|
Lolabbey
|
ooooooooh,
a ti gbo oooo,
eyin na eya se oo
|
|
|
|
|
|
ilugunboy (m)
|
@gbogbo eyin temi,
E kasan o, se owo nya.
@temi,
kilo nshele?, mi o gburo richdad?, ibo lolo?
|
|
|
|
|
|
Tawa-Temi (f)
|
@ilugunboy o lo tele de Yaradua ni China. se o mo wipe yaradua fe travel lo si china fun ojo merin, nitorina lo se lo siwaju Yaradua lati lo seto bi jije ati mimu yaradua se ma je aseyori 
|
|
|
|
|
|
ilugunboy (m)
|
@tawa
Case yardua yen ni k-leg, mo hope pe by this time lola a si le pe ni president ooo.
Hope you had a fullfiling day like i did
take kia
|
|
|
|
|
|
daychris (f)
|
e ku irole o eyin temi, se dada ni mo bayin
|
|
|
|
|
|
Tawa-Temi (f)
|
gongo a so fun yaradua loni.
anyway, je ka ma wo nkan to ma sele loni,
ti orun ba ma wo, ko si eni ti o ma escape.
but guy yen o dabi baba iyabo sa,
o dense die.
mo wish e ni luck.
|
|
|
|
|
|
ilugunboy (m)
|
E kaaro eyin ara mi, se alafia lewa bemi na se wa nibi  . Ise koni di ishee mo wa lowo o (amin). @tawa-mi  Se ore mi ti pe e lati China?  . ti eba tun ti soro, je komo pe ilugunboy ti miss e ganni oo!. Right now, won t'in deliver judgement lori case yen, so let keep our fingers cross. Adura mi ni wipe ki olorun se eyi to dara fun Nigeria.
|
|
|
|
|
|
Lolabbey
|
amin ee poooooooo,
adura tire na agba-amin
|
|
|
|
|
|
querida
|
ekasan o eyin eyan please i hope iv tried I'm nt good @ yoruba soon we'i start speakin on d net
|
|
|
|
|
|
|
|
PurestBoy (m)
|
Yo ba iya la ye gbogbo yin. emi ti fa igbo yo oo, e gba mi ejo
|
|
|
|
|
|
PurestBoy (m)
|
amin ee poooooooo,
adura tire na agba-amin
Omolola ololufe mi, se pe o wa ni eb yen. se o wa pa? omo ele to gba yi
|
|
|
|
|
|
Tawa-Temi (f)
|
Yo ba iya la ye gbogbo yin. emi ti fa igbo yo oo, e gba mi ejo
awon wo leyi oooo ta le yin ooooo won tun ti de oooo awon agbero to ti fa igbo  nibi ni awon NDLEA officials wa? awon amugbo re eeeeeoooooooo won tun nta kakiri ye efin ti po lori thread yi oooo efin ti bo gbogbo ile lori wipe purestboy(indeed) nmugbo ooooo eti won bota, eti won si kanga wahala wa ooooo
|
|
|
|
|
|
Tawa-Temi (f)
|
Eku Ise Oni oooo
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
Tawakalitu Mobolorunduro, SE O GBADUN WEEKEND YEN DAADA?
|
|
|
|
|
|
|
|
gentledove (f)
|
o ga gan ni o. se wipe a tun ni awon Yoruba to po bayi ni 'ile-naira'? eleyi ma yami lenu ke. pelu gbogbo e sha, a dupe wipe eko o ni baje, ile niajeria naa ko si ni tuka. eyin omo kaaro o jiire, eyin omo oduduwa, e kaabo sori eto yi o. o tun digba kan na. 
|
|
|
|
|
|
holythug (m)
|
o mo pe awa gan la poju ni ile nairao ye ko ti jasi
|
|
|
|
|
|
gentledove (f)
|
@holythug, mo ti jasi bayi. 'kura to wa ni mimo'. oruko e pamilerin gan ni o. bawo ni eniyan se ma je 'kura' ti o tun maa wa ni mimo. eyi ya mi lenu gidi gan ni. e sa maa se daadaa ki e si maa ja tiketi re pamo. tori tiketi naa ni awa yio fi wo ijoba orun o. e ranti omo eniti e n se. o digba kan naa 
|
|
|
|
|
|
holythug (m)
|
haa awa lamo ba se n se,
o ti ri aladua to n fa gbo, o ti ri alfa to n mutijasi o
|
|
|
|
|
|
gentledove (f)
|
@holy thug, mo jasi pa. infact, mo ti bere si ko e je ti o se wa yen. just keep your fingers crossed and ki gongo ma so. have a holy day!!!!!!!!!!!!! 
|
|
|
|
|
|
holythug (m)
|
wa sere padi mi, jeun lo
|
|
|
|
|
|
|
|
elementus
|
je so ke, oni whala jare
|
|
|
|
|
|
tope ayan
|
Eku alele gbogbo omo karoo ojire
|
|
|
|
|
|
gentledove (f)
|
@tope ayan, se wipe ayan si ku nile kaaro oojiire? topisko, se o wa pa? mo wa pa ni biyi o. mo se je dodo ati eyin tan ni. ibi ise oojo mi naa ni mo wa bayi. mo ni pe kin farabale jeun tan ki n too wa ki eyin omo naija. Aurevoir! Zegobe! Saanu! Odaabo! e maa se jeje ki e si maa ja tiketi re pamo. tori oun ni awa yio fi wo ijoba orun o. see you guys at the top!!!!!!!!!!!!!!! 
|
|
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
Tawakalitu Mobolunduro, E KU OJO META.Se o gbagbe pe o promise ni amala ati ewedu ti mo ba ti wa si ilu EKO. Mo nbo ni ose ti o nbo fun odun Ajinde. Bawo ni n o se ri o?
|
|
|
|
|
|
Tawa-Temi (f)
|
Kola bawo ni? se o wa ok? kosi problem ti o ba ti de si eko mo ma gbe e lo je amala, iyen ti sure ti o ba tide , je kin mo lori nairaland. Ba wo ni Abuja oooo?
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
Nkan ti o je ki nferan re ni wipe `o ma nsoro pelu ori pipe ni igba gbogbo`. Ti oju ba ti yeju ki owun ma yewun. It is a deal. Abuja wa bi ewa.
|
|
|
|
|
|
GeeCee (m)
|
E pele n ha hin o. Se alafia ni gbogbo yin wa? Ara o le bi? E de ku imura odun ajinde. A ba wa laye ati laaye. Amin
|
|
|
|
|
|
|
|