Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,148,779 members, 7,802,402 topics. Date: Friday, 19 April 2024 at 01:46 PM

Yoruba Peeps, Kini Oriki Ilu Re? - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Yoruba Peeps, Kini Oriki Ilu Re? (27095 Views)

The Yoruba Oriki For Twin & Its Translation - Dedicated To Twins Worldwide. / Yoruba Names/Oriki For God / Igbo Idioms (Ilu) (2) (3) (4)

(1) (Reply) (Go Down)

Yoruba Peeps, Kini Oriki Ilu Re? by rahjan: 10:39pm On Jun 28, 2010
Emi ni omo òlalomi abi isu jo orokó, omo ijakadi oloro awon omo OFFA. If u're proud of ur town and u know its praise song,lets hear it

1 Like

Re: Yoruba Peeps, Kini Oriki Ilu Re? by Idowuogbo(f): 11:19pm On Jun 28, 2010
emini idowuogbo , omo abigbeyin baba miliki , omo ola , abikere letii , omokosefowora

poster dats all i no oo , did i follow thread ? cus i tried oo forming my own cheesy cheesy cheesy grin grin tongue

2 Likes

Re: Yoruba Peeps, Kini Oriki Ilu Re? by Idowuogbo(f): 11:43pm On Jun 28, 2010
^lastly poster
esu leyin awon boyz cheesy cheesy grin tongue
Re: Yoruba Peeps, Kini Oriki Ilu Re? by tpiah: 12:06am On Jun 29, 2010
emi tpia

omo rere, omo baba

tried forming my own too.
Re: Yoruba Peeps, Kini Oriki Ilu Re? by ifuk(m): 12:19am On Jun 29, 2010
emi ni omo to ba ola ni ile kiss kiss
Re: Yoruba Peeps, Kini Oriki Ilu Re? by ifuk(m): 12:21am On Jun 29, 2010
omo oba ni ilu ondo. won man pe me ni sexi lomo ----- kiss kiss
Re: Yoruba Peeps, Kini Oriki Ilu Re? by Nobody: 2:45am On Jun 29, 2010
Idowuogbo:

^lastly poster
esu leyin awon boyz cheesy cheesy grin tongue
Idowuogbo:

emini idowuogbo , omo abigbeyin baba miliki , omo ola , abikere letii , omokosefowora

poster dats all i no oo , did i follow thread ? cus i tried oo forming my own  cheesy cheesy cheesy grin grin tongue
na u and who? grin

Idowu, fun ara e
Re: Yoruba Peeps, Kini Oriki Ilu Re? by Idowuogbo(f): 6:11am On Jun 29, 2010
^gators oooo
na me and dem so fimile baby, fimile
wetin b urs sef
sey na iwoni oluwagateway , omo alakara ,
boshen gbona ni won ma kigbe ee,
moshe tutu na lon tun shey wa ee sofun
cheesy cheesy cheesy grin grin grin grin
Re: Yoruba Peeps, Kini Oriki Ilu Re? by Nobody: 7:00am On Jun 29, 2010
Idowuogbo:

^gators oooo
na me and dem so fimile baby, fimile
wetin b urs sef
sey na iwoni oluwagateway , omo alakara ,
boshen gbona ni won ma kigbe ee,
moshe tutu na lon tun shey wa ee sofun
cheesy cheesy cheesy grin grin grin grin
yes o, kuku pe mi ni oluwa [iyawo bills gate]
Re: Yoruba Peeps, Kini Oriki Ilu Re? by IFELEKE(m): 6:59pm On Jun 29, 2010
Emi l'omo oloke tele amugun. . .Ekiti Kete O!
Re: Yoruba Peeps, Kini Oriki Ilu Re? by weblessyou: 10:08pm On Jun 29, 2010
@rahjan, idowuogbo, tpiah, ifuk



Eyin ni omo ilu Nairalandi, eyin ni omo ada erin pa osonu, eyin ni omo afi ogbon ologbon so gbon, eyin ni omo amu igboro dun, aji lala osho, aji fi ojojumon dara bi egbin, eyin lomo a visit nairaland lati fogbon kun ogbon ati lati mo kun mo, ati laughter kun laughter.

