|
kola oloye (m)
|
Ojogbon, E SEUN ti e gba mi towo-tese.
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
E kabo oooooo , Ni Oluro gbogbo Ode (Hunters) ti ile yi at ni oruko baale ati Olori ati Asiwaju, a ki yin kabo
|
|
|
|
|
|
nana (f)
|
Hello!  Olori Desola,OseO ku iranti. . . Bawo ni gbogbo eyin omo oduduwa? S'alafia ni?
|
|
|
|
|
|
Dr Ferlie (m)
|
Ojogbon, E SEUN ti e gba mi towo-tese.
A ki dupe ara eni. e ma jina siwa ninu ilu yii o E kabo oooooo , Ni Oluro gbogbo Ode (Hunters) ti ile yi at ni oruko baale ati Olori ati Asiwaju, a ki yin kabo
olu ode metodman, gbogbo awon ode tokun nko? nje mo le ri eran oya(grasscuter) ati etu (antelope) ra ni owo yin? Hello!  Olori Desola,OseO ku iranti. . . Bawo ni gbogbo eyin omo oduduwa? S'alafia ni? arabinrin nana, alaafia ni awa oooooooooooo. e ku ojo meta
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
E KAAASAN NILE O. Bawo ni ise oni o?
|
|
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
Asiwaju, ko si eran oya lasiko yi o, Baale awon Oya ku, gbogbo oya nigbo lo nse idaro baba won, Sugbon, laipe yi, awa ode nlo si oko ode fun ose kan ni igbo nairaland, Mo fi da yin loju wipe, e o ri eran oya ra nigba yen,
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
Asiwaju, ko si eran oya lasiko yi o, Baale awon Oya ku, gbogbo oya nigbo lo nse idaro baba won, Sugbon, laipe yi, awa ode nlo si oko ode fun ose kan ni igbo nairaland, Mo fi da yin loju wipe, e o ri eran oya ra nigba yen,
E ma binu si wa
|
|
|
|
|
|
Dr Ferlie (m)
|
olu ode metodman  A jibi? gbogbo ile nko? Oodua agbe wa oooooooooooo 
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
Asiwaju, E karo o,
|
|
|
|
|
|
opuro (m)
|
eku ijo melo kan o eyin omo odua awon abenilori ti be ettegate lori o koda won yin ibon fun osereka adupe pe opuro si wa kampe!
|
|
|
|
|
|
Fileki (f)
|
a ku odun ojo ibi, Mohammad ta se koja, a si ku odun ajinde bakana. se alaafia sa ni gbogbo wa wa, nitori n ko gburo awon eniyan lo titi.
ire gbogbo ko ma wa wa o Kabiyesi, ODe metodman, Dr ferlie, Aya Oloye desolar, Otunba Debson, gbogbo eniyan pata ni mo ki o. ilu yi ko ni baje o Ase.
|
|
|
|
|
|
dominique (f)
|
amin o aku odun aku iyedun awon omo leyin kristi ni nairaland emi a se opolopo odun layo ati alaafia o.
|
|
|
|
|
|
morenike09 (f)
|
amin o aku odun aku iyedun awon omo leyin kristi ni nairaland emi a se opolopo odun layo ati alaafia o.
amin osame to youOlorun afi ojo odun wa di ojo ayo ati ojo ore
|
|
|
|
|
|
debson (m)
|
Mo ki gbogbo ara ilu pe "Eku odun o" Emi a she opo odun laye o!
Baale, (oko ilu) kara o le baba. Mo ki gbogbo oloye ilu pata lai ku enikan.
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
Mo ki gbogbo omo Oodua ku abo lehin odun Ajinde. Se alafia ni gbogbo ile wa?
|
|
|
|
|
|
dominique (f)
|
e se o  , alaafia ni gbogbo ile wa, adupe lowo olorun,
|
|
|
|
|
|
djcrucifix (m)
|
oruko mi ni oluwamayowa, omodun meji din ni ogun nimi, omo eko latile ni wa, a de ron yin nise, 
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
Mo ki dede omo Oduduwa ti'le to'ko. Igab yi a tu wa lara lola Oluwa. Dede omo Lisabi Agbomgbo Akala,mo ki yin ooo.
