Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,191,626 members, 7,944,883 topics. Date: Tuesday, 10 September 2024 at 07:29 AM

YAGA!!! Happy Birthday, Wizzy Baby - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / YAGA!!! Happy Birthday, Wizzy Baby (484 Views)

Davido Ati Wizzy Lori Lambogini (2) (3) (4)

(1) (Reply)

YAGA!!! Happy Birthday, Wizzy Baby by SisiGbeborun(f): 8:29am On Jul 16, 2015
Omo olojo ibi, Ayo Balogun ti gbogbo eniyan mo is Wizkid ti pe omo odun meedogbon loni. O si ti n gbaradi lati fo lo is ilu South Africa fun ipalemo MAMA award ti o ma waye ni ojo abameta ti o nbo yi. Wizkid yio se ayeye ojo ibi re pelu awon olorin jankan jakan ni South Africa paapa julo awon ti won jo ma fi orin da awon eyan l'araya ni MAMA award. O ku oriire o. Oluwa a de e is fun wa.
Eyin ololufe Wizzy, e ya ki ku oriire
Re: YAGA!!! Happy Birthday, Wizzy Baby by Proffdada: 8:34am On Jul 16, 2015
SisiGbeborun:
Omo olojo ibi, Ayo Balogun ti gbogbo eniyan mo is Wizkid ti pe omo odun meedogbon loni. O si ti n gbaradi lati fo lo is ilu South Africa fun ipalemo MAMA award ti o ma waye ni ojo abameta ti o nbo yi. Wizkid yio se ayeye ojo ibi re pelu awon olorin jankan jakan ni South Africa paapa julo awon ti won jo ma fi orin da awon eyan l'araya ni MAMA award. O ku oriire o. Oluwa a de e is fun wa.
Eyin ololufe Wizzy, e ya ki ku oriire
aana ni ojo Ibi temi, osu awon ologbon ni eleyi nitori naa niwon nfi pe ni wizkid wink

(1) (Reply)

Ife Residents Stockpile Foodstuffs As Anxiety Rises Over Oro Festival / Trusted Bedbug Exterminators / Awon Onigbeja Kan Ti Wo Fashola Lo Siwaju Ajo EFCC

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 9
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.