Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,147,499 members, 7,797,416 topics. Date: Monday, 15 April 2024 at 04:07 AM

Ogun Ibile Awön Baba Wa - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Ogun Ibile Awön Baba Wa (1353 Views)

Meet Baba Kekere Of Oyo Kingdom Who Served 3 Past Alaafins For 77 Years / What Does "Na Wa O" Mean In English / Yara Iwosan Ibile Yoruba (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Ogun Ibile Awön Baba Wa by ogunfrayo: 9:17pm On Apr 27, 2020
Awon baba nla wa ni imo pupo julo ti aba nsoro nipa imo ijile Yoruba ati itoju pelu ati ri aye GBE. Sugbon oseni laanu wipe olaju ni ogba gbogbo aye kaan lode oni. Opolopo omo Yoruba ti so asa ati ise nu lode oni, idi niyi ti awon agbalagba se pa Lowe wipe" omo to ba so ile nu, o so apo iya ko". Idi re ti opolopo eniyan se waa un sa soke sodo, ti opolopo so gbe esin kaari. Olorun wa, sugbon a won kan wa ti oko akoso ile aye le lowo. Fun itoju ara re Lori awon nkan won yii:

*Ose eyonu
*Itusile awon agba
* Iwadi nipa oun gbogbo tinsele si o
* Etutu
* Aseje
* itoju ara fun orisirisi arun tabi Aisan
* Ipake( Hernia), Oyun iju( fibroid), Eda, Ori bibo, Ogun bibo, diabetes, stroke.
Ose atude, imule awon agba,
* Agadagodo todaju
* Itesiwaju lenu use
* Afose todaju ati bebelo.
Ekansiwa Lori ero ibanisoro wa yii: 08108458712 tabi me fi oro ranse si email wa yii: ogunfrayo@ yahoo.com. Odua yio gbe wa o, asewa.

2 Likes

Re: Ogun Ibile Awön Baba Wa by Babakolanut(m): 4:31pm On Jul 06, 2023
Ejowo kini eniyan le lo fun iwosan hernia ti yio si lo patapata? Whatsapp mi ni +2349034612092

(1) (Reply)

Will You Give Your Child Tribal Mark In This 21st Century / Dreadlocks, Good Or Bad? / Nigerian Nurse In UK Boasts Of Having A Juju Man Back In Africa

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 6
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.