Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,149,811 members, 7,806,276 topics. Date: Tuesday, 23 April 2024 at 01:54 PM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (5) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (375312 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (167) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 5:11pm On May 24, 2007
bodsibobo:

@richylaw

Akiiika, kare omo ooodua rere. Mo gba fun o. O se!!!

Ore mi , o o ni te lawujo omo adarihurun o, ede wa to da wa po ko ni tu wa ka o.

Olulayomi:

Orisirisi aso lon nbe lara alagemo. Oluwa rere gba wa o.! Unh Nairaland!!!!!!!!!!
Arabinrin Olulayomi, Oluwa layo temi na o.
Jowo dakun inu mi yi o dun ti o ba le tumo owe ti o pa yi. Kini alagemo iru aso wo lo ma n wo? se satin ni abi woodin abi lace. smiley

Segoye2
Ti mo ba ti dele ile lati ibise ni asale ma a ko e ni oun to ma se. Sugbon o da mi loju wipe o dabi eni wipe omo baba yi ni AIDS ni won o se janpata lati wa e wa le o. Tete ma pada lo si ile ife. Ori ade ki sun ta!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dollyp1cute(f): 5:19pm On May 24, 2007
segoye2:

Ewo, eni ba ro ku ro mi, ko gbe omo e dani ma relocate lo sorun .

Kini ma se bayi? kini kin so fun? ani esi wo ni kin ko si baba ode yi? emi ati omo en gbadun, owun soro jabajaba, se bi orobo omo e lon wa gbesi temi? well, odabi enipe mo ni lati salaye fun baba omo to fun mi ni pormo bi sogbo e ti se sele, ebi mi de ko ooo, e bi oyibo ti mi o gbo ni i. nitori omo yen pariwo, oni bros segoye2, usee itt tooo rubbb itt, ni gba ti mo de gbe si enu iho, nise lo lanu, logbemi, gbogbo ibe ba fee, sugbon otun wan pariwo, hooo; is enteringggg, nise lemi forgetted wipe lasan ni mon se lai si roba, mo tie ja epo sinu ibe, erun ba mi oooooo,

Kini kin so fun babi yen, kini kin ko si baba ee, ejoo eko ni ede yoruba at ni ede abinibi.

ehnnn, Wa_Do_Mio, se obo e o yun e mo? O tie da mi lohun ti oba je orobo tabi igi ishana. Sugbon tori omo oduduwa ni ee, oye ki obo e dun jinajina. Obo gbogbo awon omo nna ti owa ni agbegbe mi man dun nadu nadu. Omo aboki ti mo na ni egba ni ose to koja ti n temi lago wipe, owun ti rechargii ibe, owun de ma fun mi tan ni ote yi, emi kedere, I no de tire!.

Si Isrealite,

Emi o mo itan ile yoruba, sugbon mo mo pe ninu film ODUDUWA 1 & 2, ti e ba raa emo itan eni ti o bi ta ni ta ni, ni ile O'dua

E ati se, oro iku we, ki la gbe kilagbin, ki se amodun oyeye iku ye lori gbgbo wa. O se mi ni kayefi awon oro kabikabiti ti awon elegbe mi nko si inu tiredi yi.

Sugbon e da ekun isokuso nibi yi, aye miran wa ti e ti leso oro yi.

Ogbeni segun lo ti owo omo e bo aso, abo oro ni a nso fun omoluabi.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 5:22pm On May 24, 2007
si Richylaw,

Ejo saa, se babalawo ni yin ni? nitoripe mo fe se ogun.
ema binu pe mo yaju bere ibere yi ooo, nitori nigba ti e salaye itan yoruba, inumi dun gidigidi, ati wipe, mo ni ani daju pe e ba awon agba jeun, ati wipe, nigba ti e wa pegede si ori Esu, e ru tun wa bami,

Ejoo, ti e ba je babalawo, eje ki a rigbo, ise wa, ani lati ori threadi yi, ele bere si ni ri ise lotun losi, bi ise ti mo fe gbe fun yin lowo lowo yi, ti eba le bami see, i nu mi adun bajebaje.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 5:35pm On May 24, 2007
Oda ooo, moti gbo, botile jepe ede yin, remix yoruba ni, mokaa mo si ni idani loju wipe e ko fe gbo bi mo see tee yiinn. sibe sibe, eni lati ran mi lowo.

