Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,135,566 members, 7,751,720 topics. Date: Thursday, 29 February 2024 at 09:41 AM

Oriki Nile Yoruba - Religion - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Religion / Oriki Nile Yoruba (177 Views)

Oriki Ogun Lakaiye (God Of Iron) / Oriki Ogun Lakaiye (god Of War And Iron) / Oriki Esu - Praising The Divine Messenger (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Oriki Nile Yoruba by nagro999(m): 12:19pm On May 19, 2023
Oriki Nile Yoruba

Share

ShareÀsà kan pàtàkì tí àwa Omo Yorùba ń gbé sonù báyìí ni àsà oríkì kíkì. Advertisement 


Ní ilè Yorùbá kò sí nnkan náà tí kò ní oríkì yálà eranko , igi, ouñje , ìlú, èèyàn, bòròkìní, ìdílé tàbí orílẹ̀. Orísirísi ìdílé ni ó sì ní oríkì ti won.
Kíni oríkì gan? Oríkì jé àwon òrò ìsírí tí àwon yorùbá máa  ń Fi ki ara won. 
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwúlò ni ó rọ̀mọ́ kíki Oríkì. Àwon olórin a máa lò oríkì láti lè jé kí àwon ènìyàn ojú agbo ba à lè náwó fún won. 
Àwon òbí náà a máa lò oríkì lati kí Omo won láàárọ̀, láti jékí ó se ise tí wón bá rán- an tàbí láti fi ìdùnnú won hàn sí omo tí ó bá se ohun tí wón fẹ́. Àwọn ọdẹ náà sábà máa ń ki oríkì àwọn ẹranko nígbà tí wọn sun Ìjálá (eré).

Orísirísi ònà ni a fi ñ ki ènìyàn. Bí a ti ń ki oba béè kọ́ ni à n ki ènìyàn lásán. Oríkì Bọ̀rọ̀kìní yàtọ̀ sí ti ìjòyè  À máa ń ki ọba bí agbára rè bá se tó, A lè lè kìí sí ọwọ́ tí ó bá yọ nígbà tí ó gun orí oyè tàbí ìté, a sì tún lè kìí láti rán-an létí àwon àseyórí àwon baba ńlá rẹ̀. 


Bí Omo bá jí lówùúrò kùtù bí ó bá lọ kí bàbá àti ìyá rẹ̀, oríkì ni wón á lò láti ki Omo náà. 
Àwọn àgbà bọ̀ ...https://www.orisa.com.ng/2023/05/oriki-nile-yoruba.html


Continue
Re: Oriki Nile Yoruba by MaxInDHouse(m): 12:27pm On May 19, 2023
Ọlọ́pọndà
Oníkòyí
Àrélù
Àbú Onífẹ̀

(1) (Reply)

Her Husband Was Summoned To A Shrine And The GOD Of CHOSEN Showed Up / Should Christians Restitute After Genuine Repentance? / Is paying Tithe Mandatory? Let's See What The Bible Says.

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 7
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.