Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,149,770 members, 7,806,120 topics. Date: Tuesday, 23 April 2024 at 11:46 AM

Tani Jesu Nse? Jesu Kristi Ko Wa Bi A Ti Ngbadura - Religion - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Religion / Tani Jesu Nse? Jesu Kristi Ko Wa Bi A Ti Ngbadura (430 Views)

Tani Jesu Nse? Jesu Kristi Je Alailese / Tani Jesu Nse? - Jesu Ni Olorun / Tani Jesu Nse - Jesu Ni Eni Ti A Fi Ami Ororo Yan (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Tani Jesu Nse? Jesu Kristi Ko Wa Bi A Ti Ngbadura by Primate7: 12:49am On Oct 17, 2019
TANI JESU NSE?
JESU KRISTI KO WA BI A TI NGBADURA IHINRERE TI MATTEU, ORI KEFA, ESE KEJE TITI DE ESE IKETALA SO WIPE 7. Sugbon nigbati enyin ba ngbadura, e mase atunwi asan bi awon keferi; nwon sebi a o ti itori oro pipo gbo ti won. 8. Nitorina ki enyin mase dabi won: Baba nyin sa mo ohun ti enyin se alaini, ki e to bere lowo re. 9. Nitorina bayi ni ki enyin ma gbadura: Baba wa ti mbe li orun; Ki a bowo fun oruko re. 10. Ki ijoba re de; Ife tire ni ki a se, bi ti orun, beni li aiye. 11. Fun wa li onje ojo wa loni. 12. Dari gbese wa ji wa, bi awa ti ndariji awon onigbese wa. 13. Ma si fa wa sinu idewo, sugbon gba wa lowo bilisi. Nitori ijoba ni tire, ati agbara, ati ogo, lailai. Amin.
LATI INU BIBELI MIMO
(16/10/2019)

(1) (Reply)

What The Church Doesn't Want You To Know / Flamboyant Ghanaian Pastor,obofour Flaunts His 25 Luxury Cars With Disdain / LADIES; 7 Key Things You Must Know Before Marrying A Pastor - Rev. Akinola Tunde

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 6
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.