|
ibkaye (f)
|
same ni same ni same ni
|
|
|
|
|
|
Tawa-Temi (f)
|
Ekaaro ooooooYawn Se dada laji bi? Olowo ori mi Kola Baba Oloye temi nikan Bawo l'abuja se e jasi? ma se jeje ooo mo nri owo eee
|
|
|
|
|
|
Rich Dad
|
Halle, Halle, eee E ti ri mi o to jo meta , Ope f'Oluwa mo ti pada oooooooo many many many say Richdad no dey come back  E KU ILE OOOOOOOO GBOGBO OMO OODUA E ku ojo meta bawo ni gbo nkan se n lo?
Tawa mi, mo ti saaro ee gann ni o (I have missed you so much) :-*and my infamous useless rival (Smaller boi) Gbogbo eyin ti e yo'ju lo'ju window e ma se jafira lati ko eru yin oooo oninkan ti de oooooooo
Gbogbo eyin to ku ti mi o let d'aruko e ku i le oooo e de ku ojo meta, mo ri yin naaaa 
|
|
|
|
|
|
Tawa-Temi (f)
|
@ Richdad
kaabo
se oko o je epo
awon to ohun nko?
se dada lowa?
Ese jeje o
|
|
|
|
|
|
Abdogood (m)
|
clemcykul, I say UR FADA. I Repeatam your FADA. Na my moda lang u dey yab. yarn your own lang mowe hear. Ilu wo lo tiwa nan. On'ilu, Omo sonu ni e.  eyi temi nile, eku se oooo. ki oluwa wa pelu yi oooo.
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
Tawa-temi nikansoso, Nigbati o re mi te, o wa lo nyoju loju ferese, Fi okan re bale O SA MO WIPE Ti ojo ba ti ro, iri ko gbodo se mo (after any rainfall no more dew). Aja nla (bull dog) ni a o ra senu ona nitori awon awon akomota. GBOGBO ILE E KAAAAARO O. E MURA SI ISE ONI O
|
|
|
|
|
|
Tawa-Temi (f)
|
Tawa-temi nikansoso, Aja nla (bull dog) ni a o ra senu ona nitori awon awon akomota.   Ko le to yen Iwo nikan lo wa lokan mi bayi Maro ti anybody, mo ko ki kabo pada ni. se o mo wipe iwo lo ntoju mi bayi. Pele, bawo ni oni? yara si ise ma tete de ile loni lati lo se ounje aladun le fun e Amala gbigbona ti oni ife si ni mo ma ro fun e ki o to de ile. pele
|
|
|
|
|
|
Tawa-Temi (f)
|
Eku ise oni ooooooo
|
|
|
|
|
|
Tawa-Temi (f)
|
Eku ise gbogbo ara ile
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
EYIN TEMI, E KAAAARO O. E MURA SI ISE OSE YI O. OLORUN A DE ISE WA NI ADE O (amin)
|
|
|
|
|
|
Tawa-Temi (f)
|
Eku ise oni ooooo Ejowo talo ma bami be Kola Oloye ooooo 
|
|
|
|
|
|
Tawa-Temi (f)
|
Eku ise oni ooooo Olowo ori mi Kola Oloye ooooo  O de bami soro 
|
|
|
|
|
|
Tawa-Temi (f)
|
Kolaaaaaaaaaaa
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
Mo sese gba wipe lotito ati ni ododo ni ife re funmi. Omo rere bi iyan. Obirin bi ire sowon,obirin ti o to gboju le,eni ti o se fi ehin ti si ni o pelu. Mo ma ngbadun re ni igba gbogbo.Omo ola,omo iyi,gbera nile ki o dide. Ololufe mi tooto,woo mo ti fi ori ife ji o. Maa lo bi Bugatti Veyron, Oo lota(no rival) Baba wa nile fun o ni ojo kojo. Ma gbagbe pe Ekuro ni alabaku Ewa. 
|
|
|
|
|
|
|
|
rite2salas (m)
|
se awon omo yahoo yahoo wa ni bi?  mo fe ki a se runs papo, lol 
|
|
|
|
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
Tawa-temi, Wo bugatti Veyron.Mo fe ki o lo ma fi ra chicken ni oja.
