Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,148,810 members, 7,802,598 topics. Date: Friday, 19 April 2024 at 05:04 PM

Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju - Health (26) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Health / Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju (557687 Views)

Civil Servant Killed By Thunder In Oro, Kwara (Photos) / Ogun Ibile To Daju / The Bad Shape Of Oro General Hospital, Kwara State (Exclusive Photos) (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (23) (24) (25) (26) (27) (Reply) (Go Down)

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by dplanner: 9:06am On Aug 12, 2018
Ogun low sperm count , ato Sisan , epo eyin agric to po ati kanafuru ,a o lo po, a o ma peak milk ati oyin gidi lo . 07067796292 fun anything .
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Kemade2007(f): 2:32pm On Sep 07, 2018
Baba, e jowo mo fe ogun fun obinrin ti nkan osu re n se segesege. Nkan obinrin naa ko tun ni jade daada nigba miran ko ni wa rara
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by willy360: 1:01pm On Nov 07, 2018
Mo se iba gbogbo Agba Agba merindilogun ...

E jowo mofe Ogun ibile todaju fun isan yii

Ki kokoro funfun ayee mawa ninu igbonse eniyan.

E seun
[color=#006600][/color]
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by dplanner: 7:34pm On Nov 12, 2018
Iwo to ba mo pe aisan kan ba o ja , eyikeyi owu koje , ipa olorun ka whatsapp mi 07067796292 ka soro
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Dassyspecial: 1:31pm On Nov 28, 2018
Ejowo kinni ogun ti eniyan to ba n se esuke le lo,omo odun mejilelogbon
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Fumymy30(f): 4:45pm On Mar 21, 2019
pls i need items ewe ati egbo fun kiki agbo eela
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by biometrics: 3:30pm On Mar 24, 2019
Agbo Ela
¤¤¤¤¤¤¤
E mu ose dudu, koun ti anfin sebe ati omi osan wewe, epo gbogbo e papo kie fi ma pa oju e.
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Walexy70: 5:39am On Mar 25, 2019
No nfe Ogun fun ara wuwu
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Olufelami: 11:39pm On Jun 02, 2019
[quote author=08101646045atwp post=50668594]ASINA OWO / KIWON LE OWO NLALA BERE WA. ileke itun, ileke ifa, abere, ewe anu, ewe ela. gigun pomo ose, aofi omi agbon po ose na pelu lofinda bittu. Aoma fiwe pelu ohun OHUN; Itun loni ki efi owo million tun mi se Ifa loni ki efi owo nlala fami mora Abere loni ki efi millions bere mi. Nibiti oka bakasi lonje oka nba Ki millions oto mi wa, kiwon wafi damilola.


E Seun baba, Sugbon se aaro ni a o maa lo ose naa ni tabi ale tabi anytime? Se ojoojumo la le lo naa?
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Solutionhealth(m): 4:22am On Jun 29, 2019
kadunasouth:
Ogun eniti owu Alantakun Makoloju ni gbogbo igba
Ito akoko to lara laiti soro si eniyan wafi owo alafia re gba wawa fi boju ati orire ole lore we leyin iseju mewa tabi ki ofi omi san danu, oti segun owu alantakun niye
NB tobatun sele watun tunse ti okofini gburore ma nio

call 0811 842 8131
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Tmm23: 12:05pm On Sep 04, 2019
[/color][color=#006600]
ese gan baba awise ooo... modupe fun alufaniyi ogbo atoo ooo.... baba ejo kini ogun ti afile da omo to o un mu Igbo (India herm) duro... ese sir
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Tmm23: 12:11pm On Sep 04, 2019
baba ejowo e funmi ni number yin mofe pe yin ese oo
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Dray222: 6:56pm On Sep 10, 2019
kadunasouth:
OGUN OSOLE TO DAJU NO REPERCURSION
Okan malu dudu ti ko womi iho meta lowa lara okan yi ao ko gbogbo orisi owo sinu ikan ao tun ki ori igun bo iho keji ao ki atare bo iho keta ao wa fi ori akala tele ape ao gbe okan yi le lori ao jo ao mafi foko mu lararo. Towo nbati po funwa alefe ma la ala kala lasikoyi ejeki sara akara elepo po fun wa ni sise losose