Ogbeni Richylaw,

Tani o gbe AGE, HA!, se ipe o ti funmi ni AGE? ewo, mon bo, ma lo bere lowo e bayi bayi, Inu tin bimi. Emi o fe gbe AGE oooo, Olorun gbami oooo, Eyin irunmole, I ma wo mi niran ke, mo ba onise se ise ni ooo, i ma jen base loo ooo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by penfold(m): 5:50pm On May 24, 2007
ke san fun esan, ke wo fun ewo, omorigba e ri idi joko, ewe ata o nki to ata di, ileke ni o leke igi, oshibata ni ileke odo, sise sise lo nmu ewure ti o fi nba iya e lo,gbogbo eni ti o ba pe ori mi ni ibi, ogiri alapa,ko ma wo lu won pa, gunnugun ki ka odun akalamagbo ki ka osu,eni ti o ba bu mu ni thread yi, ko ni ka ojo meta!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ne4real(f): 5:54pm On May 24, 2007
Igbo kwenu!!!!!!!!!!!!!! no be only yoruba people dey here. tongue tongue tongue grin grin grin grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Olulayomi(f): 6:03pm On May 24, 2007
@richlaw
Wo ebi mi, richlaw, sho ri nipa ti itumo owe yen, gbagbe e o.  Sugbon idi timo fi pa owe yi ni wipe, nigbati mo ka awon nkan ti awon kan fi si ori thread yoruba yi, erin pami, unh mo miri eru si ba mi.  

Sugbon sha o nairaland yi ti fe ma di ohun miran, ko si hunmi lati ma dasii mo, kika lasan lo de ku bayi o .  Emi ko ri alagemo ri(mi o si fe ri ),debi ti mo ma mo aso to nwo, ti o ba fe mo, lo se iwadi funrara re, oluwa yi o fun o se o.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by olawa20(m): 6:04pm On May 24, 2007
e gbani e laja. se ori ero ayara bi asa ni awon omo oodua ti fe ma se juju bayi.

segoye, ti ogbeni richy[color=#990000][/color] ba je babalawo bawo ni ko se fi ogun ti o ba ba o se ranse. se Attachment nairaland le gba ogun ni?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by texazzpete(m): 6:28pm On May 24, 2007
Hmm. . . I remember reading something in the Rules a while back

PROPER ENGLISH LANGUAGE ONLY
Please use standard, proper, and clear English at all times when publicly discussing topics on the Nairaland Forum. Avoid the use of Yoruba, Igbo, Hausa, local 'pidgin', or other languages on the forum. If you find it necessary to express yourself using any of these other languages, then you must provide a translation in clear, proper, standard English so that those that don't understand the language you have used would still be able to enjoy the forum.

Looks like we got some real fat Sacred Cows over here. . . grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ThiefOfHearts(f): 6:35pm On May 24, 2007
Did you write the same thing in the Igbo Kwenu thread?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 6:49pm On May 24, 2007
segoye2:

si Richylaw,

Ejo saa, se babalawo ni yin ni? nitoripe mo fe se ogun.
ema binu pe mo yaju bere ibere yi ooo, nitori nigba ti e salaye itan yoruba, inumi dun gidigidi, ati wipe, mo ni ani daju pe e ba awon agba jeun, ati wipe, nigba ti e wa pegede si ori Esu, e ru tun wa bami,

Ejoo, ti e ba je babalawo, eje ki a rigbo, ise wa, ani lati ori threadi yi, ele bere si ni ri ise lotun losi, bi ise ti mo fe gbe fun yin lowo lowo yi, ti eba le bami see, i nu mi adun bajebaje.



Arakunrin Segoye2, Emi ki i se babalawo,mo se itebomi gege bi onigbagbo ni odun 1990, Bibeli mi ni mo gbojule o, ofin Mose ni mo si tele grin grin.
Sugbon mo ti ba won de ibi ti ojo ti n ro lati ile lo si orun, ogidi han n han n omo kaaro ojiire ni mi.
Oro re lo ka mi laara wayi, n o si sa ipa mi lati saanu re , inu mi dun wipe o fe lo o bere lowo omodebinrin yi, sugbon ki o to lo mo fe ki o pe ayajo yi, niwaju ile iya charlie, ti o ba si je wipe Naijiria lo wa lo si iwaju Aso Rock lati se etutu yi, ti o ba si je Amerika ni, Ile funfun ni  iwo yio ti se. Ki o ma so wipe:

Aro gede ni sawo won lofin ile
eji iragbo ni sawo won ni ju odan
Akoko ki ro ho mu
Epinrin bale o ro pin
poro poro bale oro po
ewe ogun bale oro gbamoko gbamikoko
adifa fun baba yekuyeku oke apa
ti won pe ni oyeku sonponna,
won ni ki ni yoo yeku nu lori awo
eji oye ni o yeku nu lori awo eji oye

Ti o ba ti so tan , ki o lo si iwaju ile awon omo yi ni agogo meji oru ki o si gbon erupe ese bata re sibe. Ogun ti se .HALLELUYAH grin
Ti o ba ni ogun miran ti o fe se, so fun mi kia kia nisiyi ti mo wa ninu ile agbara o.