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
Tawa-temi nikansoso, OK je ki nfi omiran ranse si e nitori awon oni-ilara.
|
|
|
|
|
|
|
|
tytylayor (f)
|
oko iyawo en le o 
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
oko iyawo en le o   Awa ni yen o, e ma seun gaan ni. Nkan ayo ni ao ma ba ara wa se o (amin) .E se pupo 
|
|
|
|
|
|
Bblak (f)
|
Eyin people yi funny gan o.lol Ife yin o ni pari si nairaland o. 
|
|
|
|
|
|
tytylayor (f)
|
an dupe ara eni, esi pe wa si igbeyawo yin abi osi wa ni iwaju ni? 
|
|
|
|
|
|
Tawa-Temi (f)
|
Olowo ori mi se alafia lowa loni yi? Mo ti lo ra awon chicken ti mo ma fi bae se pepper soup lale Nigbati mo gbe moto akoko yen de oja, iya oloja funrare e, lo ta oja fun mi loni. Baba oloja lo ba mi gbe eru wo inu moto mi. Awon agbero lobami clear awon danfo kuro lona Awon LASTMA, VIO,Road safety ni won se Escort fun mi. Inu mi dun gidigan pelu gbogbo ohun ti ounse fun IFE awa mejeeji. 
|
|
|
|
|
|
rite2salas (m)
|
e ma wo awon alainise yi, shey nairaland lo ye ki ti ma so oro ife, tawa temi ko tawa temi ni  shio
|
|
|
|
|
|
Tawa-Temi (f)
|
e ma wo awon alainise yi, shey nairaland lo ye ki ti ma so oro ife, tawa temi ko tawa temi ni  shio salad abi kinni oruko ee naa? kinni problem eeee? ti oo ba ni ololufe, oode wa bi kan gbalo! tabi ko lo ko sinu Lagoon mo ran e nise ni? Talo so fun eee wipe a ko ni ise? Oro wipe ibise osi, ti oti nsise, ti awon oga yin ooo gba yin laiye lati enjoy ara yin lo ro wipe ati nsise ni? Mio kin se contract worker or office assistant bi ti e. Asiko ise wa, asiko igbadun naa siwa. so, asiko igbadun ni emi ati oloolufe mi nma seere wa si nairaland. awa ti ri ara wa naa, and 'what God has joined together, let no salad or salas put assunder' Ode buruku,olodo, omo yahoo yahoo. mi ko tile le je tie, Tawa ti Baba Oloye ni mi ---  Odun, ofe ke-----  -  -  - 
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
e ma wo awon alainise yi, shey nairaland lo ye ki ti ma so oro ife, tawa temi ko tawa temi ni  shio E jowo e ma binu si nkan ti o dara. Ise Oluwa ni, E ma tuwo o.  @Tawa-temi Ololufe mi, fiye denu ,se suuru. Awon eniyan a maa se ilara nkan ti o dara. Se o ranti pe nitori awon oni-lara ni mo se fi oko kekere keji yen ranse.Oju aye ni o ri yen o. Ma binu,omo ti ile ba san-ni awo ni a ti nmo.
|
|
|
|
|
|
rite2salas (m)
|
e ma wo oyinbo ton je Tawa, lol  iwo ko mo pe ere ni emi bai she ni (yoruba is somethings difficult to type , I'm going to get me a yoruba keyboard lol)
|
|
|
|
|
|
Tawa-Temi (f)
|
e ma wo oyinbo ton je Tawa, lol  iwo ko mo pe ere ni emi bai she ni (yoruba is somethings difficult to type , I'm going to get me a yoruba keyboard lol) Hmnn ti aba fi owo otun ba omo wi, atun fi owo osi fa mo ara. Mio mo wipe ere loun se. By the way, se ori oyinbo ti ooun je Tawa ri ni? Definitely, oti ri Oyinbo ti o ko ila.  @kola Olowo ori mi, se dada loji? Bawo ni ise oni? Se ogbadun Chicken pepper soup ale ana? Mo ma jade lo fun meeting loni, so , ole se die kin to de. But ma je ko mo igba ti mo ba tide. Ki lo ma je lale oni?
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
Omo-nla. Erepa re ale ana yen po die,nkan ti o je ki npe die ki nto ji ni owuro yi niyen. Wo mi ni iyara igbalejo (guest room) ti o ba ti de. Nipa ti ounje - Amala ni mo fe.
GBOGBO OMO OODUA, E KAAAASAN, E SI KU ISE ONI
|
|
|
|
|
|