Welcome, Guest: Join Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 2,381,670 members, 5,312,859 topics. Date: Wednesday, 11 December 2019 at 09:43 PM

.. - Culture (2) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1574052 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (97) (Reply) (Go Down)

Re: .. by Nobody: 11:32am On Apr 15, 2015
.....

2 Likes

Re: .. by Nobody: 11:58am On Apr 15, 2015
..

3 Likes

Re: .. by Nobody: 12:29pm On Apr 15, 2015
..

4 Likes

Re: .. by Nobody: 3:31pm On Apr 15, 2015
Eku seh ooooo. Ejoor, Oogun wo lafi le da majele moo tia ba gbe dani? Boya ninu ounje abi ninu oti
Re: .. by Nobody: 3:37pm On Apr 15, 2015
healthFirst:
2. OOGUN OKIGBE TO DAJU

Orisirisi Oogun Okigbe lo wa; awon ti a le lo loju ogun ati awon to je wipe ti agbara won ko po pupo.

Ao ja Ewe Ewuro bi ekun owo, eyi ti ko lu rara ni ao ja, ao gbo pelu omi die, ao yo omi yen sinu ife(Cup) kan, ao bu gaari die sii, ao gbe mu. Obe tabi ada ko niran wa lehin iseju die ti a ti mun Oogun yi.

Ikilo: Eni to ba gbojule Oogun yi lati fi se ise ibi, Oogun yi ko ni sise fun lase Ajagunmole.

Ejoor, seh eleyi ni agbara re kopo abi fun igba wo ni eleyi lee siseh di?

2 Likes

Re: .. by Nobody: 3:55pm On Apr 15, 2015
Jadonjack:

Ejoor, seh eleyi ni agbara re kopo abi fun igba wo ni eleyi lee siseh di?

Beeni, agbara eleyi ko po pupo ati wipe lehin ojo die, yio kuro lara wa.

Sugbon dan wo...Okigbe to daju ni.

2 Likes

Re: .. by Nobody: 4:23pm On Apr 15, 2015
healthFirst:

Beeni, agbara eleyi ko po pupo ati wipe lehin ojo die, yio kuro lara wa.

Sugbon dan wo...Okigbe to daju ni.

Odaa, eseun. Ee ti bami daun ibeere mi akoko ooo

1 Like

Re: .. by Nobody: 4:36pm On Apr 15, 2015
Jadonjack:
Eku seh ooooo. Ejoor, Oogun wo lafi le da majele moo tia ba gbe dani? Boya ninu ounje abi ninu oti

..

3 Likes

Re: .. by Nobody: 4:40pm On Apr 15, 2015
healthFirst:

OGUN YI DARA FUN TI INKAN BAWA NINI OUNJE TABI OTI
Ika ti won n pe ni ikamudu oju ona tio to telerawon, ao fi eko elewe ko, gbogbo eyi ti o tele ra won ni oju ona ni o, ao jo pelu odidi atare kan ao sin nigbere yipo orun .ifunra loogun agba ,ti aba nifunra ao ma gbo bi awon ikamudu yi se ma hoo yuuuuunnnn,nigbati won ba fe fi ogun sinu ounje fun wa. Iba agba.

Eseun. Yio tunbo dara fun yin

3 Likes

Re: .. by Ewuro4: 5:07pm On Apr 15, 2015
healthFirst:

It's allowed but translating the Oogun in English is what is not...and it's to preserve our heritage.

Okay sir.
Re: .. by absoluteSuccess: 10:04pm On Apr 15, 2015
Jadonjack:

Odaa, eseun. Ee ti bami daun ibeere mi akoko ooo
Moremo l'Agege, hunhun. Wo, apala koni jiya to e nijo ti ewe okigbe yi ba sunko. Ooni fe se konge igbaju-igbamu ti kerikeri mbarode. Sori, to ba raye ja, wa sare kababa pelu igbonse gbigbona ati hilahilo. Ng o nii gbagbe ikilo baba to bimi l'omo: 'ogun lo lojokan iponju, ori eni lo l'ojo gbogbo'. Too eni ori yo odile. Oku nibon nro.

2 Likes 1 Share

Re: .. by scholes0(m): 1:03am On Apr 16, 2015
healthFirst:
5. KI OKUNRIN MIRAN MA LE BA IYAWO WA SUN
Ao ja ewe ewura meta ti aba yagbe, ao fi
nu idi wa, ao wa jopo mo odidi atare kan. ao po mo ori, ao mo fi pa oko ba
iyawo wa sun..

Okunrin miran ko ni le ba sun mo.

Hhahahhaahha
Eleyii pa mi lerin pupo.
E joo, ki ni o maa sele ti okurin naa ba ti fi pa oko ba iyawo e sun ??

1 Like 1 Share

Re: .. by Nobody: 5:57am On Apr 16, 2015
absoluteSuccess:
Moremo l'Agege, hunhun. Wo, apala koni jiya to e nijo ti ewe okigbe yi ba sunko. Ooni fe se konge igbaju-igbamu ti kerikeri mbarode. Sori, to ba raye ja, wa sare kababa pelu igbonse gbigbona ati hilahilo. Ng o nii gbagbe ikilo baba to bimi l'omo: 'ogun lo lojokan iponju, ori eni lo l'ojo gbogbo'. Too eni ori yo odile. Oku nibon nro.