Eku ise sir olohun ajeki o MA je fun yin o, mofe bere wipe bi a ba tin se saara yen loosose se akoni malaala alakala yen mo, and hope there won't be any side effect that will affect me in future
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Dray222: 11:39pm On Sep 10, 2019
kadunasouth:
EYONU AWORO TODAJU
ORI OLOGBO,
EWE REKUREKU,
EWE SAWEREPEPE,
ODIDI ATARE KAN
AO JO PAPO,AOLO SUGAR ONIKORO EYO MARUN MO,AOMA LA NI ARARO

Eku ise sir o olohun amagba fun yin o, amajuyinse o, ekoni sise se, sir kini ao ma fila ebu na
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by dplanner: 6:03pm On Oct 04, 2019
Aku ola JIMOH ONI, Eku ojo meta e so pe eri owo mi mo , walahi owo lo di ju ,. Mo akosejaye ati irawo re ko le mo ona abayo si ogun aye re , eleyi ko si irawo ti ko le lo yato si iwo to ba ni idiwo lara , pemi fun akosejaye ati irawo re sugbon o fe ko ooo, 07055595911, 07067796292 tabi whatsapp lori mtn. Ise yi ko ja mo fe se ogun owo tabi gbewa kan , iwo na kuro ninu osi, pelu igbiyanju, tori aiduro re , ona lo fi ja si , opo lo ti se orire lati Ara ise yi , Ko da awon ti America gan gba dun re ka tun wa so iwo to wa ni Nigeria .

ASEJE ATI OSE AWURE PELU ASIRI BIBO TO DAJU TARA
Eja aro gbigbe kan , akuko adie funfun kan , ewe ogo to po die, ewe aje to po die, egun ekun die, egun Erin die, egun efon die, ata ijosin 21 , epo , iyo, iru, alubosa, sise re , a o lo awon egun yi kuna dada, a o da sibi Kan, a o gbe si egbe Kan , a o gun eja aro, ewe aje die, ewe ogo die, alubosa, iru, ata ijosin, a o lo won pa po , a o wa fi ese fa ori akuko adie yi tu , a o gba eje re sinu igba kan , a o wa th gbogbo iye ara akuko adie yi, a o ko sinu doo , a o wa ge adie yi si koniye, a ko gbogbo ifun re si inu odo , a o wa fi adie na se aseje lepo niyo , a o wa fi ewe aje se osuka sile , ori ewe yi ni a o gbe aseje yi le , wa fi awon egun ti a lo te Ifa ogundabede, a o ro itan re le lori , a o da sinu obe na , a o wa koje ni gbigbona, a o ma yo gbogbo egun re sinu abo kan , a o wa da egun adie yi pada sinu isasun na , a o wa ko osuka yen ati ewe ogo to se ku mo tinu odo yen , a o wa gun mo ose funfun , a o fi eje adie yen po dada , a o wa ko si inu isasun to a Fi je aseje yen , a o fi omori re de , a wa ma we ni emeta lose , aro ni wiwe re , Idi isasun yi ko gbudo kanle o, a o ma ri owo ni ona kona to daju
ITAN RE
Piripiri ni aje Nke wokun, , parapara ni Ida Nke wole , bi ihuhu ni iye nla lara adie , ojo ti adie ba ti sunkun bibo asiri bayi ni orisa n fi iye basiri re, Iran awon ekun ki ba won je eran ikasin, asiri efon ki tu loju olodan , ogo mi ti de loni ki igba olowo o je mi ni Kia Kia , Mo fe gba jare owo Faye ki won da asiri owo to gbe nkan rere se bo mi loni , nitori gbogbo ara ni sefunsefun ni se are tire , ao se adura si o Opari , oni mejemu ooo, iwo to ba fe se gbo mejemu ko to se ooo. Ikilo o san ju ebo ruru lo
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Ola4ple: 9:45pm On Oct 20, 2019
Edakun monidi Ogun ti eniyan le sa si eniyan toba gbe yan ni kan boya ki ara ni oni tohun kosi wa jewo wipe ohun lohun gbe nkan nan kosi wa gbe kale
Gbogbo Ile edakun esanu mi Lori inkan yi. Wan gbemi phone wasi fi ko gbogbo owo towa ni account mi lo
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by dplanner: 2:40pm On Dec 04, 2019
IWO TO BA NIFE ATI JOIN WHATSAPP GROUP IRIN AJO OLA ATI ASEYORI (ROAD TO SUCCES )
https:///HqU7tUZ8LRV8h6tzMkBX8a or 07067796292
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by omomajemuorun: 4:39pm On Jan 11, 2020
@KadunaSouth , Edakun inu mi a dun te ba le fun mi ni Email address yin sir. Email mi re (Omomajemuorun @gmail.com)
Ewe a ma je o.
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 1:01am On Feb 18, 2020
Moki gbogbo ile aku opolopo odun ati ojo, anu oloun yio ma ba opolopo wa gbe, Amin
Ema bere sini ri owo mi pada, mo dupe lowo gbogbo awan to wan pemi wipe kinda kun ki update ikanni yi, ife Leni siwa ati ilosiwaju awan ololufe, oloun yio nife eyin na
Fun email
08028358926a@gmail.com
WhatsApp 09090305775

