|
iya aje (m)
|
IYA AJE NKI GBOGBO YIN O, E KU OJO META,E SI KU ORO ILU, SE NKAN WO NKAN? SE E HO? E MA JE KO FAYA O EYE YIN O NI FORI SOGI O.
|
|
|
|
|
|
mashaun
|
@mustay, se iwo mustay ibadan poly ni bawo.
e ku iwaju o gbogbgo ile. a ko fe adalu ede ni iha ihin o,yoruba ponbele lai labawon lafe ewo lonje "what a miss" baba oni geesi.
|
|
|
|
|
|
mrpataki (m)
|
Mo gbadun ibi bayi gan oh. Eyin omo nairaland, e ku ise. Owo yin a ma ro oke oh. Mo lero wipe mo so yoruba na dada oh 
|
|
|
|
|
|
ikamefa (f)
|
e we so oh  se gbogo e n joh! e ku ile oh! 
|
|
|
|
|
|
Mustay (m)
|
ikamefa lati ilu omo ibo 
|
|
|
|
|
|
nana (f)
|
Mo ki onile,mo ki alejo.Mo ki gbogbo odo ati agba ti mbe ni ibi yi o.Se dada ni mo ba yin? E ku bi oju ojo se ri o. Ojo na asn wa sire o. Amin.
|
|
|
|
|
|
|
|
OMUWUNMI
|
mo tun ti gbe kini ohun de o emi na ni o,eni ti gbogbo yin timo tipe tipe eni a ro pe ko le pago,bi ere bi ere o ko ile alarinrin aye o le pa kadara da.won ko le fa owo ago sehin ni, keyun o ma je ti awon awon admin, a mo ra wa. 
|
|
|
|
|
|
Mustay (m)
|
ekabo si inu klubi omowumi
|
|
|
|
|
|
benedo (m)
|
Dede olodo,awon ti yoruba won muyan'doko o po nibi yi rara, a fi ki won maa da ede geesi pelu ede yoruba,(lagos yoruba),ahhhhhhhhhhhhh e jo, ede yi dun, ede gidi si ni, eyin omo oduduwa, e pele oooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooo
|
|
|
|
|
|
jimmyxxl (m)
|
enyi omo odua. aki gbogbo yin ooooo. oluwaseun ni oruko temi.
|
|
|
|
|
|
OMUWUNMI
|
enyi omo odua. aki gbogbo yin ooooo. oluwaseun ni oruko temi.
OLUWASEUN MO KI E KABO O,MA FI OYAN YI SERE NA KI IYAN TI MO NGUN FUN E TO SETAN>
|
|
|
|
|
|
|
|
tafari (m)
|
gbogbo Ilu, e ku ojumo o. se daadaa ni a wa. baale, e ku ojo meta o. ode o dun bi? awon olori mi nko?
|
|
|
|
|
|
omoge (f)
|
Privatepartwunmi ti ju wa lo Mustay, kin se omowunmi. omuwunmi ni  se enikan ni gbogbo won ni?
|
|
|
|
|
|
janami (f)
|
kai! omowunmi! ki wa ni eleyi wa je bayi nisin? 
|
|
|
|
|
|
mdsocks (m)
|
Ba woni gbogbo yin oo, Mo ki fun yin ooo 
|
|
|
|
|
|
predi (m)
|
oga ju!! eyi tun ga laga ju!! ni bo ni mo wa lati joyi? mo ki gbo gbo omo odua rere to wa ni klubi yi!! pataki julo, gbogbo awon omo eko tin be ni bi yi--" e ko oni baje o?"
omowunmi, ah! omu eyi tun le ken ka!!
mo ki gbo omo odua ati awon tin won ba wa gbo ede wa ni NAIRA LAND, oruko awon eleyi ni ara kun rin- toyeenbramms lati Abuja, gbo gbo Abuja lo n ki yin yin o!!
e ma gba dun ara yin, naija yi, a wa san wa si rere o!
AMIN E PO JU!!!!!
|
|
|
|
|
|
Mustay (m)
|
omoge after that pic i just remembered the obo oko wumi families
|
|
|
|
|
|
omoge (f)
|
lol, the username too Omuwunmi (wunmis) lol never fails to deliver 
|
|
|
|
|
|
Mustay (m)
|
u sabi them? 
|
|
|
|
|
|
omoge (f)
|
Ta lo ron e wa?
|
|
|
|
|
|
segoye2 (m)
|
Oti to ojo meta kan bayi baale. Iku oro ilu wa yi ooooo, e de kun imura odun keresimesi ton bo lona yi, yio bawa ni ayo ati alafia oo (amin). 
