|
|
|
kola oloye (m)
|
Gbe elomiran wale ke? Mo ni eto kekere kan ti mo nse sile de e ni ibe. Atipe mo lero pe ile ma su pupo ki o to de ni.  Haba! se nitori nkan ti mo so ni o se lo hire okunrin atamatase olofa-ina?  Jowo tori Olorun ma pa eniyan si mi lorun o. O saa mo pe "no rival" ni e. 
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
WITH ALL MY HEART FI OKAN RE BALE. KO SI EWU
|
|
|
|
|
|
|
|
tinakoya (f)
|
Mo fe ba e darugbo,mo fe ba e kale, iwo ni mofe ma ji ri lo jojumo aye mi. Cont. Olo mi
|
|
|
|
|
|
Tawa-Temi (f)
|
E Kasan eyin omo oduaaa, eku iwoyi oo, se dada ni mo ba gbogbo yin, awa n gbadun ara wa ni ile southy o. Se naija dun sha. E ma jaye oba lo oo. Ikukiku kan ko ni pa eni kankan wa o,
Amin ooooooo @Kola Oloye Olomi, onitemi, ore mi, ololufe,oju kan o, sa'lada ni, lola'luwa, ko soun tio yawa, 
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
MO KI GBOGBO ILE PE E KAAASAN O.@Tawa-Temi, BAWO LO SE JE? E KU IGBAGUN ASIKO YI O 
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
AWON TEMI DA? Iroyin Ayo: Ayeye igbeyawo Tawa-temi ati Kola Oloye yoo waye ni aipe yi. Ojo kejidinlogun osu aga ni a o se introduction wa. Ilu Eko ni yoo ti waye. Ipalemo (preparation) ti o nlo lowo ni ko je ki e ri Tawa-temi lori apero yi. Sugbon yoo ba yin soro laipe yi. E se pupo.Nkan rere ni a o ma ba ara wa se o (amin)
|
|
|
|
|
|
Tawa-Temi (f)
|
Baba oloye bawo ni? se owa pa? Ise ni o je kin raye lati ojo yi ooo. Bawo ni Abuja? Ba mi ki gbogbo awon ara ile ooo so fun won wipe ma kan si won lara laipe. 
|
|
|
|
|
|
Dojo (m)
|
O ga ju! 
|
|
|
|
|
|
holythug (m)
|
o ga gan ni o 
|
|
|
|
|
|
Moyola (f)
|
Beenii o tii ga la gaju
Tongue twister nii yii, e try e tii e ba le so nii kia kia {Diz a tongue twister, try it}
"Opolopo nii ko 'lopolo, tii won sii fe gba opolo lowo opolo" {Lotz of people don't have sense, n wants sense from a frog}
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
Mo ki gbogbo ile pe e ku asan nile o.Se owo nya?
|
|
|
|
|
|
studio43 (m)
|
, uhm, are my supposed to be here? 
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
, uhm, are my supposed to be here?  CAPITAL NO
|
|
|
|
|
|
Tawa-Temi (f)
|
Eku ise gbogbo ile oooo
Mo ti pada de bayi oooo
Olowo ori mi Baba Oloye, se dada laba yin oooo
Epele, esi ku lasigbo ile wa yi ooo
Oluwa ase rere fun gbogbo wa ooo, amin.
|
|
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
@Tawa-Temi, Se o gbagbe adehun? Aya mi ti fe maa ja bayi o.Eru si ti nfe maa ba mi.
|
|
|
|
|
|
Pamperme
|
mo nipe kin ki yin ni aro yi. Se gbogbo nkan nlo letoleto?
|
|
|
|
|
|
tybanky (f)
|
E le ni be ye ooo gbogbo ile, ayi ba won si ni be lai bawon da si.