1 Like

Re: Yoruba Peeps, Kini Oriki Ilu Re? by weblessyou: 10:18pm On Jun 29, 2010
Eyin ni omo aji fi ojojumo ko poster, omo aji fi ojojumo ka tiredi.
Re: Yoruba Peeps, Kini Oriki Ilu Re? by yemooffa(m): 10:57pm On Jun 29, 2010
igunu gun de olohun la mi lapa,efufulele de olohun la mi labe.
mo ni osi ro ra lami o, iyeru okin ma je ki abe o jina lapa mi o
emi ni omo abi isu jo ruko omo ijakadi oloro awon omo offa.

omo la re,omo bu ire ikan ogbodo ju ikan lo
eni ti o ba ni ohun ko ni je iyan anama(sweet potato),oluwa re o ni de offa ti wa ni

yee my head is swelling already
Re: Yoruba Peeps, Kini Oriki Ilu Re? by nana(f): 11:00pm On Jun 29, 2010
Emi ni omo ti iya bi,ti o fi oja aran pan cheesy
Re: Yoruba Peeps, Kini Oriki Ilu Re? by isalegan2: 11:24pm On Nov 28, 2010
The following is an excerpt from an article about Orikis.    

Yoruba Oriki: A dying cultural genre?
Written by Abiodun Awolaja
Nigerian Tribune
Monday, 15 November 2010


The oriki is a time-honoured cultural form. But Yoruba youths appear to be no longer interested in it. Abiodun Awolaja examines the reasons for this change.

The Yoruba oriki (cognomen) is a form of cultural expression which is prevalent in Africa. Among the Yoruba, it is a time-honoured poetic form, a repository of traditional lore, values, virtues and accomplishments. The oriki has been described as a genre used to inspire people, and varies in length depending on whether it refers to a single individual or a clan.  It can be sung or  drummed.

Usually,every Yoruba family has its own oriki, which extols the virtues of the clan, but it is not always positive in its moral content. For instance, part of the oriki of the town where this writer hails from  reads thus: omo eluku mede mede, omo imale afeleja, omo akenigbo, keru o ba’ra ona; omo ole yilu baara ko i jeun aaro; omo asalejeje bi eni ti o robinrin ri, etc( son of Eluku; son of the spirit who fights with the machete; son of the one who cries in the forest and intimidates people of the road; son of the layabout who roams town before eating breakfast; son of the one who pets a concubine delicately, like one who has not seen a woman before, etc), which would seem to suggest that the people are war mongering thugs and fornicators.

An Ibadan oriki also describes the place as one where “the thief is justified rather than the owner of the goods,’’ while the Iseyin people are described as “ebedi moko, male’’(ebedi welcomes both the husband and lover), although the latter part has now been cleverly omitted, perhaps in view of the country’s recent millennium development goals. Some common oriki middle names also include Arike (child meant to be spoilt), Abebi (child begged to be born), Aduke (people will fight over the privilege to take care of her); Ajani (child we fought to have), etc. Interestingly, some mischievous individuals now construct parodies of the oriki genre: “omo badiye ku ata la n lo” (child of when the fowl dies, we quickly grind pepper’’)etc.

However, the glory days of the oriki seem to be gone, as most Yoruba youths are no longer knowledgeable or interested in the cultural genre. A cross-section of interviewees gave their views on this cultural turnaround.

Bukunmi Ogunsola, a 400 level Linguistics student at the University of Ibadan said the fate which had befallen the oriki in recent times was traceable to two factors. “First, parents don’t teach it to their children because they want to break their link with their extended family. Secondly, even those who know the oriki don’t recite them because they don’t want to be seen among their peers as being local or rustic. However, oriki can be relevant during inter-tribal crisis when knowledge of them could save or kill.’’

Mrs Omofolake Owabiire, a business executive, however gave the religious dimension to the question. To her, what should be uppermost in everyone’s minds is the coming of the Lord Jesus, and not oriki.“ In the olden days, our parents gave us oriki.

