Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,148,521 members, 7,801,417 topics. Date: Thursday, 18 April 2024 at 02:57 PM

Mantoosh Majlooj - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Mantoosh Majlooj (2655 Views)

(2) (3) (4)

(1) (Reply)

Mantoosh Majlooj by AdeptAdedokun(m): 2:18pm On Jan 03, 2017
[color=#990000][/color][center][/center][b][/b]
JEHOVAH-EL-NEGOMOTH
Enia mi, asiri oruko mimo ti olorun fi kepe Samuel ni ijo kini ana niyi,( Samuel 3:21)oruko mimo yi kanna ni olohun lo lati lefi ara han Samuel ni Shiloh, wo iwo omo iya mi ninu oluwa, oruko mimo yi lagbara to be lati lefi di eniti olorun yio ma fi aran han ni gbogbo igba, loju aiye ati ni oju orun, koda ti eniyan ba nlo asiri oruko yi kosi ohunkohun bi ohun asiri abi ohun ikoko kankan ti yio sokunkun si iru enibe, nitori gbogbo re patapata ni ao ma fi han,
Enikeni ti o ba nfe lati lo asiri oruko na yi fi odidi ojo meje gba awe funfun ojo meje, larin asiko awe yi ni yio ma ka oruko mimo na ni igba mokandinlogorun (99times), bayi ni iwo yio ma ka fun gbogbo wakati adura patapata, lehin kika re ni iwo yio ma ka Psalm 19 si ni igba meje, lehinti ojo keje na ba pe, haaaa! Enia mi, iwo yio ti di eniti okun fun agbara emi mimo, iwo yio ma gbo ohun bakanna ni iwo yio ma riran be sini iwo yio ma sotele gegebi Samuel ti nse, awon angeli mimo yio si ma fi arawon han fun e, lati le ma se amona re ni gbogbo ojo aiye re.
JEHOVAH-EL-NEGOMOTH
Bakanna ti iwo ba npe oruko mimo yi ni ojojumo ni owuro ati ni asale ni igba meta-le-logbon (33times) ni ojojumu iwo yio ma ri gbogbo ohunti oti sele seyin ati ohunti ohunbo wa sele, beni ti ohun aburu bafe sele iwo yio ti mo saju.
JEHOVAH-EL-NEGOMOTH
Bakanna ti iwo ba ko oruko mimo na ni igba 313 si inu iwe felefele funfun kan, ki iwo wa fi turari Vision, ati turari temple ti ati lo kunna dada si oju kiko re, ao wa we ni owu mixed colour ao ma kan lofinda olorun didun si, iwo yio wa ma fi si abe irori re sun ni ale ti iwo bafe sun, tabi ti ohun kohun ba sokunkun sio ti iwo si fe mo nipare kio gbiyanju lati se aniyan ohunti iwo nfe mo si inu re ki ofi si abe irori re sun ni ale, dajudaju gbogbo ohunti iwo ba daniyan lati mo ni awon angeli mimo naa yio fi han fun e loju orun.
JEHOVAH-EL-NEGOMOTH
Ise wa lati owo Adept Adedokun Victor Olayinka
Fun iwulo omo eniyan ati paapa nitori EGBE MANTOOSH MAJLOOJ
+2349030943883
+2337087896633
Http://www./MantooshMajlooj
@[1513918728877457:]

(1) (Reply)

Money, Osole, Owo, Kudi, Eego / 48 Igbo Proverb Most Of Igbo Dont Know(photos) / Changing Face Of The African Woman:

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 10
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.