|
|
|
|
|
|
Bolubunmi (f)
|
In fact, odun mi pe gbogbo wa ti so ede wa yi nu. awon omode gan ko mo so, especially d new kids ti won grow up ni si yi. bawo lama se se?
|
|
|
|
|
|
Fileki (f)
|
Aago onile o,
waxyweller, onisokuso omo osi lo fe ya, o ka re jare olat2k baba agba, laakaye re ko kuku ni daru.
elomi ninu omo oodua ko kuku gbon, a ni ki e wa ki e ja ka gbe Yoruba laruge, omo mi n so isokuso, a too yin ti.
mustay elenu fife. . . ju gbo gbo e lo, Oodua a gbe wa o. lagbara olo'un n o tun ma de ibi, l lee koo kan.
e ma binu ti akosile mi ko ba ye yin, kiboodu (keyboard) mi ko ni eyan oro.
tiyin tooto, Filkeki.
|
|
|
|
|
|
bolorunfem (f)
|
Ojo kerin, osu kejila, egberun odun, o le meta, leyin iku Oluwa wa. Si gbogbo oluso ede Yoruba, Mo ki yin o, gbogbo omo Oduduwa. Mo je eni ti o feran ede abinibi gidigidi, paapa julo, olufe okun yi ni mo je, koda ibi ni mo ma nwa julo teletele ki afefe Nairalandi to gbe mi lo si ori awon okun miran. Bi o tile je pe mo ma nyoju si ibi leekeekan, o pe ti mo dasi oro, idi re si i nipe oro to nlo lowo ni akoko miran le je oro laarin ore meji, nko si ni fe lati pa'kuta si oro won. E jowo mo fe ki a wa ona lati wa bi a sele mu ki okun yi dun ju bayi lo  . Yato si oro awada ti o wopo julo nibi, ko ba dara ti a ba le fi ibi yi se 'foromu' ti awa omo Yoruba, nibi ti a ti le pade fun ijiroro nipa ohun ti o ndun wa lokan, yaala nipa orile ede tabi eya wa, idile, oro aje tabi ise, asa tabi ise wa, owe, aalo, ounje, ohun gbogbo to je mo ede tiwa-n-tiwa, e je ka lo anfaani ti a ni lati 'express' (mo toro gaafara, itumo oro yen sa fere fun mi  ) ara wa ni EDE tiwa, se e mo pe 'nkan mi' ni o yato si 'nkan wa ni'. Nipa idi eyi, awon ti Yoruba won jinna yio tubo danmoran si, awon ti tiwon ku die kaato yio lagbara si. Gbogbo wa ku ipalemo odun Ileya, Keresi ati odun titun to nbo lona, alafia ara ni gbogbo wa yio fi se, Disemba ki yio di enikeni ninu wa meru lo, amin. Mo riyin na, odigba. Mo fi akoko yi ki awon arakurin mi, Shegoye2, Richylaw, Mishoo, Ayanjide, Mustay, ati awon iya oko mi bii; Ikamefa, Iyalaje, Toyinrayo ati awon ti mi o ranti daruko. Mo tun ki awon ko sako ko sabo bi i Ayefele ati Iya Aje (okunrin to nje 'Iya')  Gbogbo oju ttitun, mo ki eyin naa kaabo o  .
|
|
|
|
|
|
ettehgate (m)
|
mo ki gbogbo ile o e kuu yo to mi
se pe nkan nbe bayi ni bi?
|
|
|
|
|
|
ettehgate (m)
|
e bami ma fi idi yi sere naa
|
|
|
|
|
|
Bolubunmi (f)
|
Eleyi ma ti pu ju ke! abi ewo ni idi gelede yi? Eleyi o bosi rara o.
|
|
|
|
|
|
ettehgate (m)
|
eh, eyan mi, orisirisi idi lo kuku wa idi ape, idi arere, idi oro, idi araba koda idi mango wa ni eko
|
|
|
|
|
|
OMUWUNMI
|
lol, the username too Omuwunmi (wunmis) lol never fails to deliver  hey girl don't let d cat out of d bag,KEEP OUR SECRETS SECRET, OBOWUNMI LIVES FOREVER JUST LIKE IYA AJE,how is you?me miss you gan ni,gba be  u sabi them?  u sabi who?olofofo  e bami ma fi idi yi sere naa
mi ku oooooooooooooo,etteh pami oooooooooo, my this thn no wan go down again, e jowo e da omi tutu lemi lori, na this one them dey call FURO
|
|
|
|
|
|
Dr Ferlie (m)
|
mr omuwunmi , e ku ojo meta oooooooooooooooo. awon omoge yin nko?
|
|
|
|
|
|