₦airaland Forum

Welcome, Guest: Join Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 2,076,834 members, 4,485,147 topics. Date: Sunday, 23 September 2018 at 01:22 PM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! - Culture (65) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! (121303 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (62) (63) (64) (65) (66) (67) (68) ... (73) (Reply) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by juman(m): 1:44pm On Nov 22, 2011
Eku ọjọọrọ
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Idowuogbo(f): 3:25pm On Nov 22, 2011
Eyin temi lori ta meta ema ku le ke, oma to jo meta da gburo awon gals and bois.Bado ki le oooooo, ema she ijogbon yi osi yoju siyin la yi pe la yi jina
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by otentic19: 4:45pm On Dec 15, 2011
Hello,

I am suspecting some of my classmates in school, I believe they must be using ogun isoye, They perform exceptionally in class.Can nairalanders pls explain better on this topic as it is puzzling to me.
I also heard that Omi Ontu(quran recited in water) also perform similar purpose,

Thanks,
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Remii(m): 9:27pm On Dec 29, 2011
Eku igabdun asiko yi oo, complements of the seasons.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by subayob: 12:54pm On Dec 30, 2011
Inú mí dùn pópọ̀pópọ̀ láti jẹ́ kí ẹmò wípé Yorùbá sọ́fútiwà (multilingual word processing software) tiwà tí  a pilèkọ l'áti ọwọ́ àwọn ọmọ Nìàjíríà. Èyí tó ń s'isẹ́ bóseyẹ (bíi ká f'àmìsí sórí ọ̀rọ̀, pírííntìì, fọ́máàtì, àti  bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀lọ) t'ósìtún le s'àtúnse lórí fíàlì tí àwọn sọ́fútiwà míràn tí kòle f'àmì ohùn sírí ọ̀rò.
Ìrànlọ́wọ́ ńlá gbáà ni eléyìí yíò jẹ́ fún ìgbélórí sókè àti ìpolongo èdè Nàìjíríà bíi Yorùbá, Hausa àti  Igbo bẹ́nì owó rírà rẹ̀ kòsì kanni nípá.
tàtẹ̀ jísẹ́ ránsẹ́ sí subayob@yahoo.com tàbí pe 2348032322276 ti o ba nife láti darapọ̀ tàbí làti ràá.


I'm so delighted to inform you that Multilingual word processing software (Yoruba inclusive) is now  available, developed by Nigerians that is working perfectly (you should believe that!). All the tonal  marks can now be insert just as you type, edit documents that were not tone-marked, print, format and  many more! It is 100% supported by web browse and other word processor and it's affordable.

eMail subayob@yahoo.com or Call 2348032322276 if you're interested.
We are the developer and we need marketers all over the world to create a force that will put Yoruba especially ahead.

Yorùbá dùn ń sọ!
Yorùbá sìí dùn kọ pẹ̀lú!!

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by jamace(m): 7:09pm On Jan 05, 2012
Mama olonje, funmi ewa ati pomo. grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by PAGAN9JA(m): 10:13pm On Jan 05, 2012
[size=16pt]PRAISE BE TO LORD SHANGO!!!!!!!![/size]

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by ariyebaba(m): 8:17pm On Jan 06, 2012
EYI FI HAN GBANGBA WI PE YORUBA LO NI "NAIRALAND(I)"

EYIN OMO KA RO OJI RE, I WAJU LA O MA LO OOOOO

AMIN !!!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by FBS: 4:14am On Jan 07, 2012
Eyin temi ba wo ni o, se wa? cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by IFELEKE(m): 1:15pm On Jan 07, 2012
Mo ki gbogbo ile oo,eyin temi o t'ojo meta,se alaafia le wa?a de ku owon gogo epo roobi yi, ki oluwa gba wa l'owo awon a fe'aaje ma fe'aayo oni mo t'ara eni nikan agbon isale,won biliki won bi'a ti a ko jo gege bi adari wa l'ori le ede yi. . .
FBS
omo iya se alaafia ni? o to jo meta
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by FBS: 4:02pm On Jan 07, 2012
@IFELEKE, alaafia ni o. Aku odun tuntun yi. ile nko?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Sholaf(f): 1:24pm On Jan 09, 2012
Awa omo yoruba, ti a wa ni Idale, adura mi ni pe ki Oluwa Olorun, ki o so wa dele pelu ayo ati alafia.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Idowuogbo(f): 2:51pm On Jan 09, 2012
Ladies and gentle moi moi eku kale o, mo ki gbogbo ile se dada mo ba yin,awon temi ibo le wo le si oto meta e rora ma fa gburu o.Bado atubo ma yoju si yin Eko oni baje o cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by r231(m): 3:42pm On Jan 09, 2012
eko ti baje ooo

