|
|
|
bluehorizo (m)
|
jenny, se iwo lo ko Yoruba yen? I yen ni wipe awon ara Umuhaia na gbo Yoruba? ke kodi? dalu
|
|
|
|
|
|
jennykadry (f)
|
he he he mi gbo yoruba ,and me no fit write am bluehorizon mi am umuahia and mi fe so yoruba nbi biaaaaa  odinma
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
hee hee. ta ni eni to ko e ni Yoruba? Bawo lo se gbo? Sugbon o n try die die. Dalu 
|
|
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
Ile ti su Jenny. Mo fe lo sun. Take care ara e oo. ma je ki awon omo kekere yen ma flirt pelu e. Sebi o mo wipe Mr Kadry ma n jealous  . O ti report e fun mi wipe awon boys Nairaland ma n flirt pelu e. But mo stand fun e wipe o kan ma catch fun e pleu won ni. O daro. Darfur! Shei! ki lo wa de ibi? Go back to Sudan 
|
|
|
|
|
|
|
|
4Her (f)
|
kini gbogbo yin se nibi? 
|
|
|
|
|
|
chinesedoll (f)
|
@4HER
NKAN TI MO FE BERE NA NI YEN
|
|
|
|
|
|
Negro_Ntns (m)
|
ah, Jenny, bawo ni oo. Se dada ni? Oti pe ti mo de ti ri e gbehin, se alafia? Mase jeje oo.  Darfur, ase o gbo yoruba  Mo ti gbe sakabula sile. Lady T n 'pada bo si ibi. T'o bari ko ba soro, ada e lohun.  Odabo ooo
|
|
|
|
|
|
4Her (f)
|
@4HER
NKAN TI MO FE BERE NA NI YEN
ngba wo ni wo ngbo yoruba? lol!! nice!
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
GBOGBO OMO OODUA,E KAARO,SE DAADA LA JI. E MA SE PELEPELE O.
@bluehorizo, ilu wo ni o ngbe bayi, atipe igba wo ni o ma lo si abe Olumo?
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
Mo ki gbogbo ilu ki asiko yi o. Igbayi a tuwa lara oo.
Kola Oloye,se daadaa ni? Mo sakiyesi wipe mi o ri tawa-tienikan lenu ojo meta, Mo ku ku wa l'Eko ile. Emi ati Fashola se mu Shepe tan ni mo ni ki n wa wo bi oro ilu wa ti nlo. O ti pe gaan ti mo ti de abe Olumo gbeyin,a ti to odun mesan bayi.
|
|
|
|
|
|
replenish (f)
|
mo ki gbogbo omo yoruba n'ile l'oko ati ni ona odo. se dada ni mo ba yin
|
|
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
Jenny bawo ni? Se o wa pa? Se jeje oo
|
|
|
|
|
|
|
|
replenish (f)
|
jenny jenny omo dada, ma gbadun 
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
Jenny,o ma n da mi lorun bi o se n ko Yoruba yen. Iyen ni wipe ni wipe won n so Yoruba ni Umuahia. Eee n na tago?
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
Kemi ki lo de ti o fi update blog e mo? Jara mo. Mo gbadun blog na.
|
|
|
|
|
|
replenish (f)
|
mi o ki ni time ni, but mo ma try lati update e
|
|
|
|
|
|
LadyT (f)
|
Oga o!!! 
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
LadyT ki lo sele? Se o ti ri Darfur? Omo yen ma pa ara e nitori e. Tete yara se nka soro e.
|
|
|
|
|
|
Tetchiness (f)
|
Hmmmm. . odabi wipe gbogbo awan eyan ti lo sun! 
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
Hmmmm. . odabi wipe gbogbo awan eyan ti lo sun!  Orun ke! niwaju adajo. Se alafia ni gbogbo ile wa?
|
|
|
|
|
|
LadyT (f)
|
alafia ni O!!!! @Bluehoriz mo ri Darfar mi ni soro. 
|
|
|
|
|
|
tybanky (f)
|
E kason gbogbo omo OODUA, mo gbadun gbogbo conversation yi. Olorun yi o wa pelu wa ooooo (Amin)
|
|
|
|
|
|
Tetchiness (f)
|
Orun ke! niwaju adajo. Se alafia ni gbogbo ile wa?
alafia ni gbogbo ile wa o. Ese neyin nko? Awan iyawo ati ibeji nko? 
|
|
|
|
|
|
replenish (f)
|
Gbogbo omo oduduwa se dada ni e wa . Ojumo to mo wa loni, Ojumo ire ni
|
|
|
|
|
|
Negro_Ntns (m)
|
Ara 'binrin Replenish,
Ase oo!
|
|
|
|
|
|
lalaboi (m)
|
o ga oh! awon arugbo lo kun ibi bayi o! ki la mA ti seyi si oh!
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
o ga oh! awon arugbo lo kun ibi bayi o! ki la mA ti seyi si oh!
Se omo kekere ni iwo, be o si ti da idan mo? 
|
|
|
|
|
|