1 Like

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Ayanfeoluxyz(f): 8:12pm On Feb 18, 2020
kadunasouth:
Moki gbogbo ile aku opolopo odun ati ojo, anu oloun yio ma ba opolopo wa gbe, Amin
Ema bere sini ri owo mi pada, mo dupe lowo gbogbo awan to wan pemi wipe kinda kun ki update ikanni yi, ife Leni siwa ati ilosiwaju awan ololufe, oloun yio nife eyin na
Fun email
08028358926a@gmail.com
WhatsApp 09090305775
You are highly welcome again

1 Like

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 1:12am On Apr 05, 2020
Moki gbogbowa pata Lori ikanni yi, alafia oloun ati abore koma ba eni kokan wa, aisan okere otobi koni Yale wao Amin
Eleyi ni ogun fun ajakale arun towa lode, efi egbo igi yi kojure pelu ogo oloun alafia yio de si ago ara enina larin ojo meta
(Kadunasouth)
Egbo akogun oga loje ninu awan egbo lati fi koju kokoro aifojuri ninu ago ara ati orisirisi iba
Ebami lo egboyi ko Kuna Dada, note is very bitter
Eni ti arunyi ti wo lara, I daji sibi omode oronbo meta ema fun oronbo yi sinu omin gbona cup kan ewa da ebu akogun yi si ki ema mun ni gbigbona be die die ti eo fi mutan larin 15 mins eo ni gburo awan symptoms yi ma sugban aisan na koti lo o, ao tun se ni ijokeji ati iketa larun buruku yi ba dagbere, ti kobalo kalope 5 days is maximum ogbodo lotan patapata pelu ase oloun
Fun prevention e soak e sinu ragolis water kie ma yomu lararo kie etun ma mu omingbina le Lori once in a day ati awan omowa kole de odowa lai lai pelu ogo oloun
Sign(kadunasouth)