Olulayomi:

@richlaw
Wo ebi mi, richlaw, sho ri nipa ti itumo owe yen, gbagbe e o.  Sugbon idi timo fi pa owe yi ni wipe, nigbati mo ka awon nkan ti awon kan fi si ori thread yoruba yi, erin pami, unh mo miri eru si ba mi.  

Sugbon sha o nairaland yi ti fe ma di ohun miran, ko si hunmi lati ma dasii mo, kika lasan lo de ku bayi o .  Emi ko ri alagemo ri(mi o si fe ri ),debi ti mo ma mo aso to nwo, ti o ba fe mo, lo se iwadi funrara re, oluwa yi o fun o se o.



 


Olulayomi, mo mo wipe , itumo oun ti o n ro wipe alagemo je ninu owe re ko ni owe yi tumo si!. Looto, oro tabi egungun kan wa ni ile yoruba ni ilu egba ti a n pe ni alagemo,sugbon oun ko lan so ninu owe ti o pa. Alagemo ti a n soro re ninu owe yi je oun ti iwo gege bi omo adarihurun ma  n ri loorekore. Oruko miran fun Oga (chamelion) ni alagemo. Nitori wipe oga a ma pawoda bi o se wu, eyi ni o mu ki yoruba bo wipe "orisirisi aso la n ri lara alagemo". Eyin agba ni Nairaland se mo wi i re?

olawa20:

e gbani e laja. se ori ero ayara bi asa ni awon omo oodua ti fe ma se juju bayi.

segoye, ti ogbeni richy[color=#990000][/color] ba je babalawo bawo ni ko se fi ogun ti o ba ba o se ranse. se Attachment nairaland le gba ogun ni?

olawa20, ibi gbogbo la n kadie ale o, ko si si iku ti ko ro adie lorun, nigba ti mo ba ba segoye2 se ogun re tan gbogbo yin ni e o to wo ninu re grin , nitori wipe ni ori ero ayara bi asa yi ni n o ti fi ran n se o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by olawa20(m): 7:06pm On May 24, 2007
richylaw:

sugbon ki o to lo mo fe ki o pe ayajo yi, niwaju ile iya charlie, ti o ba si je wipe Naijiria lo wa lo si iwaju Aso Rock lati se etutu yi, ti o ba si je Amerika ni, Ile funfun ni iwo yio ti se. Ki o ma so wipe:


eyii lewu die. ni iwaju Aso Rock lohun. Baba ma le ro wipe awon ara ile atiku lo ran o wa o, ewon gbere ni o nfi sere yi o.

ogbeni richy, se ogun re da e loju. se waa le gba sile lowo Baba.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Ikomi(m): 7:12pm On May 24, 2007
Kilo n sele?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by penfold(m): 7:20pm On May 24, 2007
richy, se babalawo ni won ni idile yin ni
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 7:35pm On May 24, 2007
Baba ooo, E seun wa eku itoju wa ooo, se ko si ona mi ti a legba se etutu yi ni? nitoripe, o ye ki ona mi wa, mo ti pirinti awon egede yen, sugbon, mo wa ni nigeria lowo lowo, erun ba mi ooo, afi ti e ba fun mi ni ogun ofee lati do ora nigba ni the main wahala ba sele ni waju aso roki.

Se etutu yi ko ni gba nkan bi rechargi cardi? nitoripe, sivilasasion ni awan ri bayi ooo,

Babalawo mon be yin, eran mi lowo, mo da majemu pe ma fun yin ni omo kan lai pe yi.