I dey feel you and gbadun you guys ooooooo!
|
|
|
|
|
|
Tawa-Temi (f)
|
Olowo Ori mi, oko mi owon, mase je ki aya re ki oja mo wa pelu e kanpe iwo naa mo bi ise se ri ni enu ojo meta yi, oga mi ni ibi ise lo fe fi ise pa mi oooo, Lana, nise lo npe Tope, loni, Tope, ni igba gbogbo Tope, Tope, Tope, Tope, afi bi wipe Tope nikan ni oruko ti owa ni ilu yi. Emi lo nma pe fun gbogbo nkan pelu (coupled with) gbogbo meetings ti mo tun nma lo fun almost everyday. Mo mo wipe, oruko mi lo ma ma pe legbe iyawo e loru ti won ba ti sun. lol Ko le se ki o ma pe Oruko yen lojumo. Anyway, by next week, ise mi a dinku die, nitori awon clients wa ni won ma ma wa si office wa ni sinyi. Mo ti miss e gidigan. ololufe mi owon, olowo ori mi, pele, se ori otutu sa? Bami so fun awon ti o mo wipe ni office mi, an wa awon Marketing Executives oooo Obinrin nikan ni won nwa sa pelu 2-3 years experience. Qualification: Marketing, Business Administration & Communication Arts/ Public Relations. CV's to: editorialjobs2008@yahoo.com(Its an International coy)
|
|
|
|
|
|
Emmaxxx (m)
|
Whats all this?
|
|
|
|
|
|
|
|
Tawa-Temi (f)
|
Baba Oloye
Olowo Ori mi
Se owa pa? O ga gan ni oooo
mio de ri owo e mo?
se ise lo gbomi be yen ni?
yara si ise oooo
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
Tawa ti Kola nikan. O to jo meta. Bawo lara? Se o n toju Kola daada? A ku ipale mo oo. Ojo a ba wa laye ati alaafia. Eyin iyawo o ni meni. Omo rere lode oko.Wa finu soyun wa feyin gbomo pon loode Kola. Awon ara Egba a mo itoju aya se po.
|
|
|
|
|
|
Tawa-Temi (f)
|
Tawa ti Kola nikan. O to jo meta. Bawo lara? Se o n toju Kola daada? A ku ipale mo oo. Ojo a ba wa laye ati alaafia. Eyin iyawo o ni meni. Omo rere lode oko.Wa finu soyun wa feyin gbomo pon loode Kola. Awon ara Egba a mo itoju aya se po.
ese oooo eku ife, tin yin naa a de lori nairaland apeyin ke wa ba wa se ikomo awon omo naa ti mu oruko won wa lati orun  Baba Oloye, se owa ok? pele ooo, olowo ori mi ololufe mi owon
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
@ Gbogbo afenifere, Ni aipe yi ni a o fi account number ati oruko ile ifowopamo (bank) si ori apero yi, fun anfani awon ti o ba fe fi nkan ranse si awon ibeji. E seun pupo. Ayo onikaluku wa ko ni baje. A dupe lowo yin  @ bluehorizo, Se e ngburo awon ara ile. @tawa-temi, Se ko ye ki o kan sara simi , iwo na si ti ri ere gbogbo ise oru ti a ma nse. Se Kehinde ni ko je ki nsun daradara ni oru ana abi Taiwo ni?
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
Kola ati TawaInu mi dun ti mo ba n ri nkan ayo. Nakan ayo daradara ni a ma ba ara wa se oo. Esu o ni ya iwo ati tawa oo. Olorun a toju awon ibeji.aa wo wan dagba oo. tayelolu ejire ara isokun. E jowo e fi iwe pe wa si bi ayeye ikomo/igbeyawo yin oo. KolaMi o gburo ile oo. Ko si eni kankan ni le mo. 
|
|
|
|
|
|
kola oloye (m)
|
KolaMi o gburo ile oo. Ko si eni kankan ni le mo.  Nibo ni gbogbo ile lo?
|
|
|
|
|
|
Tawa-Temi (f)
|
baba ibeji
awon ibeji ti nwa yin ooo nibo de lo wa gbalo bayi?
se yaradua nio fun e laye ni?
oga gan oooo
sa se kio wa sile fun weekend yi.
|
|
|
|
|
|
rite2salas (m)
|
gbegborun 
|
|
|
|
|
|
bluehorizo (m)
|
Gbogbo ile e jowo e ba wa be modirato ki o jowo gbe eto yi lo si ori iyara ede.
Please beg the moderator to move this thread to culture.
rite2salas
Bawo ni Seattle? jowo ba mi fi eja ranse lati Pike Fish Market. Mo gbadun ibe yen, mo de ibe ni igba ti mo lo si Port Angeles. Se alaafia ni?
|
|
|
|
|
|