Oseun

1 Like

Re: .. by absoluteSuccess: 6:54am On Apr 16, 2015
Jadonjack:

Oseun
Emi naa dupe, Aku ojumo rere.
Re: .. by Nobody: 9:40am On Apr 16, 2015
scholes0:

Hhahahhaahha
Eleyii pa mi lerin pupo.
E joo, ki ni o maa sele ti okurin naa ba ti fi pa oko ba iyawo e sun ??

Yes, bo se ma n ri niyen...we deride whatever we don't understand but it doesn't remove or change it's efficacy. ko si nkan to ma se Oko obinrin na sugbon enikeni yato si eni to fi ewe yen nudi to ba make attempt lati ba obinrin ni ajosepo, yio kabamo.

3 Likes

Re: .. by scholes0(m): 12:10pm On Apr 16, 2015
healthFirst:

Yes, bo se ma n ri niyen...we deride whatever we don't understand but it doesn't remove or change it's efficacy. ko si nkan to ma se Oko obinrin na sugbon enikeni yato si eni to fi ewe yen nudi to ba make attempt lati ba obinrin ni ajosepo, yio kabamo.

E maa binu o, ko ri be rara, mi o fi yin se yeye, oro naa kan n pa mi lerin die lasan ni.
Amma kilode ti e n se asopo, ati ajopo ede geesi ati ede abinibi? Ko joju rara. Ti a ba fe ko ede Yoruba ki a ko o, ki o danto, ti a ba si fe ko ede Geesi, ki a se be pelu.

2 Likes

Re: .. by Nobody: 1:30pm On Apr 16, 2015
scholes0:

E maa binu o, ko ri be rara, mi o fi yin se yeye, oro naa kan n pa mi lerin die lasan ni.
Amma kilode ti e n se asopo, ati ajopo ede geesi ati ede abinibi? Ko joju rara. Ti a ba fe ko ede Yoruba ki a ko o, ki o danto, ti a ba si fe ko ede Geesi, ki a se be pelu.

Hun, otito loro te so...sugbon yio fun awon eeyan miran laye lati ba wa da si eto yi...sugbon awon Oogun wonye ni mo lero wipe ko ye ki a ko ni ede Oyinbo...idi ni wi pe, ao fe ki awon omo atohun rin wa mon nipa awon Oogun wonyi.

3 Likes

Re: .. by gawab: 9:47am On Apr 18, 2015
Yara lo si www.itanyoruba.com fun ekunrere awon itan ile yoruba lorisirisi.
Re: .. by absoluteSuccess: 10:35pm On Apr 19, 2015
Ago o, mo ki tewetagba lori ikanni yi o, eku oro iwosan ati ilera lori ewe ati egbo o. Inu mi dun lati so nipa egbogi ajebiidan kan ti mo sese pile re. Mo pe oruko egbogi naa ni 'Allicin Pride', ah, egbogi naa dara yeye! Pupo awon ara mi ti won ti too wo ni won'gboriyin fun iwulo Allicin Pride gege bii immune booster tabi 'awogba-arun'. Lowo yi, mo ni obinrin kan ti mo nlo Oogun naa fun lati wo 'iko fee'. Ogun ti a wi yi mumi feran lati wa imo sii lori bi a tile fi ewe ati egbo Ile Ibi Wa se iwosan fun koowa. Sombo ati beebeelo wa ninu oun ti a fi pelo Allicin Pride. Akoja ewe mi re o, Ki Eleduwa o je ki egbogi naa di ilumooka. Aye wa a dara, ewe a maa je funwa o, Ase.

Looking back in time, all I can say is, To God be the glory.

1 Like

Re: .. by Nobody: 4:19pm On Apr 21, 2015
..

3 Likes

Re: .. by Nobody: 4:38pm On Apr 21, 2015
..

2 Likes

Re: .. by Nobody: 4:50pm On Apr 21, 2015
...

1 Like

Re: .. by Nobody: 12:39am On Apr 22, 2015
...

2 Likes

Re: .. by Nobody: 11:39am On Apr 24, 2015
...

2 Likes

Re: .. by Nobody: 12:51pm On Apr 24, 2015
,,,

1 Like

Re: .. by Nobody: 5:43pm On Apr 28, 2015
...

2 Likes

Re: .. by Redoil: 9:49pm On Apr 28, 2015
healthFirst:
5. KI OKUNRIN MIRAN MA LE BA IYAWO WA SUN
Ao ja ewe ewura meta ti aba yagbe, ao fi
nu idi wa, ao wa jopo mo odidi atare kan. ao po mo ori, ao mo fi pa oko ba
iyawo wa sun..

Okunrin miran ko ni le ba sun mo.
wicked and wow. Better you hid it in ur native language

1 Like

Re: .. by Redoil: 9:54pm On Apr 28, 2015
healthFirst:

It's allowed but translating the Oogun in English is what is not...and it's to preserve our heritage.
i agree with you on this.

2 Likes

Re: .. by Nobody: 10:53pm On Apr 28, 2015
E FUN WA NI OOGUN AYETA ATI AFEERI
Re: .. by Nobody: 7:46am On Apr 30, 2015
walexy30:
E FUN WA NI OOGUN AYETA ATI AFEERI

Ayeta, Tidi jo, Asaki Ibon, Afobon, Afeeri, Egbe, Isuju to daju daada wa sugbon ao le fi sile lori afefe nitori awon eni ibi igara olosa...e ma binu.

1 Like

Re: .. by Nobody: 11:28am On Apr 30, 2015
...

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (97) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2019 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 98
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.