Agbore tun leleyi ( aparun/ Corona v)
Ewe awogba arun, egbo awogba arun, iyere, atare meta, eru alama ati awanka, Aidan, ata ijosi, ao lo to yio Kuna oti oyinbo ati oronbo wewe same measurements ao dasinure, mimun ni gas kokan laro laro
Note eni ti kimu oti olelo omin oronbo nikan
Emi kii mun, oronbo ni moman nfiki, osi nsise Dada
Gbogbo arun pata lo nwo pelu ase oloun
Nb ibi ti iseyi tiwa oti ati oronbo nafiki
Pelu research todomi molo oronbo nikan ode sise, ao ni ri ogun aisan lagbara oloun oba
Iba re olodumare mojuba gbogbo jawe wa egbo,
Ati awan agbagba, omisa isegun
Adua wa yio gba amin

2 Likes

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Ayanfeoluxyz(f): 6:19am On Apr 05, 2020
kadunasouth:
Moki gbogbowa pata Lori ikanni yi, alafia oloun ati abore koma ba eni kokan wa, aisan okere otobi koni Yale wao Amin
Eleyi ni ogun fun ajakale arun towa lode, efi egbo igi yi kojure pelu ogo oloun alafia yio de si ago ara enina larin ojo meta
(Kadunasouth)
Egbo akogun oga loje ninu awan egbo lati fi koju kokoro aifojuri ninu ago ara ati orisirisi iba
Ebami lo egboyi ko Kuna Dada, note is very bitter
Eni ti arunyi ti wo lara, I daji sibi omode oronbo meta ema fun oronbo yi sinu omin gbona cup kan ewa da ebu akogun yi si ki ema mun ni gbigbona be die die ti eo fi mutan larin 15 mins eo ni gburo awan symptoms yi ma sugban aisan na koti lo o, ao tun se ni ijokeji ati iketa larun buruku yi ba dagbere, ti kobalo kalope 5 days is maximum ogbodo lotan patapata pelu ase oloun
Fun prevention e soak e sinu ragolis water kie ma yomu lararo kie etun ma mu omingbina le Lori once in a day ati awan omowa kole de odowa lai lai pelu ogo oloun
Sign(kadunasouth)

Agbore tun leleyi ( aparun/ Corona v)
Ewe awogba arun, egbo awogba arun, iyere, atare meta, eru alama ati awanka, Aidan, ata ijosi, ao lo to yio Kuna oti oyinbo ati oronbo wewe same measurements ao dasinure, mimun ni gas kokan laro laro
Note eni ti kimu oti olelo omin oronbo nikan
Emi kii mun, oronbo ni moman nfiki, osi nsise Dada
Gbogbo arun pata lo nwo pelu ase oloun
Nb ibi ti iseyi tiwa oti ati oronbo nafiki
Pelu research todomi molo oronbo nikan ode sise, ao ni ri ogun aisan lagbara oloun oba
Iba re olodumare mojuba gbogbo jawe wa egbo,
Ati awan agbagba, omisa isegun
Adua wa yio gba amin
pls baba kini Ogun ti a le lo fun eni ti o n to latooju sugbon ti ayewo so pe ko ni into sugar ejowo
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:26am On Apr 05, 2020
[quote author=Ayanfeoluxyz post=88108826]pls baba kini Ogun ti a le lo fun eni ti o n to latooju sugbon ti ayewo so pe ko ni into sugar ejowo[/rquote]
Awan nkan toma nfa opo sugban die to se pataki ni ninure
Ti eyan ba lasepo pelu obinrin to nse nkan alejo lowo tabi oku die tiyio bere alejo re
Tabi obinrin ti atosi ti pe larare ta ba ni asepo
Tabi toilet disease
Iru enibe yio ni premature ejaculation, ati awan are miran to sapama sinu ago ara bi aran ati bad bacteria ati bebelo
Egbo igi tole wo aisan yi ni, bi agbo aparun, agbo atosi , tabi agbo gbogbonose, e search fun wan Lori ikanni yi oti wa nibe kie gbe lura kia ni alafia yio de
Tabi kie se eleyi
Ito latoju
Igbe adie topo ao Jo ma odidi atare kan ao mafi omi toloworo lo die die laro kutu
Igbe pepeye aojo ma odidi atare ao ma fi omi lasan lo lale katosun yio stop
Nb ti abati notice wipe ao tun fe ma to Dada man discontinue uses

