|
bluehorizo (m)
|
E kaa san li'bi dede ile oo. Adura wa a gba oo
Emi lo'mo Olowu Oduru,omo a ji fe'pe sere. A'soro kankan ko'loro oo gbo. To'loro ba gbo kini yio fi m se? Ara owu o n'binu,ara owu on ja. Awimenukuro to'wu. Owu a gbe wa ooo.
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
enle o , Omo owu ni iya to bi baba mi na, Totoro ni agbole won wa, Se kon se pe iwa baba ni emu ( oye ko ti ye yin)
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
Olorun oba o ni je ki'n mu iwa baba. Eleda mi ko. Apa'bo ni ile iya re wa ni owu? Totoro ni agbole ebi wa wa.
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
emi o mo agbole ti won ti wa ni Totoro oooo sugbon mo mo Totoro daada, Omo Ake' ni baba mi ooooooooo, se emo totoro daada ?
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
Hee! Ara'le wa'ja. Se alaafia ni dede nkan bi? Se o mo ile daadaa? Abi o kan ma ngbo itan lasan ni?
l'ori oke ohun petele
ibe l'agbe bi mi si o
ibe l'agbe to mi dagba
ile ominira
ma'yo ma'yo ma'yo ooo
Lori Olumo
Ma'yo ma'yo ma'yo oo
Lori Olumo!!!
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
Mo mo totoro daa daa mo de mo Ake paa paa. Se Isale Ake ni abi Iporo Ake?
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
itoko ni emi ti wa oooo
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
se o omo baba tope (welder) ise welder ni won n se ni totoro  ? Egbon baba mi niyen
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
owo osi ni won ni shop si ti aba n lo si lafenwa through the old bridge (enu gada)
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
Mi o mo enikan kan ni gbogbo ibi ti o da'ruko yen. Mo kan mo awon adugbo yen ni. Mo mo enu gada na. Se o ti gbe Egba ri ni?
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
Egba ni mo gbe ni gbo gbo aye mi kin to kuro ni Nigeria
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
Apa i'bo lo gbe l'egba? Baba mi ni ile si Car-Wash,egbon iya mi n'gbe ni Quarry rd. Ile iwe wo lo lo ni Egba?
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
Mo gbe Quarry Road fun Odun Medogun, Mo lo si IJEMO TITUN HIGH SCHOOL ti o wa ni HOUSING ESTATE, Mo de lo si MAPOLY naa, I read SCIENCE LAB TECHNOLOGY, Mo gbe ni ibi gas ni opposite ANGLICAN HIGH SCHOOL, I MEAN THE STREET OPPOSITE THE STREET TO ANGLICAN HIG SCHOOL, THAT PLACE WHERE THEY FILL GAS, 17 ADEOGUN STREET, BOLOWO BOJAIYE HOUSE, QUARRY
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
Adugbo awon Ajala ko ni o'daruko yen ni? Egbon iya mi ni Ijietemi. Adugbo won lo wa ni egbe Savannah Bank tele. Ti mo ba gbo e ye,adugbo e lo wa ni egbe CHS. Ni egbe ile baba tele?
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
mo mo Ijieteme daada! Sofun pe Angus ore awon Tayo Oyayomi , Ijemo titun ni Abimbola lo, Emi ati e re daada ko to di pe runs school mu wa yera die
Mo mo Ajala, dudu daada to ongbe ni Onikoko
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
Ajala dudu gannnnnnn, okuru, o fe pari die bayi
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
sorry Debola ni ooooo , kon se Abimbola
Ore awon "EBO"
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
Mo ti mo adugbo to ju we yen. Adugbo to Anglican wa ni won ko Winners si nisiyi. Mo ma n wa sere ni nu Anglican ni gba ti mo si kere. A ma nka fruits ni be,play table tennis ati ball. Lol
Debola ni aburo awon Twins. So,o mo Ayo(ebo). Anglican no ohun no lo.
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
Debola fumble,mo gbo wipe "yellow fever" ni o lo se. Ajala wa ni Port harcourt ni igba kan bayi. O mo awon Osho naa?
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
hen, so fun ebo wipe o pade ANGUS egbon CAPPADONA (LAMIDE) ore awon tayo oyayomi, ore awon yemi gbadamosi, a jo ma n play ball ni st bernedeth ni, ko le si mi mo lailai
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
osho dudu, mo mo daada, debola o fumble, oun to wun lo se nitire, Oun to je ka yera die niyen tori " awo IFE" ni emi mu ni temi, sugbon we still good friends of course
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
O ti pe gannn ti mo ti ri gbogbo won gbein. Oti to 98 ti mo ti ri ebo gbein. Mo ri Debola gbehin ni 2006. Sugbon mo le fun e ni number Debola ti o ba fe.
O le check profile me wo.
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
so nibo ni iwo funrare wa nisin ?
|
|
|
|
|
|
|
|
metodman (m)
|
okay, mo n lo jeun,
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
ok. Anytime.
|
|
|
|
|
|
ayanjide (m)
|
RICHYLAW o kuu suru o jare, maa kan si e laipe
|
|
|
|
|
|
topilobaba (m)
|
Eyi temi bawoni?
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
E kaaro ni le oo . Oju mo re fun gbogbo wa oo.
|
|
|
|
|
|
Dr Ferlie (m)
|
E kaaro ni ilu yi oooooooooo. Mo ki Baale Richylaw, olori fileki, oloye segeoye, iyalode ikamefa, olu ode metodman, oloye tokun, ati gbogbo ilu. Oodua a gbe gbogbo wa ooooooooo. Ase.
|
|
|
|
|
|
replenish (f)
|
@ metodman ati bluehorizo omo egba ni emi na sugbon abeokuta girls grammar school ni mo lo. egba wa
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
@ metodman ati bluehorizo omo egba ni emi na sugbon abeokuta girls grammar school ni mo lo. egba wa
E kaabo sori eto yi. Apa bo ni o ngbe l'Egba? Mo mo awon to lo si AGGS daadaa. Igba wo lo pari ni be? Se Egba lo si n gbe bayi? Gbeere, a da fun ee.
|
|
|
|
|
|