Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,198,176 members, 7,967,335 topics. Date: Saturday, 05 October 2024 at 04:28 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / O Ma Se O... Eya Ara Eeyan Ree Loju Titi L'abuja Yii (1213 Views)
Ogun Ti Akoba Fe Ki Okunrin Tabi Obinrin Loju Miran Leyin Eni / Awon Ara Ti Mercy Aigbe Tun Da Ni Yii / O Ma Se O, Omiyale Ni Guusu Asia (2) (3) (4)
(1) (Reply)
O Ma Se O... Eya Ara Eeyan Ree Loju Titi L'abuja Yii by SisiGbeborun(f): 1:15pm On Oct 03, 2015 |
Ado oloro meji to bu gbamu ni'lu Abuja l'anaa ti se'ku pa opolopo awon eeyan ni agbegbe Nyanya ati Kuje, koda, se ni won n ri eya ara eeyan kaakiri oju popo. Ado oloro kan dun nigba ti omobinrin kan n gbee lo si ago olopa kan ni agbegbe Kuje, ti ado oloro onibeji imii si dun ni ibudoko Jikwoyi ni Nyanya, l'oju ona marose Abuja si Keffi. http://www.sisigbeborun.com/2015/10/o-ma-se-o-eya-ara-eeyan-ree-loju-titi.html |
Re: O Ma Se O... Eya Ara Eeyan Ree Loju Titi L'abuja Yii by Nobody: 1:56pm On Oct 03, 2015 |
ki edua gbawa lowo ekun apokoje bokoharam to npa kukuru to npa gigun ni le naijeria |
(1) (Reply)
Olubadan Suspends Onido, Places Eze Ndigbo Under Baales / Ooni Of Ife And Yeyeluwa Of Ife At The Olokun Traditional Festival In Ile Ife (P / Yoruba Cakes From Mexico
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 6 |