2 Likes

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Ayanfeoluxyz(f): 9:14pm On Apr 05, 2020
[quote author=kadunasouth post=88116520][/quote] Amaa ju yin se baba!
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Ayanfeoluxyz(f): 9:18pm On Apr 05, 2020
[quote author=kadunasouth post=88116520][/quote] Amaa ju yin se baba!
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Donsmart124: 1:56pm On May 01, 2020
Ewe a maje o
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by abacusCm(m): 3:56pm On May 01, 2020
E JOWO E FUN NI OGUN CORONAVIRUS
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 5:46pm On May 30, 2020
Moki gbogbo ile aku ojo meta, anu oloun ati ibukunre yio ma ba gbogbowa gbe, Amin
Emin tiyin na nio kadunasouth
Ese pupo

1 Like

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by 08101646045atwp(m): 2:40am On Jul 29, 2020
Fun Covid-19
By Kabiesi Oonirisa.

Afi Awon alumni yi sile fun anfani gbogbo aye
Nitori ojo ti nro ti koida, akoitimo iye eniyan tomapa, ojo ekun koniro lewalori tebitara'o

Awon alumoni naniyi
*ALUBOSA*
Ao ge alubosa si wewe, ao bu si igun yara wa, omanle Asian kiaisan ni inu ile yala otiwa ninu ile tele, tabi osesefe wole alekuro ni igun ile na ati gbogbo ile ti age si.

ELENKEJI TOTUN DABIRE: ao mu alubosa ti age si wewe, ao fi si atelese wa, ao wo ibose si omanda arunkarun duro ninu ago ara ni, ositun man tun gbogbo ago arase.

*ISU OGIRISAKO*
Ogirisako naa situn dara ninu awon egbogi fun iwosan: aomu ogirisako yi aogesi wewe, ao reé pelu omidun ati osan wewe tabi omi ati omi osan wewe, tabi emu ewa jinpo odimimu, gasi kan lojumo.

*EWE EWURO*
Ewuro, imiojo, Aidan, eeru awonka, alubosa. Bakanna ao gun papo ao sa si inu ile, tibagbe odi finfin ni turari, gbogbo ohun to nje Asian afojuri ati aifojuri ni yiolelo.

Asitunlemu turari yi bakanna, kiabu sinu omi gbigbona, kia fin pelu dida bulanketi bori pelue ki orure le WO ago arawa.

*EWE EWURO*
Ao gun kunna dada, bi agunmu, kiema busi omigbigbona fun mimu ni ekan lojumo.

*EWE AKOKO*
Ao gun Ewe akoko ati ewe dongoyaro pelu eso dongoyaro papo mo ose iwe eyikeyi, odi wiwe lararo.

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni (AAA) ALUMONI AWON AKONI lori WhatsApp

ele fi orukoyin sile si ori :-
https:///8ahrCpBnxgS3qHb0L63Hp8

:- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mase fi number re si abe comment'o
Whala koni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Brayss(m): 11:33am On Sep 15, 2020
kadunasouth:
Awure OWO larin ojo meta
Ewe sawerepepe tutu taja lojo ata ijosi eyo meta ao lo yio kuna ao jo eyin agiriki meji sinu santana leda ao to iyo die si ao di bi iga ti afese olele ao gbe omi kana ao wa se jina toba tutu ao se adua owo si larin ojo meta ao koje larin ojo meta toba sise funo ogbodo ri owo dada, ti ojo meta bati koja isere ti tan





Alekun ike ati ola kolore ba alaye lorun

Iba fun awan Agbagba

(1) (2) (3) ... (23) (24) (25) (26) (27) (Reply)

Causes Of Seeing Menstrual Period Twice A Month / Postinor 2 - How Effective Is It? / Doctor in the House: Free Medical Advice Available

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 51
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.