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
@bluehorizo, Se pe omo egba re ye? nko de mo li a pade lori apero yen. Se o ko binu. Oruko re yi ne ko je kara fu mi,oruko nla yi gaju. Adura dede wa re ma gba o.
|
|
|
|
|
|
ibkaye (f)
|
 ba wo ni
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
@bluehorizo, Se pe omo egba re ye? nko de mo li a pade lori apero yen. Se o ko binu. Oruko re yi ne ko je kara fu mi,oruko nla yi gaju. Adura dede wa re ma gba o.
Baba Oloye,n ko binu rara. Se dada li dede ile wa? Apa ibo si ni'le yin wa l'egba? Li to oruko yen (bluehorizon),won ko ko tan ni. I nu mi dun, ayo mi kun pe mo r'omo egba mo'lisabi lori apero yi. E ba mi kile . Egba a gbe wa ooooooooooo.
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
E kaaro dede Omo Oduduwa. A jiire bi? Aa da fun dede wa. Adura wa a gba. oju o ni ti'wa.
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
enle be ye oooooo, mo ki baale (kaara o le baba) ati gbogbo aroro shasha ilu yi ooooo, Omo egba lemi na sugbon mi o gbo ede yen daada
Emi omo Ake majo Eru ni sinni, eko kin sin niyan
Omo Ake lemi, oko wa , wani odeda
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
Oruwo mi ti dara,awon eniyan mi po libi E kaaro o,se daada re gbogbo wa ji? E je ka ma se jeje o.Egba a gbe wa o.
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
nibo ni egba ni eyin ti wa oo ?
|
|
|
|
|
|
ayanjide (m)
|
E ku ojumo lori itakun yi o, se gbogbo nkan n lo deede, OODUA a gbe wa o
|
|
|
|
|
|
gbola h (m)
|
Asamo ni emi fe so nitemi, to di ifa fun eniyan to tori anlosi ofa, to ta ara ile re lofa, koranti pe bi ofa ko ba se lomo, a ranti mode moe ejekawatunso
|
|
|
|
|
|
Jiboo (m)
|
e yin temi, ki lon sele l abule wa naija, e je kia so wo po lati gbe Naija dide si inu imole aiye ati iran lowo olorun wa.
e je kia ma se dada nitori pe ikan ti wan pe ni HIV/AIDS wa ninu aiye ti an gbe, mo si fe ka ma ba arawa ja nitori pe nkan na la jo wa.
O da bo.
|
|
|
|
|
|
richylaw (m)
|
Mo ki gbogbo ara ilu o. Gbogbo awon oloye, eyin otokunlu, eyin abenugo oro, gbogbo borokini apede lenu bi eni je suya, koda gbogbo opuro to ri bi won se n be ni lori lagbala ijoba ni mo ki patapata o. A o ni te o a o ni run o a o ni d'ibaje o Pese niiro koko lagbala, aye wa a ma ro wa lorun ni o Ero pese ni t'igbin, a o ni je ika abamo ninu irora o. Ki Ilu yi le tu ba , ki o si le ma tu'se na ni a n ba kiirii o Dr Ferlie, e ku akitiyan, Metodman oluode, a rin pa n t'ogun o Asiwaju, abobajiro, arole gbogbo yin ni mo dupe lowo yin e ku imule dani o Ayanjide, adehun re ni wipe o o kan si mi laafin , n o ri o o se ko si nkan.
JIBOO: Ibi pelebe bayi ni a ti n mu olele je o, ojo-ojo kan n bo ti ohun ti o to, n bo wa di opo. Nipa ti arun kogboogun ti n je kurugbe, ki alawurabi ki o gba omo niyan ni o. Sugbon bi a ba wo daadaaa a o ri wipe afowofa omo eda ni o. IKORA ENI NI IJANU SI NI ONA ABAYO.
IRE
Baale of Yoruba Thread, Nairaland Richylaw
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
baale, kara o le o. Eku ojumo, e pe pe pe pe pe pe pe pe pe bi pepe nti pe,
Asiwaju dokita, Olori, Erelu ati gbogbo borokini mo ki yin oooo
ILU YI KO NI DARU NIGBA TIWA OOOOO
ASE!
|
|
|
|
|
|
ibkaye (f)
|
wish i could speak it fluently 
|
|
|
|
|
|