|
richylaw (m)
|
Desorlah aya Oloye, Oto ojo meta o. Metodman, mo wa n le lojo kojo, se bi iwo na mo pe ko si arugbo ni Ghana
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
baba, mo ni amoran kan oo. O se mi ni anu wipe dokita ko si nibi lasiko yi. E gbodo ma mu ogidi OGUN JEDI, OPA EYIN, ALE, AFATO ati bebelo tori mo jeri Olori oooo
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
arabirin yen le die oooooo
|
|
|
|
|
|
richylaw (m)
|
arabirin ye le die oooooo
Iwo fi edo le ori oronro. Sebi gbogbo wa la mo oruko to n je ki a to ma pe ni abe. Ibi ti o soro de mo ti mo koja ibe. Sugbon gegebi iwo na se mo wipe Odun Oro ma n waye ni ona Oji-le ni Oodun ati maarun ninu odun ninu ilu wa yi, fun idi eyi ojo mokanlelogun nikan ni o wa fun baba lati se yotomi ninu odun, ki ogun ma ba dobu , ki ewe o si lee ma je. A o mo bi a o se dawo le oro na ni igba ti asiko ba to
|
|
|
|
|
|
desorlah (f)
|
Desorlah aya Oloye, Oto ojo meta o.
Baale, beeni, mo rin irin ajo kekere kan ni, se daada ni mo bayin? awon olori na nko??
|
|
|
|
|
|
Fileki (f)
|
Alagba Metodman, Kabiesi ki se omode, beeni won mon awon oun ti o to ati eyi ti o ye fun won lati ma lo, ati wi pe oro l'ori eto ilu nikan ni e ni eto lati fi enu si, T'owo t'owo ni mo fi royin pe ki e dakun ki e ma se mu enu lo si ibeyen rara.
Ati wipe '' arabirin ye le die ooooo'' ti e so yen ni itumo , se e mon mi ri tele ni? e ma se ba oruko mi je l'aafin oro ilu l'ani ki e da si
|
|
|
|
|
|
desorlah (f)
|
aunti desorlah, se e wapa ?
Alagba metodman, mo wapa oo. . . .eyin na nko?
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
olori Filefi, edakun, emabibu, enu mi logboro, Loto, emi ko mo yin tele sugbon eyin arabirino de yi, ki eyin baba ma lo kan ni oooooooooo, E ma binu rara!
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
arabirin desorlah, mo wapa ooooooooo, E de si asiko to dara, mo yonu so si Olori ati wipe eru n bami ki KAbiese ma fi iya je mi oooo
Olorun ma je ki fi enu jam !
|
|
|
|
|
|
Fileki (f)
|
Alagba Metodman emi o b'inu rara. fun atunse, Fileki, Olori Fileki ni oruko mi, Ilu yi o ni baje
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
Olori e se ooooooo ibeji abiro, Oju o ni tiyin nile Kabiesi ooo
|
|
|
|
|
|
richylaw (m)
|
Ekun tagiri gbera re nija, Olori fileeki ti gbeja ara re, ko si si ohun ti mo fe so mo. Ko si iya kan fun metodman lasiko yi o. Baale kii se esu rara, a mo sa oro re ri bi i oro omode to siwo lu iroko, bo se n sa lo , bee lo n boju wehin, o se bi oojo ni Oluwere n pa nii je ni. E ma yiri e wo
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
Asiwaju Dokita, awa egbe ode (hunter) fe wa se ipade pelu kabiesi ni ose (week) to nbo. E ba wa bere asiko ti ale ba baba ni ile, Ese pupo ooo
ogun a gbe yin o ! 
|
|
|
|
|
|
Dr Ferlie (m)
|
ogboju ode methodman,
E ku ojo meta. nipa oro ipade eyin ode pelu baale, olu ode ti fi tomi ni eti. ma si ba baale soro nipa re to ba di irole.
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
e se pupo dokita, mi o tie mo wipe won ti sofun yin. A wa yin dele sugbon , a o bayin, won ni e lo ode, Arabirin pupa kan ti ori rumurumu ni a ba,
|
|
|
|
|
|
richylaw (m)
|
, Arabirin pupa kan ti ori rumurumu ni a ba,
Ekuro le wa ra ori eran se de igba
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
baba oro yin yen ko yewa dada ooooo , emo pe yoruba diluted ni awa n so
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
baba oro yin yen ko yewa dada ooooo , emo pe yoruba diluted ni awa n so
|
|
|
|
|
|
richylaw (m)
|
baba oro yin yen ko yewa dada ooooo , emo pe yoruba diluted ni awa n so
Owe ni mo pa, awon koko oro inu re ni mo si tumo si isale yi ekuro - palmkernel ori eran - goat's head igba- in this context is shopping bag, but in the actual translation it is calabash
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
kilo wa tunmo si sir ?
|
|
|
|
|
|
ibrahiem (m)
|
moni fe're' means i love y'all
atleast a hausa don talk hin own.i no try
|
|
|
|
|
|
holythug (m)
|
e kale n biyi o
|
|
|
|
|
|
marzipan73 (f)
|
can u translate to yoruba, please,
hello how are you? have a good weekend? let me know when the goods arrive. we will talk sometime soon
|
|
|
|
|
|
PERVERT9
|
e nle nbeun o eyin enia wa,a jire bi?e ku ojo meta o,e si ku oro ilu wa,oba oke o ni je ko baje o e se amin adura ke gbeto re mi.
