|
excel12 (m)
|
Do you speak yoruba? Oya lets start on this thread:
E kaasan o ,eyin temi Bawo ni ile aye yin se n lo si?
|
|
|
|
|
|
Chuxy (m)
|
be like say U no get work, make yourself useful
|
|
|
|
|
|
desorlah (f)
|
ROFLMAO, HA, HAAAA, HAAAA
What a joke! HAAA HAAAHAA, ROF, LOL
|
|
|
|
|
|
Migines (m)
|
*shakes head* this is the height.
|
|
|
|
|
|
excel12 (m)
|
Mo ni ki e so Yoruba,abi ki lo n worry gbogbo yin?
|
|
|
|
|
|
nana (f)
|
Thread kan ti wa created already.
|
|
|
|
|
|
Lohlarh (f)
|
u guys should stop actin like this, simple topic lets respond jare, funlover ejo eti poju, Se gbogbo yin wapa ni nairaland? eje ka gbe ede ile abinibi wa laruge o
|
|
|
|
|
|
excel12 (m)
|
u guys should stop actin like this, simple topic lets respond jare, funlover ejo eti poju, Se gbogbo yin wapa ni nairaland? eje ka gbe ede ile abinibi wa laruge o
Lohlarh, Omo mo gbadun e jo ! o ti poju. Bo ti le je pe Lola ni oruko ti awon obi e so e,nigbati o de Eko lo wa n funkify e.
|
|
|
|
|
|
fyneguy
|
Iroyin ni soki: E ka le o, e si ku ongbe. olusegun obasanjo loruko temi je. saaju, e gbo koko inu iroyin naa (NEPA takes light), ha! NEPA
|
|
|
|
|
|
fyneguy
|
Funlover abi kiloruko re tin je? gbe enu re soun! se iwo ko mope ale mi ni Funke etteh ni? wo ko sona nbe rara. eni ba fowokan funke mi, yo rija ejo(EFCC).
|
|
|
|
|
|
mimiko (f)
|
what da fxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxxx 
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
eniola1310 (f)
|
whatever!!!!!!!!!!!!!!!!!!
|
|
|
|
|
|
fyneguy
|
funlover funlover funlover, e melo nimo pe e? yoruba bo won ni tomode ba mowo we, a ba agba jeun. Eyi lodifa fun fyneguy to nba patricia logba. Bo ti le je wipe aunty funke dagba loju, won mere se pupo. wo, emi ni ma lo mama gbo!
Ni ti tewon, odun melo ni Deprieye lo lewon? melo ni Tafa balogun lo? fi yen le jare! ewon wa je oun tuntun bi?

Fyneguy o!!!!! Je ki n pa owe kan fun e: A o kin so fun omode ko ma dete,to ba ti le da igbo gbe. Ninu gbogbo awon omoge to wa kaakiri ni adugbo yin ni okokomaiko,o ko ri eni kokan nibe afi mama onidiri patricia aanu re ma se mi o !!! se o ti pin ogun re sile sha?
|
|
|
|
|
|
confiritch (m)
|
Eyin Yoruba Nairaland e nle fa! Awa ara Ilorin naa nki yin o. Dada la wa ni ihahin. E ku poposinsin! Ire gbangba, !
|
|
|
|
|
|
excel12 (m)
|
Eyin Yoruba Nairaland e nle fa! Awa ara Ilorin naa nki yin o. Dada la wa ni ihahin. E ku poposinsin! Ire gbangba, !
confirth,yoruba ti e yi tun ga o !!! Ilorin mesu jamba
|
|
|
|
|
|
fyneguy
|
Exceli,
emi ni ogun arindo, torin na ni mo se nje ayan o. mimi kan ole mi mi o. koko lara ota nle!. (sings shina Peters, ) ma ba e lo o, ma ba e lo, patricia, mi o mo oun ti won pe o se o. Olufunke, mi o mo nti won pe ose. O gun yan lebe, o gbe fore re, ore re o, opere pore ore koda e loun, mi o mo tan pe o se!
|
|
|
|
|
|
ennyluv_6 (f)
|
se yoruba ni gbogbo yin nso latijo yi, e si wa n funck up, yoruba to yanranti lo ye kewa ko lodo awa omo yoruba to gbamuse[/color]
|
|
|
|
|
|
ennyluv_6 (f)
|
marginis, ti o ba gbo yoruba ma reply si anything ti awon eniyan ba nso
|
|
|
|
|
|
excel12 (m)
|
Exceli,
emi ni ogun arindo, torin na ni mo se nje ayan o. mimi kan ole mi mi o. koko lara ota nle!. (sings shina Peters, ) ma ba e lo o, ma ba e lo, patricia, mi o mo oun ti won pe o se o. Olufunke, mi o mo nti won pe ose. O gun yan lebe, o gbe fore re, ore re o, opere pore ore koda e loun, mi o mo tan pe o se!
Fyneguy,alawada ni o o. mo ti rerin mo fe takiti lori aga. Ennyluv,o ye ka mora wa ju bayi lo.okan mi so pe omoge to rewa ni o. adumaradan ibadi aran eyinfunjowo omo o ti po ju
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
excel12 (m)
|
Rich dad, Wa a soriire laye.Yoruba ti o so yen je ki ori mi wu gan ni!!! O o ni ku ni kekere,eni eleni ko ni gba ise re se. Waa dagba ,wa darugbo. Owo adura mi nko?   ??
|
|
|
|
|
|
Rich Dad
|
excel12, Ti e ko ni ba je.Bo se ro si mi na lose ma ri fun lase edumare , owo adura? mo ma fi rase lai pe .
|
|
|
|
|
|
excel12 (m)
|
excel12, Ti e ko ni ba je.Bo se ro si mi na lose ma ri fun lase edumare , owo adura? mo ma fi rase lai pe .
Wa a sere paddy mi !!! Ma je ko pe ko to fi owo adura yen ranse o,nitoripe to ba pe o ma n dose!!
|
|
|
|
|
|
Rich Dad
|
excel12, Yoruba pe orisirisi, yoruba e wo ni ki a ma so? se Yoruba Eko ni tabi youruba aye atijo tabi yoruba ode oni,
|
|
|
|
|
|
rsd-chukwu (m)
|
No, I can barely speak Igbo.
|
|
|
|
|
|
excel12 (m)
|
excel12, Yoruba pe orisirisi, yoruba e wo ni ki a ma so? se Yoruba Eko ni tabi youruba aye atijo tabi yoruba ode oni,
Je ka ma so egun nigbayen. No, I can barely speak Igbo.
omo ibo,ki lo wa debi? gbo ri e e !!!!!
|
|
|
|
|
|
|
|