|
Dr Ferlie (m)
|
gbogbo awa omo oodua, a ji re bi?    ? ojo oni a san wa si rere ooooooooooooo. Ase. mo ki baale ati oloro fileki.
|
|
|
|
|
|
richylaw (m)
|
Oba nki o o, awon agba iwase ko ni doju tiwa o. Ki ajinde ara ko ma je wa. Ire loju owo nri ire la o ma ri ninu ilu wa o. Ase
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
mo ki gbogbo wa loni o, A ma lo re bo re ooo
Mo ki oba, asiwaju dokita , Erelu ati Olori o
|
|
|
|
|
|
Fileki (f)
|
A ku ojo Isegun oni o. Ire a wa wa ri o, ase! ni inu ilu yi, gbogbo wa la o ri b'atise, Kabiesi mo ki yin, Asiwaju Dr Fele,Erelu, ogboju ode Metodman, aya Oloye Desorlah, ati gbogbo eniyan.oni yo dara fun gbogbo wa
|
|
|
|
|
|
debson (m)
|
Eku dede iwo yi o!
Alo ooo!! Agbada baba mi lailai, agbada baba mi lailai, owo ni je ki je agbado oo! (Eni ba mo ko so o!)
|
|
|
|
|
|
debson (m)
|
Ejo e ma binu (ashise ni)
Alo ooo!! Akuko baba mi lailai, Akuko baba mi lailai, owo ni je ki je agbado oo! (Eni ba mo ko so o!)
|
|
|
|
|
|
richylaw (m)
|
Debson, kaabo o, ni ode iwoyi, akuko re yii ti kola orisirisi o. Ki tile si oun ti o wa ni ile aye nisisiyi ti ki i se akuko a je owo o.
1.Kolo (petty safe: awa omode ni igba yen ma n pe ni banki, iyepe amo ni won fi n se tabi ki gbena-gbena ba ni fi pako kan) le je akuko re
Awon akuko a jewo ode iwoyi miran niyi: 2. Iwe kika la ti re ile eko giga 3. Amojuto dukia eni bii ile , oko, eto isuna, adojutofo ati bee bee lo na le je akuko lode oni 4.Koda iyawo eni, oko eni tabi ale eni a ma je akuko jewo-jewo o
Bi ko ba si akuko re ninu gbogbo eyi , dakun la wa loye ohun ti akuko re wa je gaa an o
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
Enle ni beyen oooo, Olori, se e wapa? bawo ni baba laafin, E ba wa kin won ni ooo
|
|
|
|
|
|
Fileki (f)
|
e ku ojumo o, oni a dara fun gbogbo wa o, ase! Debson baba, mo ki yin o,
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
OLORI, BAWO NI IBADAN, SE WON TI SE ONA IBADAN SI ILORIN YEN TAN? ABI ONO BURUKU YEN NI WON SI NLO?
|
|
|
|
|
|
debson (m)
|
Fileki, o ka re omoluabi. Eni a ye o!
Mo ki gbogbo ilu o! a ye wa sowo, a ye wa somo, ajinde ara a ma je o!
E jo se oye otunba shi wa ni le?
|
|
|
|
|
|
ayomifull (f)
|
Bi oba wun olugon ko jiire ko kan mi, ti o ba wun aresa ko jiire oun lomo bi eyin temi ba ti jiire abusebuse.
Ao ni jakule bii 3rd term o, a o ri orriire bi ti Goodluck, oa si gba eto wa bi ti Rotimi o. E ku ojumo o.
|
|
|
|
|
|
nana (f)
|
E ku b'oju ojo se ri o eyin eniyan mi. . . Eku ijo meta o. . .
|
|
|
|
|
|
tempestous
|
eyin, omo yoruba, ekasan, se dada ni gbogbo yin wa. 
|
|
|
|
|
|
Fileki (f)
|
A ku ojumo o, o ti dara fun wa loni, Oba oke a saanu fun gbogbo wa o ase.
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
Olori Fileki, ba wo ni o, se e n gboro asiwaju dokita,
|
|
|
|
|
|
Fileki (f)
|
Alagba Metodman,o ti to ojo meta ti mo ti gburo Asiwaju dr Felie, sugbon mo ni igbagbo wi pe alaafia ni won wa, eyin nko? se ara yin le?
e ku bi oju ojo ti ri?
ilu yi ko ni baje o
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
KO TI E LE BAJE TORI KO BAJE LORI OLUGBON, KO BAJE LORI ARESA, LORI BABA WA RICHLAW, KO NI BAJE, .EKU A KE BI EKU, EJA A KE BI EJA, METODMAN A DUN BI METODMAN
ASE!
|
|
|
|
|
|
Dr Ferlie (m)
|
Alagba Metodman,o ti to ojo meta ti mo ti gburo Asiwaju dr Felie, sugbon mo ni igbagbo wi pe alaafia ni won wa, eyin nko? se ara yin le?
e ku bi oju ojo ti ri?
ilu yi ko ni baje o
Olori Fileki, E ku ojo meta. Baale Richylaw nko? E ku Ilu wa yi. Alaafia ni mo wa oooooooo. Ma kan si eyin ati Baale ni aafin ti o ba asale. Eyin eniyan mi toku se daadaa ni o? metodman mo ki yin o
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
Asiwaju dokita, mo ni ilu yi ko le baje loju eyin arorosasa , abi ki leni moso?
|
|
|
|
|
|
gilgee (m)
|
ogede kaka ojawa. ofetike ugbe gbe awahi. Mine is Unique ooo. Not Nigerian/African Yoruba sha. Na customized Yoruba be that.
|
|
|
|
|
|
richylaw (m)
|
ogede kaka ojawa. ofetike ugbe gbe awahi. Mine is Unique ooo. Not Nigerian/African Yoruba sha. Na customized Yoruba be that.
Orisirisi obe la n ri ni jo iku erin, eyi tun ga ju. Gbogbo ara Ilu nairaland, e ku akitiyan o
|
|
|
|
|
|
Dr Ferlie (m)
|
Baale Richylaw , e ku oju ojo. olori fileki nko? mo ni ki nki yin ni o.
Gbogbo ilu, ose tuntun yii a san wa si owo, omo ati alaafia.
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
eku ojumo nibe yen o
Ojo oni yi a san wa si owo, si omo ati si alubarika o , ASE!
|
|
|
|
|
|
bababuff (m)
|
E nle o! omo odua gbogbo.
Ilu she wa da bayi? Baale papa o yoju lati ipari osu februrary.
She o si kan o?
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
Baale n sise arole lowo, Olori ni ko je ki baba roju raye jade
|
|
|
|
|
|
desorlah (f)
|
Hello! 
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
yes? 
|
|
|
|
|
|
Ujujoan (f)
|
I really want to learn this language and this thread is soooo long, I can't possibly read everything. Would someone be kind enough to suggets ways for me to learn??
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
MO ki onile, mo ki alejo, e ma binu pe mo pe die ki n to de - ire ti mo ko lona ni o je ki npe. ILU yi ko ni baje lagbara Olorun. E MAA YA ISE O .
|
|
|
|
|
|
Dr Ferlie (m)
|
MO ki onile, mo ki alejo, e ma binu pe mo pe die ki n to de - ire ti mo ko lona ni o je ki npe. ILU yi ko ni baje lagbara Olorun. E MAA YA ISE O .
kaabo, oloye kola, iyawo ati omo nko?
|
|
|
|
|
|
|
|