|
stillwater (f)
|
Nope, too still to flow
|
|
|
|
|
|
|
|
Busta (f)
|
E ka san o! 
|
|
|
|
|
|
Dr Ferlie (m)
|
arabinrin busta, e pele o. e ku ojo meta. se alaafia ni e wa. bawo ni?
|
|
|
|
|
|
ikamefa (f)
|
dr ferlie ewo ni shoboloyoke ninu oro to wa nile yii?  se ewoo ni lati ran oju ni? 
|
|
|
|
|
|
Dr Ferlie (m)
|
dr ferlie ewo ni shoboloyoke ninu oro to wa nile yii?  se ewoo ni lati ran oju ni?  iyalode efunsetan  o to ojo meta o. se alaafia ni ewa??
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
E kaaro ni lee ooo. A ji re bi? Mo ki olukuluku wa ku ojumo. Ki gbogbo adawole wa o yori si rire.Ki gbogbo ona wa la si rere. Oko oba,ada oba ki won ma se ko wa lese. O di gba oo.
|
|
|
|
|
|
micklplus (m)
|
adura nla re o ! AMIN O.
bawo ni ise leni?
|
|
|
|
|
|
Tonim (f)
|
ejoo, kini itumo alabosi ? Awon meji kan (ti won nja) npe arawon ni alabosi. kini itumo re ? ese pupo 
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
Alabosi tumo si eni ti on'gba iwaju yo gbeyin yo. A fe ni loju ma feni leyin. Iru won a ma kuru ga ti won ba n ba e soro. Awon ni won ma n wipe adegun ti won tun ma n wi pe adeogun mo. Awon ni oloyinbo ma n pe ni hypocrite.
|
|
|
|
|
|
ikamefa (f)
|
Dr ferlie alaafia ni o
iwo naa nko?
|
|
|
|
|
|
nich (m)
|
E ku owuro yi o! Se daa daa le wa? Emi o mo pe yara yi nbe tele. O da, e sa ma jaiye ori yin lo. Emi ri yin na! O tun digba!
|
|
|
|
|
|
Akede-Oba (m)
|
Bawo ni Yoruba se dun so to fun yin ? Nje iwo le so nipa asa ibile ilu re ? Owe nko ; pa ikan ki a ri o. Itan na nko ; awon alo wo ni won fi to yin d'agba ? Hen , e jowo e wa fi to wa l'eti ni Yorubaland www.yorubaland.org A n'reti yin o
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
Gbogbo ile, e ma ku ojo meta . Se daada ni ile wa,awon YOU KNOW nko? E JOWO E MASE WA ISU ONISU O. Ipade wa layo
|
|
|
|
|
|
Ebonyj (f)
|
Eyin eyan mi e kasan ni biyi o , e ku ijo meta. Se dada ni mo bayin? Awon ara ile nko, se dada ni won wa? Gbogbo awa ti awa ni ilu ajo lagbara Olorun a ma ko ere oko de ile o. Agbana ko ni wo inu owo wa o. E ma tesiwaju loruko jesu. Ma tun ma rin yin lai pe. E jo wo eje ki a ma ran ara walowo nigba kugba ti a ba le se. Odi gbakan na
|
|
|
|
|
|
jamah (m)
|
Eeeeeyaaaah~Ebonyi! Awon eyan to da ma po ke! Mo sor a mi si gbogbo awon adura yen oooooo! Tiyin na adara!
|
|
|
|
|
|
Bosiano (f)
|
Aju wa se o, asa ati ise wa se pataki o se koko. E je ki a pa wopo gbe laruge, tori asa wa, ede wa, ko si ohun to da to. OJU MO KAN IMO KAN NI O. o da bo.
|
|
|
|
|
|
echolimabr (m)
|
EJO KINI ITUNMO GBENGELE ASAI GBE WA LEKE?
MO GBO ORIN YI NINU AWO ALHAJI AYINLA OMOWURA, SUGBO MO O MO ITUMO GBENGELE.
ESE PUPO.
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
EJO KINI ITUNMO GBENGELE ASAI GBE WA LEKE? MO GBO ORIN YI NINU AWO ALHAJI AYINLA OMOWURA, SUGBO MO O MO ITUMO GBENGELE. ESE PUPO.
Ayajo ni GBENGELE  E KAARO O GBOGBO OMO OODUA
|
|
|
|
|
|
echolimabr (m)
|
EKUROLE O GBO GBO OMO ODUA.
ESUN FUN IDAHUN IBERE MI, SUGBON MI O MO NKAN TI WON PE NI AYAJO O.
BENI MOSI FERAN ORIN YI PUPO,SUGBON MI OFE MA PE NKAN TI MI O MO ITUMO RE. ESEUN PUPO
|
|
|
|
|
|