Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,148,754 members, 7,802,311 topics. Date: Friday, 19 April 2024 at 12:19 PM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (45) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (197346 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / Do You Speak Yoruba? / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (42) (43) (44) (45) (46) (47) (48) ... (100) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by hotteju(f): 1:48pm On Jul 27, 2009
newbie ni miii ooo
ki lon shele?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by DrFerlie(m): 2:02pm On Jul 27, 2009
hotteju:

newbie ni miii ooo
ki lon shele?

hotteju, kaabo si inu ilu wa yii. se daadaa ni gbogbo ile wa?
ko si wahala ninu ilu wa yi, igbadun ati alaafia ni awa.
omo ilu wo ni eyin nse? se okunrin tabi obinrin ni eyin?
e kaabooooooo. cheesy cheesy cheesy cheesy


topsy25,
awo mi, agbo to feyin rin, agbara lolo muwa. emi naa mura ija fun e grin grin grin cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 2:16pm On Jul 27, 2009
hotteju:

newbie ni miii ooo
ki lon shele?

Kaabo sinu ile baba re o. Ihanyi a san e o. Bi o ba je okunrin, awon abo to dara wa nihinyi (yato si toyin o); bi o ba si je obirin, awon gende okunrin wa nibi bii Ifelepon, dayokunnu, kamotessi, dr. feli abbl.

Kaabo ooooooooo.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 2:19pm On Jul 27, 2009
Dr Ferlie:



topsy25,
awo mi, agbo to feyin rin, agbara lolo muwa. emi naa mura ija fun e grin grin grin cheesy


Ibo ni agbara ohun wa. O je lo sidahun cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ibrokay(m): 2:27pm On Jul 27, 2009
Ekuule ooo eyin ara iwaju,ekaabo ooo eyin ero eyin.
Mo ki gbogbo eyin omo kaaro oojiire to nbe ni NL.
Oruko ti emi ni Sola,mo n wa Iyawo to jinle ti osi jinna
ninu asa ile wa(Yoruba).
Omo ti o rewa ti o si leko.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 3:53pm On Jul 27, 2009
E ku deede iwoyi o se alaafia ni e wa
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 4:24pm On Jul 27, 2009
hotteju:

newbie ni miii ooo
ki lon shele?

Kabo si abule wa  cheesy
dayokanu:

E ku deede iwoyi o se alaafia ni e wa

alafia ni a wa o. Se alaafia ni eyin naa wa?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by DrFerlie(m): 4:26pm On Jul 27, 2009
dayokanu:

E ku deede iwoyi o se alaafia ni e wa

Ojogbon dayo, e yin naa e kaabooooooo.alaafia ni a wa ooooooo. awon iyawo yin nko? cheesy grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 4:34pm On Jul 27, 2009
hotteju:

newbie ni miii ooo
ki lon shele?
O Kaabo gidi gan ni.
Turaka kosi maa gbadun ara e ni hanyi.

dayokanu:

E ku deede iwoyi o se alaafia ni e wa
Daada la wa, adupe. O ma to ojo meta, anirope alaafia lewa?

@Argent kiss & Dr. Ferlie
Se wa pa?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by DrFerlie(m): 4:59pm On Jul 27, 2009
tubabie:

@Argent kiss & Dr. Ferlie
Se wa pa?

Omidan 2babie, ki lode to je wipe argent nikan ni o kiss angry angry tongue

mo wapa. bawo ni ise, ile ati body?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by hotteju(f): 5:02pm On Jul 27, 2009
gbogbo yin ese gan nii ooo
modupe, inu mi dun gan
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 5:27pm On Jul 27, 2009
tubabie:

O Kaabo gidi gan ni.
Turaka kosi maa gbadun ara e ni hanyi.
Daada la wa, adupe. O ma to ojo meta, anirope alaafia lewa?

@Argent kiss & Dr. Ferlie
Se wa pa?



sweets mi kiss kiss bawo ni, se everything wa okay?

Dr Ferlie:

Omidan 2babie, [b]ki lode to je wipe argent nikan ni o kiss angry angry :[/b]P

mo wapa. bawo ni ise, ile ati body?


Se o n jelosi mi ni? tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 5:52pm On Jul 27, 2009
argent:

sweets mi kiss kiss bawo ni, se everything wa okay?

Mo wa alright, ose wink

Dr Ferlie:

Omidan 2babie, ki lode to je wipe argent nikan ni o kiss angry angry tongue

mo wapa. bawo ni ise, ile ati body?
lol. Oya turaka kosi tun oju ese, ma frown at me mo! grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by DrFerlie(m): 6:14pm On Jul 27, 2009
tubabie:

lol. Oya turaka kosi tun oju ese, ma frown at me mo! grin

ti o ba ti kiss mi ma turaka grin grin
argent:

Se o n jelosi mi ni? tongue

mo njelosi e oooooo. bawo ni 2babie se ma kiss eee , e mi loye ko kiss now grin grin cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by DrFerlie(m): 6:16pm On Jul 27, 2009
hotteju:

gbogbo yin ese gan nii ooo
modupe, inu mi dun gan

omidan hotteju, inu awa naa dun gannnnnn lati gbayin si inu wa yi. se e gbona felifeli gege bi oruko yin? cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 6:43pm On Jul 27, 2009
Ehn? ai si ni ile ologinni mi ile di ile ekutele tope-lobi! angry
ogbeni tope, iru iwa palapa wo lo n wu leyin mi yii?
awe we e b'oyami tage lere ki mo wi si o kuo gbonyami re? so rora koloun so o o! angry
@toyin temi nikan
oyami atata kiss, se alaafia lu e se? ibeji mi sikan, se ala ni?(ekiti way of checking on my wife and babies)
mo o ri yim e oo*mayb you sent to the wrong addy again). . .will b waiting.