Ese.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by juw0n(m): 7:37pm On May 24, 2007
Eso E, ebile ti wa
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ThiefOfHearts(f): 7:41pm On May 24, 2007
Ikomi tun de o tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by marthafor2: 7:41pm On May 24, 2007
@ Texazzpete,

THanks for your thread, and as you can see, this is a yoruba thread, so if you feel like coominicating to the house, you better translate the following to the house;

PROPER ENGLISH LANGUAGE ONLY
Please use standard, proper, and clear English at all times when publicly discussing topics on the Nairaland Forum.  Avoid the use of Yoruba, Igbo, Hausa, local 'pidgin', or other languages on the forum.  If you find it necessary to express yourself using any of these other languages, then you must provide a translation in clear, proper, standard English so that those that don't understand the language you have used would still be able to enjoy the forum.

If you can't translate the above words into yoruba language to enable your post flow along line, I will advice, you search another thread like that of "Man seeking Woman",  "Looking for a Date" etc.

Thanks,

House Secretary.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by GNature(m): 7:48pm On May 24, 2007
Quote from Wa_do_mi :

mo fe ki  o fi oko e sinu obo mi ni isinsin yi - obo mi n se omi nito ripe mo fe doko.

Olorun nikan lole gba e la  grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 7:48pm On May 24, 2007
Oga ooo, awon wo niyi ooo, won tun ti de, kini won so na?, Ejo eba mi tunmo re ooo, won ti daru mo mi loju sha.

Eso ee I wo na, Mon gbadun ee jare.

Babalawo, se e yi wa ni ile agbara yin ooo, e da mi lohun kee, yeye omo nin gbomo, be be be be be lowo orun mila.

Emi, omo yoruba gbidi ni mi, botile jepe, mi oti dele mi ri, ni ote yi, ma dele dan dan, Ile ife, emi ree!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 7:50pm On May 24, 2007
Si GNature,

Olorun ma n ran eyan si eyan ni. nitorina, awa wa ni, ale ran rawa lowo, e mi a ran lowo, lori adehun pe, osanra, mo ti so tele wipe, e mi man gbadun a won eru!, Oke agun gun tan.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 7:53pm On May 24, 2007
kini e happen?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 7:54pm On May 24, 2007
oko mi tall and handsome
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by GNature(m): 7:58pm On May 24, 2007
segoye2:

Si GNature,

Olorun ma n ran eyan si eyan ni. nitorina, awa wa ni, ale ran rawa lowo, e mi a ran lowo, lori adehun pe, osanra, mo ti so tele wipe, e mi man gbadun a won eru!, Oke agun gun tan.

but ogbeni segoye2, ti ko ba sanra nko ? Se odi dan dan ni ?

kilode ti e se man gbadu a won eru ?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 8:00pm On May 24, 2007
ire tiye gbi yan ju ni tire, bami ki oko tire ooo, Oku Ise gidigidi na, O so o won ki a ri oko ti o ma ko iyawo e ni ede abinibi ree.

Inu mi dun, Oti je ebun gidi kan lati owo mi lowolowo, bere owun ti oba fee, e mi yio si fun oo lowo lowo~!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 8:03pm On May 24, 2007
Ibere pataki niyen,

se e ri, ti eba dan wo, a ye yin Sir.

Oman dun gidigidi gan nii, atipe awon ti ko sanra man dun na, ani daa daa, sugbon e mi man gbadun awon aruwo ti skiwowo ma n see wonye, ani bi, So ra ee ooo, O tun je ki ma so so ku so, mo de n gbiyan ju na oo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ikamefa(f): 8:10pm On May 24, 2007
babyosisi:

oko mi tall and handsome


grin grin grin


babyosisi:

kini e happen?



ko si ki lo n wa nibi? cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by GNature(m): 8:13pm On May 24, 2007
segoye2:

bami ki oko tire ooo


Ogbeni segoye, okunrin ni mi, bawo ni mo she maa ni oko (abi iyawo lefe so ?)

segoye2:


bere owun ti oba fee, e mi yio si fun oo lowo lowo~!

Mo fe Mercedes benz asiko
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 8:17pm On May 24, 2007
ikamefa:


grin grin grin



ko si ki lo n wa nibi? cheesy

mo wa nibi just to chat and learn yoruba
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Ikomi(m): 8:17pm On May 24, 2007
ThiefOfHearts:

Ikomi tun de o tongue

Omo ewolewo. Ma gbadun ntie.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 8:18pm On May 24, 2007
Bere owun Meta oto to
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ThiefOfHearts(f): 8:18pm On May 24, 2007
lol @ osisi.

bawo ni GNature?  smiley Ilu wo lo wa ni America gan?

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (167)

Modern Traditional Attire Of Nigeria / Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 64
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.