Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,150,259 members, 7,807,890 topics. Date: Wednesday, 24 April 2024 at 09:54 PM

Oso Owo Gidi Taara - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Oso Owo Gidi Taara (2945 Views)

Oso Owo Todaju Bi Iku, Spiritual Money / Oso Owo Tabi Anabo Owo / Oso Owo Taara (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Oso Owo Gidi Taara by Laniretiawoagba: 6:38am On Apr 01, 2018
ewe apada funfun 201, ikode 201, iye agbe 201, iye aluko 201, ao joo papo , ao lo kunna Dada ao pomo ori amon topo Dada, ao ko sinu igba olomori tuntun, ao gbele ori awo maalu funfun ao ko owo to a po sidi ree, lati bi #20,000 soke ao mafi isu pupa sidi ree, lemeji tabi emeta lodun, die die ni ooo , Ogun yii too ma gbin bi eniyan, mase beru kosi nkan toma fise eniyan, ao mamu owo ni idi re die die, sugbon ako gbodo ko owo na tan, ojo meta meta la o masun sidi re ninu yara yii, ako gbodo mun ounkoun toba je oti taba fe losun sibee, ao sope e funmi lowo mofe se nkan bayii,ako gbodo si window yara naa, ako gbodo tan INA sibee, ao ma paa ewure si ita ile naa lojo mejo , mejo, yo ma jade wa mun eje yen ni ita, ti aba tiko owo idire tan o baje ni yii oo ti ebani ibere tabi oro Miran, ki e pemi sori number yii, tabi WhatsApp 08037492173

(1) (Reply)

Mo Fe Jiggy-Jiggy / . / To Give And Collect Things With The Left Hand Disrespectful?

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 7
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.