Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,150,559 members, 7,809,034 topics. Date: Thursday, 25 April 2024 at 09:31 PM

Àwon Òwe Ile Yorùbá (proverbs Of The Yoruba People) - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Àwon Òwe Ile Yorùbá (proverbs Of The Yoruba People) (14102 Views)

Village In America Where The Yoruba Culture Is Being Practiced (Photos) / 5 Notable Facts About Yoruba People (àwon Ómó Yorùbá) / Ònkà Yorùbá: Numbers And Numbering System In Yorùbá (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Àwon Òwe Ile Yorùbá (proverbs Of The Yoruba People) by seydam21(m): 5:33pm On Oct 17, 2014
=>Ilé oba tójó, ewà ló bù kun.
(If you fail once,try again,failure is the preparation of greater things ahead)

=>Igi gogoro má gun mi lójú, à t'òkèrè latí wòó.
(Be conscious of your actions)

=>Bá mi na omo mìi, kò dénu olómo.
(Oftentimes people say what they do not mean so thread softly)

=> A kìí bá ara eni tan kí á fara eni nítan ya.
(When you are given an opportunity,dont misuse or overuse it)

=> Àgbà kìí wà lójà, k'órí omo tuntun ó wó.
(Where there are elders,things are not run
smoothly)

=>Orí tí yóó gbeni ní gbé aláwo ‘re ko ni.
(Your destiny is in your hands)

=>Eni tí ó n ko orin tí kò dùn, o maa nfeti ara e gbo.
(Be careful whatever you do,you might be affecting yourself indirectly)

=>Àgbà tí ò bínú ni omo rè n pò jojo.
(Be slow to anger)

=>Kí obìnrin to àtòrìn,Kí okùnrin to àtòrìn,ká wo eni tí ó ma lómi léyìn ese ju ara won lo.
(Competition between people reveals who is
stronger)

=>Apé kó tó jeun,kò ní jè bàjé.
(Delay is not denial)

=> Àsegbé kankan ò sí,àsepamó lówà.
(You can not hide your wrongdoings forever,someday your sins will find you out)

=>Bí iró bá lo lógún odún,òtító á padà léebá.

=>Iyán ogún odún,a máa jó ni lówó felifeli.

=>Káronú jinlè ká tó wùwà lóda,ìwà òpònú ni

=>kásekan òún tán,káwá dorí kodò lórí àsise.

=>Bi Ina njo ni jo omo eni tara eni laa ko gbon.

=>Ori yeye ni mogun, t'aise lo po.

=>akini unje akini afinihan unje afinihan ewo ni pele ara ibadan lojude ogunmola.

=>Àifète m'éte, àìfèrò m'erò, omo iya mefa kú si oko egbàafà.

=>A kò fe o ni ilu, o ni iwo yio da orin, bi o ba dá orin nà, tani yio ba o gbè é?

=> olopa ewo ni tepe,amuni nje amuni
(do not take laws into your hands)

Oya e se afikun sii, ni ede yoruba pelu geesi

#Owe lesin oro..........

2 Likes 3 Shares

Re: Àwon Òwe Ile Yorùbá (proverbs Of The Yoruba People) by kemiola89(f): 8:58pm On Oct 17, 2014
Suuru laafin yo oro n ro kuro lara eran
Patience resolves complex issues

Adun nbe leyin ewuro
Keep hopes alive, don't give up.

Iwa ni I joo oniwa loju
Objective self-appraisal can be difficult.

Bo ti wu ki oju kan tobi to, oju meji san ju oju kan lo
Team effort is superior.

ika ko dogba
we are not all equally endowed.

Eda ko laropin
Underestimate no one.

Teni be igi loju igi a ru we
The shame is on the person who cut a tree; It will sprout leaves again.

Ti eniyan ba ni suuru, ohun ti ko to nbo was seku
Patience is crucial...

4 Likes 2 Shares

(1) (Reply)

Should Nigerians Be Proud Of Speaking Pidgin English? / Top 10 Yoruba Names You Never Guessed Were Arabic Names / Your View about Nigerians Who Travel To USA To Give Birth For USA Citizenship?

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 12
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.