gbogbo naija gba n wa epo lo wo ta wa yi
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Idowuogbo(f): 4:06pm On Jan 09, 2012
^lool eko o ti baje tan,eja ka sowo po ka fi imoran to pe ye fi te se bo eyi tan ba wa danwo lowo lowo.(Kai see my swagga yoruba writing,am surely gona reach dere ayaf arrivee) cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by bolorunfem(f): 3:23pm On Feb 22, 2012
E ku atijo se daada ni? Salafia le wa gbogbo ile nko o?
Eyin temi, bawo ni o, se wa? Lele lele lelelelele, se wa?

O to jo meta, e ku afere yi o. Eyin ti Naija, gbogbo yin loke okun, mo ki yin o, gbogbo wa la o kore oko dele o. Amin.

E maa mi lengbe!!!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by kolaoloye(m): 11:55am On Feb 23, 2012
bolorunfem:

E ku atijo se daada ni? Salafia le wa gbogbo ile nko o?
Eyin temi, bawo ni o, se wa? Lele lele lelelelele, se wa?

O to jo meta, e ku afere yi o. Eyin ti Naija, gbogbo yin loke okun, mo ki yin o, gbogbo wa la o kore oko dele o. Amin.

E maa mi lengbe!!!
Bee ni, a wa bi ewa. Baba kekere nko,se alaafia ni awon naa wa?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by richylaw(m): 12:10am On Feb 24, 2012
Awon agba bo, won ni ogun omode ko le e s'ere fun ogun odun! Gbengbe gbankogbi oro!. Mo w'orere aagbon abala ede yii lehin bii odun meta ti a ti da a sile, mo si ri wipe gbigboro lo n gboro si. Ahere ti di odede, aba elewe ti di abadibadi, ileto ti di ilu nla, ko da orisirisi oruko lo ti yipada. Awon mojesin, omidan ati gbogbo odo langba to f'oju pamo ni igba atijo ti k'orin w'olu, won n wipe:

Awa yin la n'ilu o
Awa yin la n'ilu o
E mo pe wa lalejo mo o
Awa yin la n'ilu o

Bee naa ni awon agba ilu, abi ade lori bi okin s'ilekun ibode, won si t'ewo gba gbogbo ojulowo omo w'ole. Awon si na fi orin s'enu won n wi bayi wipe:
Wole,
Wole wa
Ile baba omo ki i b'omo l'eru
Wole wa

Awon agbaagba ana wonyi da? Awon onsoro ijinle abala yi da. Afefe aje ti gb'omo sonu bi oko. Ori ti gbe mutumuwa lo igberi okun. Mo ri wipe Kola Oloye n soju Oodua, beeni, ajananku o ya arara, omo ekun ba bi ekun ni o jo. Se Debosky ti ba oyinbo alawofunfun lo ni, Olori D nko, Alagba Ayangbayi da. K'oda Mukinatu a t'ohun wa gbade ti lo simi edo si abala ibomiran, Looto ni ogun omode ko le sere fun ogun odun o.
Amo o ki n to d'awo kalamu ayara bi asa yi duro, kini kan lo wa ti ko si se bo m'ole, a kii i gba abata l'owo akiti, enikan ki i gba ile baba eni lowo eni.
Gbogbo omo kaaro ojiire, e n le n be n o.
Baale
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by bolorunfem(f): 11:17am On Feb 24, 2012
kola oloye:

Bee ni, a wa bi ewa. Baba kekere nko,se alaafia ni awon naa wa?

Baba nbe labule o. Won ni ki nki gbogbo yin lokookan
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 11:27am On Feb 24, 2012
Yoruba dun so, odun ko fun mi, sugbon ko yara lati ka o. cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by bolorunfem(f): 12:12pm On Feb 24, 2012
Mo le ka, mo le soo, sugbon mo ni shalenji die lati ko, mo ni lati ronu gidigidi nitori mo korira maa se asise ede (tabon wink) Eleyi je (kini practice ni Yoruba) fun mi, o si dun mo mi.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by kolaoloye(m): 12:17pm On Feb 24, 2012
bolorunfem:

Mo le ka, mo le soo, sugbon mo ni shalenji die lati ko, mo ni lati ronu gidigidi nitori mo korira maa se asise ede (tabon wink) Eleyi je (kini practice ni Yoruba) fun mi, o si dun mo mi.
Ko si ede ti o rorun bi ede Yoruba. Asa ati ise re ko se fi owo ro ti si eyin. grin
If you were able to read that once and got the meaning it simply means you are a GURU.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by richylaw(m): 4:07pm On Feb 24, 2012
Bi ami ba n be ni ori oro ko ye ki o soro fun ni lati ka. Sugbon kereje ni ape ikowe ero ayara bi asa ti o le fi ami si ori oro yoruba. Ibi pelebe lati n mu olele je. Diedie na ni.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Ptolomeus(m): 5:17pm On Feb 24, 2012
PAGAN 9JA:

[size=16pt]PRAISE BE TO LORD SHANGO!!!!!!!![/size]

E kaabo kabeyesi ilé!
S' oro s´oro onigodo!

this is correct?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by PAGAN9JA(m): 5:39pm On Feb 25, 2012
Ptolomeus:

E kaabo kabeyesi ilé!
S' oro s´oro onigodo!

this is correct?

I am not Yoruba. i am Hausa! grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by dayokanu(m): 6:08pm On Feb 25, 2012
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by PAGAN9JA(m): 3:11pm On Feb 26, 2012
dayokanu:

Check this thread

https://www.nairaland.com/nigeria/topic-879808.0.html#msg10272753


what a dirty thread. its fit for slaves-minds.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Ptolomeus(m): 8:43pm On Feb 27, 2012
A friend who speaks Yoruba and help me know if text is correct?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by tunnytox(m): 8:40pm On Feb 28, 2012
Eyin omo kaaro oojire bi temi e je ki n fi to yin leti pe e le darapo mo awon egbe Yoruba lorisirisi ti o wa lorii fesibuku:

http://www.facebook.com/pages/EWA-EDE-YORUBAThe-beauty-of-Yoruba-language/110578842348195

http://www.facebook.com/groups/118809998193066/

Iree o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by bolorunfem(f): 5:35pm On Mar 08, 2012
Ptolomeus:

A friend who speaks Yoruba and help me know if text is correct?


what text?
Ptolomeus:

E kaabo kabeyesi ilé!
S' oro s´oro onigodo!

this is correct?

No! O ti ta Ibon ni ede Yoruba (gbaganun )

Idowuogbo:

^lool eko o ti baje tan,eja ka sowo po ka fi imoran to pe ye fi te se bo eyi tan ba wa danwo lowo lowo.(Kai see my swagga yoruba writing,am surely gona reach dere ayaf arrivee) cool
Idowuogbo, Swagga e yi tun le nle o! Bawo ni, awon Ejire nko o, esu lehin-Ibeji (ma binu o, oriki lasan ni o) grin

tunnytox:

Eyin omo kaaro oojire bi temi e je ki n fi to yin leti pe e le darapo mo awon egbe Yoruba lorisirisi ti o wa lorii fesibuku:

http://www.facebook.com/pages/EWA-EDE-YORUBAThe-beauty-of-Yoruba-language/110578842348195

http://www.facebook.com/groups/118809998193066/

Iree o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Ptolomeus(m): 5:44pm On Mar 08, 2012
bolorunfem:

No! O ti ta Ibon ni ede Yoruba (gbaganun )
Dear Madam bolorunfem:
I appreciate your answer, but I explained that I do not speak Yoruba.
Precisely for that reason I've wondered if I set the text that was correct.
Could you be kind enough to answer in English or Spanish, is essential for understanding your kind answer?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Idowuogbo(f): 9:24am On Mar 09, 2012
bolorunfem:

Idowuogbo, Swagga e yi tun le nle o! Bawo ni, awon Ejire nko o, esu lehin-Ibeji (ma binu o, oriki lasan ni o) grin

Iyalode, swagga te mi segremende la ti le.

Yoruba Badosky ni quality walaiiiii,mo tu ni awon ajasa kan to tun jeki gbogbo ni kilo.

Ema wo tin yin kekaiscene ta wa bedtttt!!!!!

Iba akoda fun yin mama,she ko wa le Ma?  grin grin grin grin grin

(1) (2) (3) ... (62) (63) (64) (65) (66) (67) (68) ... (73) (Reply)

Teach Me Naija Slang Please / HAUSALAND: Teach Me Hausa / Akan Of Ghana And Cote D'ivoire

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (0) (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2018 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 121
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.