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
e kabo, ni oruko asiwaju dokita, erelu ati KABIESI ATI OLORI
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
e kabo, ni oruko asiwaju dokita, erelu ati KABIESI ATI OLORI
|
|
|
|
|
|
mishooo (m)
|
KABIYESI OBA ALAGBARA GIGA, OBA AWON OBA, OLORUN AWON OLORUN ASEDA ORUN AWAMARIDI APATA AYERAYE, ARUGBO OJO ATOBIJU, ATOFARATI BI OKE, ATOBAJAIYE, ALADE ALAFIA, ALADE WURA, AWOLE IRO TIPILETIPILE, ALAGBADA INA, ALAWOTELE OORUN, AWOGBA ARUN MAGBEJE, ABETI-LU-KARA BI AJERE, ATAYERO BI AGOGO, ALAGBEDE ODE ORUN, ARIIRO ALA, ARINU RODE, OLUMORAN OKAN, AKIRI SORE, AFUNNIMA SE REGUN, AFINI MONA, APANLA TO SOLE AYERO, ALEWI-LESE, ALESE-LEWI, AKIIKITAN, AYI-YINTAN, APE-PETAN, AWIMAYEHUN, ALPHA ATI OMEGA, ASOROMAYE, ADIMULA, ADIMUYE, ADESINA TI SINA AIYE F¢EDA A JOBA MATI, ADAGBA MA PARO OYE AA JA SEGUN OLU SEGUN, ALABARO ADURO GBON IN GBON LEYIN ASOTITO OLU ORUN TI NJE EMI NI OLUWA AWON OLUWA OLORUN IMOLE OLOORE OFE OGA OGO OBANGIJI OLUSO AGUNTAN ENI TIRE OLOWO GBOGBORO TII Y¢OMO RE L¢OFIN OLUTUNU(Comfoter) OLUGBEJA(Defender) OLUDANDE(Deliverer) OLUPAMO(Protector) OLUKONI(Teacher) OLUPESE(Provider) OLUBUKUN(Benefactor) ABIYAMO LOJO IJA ALATUNSE ALAABO A JI DARA A GB¢OMO LOWO IKU A JI P¢ JO IKUDA AJI BORI OSO AYIPINNU ESU PADA ATE RERE KARI AYE AGBENI MA DEYIN ERU JEJE LETI OKUN PUPA GBONGBO IDILE JESSE(Root Of Jesse) EKUN OKO FARAO AKOO MA TIKA LEHIN IJINLE IFE IPINLESE OHUN GBOGBO OBA IYANU (AWESOME GOD) IRAWO OWURO JEHOVAH JIREH JEHOVAH NISSI JEHOVAH SHALOM JEHOVAH SHAMA JEHOVAH RAPHA JEHOVAH EL SHADDAI OLORUN MESHAKI SEDERAKI ATI ABEDNEGO OLORUN ABRAHAMU, ISAAC ATI JAKOBU OBA TI N TI ILEKUN TI EDA KAN KO LE SI,OBA TI SI ILEKUN TI EDA KAN KO LE TI OBA TO LA OJU AFOJU OBA TO NJI OKU DIDE OBA TO POO NI IPA ATI AGABARA OLORUN OWU (JEALOUS GOD) OBA TO PA KINIUN LENU MO FUN DANIELI OBA TO TA OJU ORUN BORA BI ASO OBA TO FI GBOGBO AGBAYESE APOTI ITISE RE OBA TI NLA ONA NIBI TI ONA KO SI OBA TO MU RIRI JADE NI NU AIRI OBA IBERE ATI OPIN OHUN GBOGBO OBA TI I NGBE NI IGA LOJU ANINI LARA OBA AIKU OBA AISA OBA A SORO MA YE OBA TI KO NI IBERE TI KOSI NI OPIN OBA TO TOYIN OBA TO TOSIN KAAABIYESIOOOOOO MIMO! MIMO!! MIMO!!! MO SE IBA RE OOOO
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
arakurin , e se gan ni o, I have been looking for Oriki OLORUN FOR A LONG TIME
|
|
|
|
|
|
jkpretty (f)
|
kilonshele nibi yi?
she wa pa?
|
|
|
|
|
|
oluomok (m)
|
ose lara gbogbo tin o, ede oyinbo ti gba gbogbo ede ibile yin lowo yin, ha o maa se lara omo tin je eruu
|
|
|
|
|
|
richylaw (m)
|
Mo ki gbogbo ile o, se alaafia ni gbogbo wa wa. Ojo aje loni , ki aje maa bu igba je o. ASE
|
|
|
|
|
|
|
|