@tejutogbona feli feli(hotteju) ati ibrokay(sola)
EKaabo si ile kaaro oojiire, se alaafia ni? inu wa dun pupo lati gba yin si awujo wa a de lero pe ee a gbadun gbogbo igba ti e ba lo lori tireedi yi
le e kan si, E kaabo.
@gbogbo ile(ajenti,tubabie,toyin,dayo,tope,dokita feli,fakaay,tejutogbona,ibrokay et al. . .)
In okun oo.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 7:02pm On Jul 27, 2009
Ifeleke, ba wo ni? o to ijo meta, se ise nlo dede?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluespice(f): 8:03pm On Jul 27, 2009
dayo, omo'luwabi ni mi
a kin j'okoloko ni le wa

ekuule oh gbogbo yin
ori ikunle ni mo wa she daada le ji eyin ti US

awon to ku, she everything nlo were were
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by oYaTo(m): 8:19pm On Jul 27, 2009
blue, mi o mo pe yoruba e dan moran to bayi oo,

oya, ile ya, je ka lo mo awo obi mi ni waran sesa,

bi ise o pa pe ni, enikan o kin pe se!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluespice(f): 8:27pm On Jul 27, 2009
ROFLMAO!!!!!!
oni yeye ni e sha grin
ko ma dupe lowo jesu pe mo si nife fun e kiss
o tie yoju sibi at all angry

bawo lara oh
she gbogbo e wa bo she ye ko wa?
o ti jeun sha? tongue
beeni iya re ni mi cool
kunle je kin gbadura fun e cool cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 8:29pm On Jul 27, 2009
@blue
ba wo ni? kiss
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by oYaTo(m): 8:34pm On Jul 27, 2009
bluespice:

o ti jeun sha? tongue

mi o ti jeun o, mo n reti ounje to ti se de mi, ko wa fi simi lenu. . wink

ti a ba jeun tan ka wa wo inu yara lo ka lo sere ife. . grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluespice(f): 9:05pm On Jul 27, 2009
ibukun mo wa jare iw nka?
sho wa pa?
sh'aran dan bo she ye?

(i dunno y im in the mommy phase today tongue )

oyato ko iranu e kuro jare
amala e'nbe l'ekunle grin grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 9:10pm On Jul 27, 2009
mo wa pa baby mii, so, where is my food? tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by MrCrackles(m): 9:12pm On Jul 27, 2009
undecided
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by oYaTo(m): 9:17pm On Jul 27, 2009
e'nkunle ke? ti aja ba lo je nko? cry

mommy shey e ma fi onje si mi lenu? cheesy


p.s: o da bi pe omidan hotteju yen wa pa gan o. .omo naa rewa gaani wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 9:24pm On Jul 27, 2009
Ko s'oro!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluespice(f): 9:36pm On Jul 27, 2009
oYaTo:

e'nkunle ke? ti aja ba lo je nko?  cry

mommy shey e ma fi onje si mi lenu?  cheesy


p.s: o da bi pe omidan hotteju yen wa pa gan o. .omo naa rewa gaani    wink
       

o f'oju jo iya e jare cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 2:09am On Jul 28, 2009
Se Yoruba ni chinedoll ni tabi o gbo Yoruba? shocked shocked
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 3:16am On Jul 28, 2009
IFELEKE:

Ehn? ai si ni ile ologinni mi ile di ile ekutele tope-lobi! angry
ogbeni tope, iru iwa palapa wo lo n wu leyin mi yii?
awe we e b'oyami tage lere ki mo wi si o kuo gbonyami re? so rora koloun so o o! angry
@toyin temi nikan
oyami atata kiss, se alaafia lu e se? ibeji mi sikan, se ala ni?(ekiti way of checking on my wife and babies)
mo o ri yim e oo*mayb you sent to the wrong addy again). . .will b waiting.
keede? ki lo n bi e ninu? kiss
Calm down jare, eyin okurin ekiti ti ni gra gra ju (but I no dey complain tongue)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 6:46am On Jul 28, 2009
Bluespice,

Emi lo de? Ki ni o fin se eyan? Kilode to oo le jokoloko?

Oya tete ma se afira bi ise ko pe ni, enikan ki pe ise
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ibrokay(m): 7:10am On Jul 28, 2009
dayokanu,
Kinni itunmo jokoloko?
Die die ooo

(1) (2) (3) ... (42) (43) (44) (45) (46) (47) (48) ... (100)

Ònkà Yorùbá: Numbers And Numbering System In Yorùbá / 20 Popular Yoruba Charms And Their Uses(With Direct English Translations) / Benin Art And Architecture

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 31
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.