But when we started bearing children, we realised that oriki really amounted to nothing. I know one Alake; she is a very dirty woman. So my children asked, ‘what’s the meaning of Alake?’ The world is now sophisticated, and the coming of Jesus Christ ought to be in our minds.”

She pointed out that in the past, some rulers were so inspired by oriki that they shot the singer, “when their head swelled up. Oriki is a satanic thing; why should we praise ourselves rather than God?”

However, to Olatundun, a Mass Communications student, “oriki is important because it takes us back to our culture and makes us remember the child of whom we are.’’


http://www.tribune.com.ng/index.php/features/13508-yoruba-oriki-a-dying-cultural-genre
Re: Yoruba Peeps, Kini Oriki Ilu Re? by tunnytox(m): 12:13am On Dec 03, 2010
Ogbomoso ni mi:
Ogbomoso Ogbomojugun, Ogbomoso omo afo'bo ja, Ibi won gbe n jeka ki won to muko yangan. Omo oreputuyii omo ajegbin je karaun omo a fi karaun fo ri mu.
Be denu oko e sinmi, be denu oko e sinmi ogun o ja ja ko ko Ogbomoso ri be denu oko e sinmi.
Re: Yoruba Peeps, Kini Oriki Ilu Re? by hammao: 12:03pm On Jun 23, 2012
ORIKI OFFA

Ede Okin Olofa Mojo,
Olofa, omo Ola nlo.
Olalomi, abisu joko, Ijakadi katakiti l’oro Offa.
Ija peki abe Owula, ti ko ba se oju ebe ni aala.
A se oju poro ninu oko.
Kiba se oju Oloko, Oloko o ba lawon.
O s’oju agunmate, O’soju agbele ya arara, O s’oju apobiirii kako.
Kini se kagun kakan orun nile Oba
Oka baaba, ni se kagun kakan orun! Ni Offa, Agbado ni agun mate,
Eree ni agbe le ya arara, Isu ni apobiiri ka inu oko.
Omo Odi meta ara tinbe ni Offa; Odi iwaju ni ti Olusan, Odi tehin nit i Olumorin,
Odi ti aarin gbungbun ni ti Olugbense, omo Ayejin.
Omo Odo meta araa tin be ni Offa.
Okan ni ki won o pa Erinla bo ohun ki ohu di Odo Okun.
Ekeji ni ki won o pa Agbo bolojo bo ohun ki ohun di Odo Osa.
Eketa ni ki won o pa Akuko Adie gagara bo ohun ki ohun di Agunloko ni Offa
Oba ni okokan ilu tito ra Agbo bolojo,
Onini gbogbo ilu tito ra Erinla.
Sugbon tikan bad i Odo Okun, ti ekeji di Odo Osa,
Nibo ki ako gbogbo omo beeree wonyi si.
Eyi toni ki won pa Akuko adie gagara lo di Agunloko ni Offa
Ti gbogbo wa npon mu.
Olofa laare ki Offa okun te te.
Olofa laare ki odogba, okan Ogbodo jukan.
Ti okan bu okan, ti okan , ti okan ba ju’kan
Oba ni ko won r’oro.
Oba o ko wa t’awa d’oro o’diran baba wa.

Peki mo ba Odofin d’imuu, mo se Ojomu kanrin kese,
Mo fi ehin Saawo balee l’oja Offa.
Offa o mo Akaa, Ijakadi l’oro wa.
Olofa laaree,
Offa o mo Akaa, nibi ti eegun eru ti mule ti oju ti omo bibi lo.
Omo okuta meta ara, mo ko ese lara akoko,
Ekeji nse mi pele, Eketa ni kin ma rora.
Akoko ni, Nigbati mi o mo ona kini mowa de ilu ete.
Ekeji ni, Nigbati mi o mo ona kini mowa de ilu ote..
Eketa ni, Nigbati mi o mo ona kini mowa de ilu owon won.
N’ile Olalomi, nibiti Omi ti won to ju Oti lo.
Ede Okin, ti mo ri Ookin bu mu, Mo fi Abata fo ese.
Ni Offa ti mo ri Abelenje bu bo oju.
Laare ki Offa okun te te.
Bata dun pantan-pantan, ohun ki mi ohun la mi.
Olalomi, tani ko sehun ninu won.
Ile yi ogba wa a lo si lloffa.
Nigbati lloffa o tun gba wa mo a lo si Offa Oro.
Offa Oro o gba wa a lo si Offa Rese.
Nigbati Offa Irese tun kere ju, a pada si Offa Eesun.
Offa Eesun ko bat un gba wa mo a ko lo si Offa Arinlolu.
Olofa se pele o!
Aro o ya bu mu, beeni ko ya bu boju.
Igunungun ni mo ri ti mo da asa j’edo.
Akala ni mo ri ti mo da asa geruu.
Olofa, Imole ni mo ri ti mo da asa la mi ni abee.
Olofa lo ni Omoo.
Kos i Omo to ju ti Olofa bi ko se Oyo.
Olofa loni Omo, gbengbenleku ni arayoku nsan.
Beni won ki Olalomi Iyeru-Okin, Olofa mojo.

