nibe ?? Arabinrin iseju e laaye boba ti je nitori abeere ona kii sina.
|
|
|
|
|
|
omoge (f)
|
hummm Kurukere kurukere oshele  iya aje where are thou  out out brief candle.
|
|
|
|
|
|
excel12 (m)
|
MOKO!!! iwo loni shoro.  baba oko mi(LOL)nkan timomaje ni bakiri o,pe mi lomo ofun toba wu e. e mio mo oun tayefele baka--toba tiri bilere!!! kini iwogaan badebi  tojubole eran nuru nie!! Minute, o go lopolopo,laakaye re si kuru.se emi lo n ba soro beyen?ma je ko mo e lara de ile oko o
|
|
|
|
|
|
minute (f)
|
wahala loko rae si. @ excel next time oro ti won ba pe e si madasi. bawo ni tie she je o  lowa bi joko si o,kosi eni tope e soro nibi. youve got smthg to post ,why not just post it and leave? now tetibeleje ko gbo mi-----laiye e ma ever sope mogo mo tie duru naa omo mi ni abi mo mo e?  ,and whats that shit up there becoming an habit? jo tori olorun ni mo fin be e,nkan toba bawa ibi niko koju mo. as frm today ,im g onna try as much as possible to stay away frm u,frm what ive read here i see u up to no good. peace out. @mishoo,it was a very bad joke,emi naa mo.
|
|
|
|
|
|
richylaw (m)
|
Minute, kii ja kii ja, omo ale lo n je be, sugbon agbaniloju gunni lobe ko fomo odo lu ni se die ninu iwa janduku. Jowo ma je ki ibinu re ma po to ba yi o. Se wa pele ni mu ni niyi lawujo o. LOL. ati Aiyefele ati Excel ore ni gbogbo wa o mo ba ara wa se o a o ni di ota. Mishoo , o to ojo meta kan, se alaafia ni. Oko okun yi ti n worin lenu lowolowo yi osi ye o be lo ye mi, ohun gbogbo ti di foyegbe. Ayan n ko ati Segoye , desorlah nko pelu bolorunfem, this guy nko ati bebe lo , eni to ba ti ri won ema ba mi ki won o.
|
|
|
|
|
|
iyalaje (m)
|
Iyalaje tunde, emini yoruba nkiwipe bariyin odun ayipo. Moki gbogbo wa patapata, papajulo ojogbon richylaw bi oluwa bani kiwon ole ranti mi. @buttyelele, ebasigbiyanju ki egbo oro richlaw ye. Ejeki amalo ede abinibi lati salaye gbogbo ntoba ndunwalokan, paapajulo nipa adanu ti onde ba ede YOruba. Eyije nkan ti otomu omijade loju eni. Yoruba bo wonni " Bi onigba basepe igbare beni omo arayie yio bape, enibape igbare ni akufo arayie yio pe ni panti." Ejeki apon ede yile nitoripe direto ninu nkan oni nkan, ede Geesi ayaloni kilode ti awagbakanri?
|
|
|
|
|
|
Nite Angel (m)
|
Enle o. Se daada ni a ba ile? Se awon omo njeun? E ku eto ilu
|
|
|
|
|
|
toyinrayo (f)
|
tani omo ekiti ni bi? e na owo yin soke. . . 
|
|
|
|
|
|
tafari (m)
|
omo ekiti ni mi. anything for me?
|
|
|
|
|
|
|
|
tafari (m)
|
ekiti kete ni mi, kilode to gba mi gbo 
|
|
|
|
|
|
champredd (m)
|
ekiti kete ni mi, kilode to gba mi gbo  Doubting Thomas
|
|
|
|
|
|
mashaun
|
wo won ,at'oba ati'joye
iru kan-un iyeka abajo. saago nbugo.
|
|
|
|
|
|
wed123 (m)
|
wakoro wakoro ijah omo etiabai denke hilaro ati? semife lala hin toni jakala refutiko abik Beni ati gkoro ti o tomi daburo nkem in si ya me ndatu ife mmega!!!
Beni. Odabo.
|
|
|
|
|
|
richylaw (m)
|
Iya Aje Niwon igba ti o dabi eni wipe afojufoda ati amoworekoja ko je ki n ranti se e n lebeun si Mr 'Wunmi (iya aje), mo fi asiko yi parowa wipe ki o fiyedenu ki o ma si se binu o. Iku ati arun logbagbe re o. Oro lo n yo obi lapo(pocket) , o n na lo n yo ida lapo (scabbard).Imo ede wa , asa wa ati isesi wa ko ni poora mo wa loju o. Tafari o mo to ojo meta, se gbogbo re n se deedee. Awon aafa wa n ko lode Kuwait. Gbona Ondo abi kini mo ri  . Looto ni o, koda won ni iwo ni oye oba kan nibe!!!  . wakoro wakoro ijah omo etiabai denke hilaro ati? semife lala hin toni jakala refutiko abik Beni ati gkoro ti o tomi daburo nkem in si ya me ndatu ife mmega!!!
Beni. Odabo.
Lati ibo sii ibo, erin n gbe mi n ko si lee da rin. A se iru awon eniyan bayin si tun ku lori ile aye 
|
|
|
|
|
|
mishooo (m)
|
Richylaw, e ku iwaju oo
|
|
|
|
|
|
richylaw (m)
|
Richylaw, e ku iwaju oo
o jare , se alafia la ri yin o?
|
|
|
|
|
|
replenish (f)
|
@ iya aje kini mo se , jowo ma binu simi ok i like u too 
|
|
|
|
|
|
jintujinta (m)
|
Ah, fraud ma lawon ara ibiyi ke. Sebi "f" lowa niwaju oruko ayefele200, bawo ni won tun sen pe ni bros. Ha ohun to tie tun wa lo terrible yen lo tun fi ba gbogbo e je. Abi homo de ni bobo yen ni?
|
|
|
|
|
|
Bblak (f)
|
Eyin temi what a miss?
ki lon sele
|
|
|
|
|
|
Mustay (m)
|
bwo ni ilu eko?
|
|
|
|
|
|