ORIKI ANOMO
Kukunduku de abewe geru-geru.
Obo Omo bo Iya.
Obo Baba, bo Omo.
Obo Oko bo iyawo e.
Adun wo labe Oori.
Ajunilo tinfi owo ola ran i lori.
Pekelola, ara idi Egungun.
Pekelola, amuyan ni igun.
Eniti Olofa otete ri ti obi Ifa re leree.
Oni: A bi Pekelola nba mi ja lawo ara ni?
Pekelola, amuyan ni igun.
Kos i nile Iyan okun odo.
Pekelola de, Iyan kun inu odo fo-fo-fo.
Ore Olofa.
Awo Ojomu.
Imule Saawo.
Eniti Olofa kotete fi ote lo.
Ti Ilu fee tu.
Won so fun Pekelola tan,
Iyan yi piriipi ninu Odo.
Pekelola, de, de, ki aye o’yemi t’omo’tomo.
smiley smiley smiley smiley smiley smiley smiley smiley smiley smiley smiley smiley smiley smiley smiley smiley

5 Likes

Re: Yoruba Peeps, Kini Oriki Ilu Re? by tpia5: 1:57pm On Jun 23, 2012
Hmm, this was when idowuogbo first joined nl, before displaying her bad mouth.
Re: Yoruba Peeps, Kini Oriki Ilu Re? by Nobody: 2:31pm On Jun 23, 2012
I don't understand most of what the guy was saying, but this is pretty cool and deep...Ijebu merchants!!! cool Who's richer than us?? No one!!

Oriki Ijebu

https://www.youtube.com/watch?v=nVuGfIhbFYk

Oriki Ijebu

https://www.youtube.com/watch?v=egMSkD_yAmk
Re: Yoruba Peeps, Kini Oriki Ilu Re? by labaks(f): 6:32pm On Jun 23, 2012
Me I be omo ikorodu o
Omo male afileja, emi omo asoko bieni seke, omo akenigbo ki eru o ba ara ona, emi omo a se ale jeje bi eni ti o ri obinrin ri, omo isu nle kosobe, omo dudu ile ti o mo obe se; pupa to mon se ti lo si ajo; tori e ni mo sen pupa si.
Emi omo eluku medemede, omo eluku medemede
Omo jamujamu to wa lona tio je ki omode koja lo soko lo mu isu.

My head wan burst, will just stop here..lol

1 Like 1 Share

Re: Yoruba Peeps, Kini Oriki Ilu Re? by herkeym001(m): 12:36am On Mar 31, 2013
Emi lomo ilorin enu dun ju iyo lo, ilu alufa Alimi, ilorin ilu awon Alufa Olohun, ilu to ji na sina to sun mo alujonna. Ilorin ni.
Re: Yoruba Peeps, Kini Oriki Ilu Re? by dareyb68: 6:24am On Jul 02, 2015
Omo opomulero moja lekan
opo ro sho op gbaga



that's all I can remember

(1) (Reply)

Throwback: Ooni Sijuwade And Fidel Castro In Cuba (Photo) / I Remain Ologbotsere - Ayiri Emami Dares Ruling House / Photos Of Oba Elegushi, Ooni Of Ife And Oluwo Of Iwo Land

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 53
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.